You are on page 1of 7

Save

Agbara Aye Awo Igba

Uploaded by Ahmod Yusuf on Sep 15, 2022

 100% (5) · 4K views · 81 pages


Document Information 
Nice
Date uploaded
Sep 15, 2022
Save
Original Title
 
AGBARA AYE AWO IGBA

Copyright
© © All Rights Reserved

Share GBEWA OLOJO MEJE ONI #2,000,000,00.PERE.


this document
awon eroja re niwonyii.
Ologbo dudu kan
Eye kowe kan
Facebook Twitter
Eye akala meji
Eye oobee 7

Odidi atare meje 7
Email
Ikoko tuntun kan
Sere tuntun kan
Asofind
Did you funfun opa meji useful?
this document
Akeeke meje 7
Ao wa de ologbo dudu yen monle fun ojo meta
kato beere ise yii kia fi mon boya ologbo dudu
yen je original (gidi) leyin naa ni ak wa jo
awon eroja wonyi papo dada,ti a ba n jo lowo
Is this content
oju meje inappropriate?
kogbodo ri,ti Report
a ba jothis
tanDocument
ao wa lo
kuna dada ao wa da si ona meji ao fi iyo
onigun merin po idakan ninu re dada,ao wa
da sinu seere yen, ao wa gun idakan toku mon
ose dudu .
Ao wa gbe seere yen kale ti yio joko si igun
yara wa,ao wa ta aso funfun yen sibe.
LILO RE:-ao ma fi eko elewe fo tinu seere yen
mu ni Dede ago kan oru gangan nio ko gbodo

le raa.
FUN ENTI O FE MA WE:- LILO RE
ao ma we ni Dede ago kan oru pelu.

AJESARA TIWON BADA OGUN SORI IJOKO


FUNWA TABI SINU BATA WA
alakan nla ooye kan tope dada,aoko ewe ogbe
ori akuko tutu le lori mole,aojo papo pelu
odindi atare kan,ao mafi omi loo
OGUN ANASARE TONI AGBARA TODAJU
Ao Wa Oruka Elelo Kan Ao Tibo Idi Adie to n
saba lowo toti ye gbogbo eyin Inu re tan,ijo to
ba ti ko
omojade ti ko wole pada,ao wa Fi ori ati epo pa
owo wa,ao lo yo,lobatan
AKIYESI-gbogbo igba ti a ba ti fe lo oruka naa
aoma fi ori ati epo pupa pa owo

OGUN TI WON BA DA OGUN SINU SHOP ABI


ILE ITAJA WA TODAJU.
Ao lo wa omi ti won fi we oku pelu ewe egusi
bara tio so sori akitan,omi yen laofi gbo ewe
yen ao fii omi naa won Ile naa.lobatan

AGADAGODO TI AFI NTU EJO KA TABI WON


BAWA DU ILE TABI OHUN KOHUN.
Ogan ti owa larin oko ao bu die,hariha igbado
ao sun,iha elepo ao sun,ao sun won ni ototo.ao
toro ogunso,ao wa era yio po,ao lo ogan yen.ao
da gbogbo e po.ao dasinu efe owu.ao fi le
kokoro ni eyin,ao wadi ni owu dudu ati
funfun, ao ran ni awo iki,ki atope ofore. Ao
yasi ni emeta.
OFORE
asugbe ni oloko nsu hariha-×3,akan ti ni oloko
nkan ogan-×3,ki iha logbe orona hagi-×3,toripe
rara lasoro eraa-×3,bi ologunso basu iseni efin
re npora si oju orun-×3,ki oro ti won nba emi l-
omo-l se yi ki oro na kopora-×3,iki kolo ki oro
na mole patapata-×3,ise niki won forijin emi l-
omo-l-×3 otan
Ti aba npa ofo yen ao mada oruko oni towun si
ati iya

ISORI/AKOYA
ao wa aso egun tororo,eni agemo,eku eliri
kan,odidi atare kan,awo agbonrin ti won nta
lori ate die.ao jo gbogbo e papo.ao ro sinu
sere,ao pa ako adie fun.
Lilore ao busi atelewo ao pe ofo si kia to dasi
eko mumu.

