You are on page 1of 24

AWURE OWO AGBOOJO

Ao fi iyerosun tefa ejiogbe si owo wa osi, a o pe ofo yi si: ajifolayin oruko ti anpe ifa, ojini kutukutu
ke gbami gbami ni oruko ti anpe iwo esu odara, akirijaowo ni oruko ti anpe eyin iya mi osoronga,
owo to wa lokun, to wa losa, ko lo ba mi ja wa loni lowo awon enia rere, tokunrin ati tobinrin - a o
fe si oju ojo, a o fi eyitoku sa ori wa ni owuro kutukutu, ni owuro lan lo ogun yi, o daju

ASEJE ASINA
, ewe afara, ewe idi,ewe tanapowo,ewe owu akese, at a ijosi, epo iyo, kindinrin malu mejeji, ao
gesi ona 8/8 iyere osun ao fi te eji ogbe, pelu gbolohun yi, gbolohun ::::::: olori ole ni lowo lowo,
agbalagba ole ni tete LA, okanjua eniyan ni won ba ohun rere lowo re, IFA jeki won ba ohun rere
lowo mi, ni owu akese bawo Oja owu okusu aparamo, igbe nlanla ni malu ke, owo nlanla ni kiwon
ma wafun mi, idi loni kiwon di eru owo nlanla wa fun mi, afara loni kiwon fa ire owo nlanla wa fun
mi, eji ogbe loni ki won GBE owo nlanla wa fun mi , adua, ao koje. Odaju

ATUDE OSE"
ewe lapa funfun mesan, ewe ewuro ojoo mesan, ewe efinrin mesan, ewe ajaobale mesan, yerupe
ago kan osan ati toru, ao gun mose, ao fiwe fun ojo meta pere lori ni ago kan oru ni wiwe re o, ti
abatiwe ose ye pari, ao tu kanhinkanhin yeka, ao sonu ni o. Odaju

ITUWO ATUDE- aowa ewe ajeobale, epo igi ajeobale, egbo ajeobale, aolopo mose aopin ose na si
ona meje, ti abafe we aowa ajadi apere kan aoko sinu re aowa we ose mejeje na lekan na telera won
ninu apere yi kain kain meje ni aofi we ooo, AKIYESI, ti aba nwe lowo aogbodo soro, aosi gbodo siju
le afi ti aba wekan tan ti atun fewe imin

ATUDE TODAJU Ewe tude egbo tude iyere ao lo ti yio kuna dada ao ra isasun tuntun ao fi se odidi
igbin kan je lepo niyo lodidi ni ao se igbin yi o akoni ge ti obajina ao so kale ao je ko tutu ao wa bo
gbogbo aso orun wa ati oruka ao wa ni ihoho omoluabi ao wa da aseje na si ilele ao kunle ti ao wa ka
owo wa mejeji seyin wa ao wa se adua itusile ao wa fi enu gbeje lodindi iseyi daju danwo kori botiri
Ike oloun ola oloun komaba alayelorun NB ori ilele cement or tiles lamada aseje yi si leyin ti ati nunu
dada ao dasi ao waje

EYONU AWON AGBA TODAJU


Ao wa Opolopo ewe imi esu ao japo ma ododo ati itanara ao jo po ma atare odidi kan ao mafi la epo
pupa lalale pelu adua odara pupo atude ni pelu odaju

EYONU¤
Ewe Akoko ati Itanna re, epo ati egbo re ao jo pelu odindi ataare kan, ao maa fi epo la ki a to sun... Ti
o baa di ojo keje ti a lo ise yii ao fi Akara elepo se sara fun enia meta pere odaju

EYONU¤
Eru oju aro, epo obo ao lo kuna daadaa ao mo mo ose Lux ao maa fi we lalale.... Odaju

EYONU AWON IYAMI TURARI NI O¤


Eku asin meta, Epo Obo, Epo Igi nla, Korowu ao gun papo, ao daa sinu try kan ao waa daa adin gidi si
ao ro papo daadaa, ao saa si ategun, ao maa fin ni alale ki a to sun.... Awon Agba won yi maa yonu
siwa
EYONU ASINA TIPATIPA¤
Ao gun ewe Afelorun kuna daadaa, ao waa po pelu Ose dudu, ao te Ifa Eji Ogbe si ori iyere Osun, ao
se Adura Isina si daadaa ao waa po pelu ose yen ao ko sinu igba Olomori, ao maa fi we ni gbogbo
igba..... Odaju

EBE/IMULE AWON AGBA TODAJU


Alubosa elewe tutu kopo die ao gun dada ao popo ma ose dudu ao wa eyin adie Oojo ao do gbon fo
lori die ti korofo eyin yi konibaje ao jo omin eyin yi sinu ose yi ao tun gun dada ao wa igba olomori ao
ko ose yi si ninu ao wa fi korofo eyin yi gun ose yi lori logan gan ibi ti ati fo eyin na ni yio koju sinu
ose, ao ti koko dogban fowo jin ibibe kato fi eyin na gun ki korofo eyin na maba fo. Ao ma buwe
nigba toba wuwa. Iseyi daju ijo taba bere wiwe re ojona ni yio bere ise

EYONU
Oga3,asin3,opolo3,eso ido,eso werenjeje,ewe ajeobale, ewe orijin,ewe kileofimise,odindi atare 3,ao
Jo po ao ma fi epo ogere la ninu fitila oloju kan. Tested ok

IMULE AGBA
Akara elepo16,eran menu,ao to akara yi round ninu ape ao fi eran sarin re ati odindi atare kan ao Jo
po ama fi otin lo lalale
Eyonu ,ogede omini ati epo obo ati igbo mimu ao gun papo mo ose ,odaju
Etutu awon eleye kan reo:- alubosa funfun ao fi din eran namo tikoiti womi tiagesi ona
merindinlogun, ao jo ako alangba kan pomo odidi atare kan ao lokuna ao da sori ipese na ao da
epopupa lelori ao daniyan si ao gbelo sorita loru oganjo, odaju

