You are on page 1of 8

OGUN IDA ABOBO LOWO EPE

Ewe Awerepèpè, pelu Òrí Aó Io ewé awerepèpè mó òrí. A ó


sín gbéré si gbere si orikerike ara, a ó fi ra kí á máa fi ra ara.
Ao maa so wipe Wá bá mi pa èpè ti wón fi mi sé yíi
Sawerepèpè bá mi pa elépè fún mi.

OGUN OUNMO TABI ARIRAN TODAJU


Ao wa Eyin ororo kan ao soro kelekele si eyin naa, iru unkan
ti afe lofun, ao wa loja ewe bomu bomu eyo mefa ao fi we
eyin yi ti koni han sita raaraa ao fi unkan di daadaa ao wa dana
edu sile ao wa gbekana bi igba ta nsun eran suya ti o baji na ao
bo eyin naa ao je tabafe ki iseyi lagbara daada ao se lemete larin osukan,
opolopo kan ni a maa ri loju aye ati orun pelu
OGUN TI OGUN KO FI NI RAN WA
Ogede Agbagba ti ategun gbe subu, ao wa egbo re Meje,
ogede ibe Meje 2. Ewe Apada 3. Ewe sawerepepe 4. Efo
Dagunro 5. Opolo ti o ku si oju ona 6. Odindi Ataare Aja Meje
ao jo papo, ao gbudo ba enikeni soro ni igba ti a ba njo Ogun
yii lowo, ao gbudo dide kuro ni ibe titi yio fi jo tan. Ti aba lo
tan to kunna daadaa, ao wa Teni Ifa Okanran Meji ao ma
wipe.... Ofo.... Ifa mo pe oo 3x Okanran Meji mo pe o 3x Baba
Oni Yeye ntuye lobi Baba oni Yeye ntuye Owo ti Ogede ba
gbe soke Arare ni yio fi naa 3x Bi omode Ba gba Dagunro mu
Aju le 3x Ki omo araye ma ri emi Lagbaja omo Lagbaja gbe
se... Ki Ogun yin Asasi yin ma ran mi Ojo ti Ogede baa so Ojo
naa ni Oro Idorikodo nba 3x Isubu Aisan ni ki gbogbo eyin ti e
ba nsa ogun simi ma waa 3x ao ma fi Epo pupa laa ni alale ki
ato sun...

OGUN IBON....
Ewe rere eyin adie kan ao fi ewe rere yi se eyin adie yen ao je.

ISORA TODAJU....
Odindin ejo ta pa lo ojo odindin atare kan ao jo po ao ro sinu
ado ato ao fi sin gebere 31 so ri.
605- ENITI NWA IYAWO....
Ori awun egungun ori esin, ewe awerepepe die jijo po ao wa
po mose dudu die eni na yio mafi we ori nikan odaju.
606- FUN AWON TO MAA N MU OTIN TABI JEUN NI
PARTY
E lo si idi igi bomubomu to ni eso lori daada, eo fi owo otun te
eso re kan fo sori igi, eo wa ja, eo fi odidi atare kan si, eo wa
jo po, ao fi sin gbere yipo owo wa, Ti a ba fi di poison mu yio
jabo tabi ko fo.
ISORA : Ise yi wa fun, ti o ba wa lara wa ti ija ba de teyan
kan dede gba yin leti , eo ni gba pada o, eti eni to gbayin
yen a maa jera diedie in,
Eo lo ra eran elede tutu tio ni iyo, Eo wa ge si meji, eo fi abere
to ba ni okun nidi meji gun eran kookan, eo wa lo ju sinu ile
ijalo, to ba ti jera tan eo wa fi abere kookan sin gbere kookan
si igeti wa, Ero re;- eo gba eti eniyen pada, koda e le gba nkan
etutu ke je funra yin.

SETA TO GBONA
Ori oka kan to mu siga, akeke to pe meje, odidi atare kan, ao
jo po, ao fi sin gbere 9 si ori, 9 laya otun, 9 leyin osi, ao fi omi
lo iyoku lesekese. Eni toba peri eni to lo ogun yi nibi, o nlo
niyen o.

