You are on page 1of 1

ELEYI NI IWE ATUDE TODAJU

EWE IYALODE PUPA

EWE IYALODE FUNFUN

EEPO OBO TO TOBI DIE

EYIN ORORO TOMO KAN

Aofi eepo obo tele inu ikoko oru,ao ko ewe iyalode pupa lelori,aowa fi eyin ororo yan le ori ewe iyalode
pupa yan,aowa ko ewe iyalode funfun le mole,ao bu omi si aose lagbo, toba di ni ale tia fe sun ao ko
gbogbo awon ewe yan si ilele ni ile iwe,ao duro lori won aowa bo eepo eyin naa aose adura si,aowa ju
senu aoje tan aowa fi agbo yan sanra,aowole losun laijade sita mo.

IKILO PATAKI:- FI COMMENT RE SE ADURA TOBA WU E FUNMI, (LIKE COMMENT AND SHARE. MASE
AFOJUDI OO KOLEJE FUN OO)

FUN IWO TI OFE BA IFA NI GBOLOHUN ABI OFE YE ORO AYE RE WO ABI FUN IRANLOWO LORI ISORO ABI
OGUN TI OUN DOJUKO CALL OR WHATSAPP TI O BANI IGBAGBO (( +2349151788494))

You might also like