OGUN ISOYE

Ori akuko adie togbo dada ao fi sinu agbada ijo nkan ao ko ewe akoko bomole ao fi odidi atare kan si
ao jo ao lo kuna ao da oyin si ao ma fi ika arin ropo ao ma la isoye yi dara otun sise fun awon omo
keke tiwan lo ile iwe ao so wipe ki wan ki ika arin bo kiwan la, inu roba ti owo (hand) lewo la dasi ti
ao ti mala

OGUN TUDE TOODAJU. Egbo lapa funfun ti ori akitan,,,Egbo lapa pupa ti won fi se ogba School (ile
iwe),Aso funfun opa kan,,opolo aye kan.ao ge egbo lapa funfun ati pupa si ona 16,kekeke.ao ko won
si enu opolo yen,ao wa mu aso funfun yen ao di ni osuka ao gbe sinu Koko ijokan .ao gbe opolo yen
si pelu atare kan,ao jo po ao fi ose ko,ao ma fi we

ATUDE AWON AGBA..Egbo lapalapa eyikeyii.. Ao ge kekeke si inu ike kan.. Ao wa Alangba eyokan ao
jo papo pelu odidi Atare kan ao lokuna dada .Ao wa da sinu egbo take kekeke yen........ Ao wa da
HOT Sinab tabi Omin lasan sii.

Thehomeofsuccess@gmail.com
call or whatsapp or viber 08027449908 or 08064941611
also available on facebook use my email
Posted by Baba ogbagba at 03:10 1 comment: Links to this post

Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest

Labels: SECRETS OF MEDICINE PART 2

Tuesday, 23 February 2016


SHORTLIST OF MEDICINE

SHORTLIST OF MEDICINE ( PAID & SERVICES ONLY )..

(1) Asina ( open way


(2) Afaro ( crowd puller
(3) Omo wiwa ( seeking for baby )
(4) Arobi ( back to sender )
(5) Atude ( release from bondage )
(6) Agadango (Padlock )
(7) Aseta ( kill enemy )
(8) Ape ( call ur girl back )
(9) Apayo ( kill and rise back )
(10) Egbe ( Disappear )
(11) Eyo moto ( escape from car accident)
(12) Atude Ewon ( release from prison )
(13) Awure Ola ( Good wealth)
(14) Ero Asasi
(15) Iferan ( love )
(16) isoye ( memory recall )
(17) Ere Ink ( exam pen )
(18) Afako ( increase ur Dick )
(19) Atosi ( STD )
(20) Ere Akasifu ( exam hanky )
(21) Isiju ( invisible )
(22) Awarida ( menstrual un-stop )
(23) Turari Eyonu
(24) Isora ( body secure )
(25) Asiri Bibo
(26) Oju didun ( eye pain )
(27) Ayeta ( bulletproof )
(28) Afunje ( lovw medicine
(29) warapa ( Epilepsy )
(30) Amubo ( failures in everythings)
(31) Aiku ( increase ur death Age )
(32) Emere ( evil spirit children )
(33) Asiri Owo ( secret of money
(34) ise gbigba ( winning contract job )
(35) Idani lare Ejo (court winning Case)
(36) Etutu awom Awon Agba
(37) Awure okunrin ( looking for rich guy )
(38) Awure Obirin ( looking for rich girl )
(39) Aferi ( invisible
(40) Tiro ti afi nko owo
(41) Etutu Awon Agba
(42) Ropa rose ( stroke )
(43) Afose to daju ( command charm,
(44) apayo ( undead)(
(45) oso gbowowa ( medicine to see unknown person to give u hurge money
(46) ijo aworo ( plenty members for ministry
(47) amubo ( promise and fail
(48) fibroids ( IJU
(49) Tito iferan ( EYE LED TO CATCH MALE OR FEMAL
(50) Cancer of any part inside or ouside of the body ( Arun Jejere )
(51) Osole gbawojo ( medicine to collect money outside country, especially on Net

I still have a lot of medicine which can not be listed above

SHORTLIST OF MEDICINE ( PAID & SERVICES ONLY )

Thehomeofsuccess@gmail.com
call or whatsapp or viber 08027449908 or 08064941611
also available on facebook use my email

Posted by Baba ogbagba at 06:39 12 comments: Links to this post

Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest

Labels: SHORTLIST OF MEDICINE


Monday, 8 June 2015
___OSANYIN: Lord of Plants__

___OSANYIN: Lord of Plants__

The Pantheon of the Yoruba is a complex interweaving of ORISHAS, deities whose domains and
qualities form an intricate pattern of interdependence. Osanyin, lord of all plant life, is an ORISHA
whose domain inexorably intersects with all others. The qualities of herbs are recognized for both
spiritual and physical well-being. It is believed that the force that drives the universe, known as ASE,
is in part locked up plant life awaiting use by those who have the knowledge to unlock it. The rites
indigenous to the faith of the Yoruba could not exist without the herbs provided by Osanyin and the
ASE within them. It is by his invocation and permission that the primary rituals of consecration are
realized.

Osanyin’s knowledge and dominion over herbs is retold in the sacred texts of the Ifa in the following
story:

Osanyin was lame, missing one leg and arm, blind in one eye. But his older brother Orunmila wanted
Osanyin to feel worth. Orunmila arranged to leave Osanyin on the farm early in the morning with the
instruction to pull weeds from between the rows of crops. When Orunmila returned in the evening,
he found Osanyin in the middle of the field weeping, without a single weed pulled. Orunmila asked
his brother why he was weeping and why he had not completed his task.

Osanyin replied, “You have asked me to pull the weeds, but there is not one weed here.” He pointed
to one plant, and said, “You would have me destroy this, but this will cure ailments of the heart.” He
pointed to many other plants, identifying their spiritual qualities and medicinal use. Orunmila was
taken by surprise that his brother had such deep knowledge.

