You are on page 1of 21

(1)*EYONU AWON AGBA TODAJU COMFIRM

Eyin adie ibile meta,

Orogbo meta

Obi abata olojumeta meta

Atare meta

ao ko gbogbo e sinu ape tuntun awa ko ewe dagunro pipo bo mole, ao jopo ao lokuna daada awa toju
fitila oloju kan ao ma bu ebu yi die sinu re lale ao da epo pupa ogere le lori ao ma fi ika oba arin tola.

Ako gbodo jade sita mon di ojo keji.

pelu ogo olorun iwo toba riseyi se wa yin olorun.

AWON APERE TO MA RI

wa mon la awon ala toda. Otun bawon lala jakujaku mon awan agba ma yonu sio. Ona si ma si, o ma la.

KEFUN MI LABO ogun gidi ni walahi.

ire o!

*Eyonu owo todaju ori olongbo tonirun ewe biranu egbotude atare odidi 1 aojopo aopomo ose pelu
lofida bintu 1 aomafiwe

*OGUN ASHINA ALASEJE FUN ENI TI KO BA RISE

Ewe Atewogba 16, Ao loo, Ao fa sinu Obere kan, Ao bu Ogiri Ijebu si. Ao fi Eran Elede se je lobe pelu
adura pe ile ki nle ki Elede ma wu, ki Emi Lagbaja je Ifa Owo, Ifa Iyawo, Ifa Ile kiko, Ifa Moto rira, Ifa

Omo bibi, Ifa ohun rere ni sise

*ERO IGBONA>EWE RERE,EWE EWURO,IGBE ADIE,EPO OBO,AOLO GBOGBO SE PO_AOFI


OMI DIE,EPO DIE,OMI AGBON DIE,ORI,PO PAPO AFIPARA

*AKO JEDI TAB IGBE EJE >EWE EWURO PELU EWE EFINRIN,AFI OMI OSAN WEWE
GBO ,DRINK IT FOR 2WKS,USE TCTRACYCLIN CAP WITH IT

*HAIR CONDITIONERS>DA OYIN GIDI PELU OLIVE OIL,KI OFIPA IRUN NA,FI WARM
TOWEL BO FUN 3OMINS,KOTOFO, KONI JE KIRUN RE OJA

*OGUN IKO TODAJU>IMI ORUN,AOLO KUNA DADA,EPO PUPA LAO DASI,A O MALA NI
GBOGBO IGBA>

ALEKO TABI IDAKOLE TO CONFIRM>ORI EJO SEBE KAN>IGI OSUNSUN>ODIDI ATARE


KAN>AJO PAPO,AFISIN GBERE YIPO IDI WA,
*OGUN IBON TODAJU

Ao lu ori eyin adie ororo kan,ao ko gbogbo omo inu atare sinu eyin na,lai jekio bo danu rara,ao so sinu
ora,ao so lenu,ao fi ito alaboyun se eyin na jina,ao je eyin na.ao ko epo eyin na sara nkan elemi,ao yin
ibon si wo-odaju kole ba rara

*OGUN IRIRAN TODAJU

ori akala 1,odidi atare 1,ori ikun 1,ao kowon sinu fila tiwon fi aso ofi ran,ao jo papo,ao mala ni araro,ao
mari iran kedere.

*Arobi to je pe ti won ba sa siwa ti onitoun ko

ba jawo Walai yio ku danu ni

*Ise na re

Opolo ijokun nla kan

Atare odindi kan

Sise re ao fi Opolo tele ape ao bu iyo le lori

niwonba ao fi atare si legbe ni aro ti o ba di

irole ao lo gbe kana ti o ba jo tan ao joko lori

odo ao gbe ese lori olo eni ti yio bawa sin yio

duro lori olo bakana, yio bere sinsin re lati

iwaju ori de ibi ti Irun pari si leyin orun

Kojube lo, odijo ti opolo ba to ba iyo di ale

enikeni to ba sa siwa ti ko ba jawo yio ku kile

tosu asiri ni

*Etutu iferan

Ewe omoloju eyele pelu ESO ori re ati itakun re, padi at are Aja kan ,ao jopo ao ma fi pese pelu akara
elepo pupa mefa fun Ojo meje ao fi epo pupa si ao GBE sita

