You are on page 1of 1

1- EYONU AWON AJE

Odindi okete tutu, ao ge gbogbo iru re ati ori re kuro. Ao tu ifun re danu. Ao fo dada. Ao wa
ge okete yen kekeke sinu awo sobi tio ba di ale, ao fi eko kan le lori. Ao bu opolopo epo
pupa le, eepo iginla die, eepo obo die, orogbo kan, obi abata kan, atare kan. Ao ko le lori. Ao
gbe siwaju ita gbangba ile wa. A ki gbesi orita meta rara o. Ako gbodo jade mo ti abati gbe
sita. Bi ile ba ti mo, ao lo ko gbogbo ohun ti o wa ninu awo yen yatosi orogbo ati obi pelu
atare. Ao wa fi ori okete yi tele inu ape. Ao fi okun ti oku si oju ona si ati ewe kilefimise ati
gbogbo ohun ti ako ninu awo ipese yi. Ao jo po. Ao fi epo pupa si ori aro meteta. Ao wa jo ,at
a ijosi ni ao ma fi ko ina re , ti abati jotan ao tenu ejiogbe ao pe ohun re si

lilore: ni ale ao bu epo pupa sinu abo loto lona meji, ao bu etu yi si ona mejeji ao fi iyo sinu ikan
ao la iyen, ao fi eyiti ako fi iyo si yen para ako gbodo jade movtiti ile yio fi mo.

Ohun Re : ise kii se aiye ku emi l omo. l ma se ise laiye mi edi ki di ile kin ma sise laiye mi ki edi ma
my mi, ebo riru kii mu ogun , odifa fun alafia nigbati onti ikole orun bo wa si ikole aiye,
nigbati ode ile aiye , osho ile ni awon yio gba nkan tie lowo re, oni sebi moti rubo fun esu,
won kini ofi rubo, oni ewureewure ewure, woni awon kofe oni obuko, woni awon kofe, oni
ikeregbe dudu toun ti omo redede labe, woni awon kofe, oni emi ( kini) eo gba, nigbati ogbe
okete de. ode oya enu koto orin awo bo silenu, onse iya gba okete gba okete, iya osoronga,
iya gbokete ma gba eniyan, iya osoronga, owo ti mo ni ti yin ni,aso ti mo ni ti yin, kin di eniti
gbogbo aiye yoo ma mo si rere lati oni lo, adura.

You might also like