OKIGBE IGI TODAMILOJU


Eyin igba ijapa, odindi atare kan, apola igi, ao bu die lara re,
ao jo ninu ikoko titun ni ihoho...
Lilo Re... Ao duro lori odo, ao singbere meje sori, meje is aya, meje
si eyin, ao sin meta si all joint ara wa... gbogbo igi ti won ba
lamon wa koni wole, yio si da sonu...

OGUN IBON....
Ewe rere, eyin adie kan, ao fi ewe rere yi se eyin adie yen ao
je.

OGUN OFE TODAJU


Ao wa eye alapandede eyo kan, ao jo pelu odidi atare kan, ao
fi mu eko gbigbona ti aya eniyan naa bati ja ofe yio gbe enia
naa.
Ewo re : ema fijale ooooo oku nibon ro epe mi si ori ero
ibanisoro mi 08130619602, fun awo ogun miran ti akole fi si
ori afefe

OGUN IBON
Ekuro OJU ona 16, ewe ailu 16, odidi agbon tojabo funrare
kan, ao jo pelu odidi atare kan. Ao maa fi foko mu
laaro.Tiwon ba yinbon siwa, ota ibon o maa gbon sile lara wa
ni. A le dasi adie lenu ka yin bon si wo.
638- OGUN IBON
Ao gbo ewe tangiri pupo laifomi si, ao wa fun omire sinu igba
olomori, ao tun fi omi ewe yen gbogbo ara igba pelu omori re,
ao wa fomi yen se rice je. opolopo eniyan le je. A le yinbon si
igba yen wo.
639- OGUN IBON
Agbon kan to jabo funrare, oga gbigbe/ Tutu kan, ESO ose
kan ao Jo pelu odidi atare kan.Ao maa fi foko mu.
Tidijo 1.) Ao GBE koro agbalumo kan mi , ao yo kuro ninu
igbe wa, ao gbalawo Alegba.
Ao GBE eyin ope kan tojabo furare mi, ao yo kuro ninu igbe
wa, ao yi laso funfun ao dilowu funfun aogba lawo funfun
aoma fi sara.

ISORA
Ao da ounje okele ti ale je tan si ori olota pelu obe, ao wa pe
Ohun re si. Ota nlanla titi sanmo bosile aye, o gbo hai tagiri loruko
tanpe Iwo ile, oso nibe nile tin deru ba emi L omo L ile pa, aje
nibe nile tin deru ba emi L omo L ile, Emere ni, alfa ni, pastor
ni, woli ni etc niba be nile tin deru ba emi L omo L ile pa
gbogbo won. Ko ju belo sugbon olagbara.
641- IMULE
Eyele eyikeyi, Aoge apa re mejeji laye, aoko apa mejeji yen
lori ara won ninu agbada, aofi awo ekun le lori pelu edan tako
tabo, aojo po. Aolo kunna. Aowa naro awon edan mejeji yen
segbe ebu yen pelu owo osi wa, aofi owo otun gba awon edan
yen lori lemeta, Aowa sope.
Motidi imule loni oo 3x, wiwi ekun opanrangandan 3x, aiwi
ekun opanrangandan 3x, odifa fun nana tisawo won lode
esumoba, emi eleye, eyin eleye, eleye kiba eleye ja, eleye kiba
eleye binu, eleye kiba eleye wijo, emase bami ja, emase bami
binu, emase bami wijo, ewa sina owo nlanla fun mi (adua).
Aofi ebu yen fokomu lekanna ni. Aowa ko awon edan yen
sinu apo aso funfun kekere kan, aoma fi rori sun.

EBE AGBALAGBA
Ewe egele,akaraba idi esu,iye igun,odidi atare kan,a o jo po,a o
fi te ifa eji ogbe. OFO RE. Aso felefele ni aso
laketu,ologinigini ni awo irada,odifa fun orunmila nijo ti awon
eleye ni won o paje,oni won o nile mu oun,bi igun ba je ebo,a
darijin igba,pakata idi esu ki yan esu lodi. A o sin gbere 16 si
ori ati eyin
ONMO Ewe Alupaida to ni eso, Atare odidi kan Lilo re : ao lo papo, ao
ma fi foko mu ni ihoho ni ale ati aba fe sun.