*ELEYI NI IPESE TI AFI NTORO NKAN LODO AWON AGBA LAGBA

Adan gbigba Kan, oga gbigbe Kan, ewe amunimuye, ewe ahan ekun, ata ijosi, epo obo, odidi atare
kan,ao jo papo,
LILO RE : - Ao bu die ninu ebu yi ao teni ifa ejiogbe ao pe ofo re si tia ba pe ofo si tan tan ao da lori eko
elewe kan tia fi pepe gesi mefa ninu awo ipese, ao wa gbesi ita gbangba

OFO RE: - Asaretete bemo lori omo ogun, aposese bemo lorun omo ija, oriku kiijeki koogun oje
(aniyan), Asaretete bemo lori loruko ti anpe eyin osho, oriburuku kiije koogun oje loruko ti anpe eyin
iyami aje gbogbo nkan bayibayi ni kie wa lo bami se wa loni (aniyan),

Ao wa da sori eko ao wa gbe si ita gbangba, ao wa bu omi won ipese Yi, koju bayilo

*EYONU AWON AGBA TANFIRI OWO GIDI

EWE ALUPAIDA 201, OMO OLONGBO KAN, (8) ODIDI ATARE KAN, AOJOPO AORO SINU
ADO ATO AOLOWA EYIN IBILE KAN AOFO AOFI EYIN YE PARA ADO YE LEYIN NA LAO
SESE RO EBU YE SINU ADO NA OOO AOGBEKO SOKE AOMAFI OYIN GIDI LA ISE TO DAJU
NI OOOO YIOBAWA LARA MU

*FUN ENITI OBA NSISE TIKO LAKOJO, FUN ENITI OWO � RE KOBA JISI OWO �

Ao wa eku � eliri kan, odidi atare nla kan, ao jo papo, ao lo kuna dada, ao fi singbere yipo orun owo �
wa mejeji yika, ao wada etu yoku sinu ogere epo pupa, ao la gbogbo re tan lekan soso Odaju.

*OSE IFERAN AIYE

Ewe ogangan, eran elede, ao lo papo ma ose dudu, ao fi ito idi wa po papo, ao ko

sinu igba olomori, ao mafi we laraaro ise na gbiyanju pupo �

* AAGBA TI AFI NRI NKAN GBA LOWO AWAN EYAN ODAJU

Ao wa obi abata ipa, ati obi abata ifin, ao jo papo ma odidi atare kan, ao da sinu oyin gidi, ao mala
laraaro

Walahi ti aba bere nkan lowo awan eyan wan ama se fun wa loju ese ni

E gbiyanju e wo �

* Ogun bi eniyan banwa ise gidi

Ori eyele gbigbe kan

Oga gbigbe kan

Ori ijapa gbigbe kan

Ileke segi

Irun afin

Abere 7

Sisere
Ao ao jopo ao teni ifa ejiogbe

Ofore, ori eyele kiburu kari loko kamuwale bi afin bawoja, tomode tagba ni wo, abere loni ki efi ise bere
emi L omo L loni, ao ro sinu ado kan, ao to die nibe ao fi sin gbere 7 siwaju oriwa, odaju oo..Dan woo ki
e fun ile labo �

* Ogun apamonwo owo To Daju

Ibepe tikogbo kan

Eja ojiji tutu kan

Odidi atare kan

Sisere

Ao jo papo ao lo ti yio kunan dada ao fi sin gbere randi owo mejeji,

*OSOLE GBEWA

koro owu akese ekunowo kan, owo eyo ti ko luju 201, ao lo mejeji papo, eran monu ekiri kan, oga aye
meta, atare meta, ao jo meteta papo mon ra won, ao jo meteta papo, ao da mon eyiti alo yen,

ao po mo ose #300 ao fi aso funfun boo inu igba Tama KO OSE nasi

Aowa gbe pamo fun ojo meje, ago mejila si ago kan ORUN (night) ni ao mawe, aso funfun ni ao ro sidi
Taba felo wee. odaju.