Ofore inu konbi egun ko yowo ninu aso×3,inu


konbi orisa koyo ese×3,inu konbi ode kopa
agbonrin ori ate ×3,eni ban binu emi langbaja
omo langbaja koba arare lodilodi.ase waa
Ao so ohun ti abafe si kato dasi eko

OGUN IWOSAN IKO ELEJE


Epo oruru
Eru awonka
Adi eyan
Ori
Epo pupa
SISERE:-ao Se lagbo ninu ikoko pelu omi ao ma
mu Ni sibi meji lararo ati sibi meji lale

IFERAN ONI KOKORO TODAJU....


Ewe amunimuye
Ewe awerepepe
Iru woro
Iyere
Ojulowo eja aro
Ao lo awon ewe yi papo mo iyere, ao fi se eja
aro kan je lepo niyo, ati iru, ao so agadangodo
kan sinu obeyi, ao se mo, ti o ba ti jina, ao so

sori osuka, to ba tutu, ao gbe aseje yi dani ni


ihoho omoluwabi, ao ma pe ohun re si ao wa
 je....
Ohun re......
Lamorin omo lamorin
Emi lamorin omo lamorin ni mon pe ooo
Ibikibi ti obawa kowa jeminihoooo
Sawerepepe kolope lagbaja omo lagbaja tiise
ayami wa funmi loni
Emi lagbaja omo lagbaja tiise okore ni mo n
peooo
Amunimuye walo bami mu iye lagbaja omo
lagbaja tiise ayami loni
Iyere walo bami mu iye lagbaja omo lagbaja
wasi odomi loni
Iyo loniki ki lagbaja omo lagbaja mayo momi
kakiri lojojumo
Aro loni ki lagbaja omo lagbaja maro momi
kakiri lati oni lo
Oroti moba baso ni kogbo
Tori wipe oro ti kokoro baba agadangodo so
niigbo,
Obe ti emi lagbaja omo lagbaja fejeyi kogbodo
duro si inumi, inu lagbaja omo lagbaja ni kolo
sokale si kia kia timoba tije tan......, ao wa so
ohunkohun ti aba fe si ao wa je obe na, leyin

na ao wa mu agadangodo na ao ti pa, ao lo ju
sinu odo nla haaaaa iseyi gbona
LILO RE: A o ma mu ni gaasi kan ni owuro
kutukutu pelu adua fun owo nla.
AKIYESI: Ti fanta yi ba ti nlole lori ise yi, a o
ma bu Fanta miran si pada

IFERAN ONI KOKORO TODAJU....


Ewe amunimuye
Ewe awerepepe
Iru woro
Iyere
Ojulowo eja aro
Ao lo awon ewe yi papo mo iyere, ao fi se eja
aro kan je lepo niyo, ati iru, ao so agadangodo
kan sinu obeyi, ao se mo, ti o ba ti jina, ao so
sori osuka, to ba tutu, ao gbe aseje yi dani ni
ihoho omoluwabi, ao ma pe ohun re si ao wa
 je....
Ohun re......
Lamorin omo lamorin
Emi lamorin omo lamorin ni mon pe ooo
Ibikibi ti obawa kowa jeminihoooo
Sawerepepe kolope lagbaja omo lagbaja tiise
ayami wa funmi loni

Emi lagbaja omo lagbaja tiise okore ni mo n


peooo
Amunimuye walo bami mu iye lagbaja omo
lagbaja tiise ayami loni
Iyere walo bami mu iye lagbaja omo lagbaja
wasi odomi loni
Iyo loniki ki lagbaja omo lagbaja mayo momi
kakiri lojojumo
Aro loni ki lagbaja omo lagbaja maro momi
kakiri lati oni lo
Oroti moba baso ni kogbo
Tori wipe oro ti kokoro baba agadangodo so
niigbo,
Obe ti emi lagbaja omo lagbaja fejeyi kogbodo
duro si inumi, inu lagbaja omo lagbaja ni kolo
sokale si kia kia timoba tije tan......, ao wa so
ohunkohun ti aba fe si ao wa je obe na, leyin
na ao wa mu agadangodo na ao ti pa, ao lo ju
sinu odo nla iseyi gbona

ADODUN ORI OKO


Eyo atare kan
Eyo kokoro Inu obi kan
Ao lo papo ao fi sin gbere kan soso sori oko wa.