Gifts to Priests:
Orunmila then asked Osanyin to teach him and the other ORISHAS how to use the herbs for spiritual
and physical healing. Osanyin gifted each deity with the herbs and sacred knowledge most
compatible with their individual spirits. In turn, the ORISHAS imparted this knowledge to humankind
by instructing the priests of their respective cults.

In many ways, Osanyin’s use of only a single arm, leg, and eye can be equated with the mystery of
his power. When we view plants, most of us see only the outer green; it takes a person deprived of
other senses and abilities to see the inherent energy within. Osanyin, although lame, is powerful just
the same. Through the deprivation of certain functions, he has been gifted with one more potent.
Without Osanyin, the other ORISHAS would not have the power to unlock the ASE that exists within
herbs.

While in the Diaspora, initiation rites are no longer performed directly on the “chosen” of Osanyin.
But in Yoruba-land (Southwestern Nigeria, Benin and Togo) the priesthood of Osanyin still flourishes.
His priests are distinctive, a cult not given to trance, as are the other cults. These priests speak
through a direct link to their tutelary ORISHA as if their tongues were being rattled by a divine
ventriloquism. Speaking in a high pitch, uttering as their ORISHA directs them.

Birds and the Occult:

Osanyin’s voice as heard through his priests is said to be birdlike. The deity has a strong association
with birds, especially owls. The Yoruba associate birds with knowledge of the occult, secrets and
“witch-like” powers. This is not lost on Osanyin, whose knowledge is deeply esoteric. The iron staff
by which an Osanyin priest is known often is shaped like plant branches shooting out of the ground,
surmounted by a lone bird with wings spread in flight.

This is consistent with the persona of the ORISHA. Osanyin is typically seen as a loner who wanders
the fields. He is given to be moody, but if understood he is more a cautious, thoughtful ORISHA, not
given to grand gestures. Osanyin is to himself, picking his herbs, and communing with nature. His
messages and nature are enigmatic, like his voice.

As we recognize, without Osanyin the rites of the Yoruba could not take place. This is true whether
the priest is in Yoruba-land or in the Diaspora. All rites must include herbs and plants of nature.

The Yoruba classify herbs by each ORISHA as well as by the elements—EWE AFEFE (leaves of wind),
EWE INON (leaves of fire), EWE OMI (leaves of water) and EWE ILE or EWE IGBO (leaves of the earth
and of the forest). Adherents also classify herbs as male and female, as well as herbs of day and
herbs of night and by those that incite or calm.

Sacred Gathering:

Before any rite can begin, the priest must collect the herbs necessary to make the lustral water
known as OMI ERO (sacred water/herb water). Collection of herbs is usually done in the forest or a
field. Before any plants are taken, a prayer is made to Osanyin, explaining why the priest is in the
deity’s abode, what herbs the priest would like to take and what the herbs will be used for. Offerings
of money, kola nuts, and gin are usually made.
So sacred are plants to the Yoruba and their spiritual descendants that many of the herbs have their
own sacred songs. In the making of OMI ERO, for instance, the priest will sing these ancient songs
over the herbs as they are being used. With these sounds the priests become imbued with the ASE in
their own voices, as well as serving to remind the herb of the qualities that they bring to the sacred
rites.

So perhaps the next time you find yourself in a field of “weeds,” you might remember that each has
a quality that can either heal or curse. Each is known to Osanyin and perhaps, after calling his name
and praying to him, you might hear his birdlike voice gently instructing on their use.

PRAYER TO OSANYIN:

Gentle, easy lift


Cool headedness
Walnut shell cut the dog’s mouth
Herbs is a child of the morning
Medicine is a child of the morning
Greeting Herbs (Greeting Osanyin)

thehomeofsucces@gmail.com

whatsapp 08027449908 or 08064941611


also available on facebook use my email

Posted by Baba ogbagba at 01:38 1 comment: Links to this post

Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest

Labels: ___OSANYIN: Lord of Plants__

Monday, 23 March 2015


THE USE OF HONEY ENGLISH LANGUAGE
1. EYES SCRATCHING; Mix white Onion with Honey and drop it into your eyes.

2. STOMACH PAIN; The person that has stomach pain, mix ground bitter leaf with Pure honey use
two table spoon after meal.

3. WOUND; Grind Bitter leaf with Pure Honey rub it.

4. CHILDREN TOOTH-ACHE; Mix lime juice, with honey , give him one spoon 3 times daily.

5. TUBERCULOSIS; Grind ginger atale,salt, Garlic and Bitter- Kola use them with Pure Honey use table
spoon 3 times daily.

6. SLEEPLESSNESS; Drink honey every night.

7. MENSTRATION PROBLEM; Use 4 tablespoon of honey of honey 4 times daily.

8. RHEUMATISM; Grind Bitter leaves with Pure Honey use to rub it and take 2 tablespoon 3 times
daily.

9. WEEK LOW OR BOIL; Grind Bean, mutter, with Pure Honey use it to rub the place.

10. ULCER; Use 3 spoons of honey early in the morning 1 hour before breakfast.

11. SEMEN BOOT (Fun ato kiki); Mix one egg with

5 Tablespoons of Honey . use it immediately.

12. ASTHMA; Mix snail water (Omi Igbin) with Honey .Usage . ADULT 3 Tablespoons 3 times .
Children 1 Tablespoon 3 Times.
13. PILE; Grind Saint Leave (Efirin) Lemon juice mix it with Pure Honey . 2 Tablespoons 3 Times daily.

14. EARACHE; Get warm Water with Small Salt and mix with Pure Honey . Usage. Put a drop inside it.
15. MOUTHACHE; Mix lime juice, Salt with Pure Honey use it to wash your month 3 times daily.