AGBO IDOTI ABE TO NFA ISUNKI NKAN OMO OKUNRIN ATI


IDAKOLE Bara totobi dada kan, ope oyinbo(pineapple) kan epa ikun ati
kanun gidi die Ao fo bara na yio ma dada ao ge kekeke ao ko sinu oru
agbo tabi koko ao tun ge pineapple na kekeke ao kosi ao ko epa ikun
lelori ao ge oun na kekeke ko po die ao ge kanun gidi ni wanba si ao wa
bu omi toma dada si ao de ao wa se ti yio jina dada apere toba ti jina omi
agboyi yio duduwa lekannan oti jina nu ni ao so kale toba tutu dada ao
ma mun ni tonbila kokan lojojuma leyin ose meji tanti lo agboyi ao lore
ra ogede agbagba dudu to gun dada ao bo epore ao so sinu koko tolegba
akogbodo ge ao bu omisi pelu oyin gidi sibi mesan ao se to ba jina ao je
gbogbore lekannan ise ya NB ti oko bati ni iyawo agboyen nikan ni kose
mase ti ogede o! NB agboyi yio ma kowa ninu yio ma lowa ninu emase
beru idoti yen lonko ni abewa ti eyin gan base igbanse eru yio bayin pelu
nkan idoti tama ya jade, ao si riwipe nkan omo kunrin wa jipepe yiowa
bi ose ye kowa yio si ma sise daradara ti yio si yojade pada fun eniti tie
ti sunki
IKIYA AKEREKORO KAN RE DANWO KEJERI SI ISE RE : Iya
odo, ao bu omi tale mu tan lekan soso si. Ao wa ju orogbo kan si, ale
taba fe sun lao se ise yi, tobadi owuro ojo keji ni idaji ki awon arale toji,
ao da omina sinu abo kan. Ao wa je orogbo yi tepotepo. Ao mu omi yi
le. EWORE akogbodo ba enia pin orogbo je mo.

OGUN ORUKA IJAKADI Ako alangba, ewe amunimuye, obukotoyo,


ewe ina, ewe aluro ewe patanmo, ao lo gbogbo re po, ao ko si enu
alangba yen, ao fi pelu oye oruka ti a ba fe, ao lo ri mo ona ti gbogbo
enia ba ngba koja di ojo keje, ti enia ba fe ko a o fi ori pa owo mejeeji

OSE ISORA FUN FAMILY TOGBONA. Ao han surat yasin meje, ewe
kilofimise. Ao gun ewe yi mose dudu. Ao fi omi hantu yi po. Ao ko ose
na sinu ike funfun. Ao ma fi we 703- ENI TON FARA KO OWUN
ALANTAKUN Ewe tude, egbo tude, enpo obo, igi nla, ewe
monfowokanomomi. Ao gun mo ose. Ao po turari bintu mo odi wiwe.

IPESE TOGBONA KOSI OUN TIOLE YANJU... Ti obanje Turkey


maranti awon aye kofun awon na ni ounje tiwon kiwon maba fune lorun.
iwoti inkan bale fun abi okoju isoro kan ti owamo ona abayo. boya
wongbe isewa sodore ti owaripe owo ayeni tosife dawole ise yen..
gbiyanju koni ipese yi nile kogbe fun awon mummy. komaloru eru eleru
ko ma fa tie lowo.... Ifun okete, Alangba adaripan1, Eso werenjeje topo
die, Ikode1, Odd atare1. Aojo papo aoro sinu igo kan aonije kidi igo yen
kanle ... aomafigbe ipese ... eran ..ekuru..eko...e.t.c..... hmmm... kosi
inkan tioyanju koda amanfi toro owo lodo awon agba.. odaju

OOGUN AGBELEPOTA TO DAJU A o faa gbogbo irun ori wa


patapata, a o jo pelu ori ejo agbagi {black cobra} kan pelu odindi atare
kan, a o wa fi gbogbo ebu yi foko mu laago kan ooru / ti eeyan ba se ise
ibi tiwa, ejo yio ge enina je loju oorun ni o.

ebe awon agba dada, ati iyonu, ati imule

You might also like