Katowe oseyi tan amari owo toto #200,000

Two hundred thousand �

*AWORO ASIRIBIBO TO SISE FUN 41 DAYS

a o wa tagiri nla to kawo to laje lara dada eyo kan,a o pansan re,a o wa ko gbogbo egusi inu re kuro
dada,a o wa ko owo eyo tiko luju 41 si inu tagiri yi,a o wa gbe oga oye kan le lori owo eyo yen ,a o jeki
oga yen kori soke,a o gbodo dori e kodo ninu tagiri yi,a o wa fi ideri re de pada,a o wa we ni owu dudu
ati funfun tibi kankan koni yo sita rara.a o wa fi ko si enu ona abawole.mofi christic ati olorun bura ao
daju gan.larin 41days yi a o gba alejo pataki,sugbon kari wipe a bere owo gidi lowo won tori aworo
asiribibo owo ni o.NOTE DIS: 41days ni aworo yi mafi sise o,leyin 41days a o yo kuro a tun tun emi
se.danwo ko fun ile labo.

*Oshole kiakia... okan aja okan elede atare meje aojopo aopinsi ona meje aomafi otilo larolaro fun
seven days. Enitobalo larin ojo meje tikobari owo kolomurasi Oro ayere �

*OGUN BREAST CANCER ATI KIDNEY PROBLEM...

Ao wa Opolo ijoku ayekan, ao wa ose fun topo die ao wapo ose yi lomi die tikoni roju aowa te perese
aowa gbe opolo ayeyi si arin re aowa yi ose yi mo lara ti opolo naa koni han mo rara ao wagbe sinu ape
ijogun wa aowa ko awon eroja yi le lori , Ori manmana tutu eyo kan, Oga gbigbe Meta pelu odidi atare
nla kan ao wako ewe efo gbure bo lori odi joji to abati danasi kia sare fi omori bo kia gbe okuta le mole
ki opolo maba fobo sile ooo ti aban Jo lowo aoma bu ata ojosi sinu inare titi ti yio fijo tan, ao walo tiyio
kunna daada enina yio mafi Red wine lo larolaro ODAJU gidi gan Tested and confirmed

E Danwo ke fun ile labo

* IPESE OSOLE OWO AWON AGBA

- eiye Alapandede ooye 3

- eso werenjeje (oju olongbo) lopo

- odidi atare meta

Ao jo gbogbo nkan wonyi, ao ni pa awon eiye wonyi kia to jo won o, ooye be ni won ma lo sinu ape o, ao
ko eso werenjeje le lori daada pelu odidi atare meta, ao ro sinu igo funfun ti ati tunse to mo daada, ao so
okun aso funfun si lorun, ao fi ko soke, ko gbodo kanle mo,

Oru ojo friday lo daraju ki a se ipese yi, ao lo ra eran ede ti amo si elede, ao si tun ni awo ipese meta, ao
ge eran yi si (16) sinu awo kokan, to tumo si, awo kan ekiri eran (16) lo ma wa nbe, leyin eyi, ao bu epo
pupa le lori ninu awo ipese kokan, ao wa bu ebu yi le lelori ninu awo kokan, ao wa se adura owo iye ti
aba nfe si larin 50k si 100k, ao si lo gbe si orita meta ona meta .

N.B.: ao je ki ibere wa je eyokan, ti o ba je owo la need, owo Nikon ni ki a bere oo, ki a si so iye ti

aba nfe,

- ipese meta yen duro fun ibere ohun kan soso tie fe. ti eba tun need nkan mii, eo tun se ipese mii, be ni
eo ma lo ebu na titi yio fi tan, Odaju

* Osole onfa owo

Ewe bara eyo mesan

Eru alamon topo

Eyele funfun kan

Ose dudu

Igba olomonri

Sisere

Ao gun ewe yen pelu eru ao gunmon ose dudu, ao wafi eje eyele po ose yi ao kosinu igba ao wade pa ao
logbe pamon ti oju keji kogbodo ri fun 16 days, leyin ojo yen ao mafiwe, eyele ti agba ejere ao logbe ile
lori akitan ao bo monbe, odaju gidi

*_OKIGO_TODAJU
Ao wa afoku igo toba fo soju titi oloda, ao mu die ninu re, ao lo tintini ninu re papo ma eyo atare kan
soso, ao se bee lona mejila, ao mafi ikookan singbere kan sosos si orikerike ara wa

