You are on page 1of 7

1

Elarowa i elarowa ii elaruwa iii


Akinsala. Akinsala, akinsala
Etigure, etigure, etigure
Abeni ade, abeni ade, abeni ade
If mo pe o, ifa mo pe o, ifa mo pe o
Orunmila mo pe o, orunmila mo pe o, orunmila mo pe o
Tati were ni tekute ile
Asun parada ni ti igi aja
A biamo ki gbo ekun omo re k omo tati were ogbo loni ki
ogbo ogba loni ki ogba iba baba oro to kete baba ileso ni
ile gbo iba baba iba yeye iba oluwo iba ojugbona iba ara
mon da tin ko omo ni ifa oju ala ajaba ki iba ose
ORIN. CANCION
Adupe ho lowo olorun
Adupe ho lowo olorun
Orun ti asun to ji was aye
Ojumo mo ho oyele ho
Ojumo mo ho otele ho
Aji awa gbo ore ore owuro ho
Aji awa gbo ore ore owuro ho
2, EMPITSAR
Subu lade ojire,iyeloko ojire, ojikutu lowofun ojire, ifa aji
aluko loni, afeyin ti igi akoko, awadebi ti yo gbe ko gege,
tako tabo ewa, bawa ni ijokoho, onakona ti oba sanmo
omikun ona kona bi omi ba san mono mi osa, emi oye emi
oye lan ke mon ojo, bojo ni iwonran gbogbo aye lonri,
ekorere wa sin wa o, akoko eruju ekorere wa o, akoko
eruju igba owa lo di fa fun awa, owa oko gi gbedu, omo
oko yeye won ni ti owo ji ki ofi ori bale ki omo ki bara
apetu, owani tori kinni, owan tori ko ba se ku,owa owo

okumo, igbo ifa aji afori bale ki o, igbo won ni tio ba ji ki


ho fi ori bale ki ho, owa n tori ki ni owa ni tori ko le ba ni
ire gbogbo owa ji owa ni ire gbogbo.
3, I DUPE. GRACIAS
Orunmila ni ka sope, ifa ni ka sope, oni ti omo eku ba ji ko
sope lowo Eledumare,oba ada ni waye oni ohun yo fi ona
aiku han orunmila ni ka sope ifa ni ka sope, oni ti omo eku
ba ji osope lowo ohun Eledumare, Eledumare, ni ohun yo
fi ona ai ku, bi omo eniyan ba ji, ni kutukutu owuro koso
lowo eledumare oni ohun yo fi ona ai ku han idin owonrin
rosun asope, elawori asope orunmila asope lowo re adope
ni pa ase orun mila, bara agboni regun Ase Edumare
4, IDARINGIN ESE. PERDON
Oni toki lawo ode egba, ole obu iyepe sese lawo ode ijesa
okete abori bobo a dif a fun odun ela omo larogun ti o sese
kanra kan ti o se ara du e ri, bara petu ni ka wa be ho,
barapetu mon ti gbe be ije be de lawo olugbebe ti aba ti
rawore be ni aje bebe ni igbin de omo oni ipere akoko ifa
yo poro si awo ni ile yo poro si awo loni a ti oni kalu ku
wa ho. ASE
5, IRIN AJO
Apalan ba atisa adi fa fun ade, ti se yeye onilu, oni ibi ti o
sun won lomo ohun loyi, ade loni ki ode obobo loni ki
apada bo ni irin ajo, ewo orisa eye keye ki fo ko fi orisa, bi
na bako odi owo eni tin fe ina, borun kobaranmo odi owo
olodumare, a dif a fun aina ka tin se awo lo si ilumokun
won ni ayan ni yo yan, era ni yo rin, ifa ni bi ise tohun
ayan ko ni yan, era koni rin, eni ayan bayan ni kuso si inu