OHUMO ARIRANOHUMO ARIRAN

OOYE EJA ARO IBILE KAN,KONKO OOYE


KAN,ORI OLONGBOOOYE EJA ARO IBILE
KAN,KONKO OOYE KAN,ORI OLONGBO
GBIGBE KAN,IYE AKALA KAN,ATARE KAN,ODI
 JIJO PAPO AO LOGBIGBE KAN,IYE AKALA
KAN,ATARE KAN,ODI JIJO PAPO AO LO
LEBU AO MAFI HOT LO PELULEBU AO MAFI
HOT LO PELU OFOREOFORE
OFORE:-OFORE:- BI EJA BASO LOMI ARILE
OMI,BI KONKO BASO LODO ARILEBI EJA BASO
LOMI ARILE OMI,BI KONKO BASO LODO
ARILE
ODO, BI OLONGINNI BA GAJA OJURE ATOLE
ATOKO,BI AKALAMAGBOODO, BI OLONGINNI
BA GAJA OJURE ATOLE ATOKO,BI
AKALAMAGBO
BAKU EGBERE A GBEODE ORUN MO,
EMILAGBAJA OMO LAGBAJABAKU EGBERE A
GBEODE ORUN MO, EMILAGBAJA OMO
LAGBAJA
INKAN TI AWON EYAN BA BAWA SI ODO MI
KIN MA MOINKAN TI AWON EYAN BA BAWA
SI ODO MI KIN MA MO

APASE OJU INA TODAJU


Isenare
Owo eyo tikoluju kan

Odidi atare kan


Sisere
Ao mu owo eyo mo owo sun lale ti
obadi ojo keji yio ti jabo , Ao mu Eo fi pamo Ao
ba obinrin abi iyawo yii
lajosepo ,Ao wa aso kekere kan
Ao fi nu oko wa ti aba ti setan pelu oju
abe obinrin yen , Ao wa ta owo eyo
yen sinu aso yen Ao jo lesekese pelu
odidi atarekan , Ao lo ebu re daadaa
Ao fi singbere si apa osi wa yipo ( bi
ifunpa ) ...Ofore...orun nigba towo
omode , orun nigba towo agba , ti oko
 bari obo apo tenu re le Ao wa
na owo osi yen si eniyan pe bami mu
ada , obe abi ibon owo re

*ASIRI OKIGBE TENTE LOSU NLE*


Isenare
Opolo ijokun oye kan
Oruka dudu lopolopo
Esuru

Ao ko oruka yen senu opolo yen ti yio wonu re


daadaa , Ao wa gbe opolo na sinu pot Ao wa
mu
isu esuru yen Ao ge si wewe Ao ko sori opolo
yen , Ao wa bu omi le lori Ao se ti yio jinna
daadaa..Lilore.. Awon toba fe lo oruka yii yio je
ninu esuru yen die die ka to ma ki oruka yen
bowo awon toba je isu yen ni yio ma lo oruka
yi

AKO IFUNPA ELEMI MEJI


Ako alangba meji
Eyo atare mesan
Orogbo kan
Egungun ajiyo die(otiye awon agba)
Aso akisa ori atan
sisere
Ao mu alangba mejeji ao ge ori won ,
Ao so ara wa danu Ao mu ori alangba
kan ao ko eyo atare mesan si lenu Ao
tun fi egungun yen ha lenu na , Ao wa
ta sinu aso akisa ni koko , Ao tun mu
ori ako alangba keji Ao fi orogbo ha

lenu Ao ta ohun na sinu aso akisa yen


na ni koko...Nb..sugbon awon koko
yen ko budo kan ra won oooo , Ao wa gbe
won sibi to ba gbona ki won le
tete le gbe , Akii sa sorun lehin tiwon
bati gbe daadaa , Ao wa we ni owu
dudu ati funfun , koko yen ko budo
kan ara won oooooo Ao wa ran ni onde bi
awo dudu ni ifunpa , ti ifunpa bawa
lara wa enikeni toba pade wa loju ogun
lati bawa jaa jinnijinni yio mu koni le se nkan
kan rara ati rara fun wa , kosi
eniti yio pade oku lona ti jinnijinni
koni mu , owo gidi niii , tiwon ba
yinbo fun wa kole bawa lai lai

AGBERO ARUMASO TODAJU


ISENARE
Isasun tuntun kan
Oruka ibile
Odidi atare kan
Ao ya gbe idaji laiti soro si enikan kan sinu
isasun

Trusted by over 1 million members

Try Scribd FREE for 30 days to access over 125


million titles without ads or interruptions!