Ki nse wipe mofi ogun yi sile fun awan omo alaigboran, mokan fi sile ni fun anfani gbobo ile nitori ojo
idagiri

Ogun loni ojo kan, iponju ori loni ojo gbogbo

#_AYETA_IBON_TODAJU

Ao ja ewe rinrin oojo ti yio po dada, ao fi omi toba clean dada gbo, ao fi ase filter re dada, ao wafi omi
yen se rice, ao wa je opo eyan le je ninu re, gegebi iyawo ati awan omo wa, ti abafe dan ogun yi wo, ao
fun adie ni die je ninu rice yen, ao wa yin ibon � fun adie na wo

2.Ao wa ito ( urine) alaboyun, ao fise eyin adie ibile kan, ao je eyin na tepo tepo eewo niki ibon tun wole
siwa lara

E gbiyanju e wo

* ASINA ATUDE

Ewe ewuro ojo, epo obo, eru alamo ao gun papo oronro malu lama fi po ose yi omin kogbodo kan ao ko
sinu roba fun fun ao wa so ori niwan ba si ao gbe sinu orun toba yo ao tun po papo ma ose yi taba tipo
tan idire ko gbodo kanle mon ao ma fiwe ni ojo merin larin ose sunday monday tuesday thusday ti aba
lo ose yi yato si awan ojo wonyi koni sise mon, taba si fe se ose yi arin ojo mererin yi lalese tabase yato si
ojo mererin yi koni sise..O DAJU

*AWISE TA FI MO SE ADURA TI YO SI SE:-- ORONRO OWUKO, OBI ABATA MEJI, OROGBO


MEJI, IYE AGBE KAN, IYE ALUKO KAN, ATARE ODIDI KAN, AOJO GBOGBO RE PAPO,
AORO SINU ADO IJAMO, TI ABA FE LO , AOSI ADO NYEN LENU AOTA DIE SENU AOMO SE
ADURA TOBA WUWA.

2, OGUN OGBENU :-- EGBO OSUNSUN, AOFO ERUPE ARA RE NU , AO MO SUN NI INA AOMO
KAN SINU APADI AO SE GBOGBO RE BE , AO WA LO YIO KUNNA , AOMU ATARE AOFI BO
IRIN AOSUN NI INA AOLO OHUN NA, AOLO ALOMU PAPO MO , AOMO FIMU EKO TO
GBONA DIE DIE.

3, ERO MOGUN:- IFUN AKO OKETE, IF U AKO IKUN, IFUN IJAPA, ESIN PUPA , AOKO SINU
IGO , AOBU ADI ADI EYAN SINU IGO, ENIYAN BALU MOGUN YIO MU.

4, AFERI TODAJU GIDI GAN:- OJU OSI ETA, OJU OSI ABIKU, OGBO DANDABIRIDA,
IMUNMUNA, ODIDI ATARE AAJA, ORU KEKERE KAN, AO KO SINU ORU, AO WA LO OJU
ODO, AOFI OWO TUN PEPE ODO TO SUN MO ODO TOSUN MO ODO SE DARADARA, TI OBA
DI LORU , AOFI ENU GBE ILE AOFI ENU GBE GBE ORU NA SIBE TI OBADI OJO MEJE AOLO
FI ENU WU NI ASIKO TI AGBE SIBE AO WA MU WA ILE NI ORU NA , AOJO NI ORU NA, AOTI
TOJU ADO IJAMO SILE AOTI FI ASO WAJI GBA, ONU NI AORO SI NINU .

LILO RE:- AOSE IKORUN SI , AO BU SARI, AOSO ADO NA SEHIN.


5, OSOLE OWO ASIRI BIBO:-- EWE ABOO, EWE BOBO AWODI, EWE ALUPAIDA, EWE
ORIJIN, AOJO PAPO, AO MA FI RO EKURU FUNFUN JE, AOPO EJE AKUKO ADIE AORO MO
AOKOJE .

EWO : AKO GBODO JE NINU ERAN ADIE NA.

