You are on page 1of 2

Ase agbe kale egbe yi fun iranlowo omo eda eniyan lori egbogi ibile lorisi risi.

Egbe yi yio ma se iranlowo fun eni ti o ba ni awon isoro won yi.

*ONA ABAYO SI ARUN ARA*


1=STROKE.
2=EGBO ADAJINNA.
3=NKAN OMO KUNRIN TI KO GBERA.
4=AISAN OLOJO PIPE.
5=OBINRIN TI KO RI OMO BI.
6=AISE DEDE OKO LODO AYA RE
7=OBINRIN TI O HUNNI OYUN, SUGBON TI O MA WA LE
8=IJU ATI EDA.(etc)

*ETO IGBESI AYE WA*


1=EGUN IDILE
2=ALAKALA
3=ONJE OJU ORUN
4=IMUNLE AWON AGBA
5=EYONU TO KAJU E
6=IPESE NLA
7=ATI BEBELO (E.T.C)

Awon anfani yi wa fun gbogbo omo egbe kookan ati fun eni ti omo egbe ba mu oro re wa.

Egbe yi setan lati ran eni ti koba ni owo lati se itoju ara re lowo.
Ti irufe eni na ba ja ajabo kuro ni inu isoro ti o wa tan, yio da owo ti egbe fi se itoju re pada si apo egbe ni ilopo
meji.

Anfani wa fun omo egbe kookan lati so nipa ise kan ti o ba ri ninu egbe ti o ba wu lati se, egbe yio se Iran lowo
owo ati aduroti fun eni na ni ibikibi ti o ba wa.

Ao ma se eto yi pelu ibura nla larin gbogbo omo egbe.

Ti eto yi si tun ma wa ni akosile ti o yanju ni inu ile egbe.

Eni ti o ba ni Owo lowo lati se itoju ara re a aye wa fun irufe eni na o, ki eni na fi to egbe leti ona ti o ti fe
iranlowo egbe, egbe yio duro ti eni na.

Odi eewo fun omo egbe kookan lati ma fi asiri inu ile yi sile ita fun eni ti ki se omo egbe, eni ti oba se be ijiya
nla nbe fun iru eni be.
Eje ki a jo fi owo sowo po fun agbe kale eto yi, fun a agbega egbe wa, ki Olorun ran wa lowo.

You might also like