16. MEASLES; Grind Bitter leave with Pure Honey use it to Rub the body and take 2 tablespoons full 3
times daily.

17. STOMACH PAIN AFTER DELIVERY; Use 2 spoons Honey 3 times daily.

18. BED-WETTING; 2 teaspoon of Pure Honey every night.

19. COUGH; Mix Honey grinded bitter kola


(OROGBO ) use one spoon 3 times daily

20. Always use honey to drink pap (OGI ) or TEA.

21. RED EYES ; Use pure Honey 2 times a day.

22. RUNNING STOMACH; Ground Cucuribitaasess


( EWE EJIRIN) together with Honey and use 3 times daily.

23. DIABETES; Water from Bitter leaf mix together with Pure Honey and use it 3 times daily.

24. STROKE; Mix your urine with Pure Honey and take 3 spoon morning and Night.

25. HYPERTENSION; Ground Garlic with Pure Honey and take this 3 spoon Morning and Night.

26. MANPOWER; Use Unripe plantain, boil one with


Pure Honey.

27. BLOOD MEDICINE; Ground Bitter-leaf and Pure Honey and use 3 spoon 3 times daily.

28. RUNNING STOMACH; Mix salt together with Pure Honey and use 3 spoon 3 times daily.

29. SKIN SMOOTHEN; Mix Pure Honey together with coconut oil and rub it on your body.

30. FOR SHAVING; Mix Poplitionaces (ETU ) with Pure Honey and rub it after shaving.

31. SKIN DISEASE; Ground graminces (eru awonka) and Sulphur (IMU OJO) with Pure Honey and rub
it on the affected parts of the body.

32. WORM; Mix salt and lime juice with Pure Honey and use 3 spoon 3 times daily.

33. IRREGULAR-MENSTRATIONS; Grand GARLIC and mix it with lime juices and Pure Honey and use it
3 times daily.
34. TYPHOID FEVER; Grand Garlic mix it with egg and Pure Honey and use 4 spoons 3 times daily.

35. FIRE BURNS; Use Pure Honey to rub the affected part.

36. CHILDRENS RASHES; Ground Gramicees (ERU AWOKA) Poplitionazees (ETU) Sulphur (Immi OJO)
with Pure Honey and rub it to affected part of the
body.

37. BLOOD; Mix Lime juice and Fresh egg and Pure Honey and use 3 spoon 3 times daily.

38. BODY HEAT ; Get liquid from Bitter leaf and mix it with Salt and Pure Honey and use 3 spoon 3
times daily.

39. STOMACH-PAIN; Use Salt and Saint –leaf (EWE EFIRIN) together with Pure Honey and use it 3
spoon 3 times daily.

40. GONORRHEA; Lemon juice mix with small mutters and Pure Honey and use 3spoon 3 times daily.

41. DIABETES; Use Pure Honey to drink Pap or Tea.

42. Starting from 40 years, use Pure Honey to drink Pap or Tea and it is for good health.

43. To reduce fatness ; Use Corn –leaf as a tea with Pure Honey .

44. FOR OLD AGE; Use Pure Honey to drink.

45. FOR FAMILY HEALTH ; Use Pure Honey with Oda Herbal Tea. It will give you strength and energy.

46. HYPERTENSION; Use Pure Honey together with Oda Herbal Tea.

47. WEIGHT REDUCTION ; Take Pure Honey mix together with boil Corn –leaf and drink.

48. HEADACHE; Lime juice with Pure Honey and take 3 times daily.

thehomeofsuccess@gmail.com
call or whatsapp 08027449908 or 08064941611
also available on facebook use my email

Posted by Baba ogbagba at 05:47 2 comments: Links to this post

Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest

Labels: THE USE OF HONEY


VARIOUS WAYS OF APPLYING NATURAL HONEY

VARIOUS WAYS OF APPLYING NATURAL HONEY

1.EAR PROBLEM: Put small salt and honey in hot water when it cools put 2 drops into the ear before
going to bed.

2.HAIR BREAKAGE: Mix honey with olive oil place it on fire to warm it, then treat your hair with it
then wash after 10-15 minutes by using warm water.

3.TYPHOID: Mix Aloe-Vera juice with garlic juice then put lime juice and honey 3-spoons in the
morning and evening.

4.RHEUMATISM: Grind galic,lime


juices,honey,palm kernel oil, mix them together properly, be using it to massage the affected part of
the body after you must have used hot water to press the part then take two spoon before going to
bed.

5.FOR GOOD ERECTION : Slice three big onions add small water then cock for 10-15 minutes when
the onion is soft, extract the juice, mix with honey
of the same quantity, then cook again for 5-10 minutes. Then store it in a bottle when it cools 2-3
spoons in the morning and evening after meal.

6.COUGH: Grind dried bitter kola and mix with honey, lime juice, palm oil, 2-3 spoon morning,
afternoon and evening.

7.BOOSTING OF SEMEN: Mix five spoon of honey with one raw local egg, one spoon of grinned
ogbono – Irvingia gabonensis(GOOGLE), if you like put milk take it once do this just three times in a
month is enough [that is a booster for you].

8.ASTHMA: Mix snail water with honey. One spoon in the morning and evening.

9.IRREGULAR MENSTRUATION: A week to your period be putting Aloe-Vera juice and honey in hot
water for drinking one small cup in the morningand afternoon.
10.BURNS: Apply honey to the affected part immediately to avoid wounds.

11.WOUND: Wash the surface of the wound very well then be applying mixture of honey and aloe-
Vera juice.

12.ULCER: Take three spoons of honey everymorning, an hour before breakfast.

13.BEDWETTING: Squeeze bitter leaf and scent leaf with water, with the addition of salt, then
remove the water and and mix honey with it a cup not more than a tin of milk in the morning and in
the evening before going to bed.

14.ABDOMINAL PAIN AFTER DELIVERY: Add 3 spoon of honey to hot water and use it to press the
stomach of the woman and take 2- spoons of honey 3 times daily.

