You are on page 1of 2

ASIRI BI A SE NLO AYAT QUR'AN 3 VS 83

Ona po pupo bi won se maa nlo ayah yii. Sugbon maa se alaye

awon won yii, fun gbogbo eyin ti e maa nbere ape iferan.

Ayah yii obinrin le fi pe okunrin, be sini okunrin le fi pe

obinrin, bi enia baa je waa lowo ale fi gba owo naa, bi a baa fe

yaa owo ale lo, ale fi win contract walah talahi. Mo tun fi

olohun bura. Ko si ohun ti a le fi se, bi iwo ati enia ba nja o le

fi settle ija naa, ki a to sun ni ale, ao se aluwala, ao joko adua

yii. Ti o baa je wipe o fe saa si ololufe re ki o baa le feran re

daadaa, ojo meje ni waa fi saa ayah yii {hafagherah dini lahi

yabghunah walahu hasilamo maan fihi samowati waliharid

tohan wakariha wahilehin turi (aniyan)} ao ma ka ayaa yii bo

sugbon bi a ba ti de ibi last word jahuna ao ni pe jahuna yen


oruko eniti a fe saa si ni ao fi replace jahuna... fun apere oye ki

ayah naa pari bayi wahilein turi jahuna, sugbon kaka ki a pe

jahunah yen oruko omoge tabi okunrin naa ni ao maa daruko.

Ao waa maa saa be ni igba 41 times fun ojo meje gbako...., ti o

baa fe fi win contract tabi interview sa maa replace jahunah

yen si oruko manager ile ise naa tabi eniti o fe interview waa

tabi bi ao baa mo oruko won ao maa daruko ile ise naa...

sugbon onka iyen maa je 71 times... pelu aluwalah

You might also like