Start Free Trial

Cancel Anytime.

yii Ao wa fi odidi atare kan si arin igbe na ,


pelu
oruka ibile to ba wuwa Ao wa fi awo lili bo
igbe na
mole ninu isasun yen , Ao wa jopo Ao yo oruka
yen...Lilore.. A ma ki oruka yen bowo tiwon ba
gbiyanju lati gbowo soke owo won yio duro
sibe ni,

AFOSE ATI EPE ELEWUJI ONIYO


Aobu iyo ibile Lori idi igi efinrin lowuro
kutukutu laiti soro so eyan,aofi owo gba ewe
efinrin na. Lemeta aowa bu iyo yen senu aowa
sepe wipe
Aosope ojoti efinrin bafi oju kan iyo ojona
niku,aotu ito iyona Sara ewe efinrin yen,aotun
se be bi emeta, aowa kuro nibe aolo Ile,aolo
sibe ni irole,aowa ja awon ewe ti oku sori
efinrin yen,aoko ewe na sinu ape,aogbe Ori ejo
ogbadu kan le Lori, isawuru nla kan le
Lori,atare kan le Lori,aojopo aopo lose dudu
aoko osena sinu iwo igala aofi ikoti baba ati
ikoti ide gun Lori
Lilore
Aoma yo awon ikoti won yi aofi ba enu
lemeta,aoso wipe ojoti efinrin bafi oju kan iyo
ojona nilo sorun 3*,enu ejo ni ejo finpe oro
3*,ojoti isawuru bafi ojukan odo niba odo lo 3*

ASIRI TAFINMU OLE TODAJU


Omo ologbo tio laju kan
Ikoide kan
Aso waji dudu
Owu dd ati ff 
Sisere
Aogbe ologbo yi sinu aso waji,aowa fi ikoide
kan le lori,aowa fi aso na wepo dada looye bee
nio,aowe lowu dudu ati funfun aolo ri mole
siwaju ile wa

ASIRI ATAMATASE ASETA TAPA OTA KONI


KAWA,TAOFI BLADE DANWO.
ELOWA ENU OPIRI DIE
PONMO EOGE SI 16
ATA IJOSI 16
,AOWA LO GBOGBO AWON KINIYEN FISE
,PONMO NA JE LEPO NIYO AOWA SO
SORI,OSUKA ASO FUNFUN,LEYIN NA EOTU
BLADE META TABI IYEKIYE SIWAJU YIN,EOWA
 JE ASEJE NA LAISORO,LEYIN EYI,EOMU
MARAYA DIE LE LORI EOWA MAJE BLADE

AGBAKO ASIRI ORUKA TAFIN FO OTAWA LOJU


 

AAYAN MERIN
ORUKA EYIKEYI
SISERE.AOLO INU IGBO KAN,AOKO AWON
ORUKA YEN SI ILE NLE,AOWA KO AWON
AAYAN NA LE LORI,AOWA YA IGBE IDAJI LE
LORI,AOFI SILE FUN 3DAYS LEYIN EYI HMM
AOLO FI IGI KO KURO NIBE,AOWA SA SINU
ILE KOGBE,OORUN KOGBODO KAN ISEYI
O,AOWA LOWA EWE OLUGANBE TUTU,OHUN
LAOGBO KAFI WE OWO WA DADA KI ATOLE
FI OWO KAN ASIRI YI,
LILORE
NI OJO TI EBAFE LO EOFI EWE OLUGANBE
TUTU WE OWO YIN NA O HMM EOWA KI
ORUKA NA BOWO LOBA OTAWA,TI OBA TIN
LO AONA IKA AARIN TI ORUKA YI WA SI OTA
WA,AOWA WI AWON GBOLOHUN WON SI .
BI AAYAN BAKU OJURE MANWA NILE NI AMO
KOKIN FI RIRAN,ANGBO OJU ILE AMO KOKIN
FI RIRAN,KI SOBI TODI EGBO OLUGANBE
LANKESI OYA L BOSEN LO TI KI OJURE KO
FO.HMMM AO GBO IROYIN KI ILE TOSU O PE
ENINA TIFO LOJU,HAAA ISEYI NI ERO AMO
HMMM KOYA O OGBA ITOJU GIDI GBO AWON
AAJO TI WON BAFE SE FUN ENINA EWE
OLUGANBE GBODO POJU NIBE TORIPE,ENI
TAFI SE IWOSAN FUN