15.HYPERTENSION: Use snail water, honey, lime juice to cook garlic, Ginger pepper ,for 10-15
minutes, then remove the liquid. Use 2 spoons after break-fast.

16.SLEEPLESSNESS: Mix five spoons of honey with one cold pure water then take once and go to bed.

17.CATARRH: Mix lime juice with honey 3 spoons in the morning, afternoon and evening.

18. MEASLES: Extract bitter leaf juice, mix with honey, palm oil and alcohol use it to rub all the body
and take two spoons in the morning and night.

19. TOMMY TUCKING: Take a glass of warm water with honey and aloe-Vera or garlic.

20.WITHLOW: Honey, palm oil, lime juice with grinned bean[5-10] mix them together properly be
applying it on the affected part by the help of cotton wool.

thehomeofsuccess@gmail.com
call or whatsapp 08027449908 or 08064941611

Posted by Baba ogbagba at 05:36 2 comments: Links to this post

Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest

Labels: THE USE OF HONEY..

ANIMALS AND THEIR VARIOUS YORUBA NAMES


ANIMALS AND THEIR VARIOUS YORUBA NAMES
Cobra - Ọka
Ox , Bull - Malu
Spit - Snake
Snake -Ṣebe
Dog - Aja
Grass cutter-Ọya A scaly animal/Pangolin -Akika
Crocodile -Ọoni
Alligator -Ahọnrihọn
Pig -Ẹlẹdẹ
Vulture -Igun, Gunnugun,
Wood-Carrier -Arigiṣẹgi
Hawks - Asa
Palm Bird -Ologiri
A species of Bird -Olofẹrẹ -
Sparrow -Ologoṣẹ
Peacock -Ọkin
Squirrel -Ọkẹrẹ
Rabbit -Ehoro
crickets -Okinrin
Pouch Rat -Okete
Wild Goat -Edu
A species of Deer -Ekulu
Shark -Akurakuda
Rat/Mouse -Eku/Ekute
Earthworm -Ekolo
Sing Bird -Ẹyẹ-Orin
Partridge -Aparo
Horse -Ẹṣin
Donkey -Kẹtẹkẹtẹ
Camel -Rakunmi
Ass -Ibakasiẹ
Bat -Adan
Pelican -Ẹyẹ-Ofu
Water-bird -Osin
Dove -Adaba
Viper -Paramọlẹ
Sea-Gulls -Pẹju-pẹju
Yellow-haired Monkey -Sọmidọlọti/Oloyo
Sea-Bird -Yanja-yanja
Mosquito -Ẹfọn/Yanmu-yanmu
A species of Beetle -Yanrinbo
Raven -Ẹyẹ-Iwo
Snail-Igbin/Aginniṣọ
Freshwater Snail-Iṣawuru
Steer -Ẹgbọọrọ-Akọ Malu
Trout -Ẹja
Buffalo -Ẹfọn
Monkey-Ọbọ .
Ape -Ẹdun
Lizard-Alangba, -
Lobster-Alakasa
Boa-Constrictor Ere
Boar Ẹlẹdẹ-Igbo,
Gorilla, Baboon -Inaki, Inoki, Iro
Chimpanzee - Elegbede
Phython-Constrictor -Ojola
Electric Fish -Ojigi
Scorpion -Ojogan/Akeekee
Toad -Kọnkọ
Antelope -Egbin
Tick/Flee -Eegbọn
Hippopotamus -Erinmi
Rhinoceros -Ẹranko bi Imado.
Reynard (Fox) -Kọlọkọlọ
Hyena/Wolf -Ikoko
Giraffe -Agbanrere
Cow Abo-Malu
Crab -Akan
Wild Pigeon-Oriri
Porcupine -Oorẹ, Eerẹ, Ojigbọn
Black-Ants -Tanpẹpẹ
Centipede -Tanisanko
Millipede -Ọkun
Frog -Ọpọlọ
Chicken-Oromọ-Adiẹ
Nocturnal Animal-Ajao
Hound-Aja-Ọdẹ -
Elephant-Erin/Ajanaku
Sheep-Aguntan
Ram-Agbo
Woodcock -Agbe
A species of Woodcock-Aluko
White-feathered Bird -Lekeleke
Chamelon Ọga, Alagẹmọ
Crane-Bird -Akọ -
Parrot -Odidẹrẹ
Ostrich -Ogongo
White-Ant Ikan, Ikamudu
Tortoise-Ijapa
Tiger-Ẹkun
Lion-Kiniun
Pigeon-Ẹyẹle
Pig/Swine Ẹlẹdẹ
Eagle-Idi .
Guinea Fowl-Awo
Guinea Fowl-Ẹtu
Guinea Pig-Ẹmọ-Ile
Jelly-Fish-Ẹja-Odo
A species of Bird-Afẹrẹgbojo/Afe-imojo
Spider-Alantakun
Butterfly-Labalaba
Bee-Oyin
Cockroach -Ayan
Cricket-Irẹ
Crab -Akan
Housefly-Eṣinṣin/Eṣin
Gnats -Kokoro - Ojuọti
Wall-Gecko - Ọmọnle
Mouse - Eliri
Colt Young Horse - Agodongbo
Woodpecker - Akoko
Palm-Bird-Ẹga
Insect-Ipin
Red-Ant-Abonilejọpọn
Civet-cat-Ẹta
Zebra-Kẹtẹkẹtẹ-Abila -
Owl - Owiwi
Lice - Ina-Ori
Bed-bug -Idun
Leopard-Amọtẹkun
Hind Abo-Agbọnrin
Cat-Ologinni
Turkey-Tolotolo
Swallow - Alapandẹdẹ
Kine - Abo-Malu
Stallion - Akọ-Ẹṣin
Gadfly-Iru, Eṣinṣin- N la
Duck - Pẹpẹyẹ
Jackal - Akata/Ajako
pelican -- atiele
thehomeofsuccess@gmail.com