* Dan atude ebe awon agbayi wo kokuro ninu igbekun aye

Adie opipi kan totobi

Obi ifin ao gesi 201

Obi ipa ao gesi 201

Eyo atare 201

Ewe alupaida 201

Efun die

Osun die

Ata ijosin agolo kan

Sisere

Ao fun adie yen lorun pa ao wala laya, ao ko ifunre danu ati edore, ao wako awon eroja yi sinu adie yi,
yato si ata ijosin yen, ao gbesinu koko tuntun, ti abanjo lowo ao mata epo pupa si ori aro meteta, ao
simaju ata ijosin yen sinu aro diedie titi yio fijo tan, ao lo ti yio kuna dada, ao rosinu ado sere ao gbeko
tori idire kogbodo kanle, ao mafi fo eko mu lararo, lodanwo, odaju far

* EDA NI GBOGBO ISE YI OSI DAJU DADA.

1,EDA:-- EWE JELERUN, AOLO AOFI ORUKA IDE SI AOSE JE LALE, AO MO FI ORUKA IDE
BO OWO.

2, EDA:- EWE ENU OSO ILE OWULE EWE, AO GUN MO OSE AO MO FI TABA LARO LALE TI
OSU YIO FI PARI.

3,EDA:-- EWE EMU AOLO AO FO EYIN ADIE SI AOFI EJA ARO SI AOSE JE TI OSU BA PARI.

4,EDA:-- EGBO LALII AOLO AOFI OMI GBIN SE IGBIN NA JE.

5,EDA:-- EWE JOKOJE 10, EWE EMO 10, AOLO WON PAPO, AOFI EKU EMO SEJE TI ABARI
NKAN OSU LAOJE KI AOTO IYAWO WA PADE.

6, EDA:-- EGBO AJEOBALE, EWE BONNI OBI GIDI 6, KANHUNBILALA, PADI ATARE 3, AO
GUN GBOGBO RE PAPO, YIO MOFI FOKO TUTU MU LARO LARO TI OBA BERE YIO SE FUN
17DAYS, ILARIN 1/4 SIBI LAO
MO LO.

7, EDA:- EWE PATANMO , OBI ABATA KAN, AOSE WON PO AO MO FOMI RE TABA LARO
LARO.

8,EDA:-- EPO OBI AJOPA 5, ATARE PADI KAN, IRUN ORI TI WON FIHA IHO OGIRI ATI EJA
ARO 5, AOJO PAPO, AO MO FI FOKO MU NI IDAJI .

9, EDA:-- IGBIN KAN, AKASU EKO KAN, EYO ATARE 203, AOJO PAPO, AOMO FI FOKO TUTU
MU NI IDAJI.

*AGBO IBA TYPHOID TODAJU: aisan typhoid je aisan kan ti ko se fi owo yepere mu,eniti aisan yi
banbaja lowo,eje ara onitohun yio bere si ma dudu,isale inu le ma gun elomiran tabi ki o mu efori lile
dani ati awon apere miran sugbon Aseda fi ase si ara ewe ti anwo aworan re yi pupo.Ewe yi ni awa mo si
KOROPO ni agbegbe tiwa,ewe yi wulo gidi fun iwosan iba typhoid gidi laisi iye meji nibe ,ao wa tutu
ewe yi,ao sin nu pelu omi tio mo,ao fi iyo isebe die si,ao gbo pelu omi niwonba die ,onitohun yio gbe
mu ,ao ni fi isan logba lase edumare

*Egbe yi koni baje,eleyi ni osole kekere ti moko ko muwa ki efi igbagbo danwo,ao wa ori elede tutu sinu
koko ti afin jo hunkan,ao fi epo ijebo bolori dada pelu atare kan,ti aba jo tan ama lo leyina ama pin si
ona meta,ikan ose,ikan sinap,ikan oyin,larolaro.Adua wa yi o gba,

Ewe AMA je funwa oo

*AGBO ILE TUTU :- OBI GBANJA GBIGBE, OSAN WEWE AO FUN OMI RE , OYIN IGAN , OMI
OGBEDE ODO, AOGUN AOFUN PAPO, AOPO PO SINU IGO AOMO LO SIBI IMUKO KEKERE
KAN.