ASIRI TI AFINSO OBINRIN TOJEPE BI


OKUNRIN MIRAN BAGUN YIO KU KILE OJO
KEJI TOMO
OGA OOYE TOJE OGA IBILE KAN
IKOIDE OJULOWO KAN
IKOKO KEKERE KAN
SISERE.
AOWA MU OGA YI ,AODU EJE RE SINU IKOKO
KEKERE YEN,AOFI IKOIDE RO PAPO
DAAADA,AOWA TO EJE TOWA LARA IKOIDE
 YEN SI OBINRIN NA LENU LEMETA,ALELO
FUN OBINRIN MEJI META,AWA NA YIO TUN
LA NIGBA MEJI
 koju be lo iku tinbe Lara eni Toba sun mo won
yato si awa tabawon la eje,leyin na awa yio wa
to eje arawa la iye lero re fun enitoba
gbon,eyin tese ise Sara iyawo yin,egbodo la eje
arayin o,aijebe ojo teba ba obinrin mi lopo
eopa omo olomo danu nio

ASIRI TI ANFIN GBA ETOWA LOWO EYAN


TODAJU DADA
Isenare
Ewe Isaju oojo
Ewe oriji oojo
Iyere die

Epo die
Eku ago kan
sisere
A o di ewe oriji, ati ewe Isaju mọ Aarin ẹṣẹ wa
sun, ti ilẹ ba mọ to ba da
silẹ, a o ṣaa, a o wa lọọ papọ mọ iyere, epo
pupa ati iyọ, a o fi
eku ago see lasejẹ pẹlu aniyọn, a o lọ ba
onitọhun, to ba ni nkọn
yẹn lọwọ, yoo fun wa.

ASIRI AGBAKO OHUNMO AGBAYE


IKOIDE KAN
EWE ALUPAIDA
OGA OOYE KAN
IGBA KEKERE KAN
ODINDIN ATARE KAN
ASO FUNFUN TEERE KAN
SISERE
AOFI IKOIDE KAN TELE INU IGBA KEKERE
 YEN,AOKO EWE ALUPAIDA LE LORI,AOWA
GBE OGA OYE LE LORI,PELU ODINDIN ATARE
KAN LEGBERE,AOWA DE IGBA NA,AOFI ASO
FUNFUN TEERE DIPO DADA,AOLO GBE SI
ORITA META NI AGO MEJILA ORU,AOWA JI

LOGBE WALE NI OWO AGO MARUN SI


MEFA,AOWA GBE SINU APE IJOGUN AOWA
DANA SI AOWA JOPO,AOLO KUN NA,AORO
SINU ADO KEKERE KAN AOGBE PAMO SIBI
OWO,AOWA MAFI MARAYA LO LAROLARO KI
ALEJO TODE MOSEBA AGBA O
AKIYESI
AOFI EPO YIKA IGBA YI LORITA META O KATO
gbe WA SILE O

ASIRI ASETA ERU TETEREGUN BADI


Eso Ori TETEREGUN Kan
Ikoko aseje
Ata ijosi die
Epo ATI iyo
Sisere.
Efo igbin Yi,eyo kuro ninu ikarahun efi nkan
fo dada,egbe sinu isasun yen,elo eso
TETEREGUN yen edale Lori,elo ata si pelu,ewa
bu epo ati iyo si,ese kojina dada,aoso sori
osuka aso funfun eje ko tutu dada hmmm eje
kase adura isegun ota si, aowa je aseje Yi
haaaa lotawa ba daran,loba Kan agbako
Akiyesi alelo isasun yen fun nkan Miran
koburu

ISORI MAPERI MI FUN IBI


Ori eye awo Kan
Eha odo tiwon tilo dada
Eha olo ti won tilo dada
Epo iroko die
Epo igi nla die
Epo apa die
Sisere
Eko awon ekan won Yi sinu ape,ajopo elo
kunna dada,ero sinu ado ijamo kekere
kan,hmmm loogun bade niyen
Lilore
Enikeni taba Fe sin fun,yio joko Lori Odo,tabi
duro Lori olo,ki esere ma kanle,eowa fi
singbere yipo Ori re bi odo

