You are on page 1of 1

*OSHO EYONU TIPATIPA TI WON PE NI (OLOFUTU)*

👉Ori aja dudu,


👉igba eyin ijapa
👉odindi oga gbigbe meje,
👉atelewo inaki,
👉ewe kole orogba topo daada,
👉ewe aje tutu, pupo
👉odindi ologini dudu kan,
👉ori omo elede,
👉atare odidi meta,

ao jopo ao fi aso funfun te inu igba aje aofi egberun kan #1000 le ori aso towa ninu igba yii,, aopo ebu yen mo
ose gana ao gbe sinu igba na ao wa fi owo eyo tiko loju te ifa ejiogbe le lori ao gbesi ibi ti idire koti nikan ile ao
mafi we ni ojo ikini osu, ojo ti osu ba pin si meji,ati ojo ti osu ba pari........odaju

You might also like