EDA IBULE :-- AO WA IGBIN KAN, AOGBE JU SINU INA AO SUN AO MO GBON SINU
NKANKAN TITI AO FI SUN TAN, AOWA LO PELU KANHUNBILALA, ONI TOHUN YIO MO FI
MU EKO TABI KI AMO FI OMI LO DIE DIE.

EDE ORO:-- AO WA EPO OBI GIDI GBIGBE, AO WA IBO OJU IGBIN , PELU IYERE AOLO
PAPO, YIO FI MU EKO GBIGBONA.

AGBO IBA;-EPO MANGORO, EPO IYEYE, EPO RERE, EPO IGI OSUN, EPO IGI EERU, EPO
OGANO, EWE KOFI, ALE LO EERU ALAMO TI AKO BARI IGI EERU AO SE YIO JINA AO MA
MU.

EBE IGBONA:-- AO TOJU YANRIN TUTU AO GUN SUSU AO FUN OMI RE, AO TOJU IGBIN 16,
AO KAN NIDI AORO OMI RE DARADARA, AO WA PA OMI RE PAPO. AORO SINU IGO,
AOGBE SIBITI AKO TI DA INA AOMO FI PARA ASI LE MU DIE.

OSE ALAKALA:-- EEPO OBO , EWE EGELE, EWE AJEOBALE, AO GUN PAPO AO PO MO OSE
AO OMI GBIGBONA WE.
BI OBIRIN BARI IDADURO:-- EYO ATARE 9, KULUSO 9, ISETA, EMO AJAO, AOLOPO AO FI
SIN GBERE MEJE SI ETI PASE OBIRIN NA.

TOBIRIN KOBARI ALEJO:-- EGBO TEYO, ETU IBON, EPON AKUKO MEJEJI, ATO OROGBIN
YIDI SI AO LO PAPO AOYI RINNDIRIN DI AO FI MU EKO TUTU.

OKA ORI OMODE:-- ODIDI ALAKAN KAN, AOLO YIO KUNNA AOPO MO OSE AO MO FI WE
OMO NA NI ARA.

OGUN EDA:-- IPANUMO ABO, PANUMO ABAFE, PATANMO, IRU KERE ENU AGBADO, AOYO
TI YIO PO DARADARA AOJO PADI ATARE KAN MO OBIRIN YIO MO FI FOKO MU.

ONJE OJU ORUN :-- ESO AGUNMONA 3, EYO ATARE 3, AOLO PO AOFI SIN GBERE YIPO
ORUN.

ALAKALA:--EWE AILU, EWE ORONBO WERE, EBO OBOO, IMI OJO, AOGUN MO OSE
FIFIWE.

AGBO OMODE:-- AIDON, ERU, EWE EJIRIN, ALUBOSA ELEWE, AO SE LAGBO YIO MO FIWE
AOTUN MA FUN MU.

GIRI:-- SUNADARE AOLO, SINU OMI AO MO BU FUN ENITI OMU NI SIBIKOKAN.

GBERE STROCK:-- EGUNGUN KINIRUN, EGUNGUN EKUN AOLO PAPO AOFI SIN GBERE
MEJEMEJE NI GBOGBO ORIKE .

EHIN DIDUN :-- ORI IJAPA ATI ESE RE MERERIN, ATARE EYO OGORUN (100) AOJO PAPO
GBERE KAN ATANPAKO ESE OTUN, GBERE META NI IBARA IDI. �

* Asina agbekole

omi agbara ojo

Ifun ako adie

Ifun abo adie

Ewe arunpale

Akeregbe kekere

Sisere

Ao ro omi agbara sinu akeregbe, ao wako ifun adie mejeji sinu re ao wafi ewe arunpale di enu akeregbe
yen ao soko si enu ona ile tabi office wa, odaju far

*Asiribibo) eko elewe kan ogede agbagba topon Dada odidi atare kan ao gba aso Lara eko yi ao ti atare
ye bo inun eko yi ao fi ewe eko yi pon pada ao gbesi inun ape pleu ogbede odi jiji ao po mon ose dudu ao
mafi we confirm ni�
*Ogun_iko_todaju

a o pa epo igi isin die, okuta ni a o fipa epo yi, ti aba npa epo yi lowo eyi toba jabo sile a ko gbodo mu mo
a o te aso kan sile tabi ki a tewo si abe re iwonba die ni, ao sa(dry) ki o gbe toba gbetan a o lo pelu sugar
oni koro meta a o mafi epo pupa laa die die mofi olorun bura ogun gidi ni