ASIRI ADO AGBARA ELEYE TON SISE IMULE


ATI AGBARA AYE TODAJU
EYE ALAPANDEDE KAN
ADO IJAMO META.
EYE EGA OOYE KAN.
IKOIDE KAN
ASO AGBA KAN
ASO DUDU

ASO PUPO
ASO FUNFUN.
ATARE ODINDIN KAN
SISERE
AODI AWON ADO META YI SINU ASO
DUDU,ASO PUPA,ASO FUNFUN,NI OTOTO
NIO,EJE TOBA DI ALE,EJE KAWA EWE ORIJI
DIE SI IGBERI WA,KAWA TO AWON ADO YEN
LE LORI,EJE KAFI PILLOW WA LE LORI,LEYIN
EYI EJE KAFI EYIN LELE,TI ABATIJI NI IDAJI
OJO KEJI,EJE KAFI DUDU,PUPO,TELE APE
TUNTUN,LEYIN EYI EFI EYE ALAPANDEDE
KAN,ASO AGBA,IKOIDE,ATI ODINDIN ATARE
KAN LE LORI,EWA KO EWE RORO OOJO LE
LORI,EBAMI JOPO,EWA BAMI LO KUNNA
DADA,EWA TU ASO FUNFUN ARA ADO IJAMO
EYOKAN TOKU YEN,EWA DALU LORI,
EOGBODO KO KURU INU RE DANU O,TOH EWA
RO ETU YI SINU RE,EBAMI FI ASO NA DI
PADALEYIN TEBA DI ADO YI TAN EBAMI LA
EYE EGA YI LAYA,EBAMI KI ADO IJAMO YI BO
NINU,EWA GBELE SINU ILE ISEYIN,EFI EWE
ORIJI TEFI SI IGBERI DIE TELE,EDU EJE
AKUKO ADIE KAN LE LORI,EFI EPO PUPA RO
IYEFUN AGBADO,EBU DIE SINU KOTO
NA,ETUN FI EPO DIE SI,EFI OTI DIE SI,ATI OTI
DIE,EWA GBE EYE NA SINU ASO FUNFUN
MIRAN,EBAMI DI DADA,EGBE SINU KOTO
NA,EKO EWE TOKU BO MOLE,KESE ADURA SI
GEGE BESE FE,IRANLOWO NLA LATI OWO

___

AWON AGBA,EBAMI FI NKAN BO ORI IHO


 YEN,KETO DA IYEPE LE LORI, ASIRI
AWON AGBA NLA NIO,EORIPE IYATO NLA
MAWONU ISEYI,GBOGBO ADAWOLE ASIMA
 YORI SI RERE,
MAJEMU
EOGBODO MA GBE IPESE EMETA LARIN ODUN
LATI MA DUPE LOWO AWON AGBA,

ASEJE AYIRAPADA ALADO ISORA GIDI


Ako alangba kan
Atare kan
Atare aja kan
Ewe owo tutu die
Ikoide kan
Eso bomubomu kan
Isasun kekere kan
Sisere re o
Ao mu ako alangba yen ao ge
ori re , ao wa ki ikoide si enu re
pelu ewe owo tutu die , ao wa
 jo papo pelu odidi atare kan Ao
wa lo etu na kuna dadaa , ao

tun mu ese re mererin ao ko


sinu isasun ao jo pelu eso
bomubomu pelu atare aja kan ,
ao wa lo etu yiii kuna daadaa ,
Ao da etu yii mo etu alakoko
yen , ao wa ge eran malu si
ona mesan fun okunrin meje
fun obinrin , Ao wa fi otin san
eran yen nu daadaa , ao wa ko
sinu isasun aseje , ao wa bu
epo pupa si pelu iyo , hot le fi
ma se omi re , ao da gbogbo
etu yen le lori ' Ao wa se laseje toba tidi ago
mejila oru , ao
wa bora si ihoho omoluabi ' ao
 joko sori odo ese wa koni kan
lee , ao wa ko aseje yii jee
lesekese , ao mu otin le lori
kato lo sun , toba tidi ago kan
oru yio di ado sinu wa , yio ma
sise isora , fun wa ogun gidi
niiii , kasi ma mu otin die

Trusted by over 1 million members

Try Scribd FREE for 30 days to access over 125


million titles without ads or interruptions!