igbo eni era barin ni kuso si a luju on, ifa ni a lore abo re
ani sije. Ase Edumare.
..
6, I JUBA
Ajirawo lawo ajirawo, ajirase rase lawo ajirase, ajirawo
rase, lo di fa fun esin ajiraworase mo yin ho, ajirawo rase
awo rere, ti a ba ji ki eledumare kawe owo eni fini, kawe
ese eni fini, kawe gbogbo ara eni ko fin ninini, tori ara eni
edumare gbe ibi okun kun edumare ki ki gbe ibi eri
edumare ki gbe ibi, egbin orunmila eri gi alo, je ki ona re
ko la fun wa o. ASE
7, IPABI
Aji mo bi kan ile lo di fa fun ala moye awon, agba to ba ji
to fi obi kan le ori awon adgrugbo ke lese obarisa, kanna
jan gbon ori e abeso jingbini a di fa fun olomo, I ti jogun
etan, ire gbogbo ni towo eni igbin de omo oni ipere akoko
ifa oporo sawo nile ifa ho poro lona, kato feyeyin ti ka to
jogun iregbogbo, ire gbogbo ni towo eni moto ki lawo
moto ki motoyin lawo motoyin, motoyin bun ban bo lori,
adi fa fun kowe oya, omo adaba oke tin bo ra kin rakin,
orunmila lode ero opo ero ofa eyan to bafun ikin lo bi ara
je so hun rere erin ke erin sese adi fa fun kowe, ti yo pa bi
lafin, oni mo pa we, le meji logbogba, losese wa gba, eti
ko ko re ni, adi fa fun lan ta kun, tin lore raye eleru,
baduro bawure ire awa ko sai gba, bi a bere ti awure ire
awa ko sa igbo, bi ajoko bi awure ire wa ko saigba, alaba
lasa, alamun lasa, a di fa fun orunmila tin lore gbe kolobo
ni iyawo, bal aye kolobo fi enu ara re wure, kolobo fenu
ara re wure kolobo ire kan eji kan ti aba su loni ki
eledumare ba wa mun wo ile ase. Ase Edumare

8, Ifa itanije leyuin igbana


Iwure la ti enu okunrin
Iwure la ti enu obinrin
9, ORIN IPARI. LA CONCION DE TERMINAL
Awure tan anre le baba Edumare mo ba wa lo
Awure tan anre le baba Gbogbo Irumole mo ba wa lo
,,
,,
,,
Ejiogbe mo ba wa lo
,,
,,
,,
Oyeku meji mo ba wa lo
,,
,,
,,
Iwori meji mo ba wa lo
,,
,,
,,
Odi meji mo ba wa lo
,,
,,
,,
Irosun meji mo ba wa lo
,,
,,
,,
Ownrn meji mo ba wa lo
,,
,,
,,
Obara meji mo ba wa lo
,,
,,
,,
Oknrn meji mo ba wa lo
,,
,,
,,
Ogunda meji mo ba wa lo
,,
,,
,,
Osa meji mo ba wa lo
,,
,,
,,
Ika meji mo ba wa lo
,,
,,
,,
Ologbo meji mo ba wa lo
,,
,,
,,
Otura meji mo ba wa lo
,,
,,
,,
Irete meji mo ba wa lo
,,
,,
,,
Ose meji mo ba wa lo
,,
,,
,,
Ofun meji mo ba wa lo
Awure tan anre le baba Ose eleru mo ba wa lo
Awure tan anre le baba Gbogbo Irunmole mo ba wa lo
Awure tan anre le baba Gbogbo Odu mo ba wa lo
Awure tan anre le baba Edumare mo ba wa lo.3
KIKI LE SE SE BERE.. KIKI DE COMIENSO
To to n to in ri iru awo bawon yi awon gi di gba lo fi sin de
borun adi fa fun orunmila tin sawo losi otuferere wope
ogun ni po ki ho won kiki won ko rege be ni won ho da ifa
(hin)won pe da lu won pe dafon (hin)won pe aberin je ni
ode isanlu(hin)won pe kinrindini ode idinta(hin)won kiki