call or whatsapp 08027449908 or 08064941611

Posted by Baba ogbagba at 05:35 1 comment: Links to this post

Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest

Labels: ANIMALS AND THEIR VARIOUS YORUBA NAMES

DIFFERENT BETWEEN OSO... OSHOLE... & AWURE


DIFFERENT BETWEEN OSO... OSHOLE... & AWURE

OSO... also called money rituals or blood money. Some people don't know the differences between
oshole and awure.. oso is what they use human being for the preparation of the wealth... and some
of the results of oso it's. . E.g.. to see money inside big pot by chanting the name of the person you
used. The money will dissappear inside the pot within some hours. And also can be used by sending
ghost or spirit of such person to goto the bank or anywhere to bring u huge money.. or carried
calabash on top of such person head and be picking money And it has big repercussions like. E.g.. not
live long. Suddenly death. .earing ghost voices anywhere you go. And some people's got mad
immediately they did it. Because it's not compatible with his star......
beware of wicked people they will told you that it's basiri ( good fortune ) or oshole ( wealth booster
) what u have to notice from their talk. It's to know how it will work for you. Once u detect how it
will works. So try and run for your life....

OSHOLE or AWURE NLA or AKO AWURE or OSHOLE TUTU ( wealth booster) this is the best thing
to do it has no repercussions and powerful than AWURE.. any OSHOLE it's require ANIMALS AND
SOME LEAFS OR BARKS no human blood shed.. it's good for those who is looking for progress
especially the person that has the particular job that is doing. Oshole can not drop money in front of
you oo.. it's not a magic or miracle it will just boost you work and your progress.
AWURE ALSO CALLED APEDE. ... Awure it's good it's also work for progress of anything human being
is doing.. it's has no blood shed of HUMAN BEING or ANIMALS. It's only has some leafs , barks .. and
anything that has no blood.. though some required Ants.insect..e.t.c no repercussions

N:B... my advice for people's that is reading this blog. Is to be careful of all those uselss people that
need you to run business. Everybody need money. Why can't he do it for himself.. so be careful
thanks.....

Thehomeofsuccess@gmail.com
call or whatsapp 08027449908 or 08064941611

Posted by Baba ogbagba at 05:33 5 comments: Links to this post

Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest

Labels: DIFFERENT BETWEEN OSO... OSHOLE... & AWURE

THE SECRETS OF MEDICINE ( FREE & 100% CONFIRMED )

OGUN AJEOGUN
Ewe Ela, Atelewo inaki, oko ataare kan, ewe aAjeobale, epo obo ao jopo ao fi sin gbere yii orun
owo mejeji ka . please do this first before doing all my medicine to make it work for u

IMULE AWON AGBALAGBA KIWON MALE DIWA LOWO-------


igbin apinu kan,oga gbigbe kan,eku asin kan,ewe egele,yerepe,ewe kileofimise,ewe ajeobale,opolo
gbigbe kan,odidi atare kan,aojo papo aolo kuna,aote ni osa meji,aope OHUN RE--igbin kiise eran taye
nje,oga kiise eran apata,bi abamu opolo lodo ti koba jo konko,amansole ni,eyin eleye e gbe mi ju
sile,e je kinri aiye temi se,agbe sole ni tewe egele,akopada niti yerepe,aje kan ki gboju koje eku
asin,aje kan ki gboju koje oga,aje kan ki gboju kobale igi ajeobale,ki emale ba lemi mo,modi igi
ajeobale emi--omo-- tidi ewe kileofimise loni-adua.aomafi epo pupa la lalale.

OGUN ISOYE
Ao waa KuluSo meje, koriko ti esin jeku meje, igori aseseyo mariwo ope, ikodie kan, ebose akuko
adie ati irun abiya adie naa, ao wa lo be ogede abo, ao fi ataare aja kan le lori, ao re ogede yen pelu
ataare yen ao mun wale, ao jo po, ao maa fi epo pupa laa ni araro fun ojo meje ki ato so oro si enia
kankan

ISORA /AGBELEPOTA TODAJU GAN..


....ORI AWONRIWON KAN,PATAKO ESIN,ISU OGIRISAKO,ODIDI ATARE KAN,AOJO PAPO AOLO AORO
SINU ADO ATO KAN,AOMA BU DIE SOWO PE OHUNRE,EJIOGBE NI IFA RE.....OHUN RE....ORI NI
AWONRINWON NI TIFI PE LAIYE,OKO NI AGBE NFI ISU OGIRISAKO SI DI EEMI,KUTAKURA KUTAKURA
AIYE NI FI ILE SILO,KI GBOGBO AWON OTA MI,KIWON FIMISILE SAIYE LO,EMI.....OMO.....NI KINREYIN
AWON OTA MI.

EYONU ASIRI BIBO

----epo obo,aogun pepe,aoda sinu ape,aidan pupo aose lelori,odidi atare kan,aojo po aomafi omi aye
lo lararo pelu ofore---oni dandan ni taidan3x bokunrin ori owo bobinrin ori owo bomode ori owo
bagba ori owo,dandan niki emi----omo---ri owo nlanla loni,ki okunrin ati obinrin ma gbe owo nlanla
wa fun emi----omo----.ti oba wuwa alete ejiogbe si die ti afe lo,tabi ki ape ofore nikan si ki asi
lo,odaju gan

OSHOLE NLA
1. Ori Inaki kan 2. Ori Ekun kan 3. Odindi Eiye Okin kan 4. Ori Ere Nla kan ati Ase re 5. Opolopo Ewe
Orijin 6. Odindi Ataare 16 Ao jo gbogbo re po... Ao da opolopo ewe Orijin yen le lori ao wa jo dadaa..
Ao lo kunna. Ao pa Adiye Akuko kan Eje re ni ao fi pa ara Igba ti ao da Ejo oogun yii si.. Eni ti o ni
ogun yi ko gbudo je ninu Adiye yen... Ao ma fi Oti Schinap lo Ogun yi ni dede ago 1:00am oru ni ojo
meta meta... Ao gbudo ba Obinrin lo po larin Ojo Meta lehin igbati aba lo ogun yen tan.... Obinrin ti o
se unkan osu ko gbudo fi owo kan ose yen oo

Aworo

Egbo orogbo, eru, ako okuta, omidun ogi, ao fi iyo tele inu oru, ao ko okuta ako si, ao ko egbo orogbo
le, ao da omi ogi lelori

OGUN ALEKO TO DAJU

Orogbo, obi gbanja, etu ibon, ako okuta, esuru funfun, ege ti a nfi ngun iyan je, ogede agbagba dudu,
agbado, iyere ao fi sugar die si ao gun po ao maa fi foko tutu mu.