Start Free Trial

Cancel Anytime.

leekan kan yio ma fun ni


agbara , sugbon aseje yen
lagbara gan oooo toba tile je
ma iyemeji iseyii ooo , ise yii wa fun idabobo
fun eniyan..Ewore..
ojo ti aba ti ba obinrin to nse
nkan osu lajosepo ni yio bajeee,beeni kosi ewu

 ALEMO ISOKO OBINRIN TOYA ALE


oga aaye ao ro iyo kun lenu ao gbe sile titi oma
fi Ku,emo agbo
topo die ao jopo pelu odidi atare kan,ao fifun
obinrin naa Kofi fo
eko mu,Oko re naa yio mu ninu re ao toju eyiti
oku pamon,,eleyi ti
atoju pamon iyen ni erore
Ti okunrin Miran bati ba obinrin naa lopo
konile dide lorire re afi
tiwon ba fun ninu Ogun toku yen fifo eko mun
fun ni yio to dide.

ASIRI KI AFUNJE OBINRIN TABI ADODUN


WON MALE RANWA
GBOGBO IFUN INU AKO PEPEYE KAN

ATARE ODINDIN KAN


ADIN DUDU DIE
SISERE
AOJO IFUN NA PELU ODINDIN ATARE KAN
AOLO KUNNA DADA AOWA DA SINU ADIN
DUDU
LILORE
AOMA LA ISEYI DIEDIE AOTUN FI PA NKAN
OMOKUNRIN TI OBINRIN BANLO ADODUN
TABI OHUN ASIRI MIRAN FUN WA HMMM
WALAI ISENA MABAJE KODELE MUWA
LAILAI

AGBARA ASO FUNFUN ASETA


Eo wa aso funfun ilaji opa , ewe ajeobale die ,
ewe orijin die , ewe iyalode
funfun , ewe mutemiro (ewuro) , epo obo , igi
asorin (igi nla ) , odidi atare kan...
SISERE ... Eo te aso funfun sile Eo ko awon
eroja yen si Eo wa fi aso yi di papo
dada Eo gbe sinu ape Eo jo Eo wa ro sinu igo
kan ...LILORE... Eo ma tosi owo
Eo teni oba ifa Eo pe ofo re si Eo wa fi omi lo ...
OFORE... aso funfun balawu
laso oku , ala funfun gboo laso igbeyin , eyi ewi
ni mowi , eyi epe nimope , oso

ile lonba npe ori emi L omo L ni ibi araye oooo


efun laso funfun balawu korin
dabora , efun ni aso ala funfun gboo korise
ibora , aje aye lonba nperimi ni ibi
tabi alufa ni woli ni , adahun se ni , baba lawo
ni , onisegun ni elebologun ni ,
omode ni agba ni okunrin ni , obinrin ni won
perimi nibi tofe ma di emi Lomo L
lowo efun won laso funfun kiwon rin dabora ,
ebami fun won laso ala funfun
gboo korise ohunse aso ibora Eo wa da senu
Eo fi omi lo igbakugba
lale lo iseyii

ASIRI AGBARA ISEGUN OTA ONIWO ETU


IWO ETU MEJEJI
 JELEJELE IRU OORE
KOKORO GULUSO META
ASO DUDU DIE
ASO PUPA DIE
EKANNA OWO ATI ESE MEWEWA
SISERE
AOJI LOWURO KUTU KI OORUN TOYO,AOFI
ASO DUDU WE IWO ETU KAN,AOFI ASO PUPA
WE ARA IWO ETU KEJI KOMABO IHO OJU IWO