won koregede be ni won ho da fa(hin)won ni ibo ni awo


ku si(hin)won ni awo tan ojare(hin)won ni ibo ni awo ku
si(hin)won ni oku oke igeti ni le baba ni (hin)orunmila
lose If fun won lotu ife rere(hin) oni ki otun ijebu koru
Ewure merindinlogun(hin) oni ki osi j ebu koru ewure
merindinlogun oke merin(hin)oni ki agbagi ije bu oru en la
merindinlogun oke merindinlogun ko ti toro kun mojo
omo e le(hin)won fa toro k mojo le orunmila lowo (hin)oto
base kapo baba ba se ikapo(hin)obi iyan okoro lenu ole
akasu ikoro lenu imete (hin)kelebe be i le be soko fun
orunmila ho (hin)toro kun mojo tobi omo, medoogun fun
orunmila ho (hin)wope ogun nipo ki ho won kiki won
koregede beni won ho da ifa (hin)won pe da lu wonpe da
fon won pe aberinjo ni ode isanlu krindin ni ode ise ta won
kiki won koregede be ni won da ifa (hin)won ibo lawo
kusin (hin)awo fan awo ku ojara(hin)won ni bo lawo ki
si(hin)won ni oku oke igeti ni ile orunmila ho
(hin)orunmila lose ifa fun won lotu fe ni ijosi (hin) ki
orunmila to kuro lotufe ni josi (hin) ora eru kan egbefa ora
akeke egbe fa ho(hin) oni eni ti ko ba mon itan oni bgde
egbo si le kun na fun (hin)ki orunmila to pada de
ile(hin)ko bo ho kun mojo ti do oko lo(hin)olofe olugbo
obi erin fun olugbo (hin) obi efon fun olu odan ho(hin)obi
etu fun oni bebe ijo(hin)obi okete fun won ni imo okiti
ho(hin)igbati toro kun mojo yo ode orunmila lo hun ofe
toro kun mo mon (hin) won ki orunmila ki ogba toro kun
mojo morentelu orunmila lo huno fe toro kun mojomo
won ni ki orunmila ko gba toro kun mojo ni mesin lare ho
(hin) orunmila lo hun fe toro kun mojo mo(hin) won ni ki
orunmila ko gba torokun mojo lepo ajadi(hin) won ni oku
omo kan soso ti toro kun mojo yo bi fun orunmila ho(hin)
igbayi lowa to gba toro kun mojo pada ho(hin) owa bi
edn fun orunmila ho(hin)omo ologungun apero(hin) omo

oloro agogo (hin)a fin ju omo tin gba ido ba le baba


re(hin)oni be ni ho omo irunmole en le ho (hin)igba totu
ife daru lojo si(hin) won ni ta ni yo ba won totu ife se(hin)
erin ni mo kan igbon igbo nagbo ho (hin) won ni ta ni
nkan ile kun o la ikeke ikeke(hin) oni tanun keke kun ola
omele won ni fa ni kan ile kun ola nigba Kumba ho(hin)
erin lo hun omo olugbo ni(hin) oni bo ni oye la gbo mo se
ri oni beni won je be beni won mou aboun ile won bi we re
Gabn won. towo ola bosun o opokirimole esin o baun jo
ko won lesin e selekun komolo efan ni mokan igban igban
mokan o won ni tani kan lekun ikeke won ni tani kan
lekun ola olele le(hin)won ni tani kan lekun ola nigba
Kumba ni gba Kumba ho (hin)oni ohun ni etu omo oni
bebejo ohun omo okete omo oni mo kiti ho(hin)won ni
gbogbo won ki se elekun won mo lo(hin) edn ni mokan
mokan igbogbon ho won ni tani kan ile kun ola ikeke tani
kan lekun ola olele olele tani kan ile kun ola ni gbakugba
ni gbakugba ho(hin) edn ni ohun omo olugbo ni won ni
bo ni oye la gnomo seri(hin) oni beni won je beni won
Omun be opo won ko ti ri pun muele esin oba won ko jo
ko agun won ko to wo ala bosun ho(hin) won ledun ki se
elekun komolo (hin)edun ni to ba di oro mi oroan mi oro
itan ho(hin) tomo keke kere ba ko iyan a le kere awon
agbalagba wa si fi oro itan bale ho oni ki baba ohun oto
kuro oye lagbe moro josi ora efukan egbe fa ora akekere
egbe fa ho(hin) oni en ti oba mo fun oni bode ogbodo
silekun kun fun (hin)baba mi lo se ifa fun won won loke
ilagba more josi(hin) be ni won je beni won mun beni opo
won kiri ti mun le esin oba wonjo ke(hin)a gberi kuku
sebe eru baba mi ni(hin)won ni edun abi owo wolo wolo
edun ni owo ohun wolo wolo olohun fin se bi fun eriwo
osin j e(hin)oni iru ohun ti e mi ti e mi lohun f igba ile fun
eriwo osin joao (hin)eyin ohun gburo lohu fi pon eri wo

osin wa ile aye eyin itan odun ni ile esi esikun fe dun(hin)
edun ni ti ba kuro kole gba ho ikeke hai se ko le gba ho ike
ke ai se ko le gba ho tin ba kuro ko yo fo ho ikeke aise ko
yo fo ike ke ASE.

You might also like