Awure owo/OSHOLE OWO


Ori aja gbigbe kan. #100 tuntun ao ki si eti otun. Ao wafi #20. Ao wafi #200 we igbo ao kisi enu ori aja
na. Ao wafi ewe sawerepepe su osuka ao gbe ori aja na si. Ao wagbe gbogbo re sinu agbada ao fi
odidi atare kan. Ao jo papo ao mafi oti schinap lo laro laro

Aworo

Ewe ogbo meta, ao gun po mo ose dudu,ao le mo ara amu omi, ao ma po mole lararo

.Awure owo gbigba

Afara oyin, ipe ire, odidi atare kan, ao jo po, ao ro sinu igo, ao ma bu sinu ipara diedie.

Eyonu aye.

Eepo obo, imi ojo, iyere, ao lopo, ao da sinu adin eyan, ao ma fi para.

Apa mowo owo.

Atare aja, korofo tadie pa ku, ao lo ti yoo kuna, ao fi sin orun owo mejeeji yika.

Ariran ounje.
Irula didi kan, ataare odidi kan, ao jo po, ao fi sin orun owo mejeeji yika

Afaro./ AWORO
owo ati ese elede mererin,ewe ahoyoyo ao ko tele isasun,ao ko owo ati ese elede ye si lori,ao wa ko
ara eran elede ye ti koni egungun rara si lori,ao de pa,ao lori mole ninu shop tabi ile ise nla.odaju

ROPAROSE ( STROKE )
eku asin 11,atare odidi 11,ori oka 6,oga gbigbe 11,ao wa gun ninu odo ti yoo kunna,ao gbodo fi
owo ko o,ao wa gun ni agunmu,ao ma fimu eko gbigbona sibi kookan.

OGUN TI OBINRIN KO BAA LOYUN


Eku Emo kan, Ewe Patanmo, Emo Agbo, Emo Ajao, Odindi Ataare kan ao jo ogun yii papo, Obinrin
naa yio maa fi foko tutu mun ni ojo keji ti o baa pari nkan osu re...... Ko gbodo ri Okunrin fun ojo
marun .

ATOSI
.Ao toju Bara nla kan, ao wo gbogbo omo inu re danu, ao be epo ara re pelu ao waa ge si wewe sinu
Ogidi emun tabi omi Oronbo ao daa Kaun bilala si.. Lehin ojo keta ni ao mamu ni Gas kekere kookan
lararo.

AYETA IBON
Ewe Bomubomu gbigbe 16 . Eyo Atare 16 . Ewe Owo Gbigbe 16 ao lo papo, ti o ba je wipe Awon ewe
yen je tutu, ao sa si ategun a gbudo sa si orun o, ao lo kunna daadaa, ao fi sin gbere lati isale ese waa
de arin ori. Odaju.

Aworo.
Ifun akuko adie, ako alangba 1, ewe sawerepepe, odidi atare kan, aa wa ko gbogbo re sinu akeregbe
kekere, a awa da iyo le lori, a wa fi aso funfun di lenu, a wa so ko si enu ona abawole.

Awure ose itaja.


Igo oyin gidi kan, lofinda bintu merin, ori osin, ori ere, ose dudu, awa gunpo, ao ko si inu awo
tanganran olomori, ao wa we laso funfun, ao wa ma fiwe lararo.

Osole.
Ipe ire mesan, odidi ejo kan, odidi awo lili kan, padi atare kan, a jopo aa lo kuna, a ma fi foko mu
lararo.

AFUNJE
Awo Ewure dudu, Ewe Amunimuye, Irun Abe, ekana owo mewewa ati ese mewewa, irun Ipenpeju
die, irun Ori die ao jo pelu Odindi ataare kan, ao maa fun enia je.

Ise anu.
Obi ifin kan, a age si 201, obi pupa kan, a age si 201, eyo atare 201, ao fi omi omu po papo, ao ro sinu
ado ijamo kekere, ao fi awo ijimere ran, aa wa ma fisapo.

Awure owo.
Oga aye, tagiri, igbe ewure to bimo re, igbe aguntan to bimu ri . ose dudu 300, ao gun po, ao
ma fiwe lararo:
(gbolohun re) “boro boro lewure su mi re, boro boro laguntan su mi re, ojojumo ni tagiri nka owo tie,
aba ti alagemo bada ni orisa oke ngba, mo daba ki won ma mu nla nla wa fun mi loni.

Awure owo.
Egbo iroko, egbo ipon, karagba idi esu, ose dudu, ao gun gbogbo re po, ao ma fi we lararo.,
gbolohun: “ipon loni kan pinre temi fun mi loni, iroko loni afaro.

