You are on page 1of 1

1- OBE EYONU OWO

Eyin adie ororo iyekiye ewe rinrin ewe ominsinmisin onitakun.iyere die aolopo aopomo
eyinyen. Ao se lobe, ao so si ori okuta meta. Idi re kogbo dokanle. Ao fi iyere o sun te
ejiogbesi aope hutubasi aowadasinu obena aowaje odaju.

2- EYONU GBOGBO AYE.


Eyin ibile ti ko dimo meta, enu igbale to po pelu atare kan, ao jo, ao ma fi fo Eko tutu mu
tabi kada sinu oyin original, ao ma la laro

ATI lale. Ofore.gegege langbe eyin adie gegege ni ki omo araye

ma gbe emi-L-omo-L funrara igbale ni fi enu re tunle se furara omo araye ni ki won ma fi enu
wan tun te mi L-omo-L se.

3- EYONU
Ewe akoko ati itanna re, epo ati egbo re ao jo pelu odindi ataare kan, ao maa fi epo la ki a to
sun... ti o baa di ojo keje ti a lo ise yii ao fi akara elepo se sara fun enia meta pere odaju

4- EYONU TODAJU : Owo osi olongbo, ewe agbosa, ewe mafi owokanomomi, ewe
orijin, ewe ajaobale, epo obo, odidi atare kan, ao jo papo, ao pin si ona meji, ao fi
idakan po ose, ao mafi we laro laro, ao mafi idakeji foko tutu mu laro laro.

5- EYONU IFERAN
Ewe iyere osun, ewe akonimora, ataa abalaye die, esinsin die, eresile, ewe orijin, imi ojo die, ao gun
mo ose dudu, ti a baa ngun lowo, ao lo fi owo mun ogun inaa (eye ina inu aro), ao jusi ose yen, ao
gun papo daadaa, ao ko si oju glass ti awon enia ti wo daadaa...

ao teni ifa eji ogbe, ao pe gbolohun yii sii, ao maa we larolaro.

- Otaa ile, otaa ode, e femi toripe apeji ni ti orijin 3x.


- Oso ile, aje ile, aje oko, e femi tori pe apeji ni ti orijin 3x,
- Omoge ilu yii, arugbo ilu yii, okunrin ilu yii efe emi lagbaja toripe apeji ni ti orijin...
Sebi e so wipe iwa ataa ko sun won besi ni e baa ata re 3x.

You might also like