NA O,AOWA IBI OWO KAN NI IBITI OORUN


 YIO TILA WA SAYE AORI IWO ETU TONI ASO
DUDU YEN SIBE,AOWA MU DIE NINU
 JELEJELE IRU OORE YEN SI,PELU GULUSO EYO
KAN PERE TOSIWA LOOYE NIO,AOWA KO
EEKANNA ESE WA MEWEWA SINU RE,AOWA
FI ESO AFOLA DIE SI AOFI ASO DUDU BO
MOLE,TOBADI ALE TI OORUN TIWO,AOWALO
GBE PELU ASO YEN AOGBODO SIWO,AOFI
SINU APE AOJO LALE NA,AORO PAMO SIBI
KAN.
IPELE KEJI
AOTUN SE EYOKAN TOKU LALE OJO YEN
BEENA,AOFI SILE DI AARO OJO KEJI,AMO ASO
PUPA LAOFI BO OHUN KOLE NITIE O,AOWA
LOGBE NI IDAJI KI OORUN TOYO AOJO OHUN
NA LOTO,AORO SINU IKE KAN
LILORE
EYI TASE LOSAN AOFI SIN GBERE 41 SORI
NIKAN,AOLA EYI TOBA SEKU
PELU,OTI,AOTUN FI EYOKAN TOKU SIN GBERE
MESAN SI IWAJU IKUN WA,MESAN
SEYIN,MESAN SEGBE OTUN ATI OSI,AOFI ETU
TAJO LOWURO YEN PA AOFI EYI TOKU FO EKO
MU
OFORE KATO SIN
WOJOWOJO KAN KOGBODO TO IPA ESE
OJO,AWORAWO KAN KOGBODO TO IPA ESE
OORUN,ODI OJO TI ATANPAKO BAWO INU

IWO ETU KETOLE RIMI MU,KODERUJEJE


LEYINLEYIN LOMO ERANKO NFIRU TIE SI,
OHUN YEN LAO KOKO PESI KATO FI PA OJU
GBERE NA

ASIRI AGBARA ADO ATONA TODAJU


ADO IJAMO KAN
ORI EJO MONAMONA KAN TOLASE
ORI ALABAHUN KAN
IYEPE OKUN DIE
IYEPE OSA
IKOIDE KAN
EWE ALUPAIDA OOJO TIO LUJU
IGI AKOKO KEKERE KAN
SISERE
AOLU ADO IJAMO NA LORI AOKO IDOTI INU
RE KURO AOGBODO FE ATEGUN SIO,AOWA LO
GBOGBO AWON ELOJA NA PAPO AOKO SINU
ADO IJAMO NA TI IKANKAN KOGBODO
SEKU,AOWA FI IKOIDE YEN SI EGBE IGI
AKOKO YEN AOFI DE ADO NA LENU PA HNNM
OTIDI OSA NIYEN
LILORE
AOTE ASO FUNFUN KAN SILE AOGBE ADO NA
LE LORI,AOWA PE OFORE AOWA SOPE NJE
Trusted by over 1 million members

Try Scribd FREE for 30 days to access over 125


million titles without ads or interruptions!

Start Free Trial

Cancel Anytime.
Share this document
    

You might also like

Document 42 pages

temidire
Silver Katy
95% (21)

Document 61 pages

Iwe Oro Inu Jagun Jagun


Adekunle Obas
100% (3)

Document 55 pages

IWE ASIRI OGUN


ISENBAYE... VOLUME 1
Abdulsalam Adam
100% (7)

Magazines Podcasts

Sheet music

Document 58 pages

IFA_ACCOUNT_FOR_MULE
RO N-converted
Olafojuhan Samson
89% (36)

Document 13 pages

AKANSE ADURA VOL 1


Tunde
90% (20)

Document 154 pages

New Asiri Aye 1-1


Ayomide Israel
100% (1)

Document 3 pages

Ogun Aleko to Daju


Paulo Santos
72% (18)

Document 11 pages

Iwe Ogun Ibon ati ada


Fol.1
woli adejorin
88% (8)

Document 41 pages

ASERI ewe
Ifasegun
93% (15)

Document 23 pages

love-collection.docx
Anonymous BZMrf3Jkv
92% (24)

Ebook 544 pages

Practical Manual For IFA


Professionals
Chief Fama
 5/5 (2)

Document 4 pages

Lavatorio de Ozain
Agar.Chris
100% (1)

Show more

About Support

About Scribd Help / FAQ

Press Accessibility

Our blog Purchase help

Join our team! AdChoices

Contact us Publishers

Invite friends
Social
Gics

Scribd for enterprise Instagram

Twitter
Legal Facebook

Terms Pinterest

Privacy

Copyright

Cookie Preferences

Do not sell or share my


personal information

Get our free apps

Audiobooks • Books • Documents • Magazines •


Podcasts • Sheet music • Snapshots

Language: English

Copyright © 2023 Scribd Inc.

You might also like