ATUDE RIRISE BI WON BAA DE OWO ENIA


Ao waa Odindi bara kan ao gesi 16 ao ko tele ape ao wa gbe ori Olongbo tonirun le lori ao fi odindi
ataare kan si legbe ao jo ao popo ma ose dudu ao mafi we owo wa mejeji pelu Gbolohun yii Iba
akoda iba aseda iba eyin aye ewa tumi nide edi kidi bara ki gbogbo ide owo mi kotu danu ki owo
mi bere si ya fun owo nla nla ki magba ise kekere owo nla nla, ao maa se adua to ba wuwa si eyan
pupo lelo ose
Awure.
Ori ikun kan, ori agbigbo(dododo) kan, padi ataare kan, ao jopo ao ro sinu ado ide. Lilo re> Ao bu
die si owo ao pe ofo re so ao da senu ao fi hot sin Ofo re> Agbigbo oma kuu eru o (3ce), ikun(remi)
loni ki efi owo owoyin kun owo towa nile(mido), ikun loni ki efikun owo mi

KOKORO OMUN OBINRIN


Ewe Egele, ireke, ogede wewe ti ko gbo, eru, epo pupa die ao fi omi orombo si ao waa se ao maa
fi we omu naa ao si maa mun ni ibe

OOGUN OUNMO TABI ARIRAN TODAJU


Ao wa Eyin ororo kan ao soro kelekele si eyin naa, iru unkan ti afe lofun, ao wa loja ewe bomu bomu
eyo mefa ao fi we eyin yi ti koni han sita raaraa ao fi unkan di daadaa ao wa dana edu sile ao wa
gbekana bi igba ta nsun eran suya ti o baji na ao bo eyin naa ao je tabafe ki iseyi lagbara daada ao se
lemete larin osukan, opolopo kan ni a maa ri loju aye ati orun pelu

EYONU AWON AGBA TODAJU


----eyin adie ororo 3,aofi tele ape,aoko epo obo lelori,odidi atare kan,ewe anu,ewe orijin,ewe
ajeobale,ewe owo,ewe oyo,aojo gbogbo re po,aolo iyo mo,ogbe iyonu ni ifare--OHUN RE---
haa!3x,olukibinu olu 3x,osinkibinu osin 3x,obajalaye ki binu oba ajalorun 3x,oba ajalorun ki binu oba
ajawole 3x obajawole ki binu oba aja dobiridobiri 3x oba aja dobiridobiri ki binu oba atiledilele 3x
otoku ilu ki binu ko iyosile komaje 3x oso ki binu kiwon ko iyo sile kanmaje 3x enikan ki fi oyin senu
kotu ito 3x beni enikan ki fi iyo senu ko pose 3x mulobe ni oruko ti ifa npe iyo,yowon ninu gerege ki
omode mayonu simi,ki agbalagba ma yonu simi------emi-omo----lati oni lo.eyiti abafe dasinu oyin
laote ni ogbe iyonu ooo,aomala lararo

please do MY AJEOGUN first, before doing all my medicine to make it work for u

Do it is working perfect

thehomeofsuccess@gmail.com
call or whatsapp 08027449908 or 08064941611

Posted by Baba ogbagba at 05:31 34 comments: Links to this post

Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest

Labels: THE SECRETS OF MEDICINE


VARIOUS TYPES OF ASE ( COMMAND ) AND THEIR USES.
VARIOUS TYPE OF ASE & THEIR USES.

This type of ASE could be Either God given (born with) or Acquired. The
acquired one could further be divided into the following.

1. Physically Prepared (Herbs & Formulas)


2. Passed on (Psychically, through touch, swallowing of Objects, a gaze, or
other methods)

3. Developed through austerities, observances of fasts and penance.

4. Regular practice of a particular process ASE could be in * the form of the


spoken word, * the nature of an object (eg. the poison of a snake is its ASE and
its nature to sting), * aura that an entity posses or anything peculiar to a
certain character. Herein I focus solely on the spoken word & how it is
developed the African way, through the Yoruba mystical system or practice.
Based on my definition of ASE I will state the major charms that represent ASE,
its process of preparation, how they work and their degree of potency. We
have the:

1. Mayehun

2. Afose

3. Gbetugbetu

4. Olugbohun

1. Mayehun Means "Refuse me not" -- It is used when you want a person to


grant your request. It could be used in wooing a lady, request for money from
a neighbor, a tight fisted friend or a wealthy man. Note it must be in a polite
manner. There is a simple incantation that goes with some Mayehun formulas.

. 2. Afose Afose means "Speak and come to pass" or "Speak and happen." This
is a quite advanced form of ASE. It is usually prepared with black soap and put
inside an animal horn; it could be a Ram's, Cow's, Antelope etc. There are
various formulas and some are quite powerful. However note that it is not a
general rule that all Afose be mixed in Black soap and kept in horns. Whatever
is spoken might happen immediately or later in future depending on the
potency of the charm or the nature of issue the ASE is addressing. Our
forefathers possessed some Afoses that they used to control nature elements
like rain, fire etc. I personally had one that I used to stop a car from starting; I
have personally seen one that was used to dry up a very big tree in three days.
The tree was cursed with that Afose. With the Afose you could place a curse
(Epe) on any object. A chameleon is usually one of the ingredients that plays a
prominent role in its preparation, at times the head of a black cobra is used
too.

3. Gbetugbetu is inform of black powder inside gourd or ado ide . This is more
of a hypnotizing charm. The person under the spell doesn't really know what he
is doing. It is used in compelling people to do the most impossible things.
Things they would naturally not do or refuse to do. It is somewhat difficult to
prepare but there are some simple formulas too, however they also vary in
degree of potency. The powerful ones that I know has in it as part of its
ingredients is the sand of a grave person. To illustrate its power I would narrate
an incident that happened which was manipulated by the use of Gbetugbetu.
Our forefathers used it when they were attacked by a gang of thieves; they just
commanded them to fight (each other) or hand over their weapons.

4. Olugbohun The "sound picker." It is believed to be a powerful spirit that picks


whatever is said and makes it happen, if not immediately very soon. (Even if u
mistakenly curse your children out of frustration.) Now this is not a genie that
will drop things physically in front of you, like food, wine and a flying carpet.
However it will create a situation that will cause your request to be met. It is not
kept in the house but far away in the bush and its consulted only once in a
while. It is very powerful, and can be used in the arts and practice of black
magic, if the owner is a bad person.

You might also like