* AROBI PADA SI ORI OTA

ti ota bapo fune lo gbiyanju arobiyi kio man fi oju awan ota re han enman

Ori oka toni ase

Ijalo ti awan peni eerun

Epo igi apa

Epo igi iroko

Epo igi araba

Egun osusu

Aoko awan epo igiyi tele ikoko,ati ori oka,aofi atare le,ao man jo tio bati fe jotan.ao da ijalo si kio jo
papo,aolo kunan dada aopo lose,dd

Ao ko sinu igba tabi ike,

Aoman fi we,tabi kia man fi fo ori.nikan

Enikan ki gun ori oka.ko pete oka pa oka.enikan ki gori eerun kio pete ijakadi,enikan ki gun ori egun
osusu ko pete erinrin,

Bi omode ba dari so apa apa apa,bi omode badari so iroko iro iroko ako,bi omode badriso araba,araba
apa pata pata,igbe rara laran nke wole,igbe rara,

Okunrin ni porimi nibi igbe rara laran ke wole igbe rara,obinrin ni pe orimi nibi igbe rara lara nke wole
igbe raraaaaaa�

*ORUKA MALOYUN TIO DAJU (PREGNANCY PREVENTION RING): ao lo EWE AFUA TUTU
loju olo, ao wa AKO ALANGBA (adanripon) kan,ao la ni aya ao ye IFUN alangba yen si egbeegbe,ao
wa ko afua ti a ti lo yen si IGBAYA re,ao ko ORUKA iye ti o bawu wa si ewe yen lori,ao tun wa fi ewe
afua yen bo oruka lori,ao wa gbe sinu AGBADA,ao jo, Ao yo awon oruka yen kuro ninu re bi o ba ti jo
tan, OBINRIN YIO MA KI ORUKA YEN BO OWO TI O BA TI FE SE ERE IBALOPO, IKILO:EBU
TI O KU NINU AGBADA NI OBINRIN TI KO BA FE BI OMO MO LAILAI YIO FI OMI LO TABI
KI O FI FO EKO MU, ejowo mo fi Aseda ti o ni emi onikaluku beyin 'oruka ni ki e lo e ma lo ebu o,

*OGUN AWURE OWO TODAJU GIDI.. EWE BOMBOM. ERU. EPO OBO. EGUN GUN ORI AJA
DIE AO WA LO GBOGBO E PAPO AO GUN MO OSE DUDU AO MA FI WE LARARO TABI KI
AMA FI FOWO WA. AO MA PE OHUN YI SI PE BOMBOM LONI KI TOKUNRIN TOBINRIN
BOMI TOWO TOWO. OBO LONI KI TOKUNRIN TOBINRIN MA BO LODO MI TOWOTOWO
OWO WON. ERU O O O WALO RU TAKO TABO WA FUN EMI LAGBAJA. TORI WAGBA
WAGBA NI A UN PE AJA. AO SE ADURA SI OTAN WALAI TALAI ENIKENI TIO BA UN LO ISE
YI YI O GBA PE EGUN JU EGUN LO ORISHA JU ORISHA LO TENU KO DANWO �

* OSE EYONU TO DAJU

Omisnmisn Eyikeyi Ewe Lapalapa Ff ( 16 ) Ati Lapalapa Pp ( 16 ) Oyin Gidi .Ao Ko Gbogbo Ewe Yen
Sinu Odo Ao Gun Dada Ao Wa Ko Ose Si Ao Tun Gun Tia Ba Ko Ose Si Tia Gun Ao Ma Fi Oyin Gidi
Si Ao Fima Gun Aba Gun Tan Tia Tiri Pe Oyin Yen Dun Dada Ao Wa Ko Ose Naa Sinu Igba Olomori
Ao Te Ifa Ejiogbe Lelori Ao Jeki Owowa Ote Ose Naa Ki Iho Lewa Ni Oju Odu Yen Ao Wa Fi Epo
Pupa Ati Adin Ati Ori Si Oju Awon Odu Yen Ao Wa Gbe Sinu Orun Ti Ori Ati Epo Ati Adin Yen Bati
Yoo Ao Fi Omorin Igba Na De Ao Fi Owu Dd Ati Ff We Dada Ao Lo Gbe Pamon Fu Ojo 7 Leyin Ojo 7
Ao Lo Gbe Odi Wiwe Laro Laro Pe Lu Kanikani Tuntun .Akiyesi . Ibi Ti Aba Gbe Pamon Si Oju Mi
Ko Gbodo Ri O �

* ASEJE TIA FIN RI OWO,

ofe kia fi asejeyi wa owo awe romodon kale nio

Eresile itanan tananan gbowo 9

Omo atare 9

Iyere 9

Igbin apinu kan

Aolo gbogbo ernja yi papo,aoge igbin si 9

Aofi seje lepo niyo

Odaju

* AGBO ILE TUTU :- OBI GBANJA GBIGBE, OSAN WEWE AO FUN OMI RE , OYIN IGAN , OMI
OGBEDE ODO, AOGUN AOFUN PAPO, AOPO PO SINU IGO AOMO LO SIBI IMUKO KEKERE
KAN.

EDA IBULE :-- AO WA IGBIN KAN, AOGBE JU SINU INA AO SUN AO MO GBON SINU
NKANKAN TITI AO FI SUN TAN, AOWA LO PELU KANHUNBILALA, ONI TOHUN YIO MO FI
MU EKO TABI KI AMO FI OMI LO DIE DIE.

EDE ORO:-- AO WA EPO OBI GIDI GBIGBE, AO WA IBO OJU IGBIN , PELU IYERE AOLO
PAPO, YIO FI MU EKO GBIGBONA.

AGBO IBA;-EPO MANGORO, EPO IYEYE, EPO RERE, EPO IGI OSUN, EPO IGI EERU, EPO
OGANO, EWE KOFI, ALE LO EERU ALAMO TI AKO BARI IGI EERU AO SE YIO JINA AO MA
MU.

EBE IGBONA:-- AO TOJU YANRIN TUTU AO GUN SUSU AO FUN OMI RE, AO TOJU IGBIN 16,
AO KAN NIDI AORO OMI RE DARADARA, AO WA PA OMI RE PAPO. AORO SINU IGO,
AOGBE SIBITI AKO TI DA INA AOMO FI PARA ASI LE MU DIE.
OSE ALAKALA:-- EEPO OBO , EWE EGELE, EWE AJEOBALE, AO GUN PAPO AO PO MO OSE
AO OMI GBIGBONA WE.

BI OBIRIN BARI IDADURO:-- EYO ATARE 9, KULUSO 9, ISETA, EMO AJAO, AOLOPO AO FI
SIN GBERE MEJE SI ETI PASE OBIRIN NA.

TOBIRIN KOBARI ALEJO:-- EGBO TEYO, ETU IBON, EPON AKUKO MEJEJI, ATO OROGBIN
YIDI SI AO LO PAPO AOYI RINNDIRIN DI AO FI MU EKO TUTU.

OKA ORI OMODE:-- ODIDI ALAKAN KAN, AOLO YIO KUNNA AOPO MO OSE AO MO FI WE
OMO NA NI ARA.

OGUN EDA:-- IPANUMO ABO, PANUMO ABAFE, PATANMO, IRU KERE ENU AGBADO, AOYO
TI YIO PO DARADARA AOJO PADI ATARE KAN MO OBIRIN YIO MO FI FOKO MU.

ONJE OJU ORUN :-- ESO AGUNMONA 3, EYO ATARE 3, AOLO PO AOFI SIN GBERE YIPO
ORUN.

ALAKALA:--EWE AILU, EWE ORONBO WERE, EBO OBOO, IMI OJO, AOGUN MO OSE
FIFIWE.

AGBO OMODE:-- AIDON, ERU, EWE EJIRIN, ALUBOSA ELEWE, AO SE LAGBO YIO MO FIWE
AOTUN MA FUN MU.

GIRI:-- SUNADARE AOLO, SINU OMI AO MO BU FUN ENITI OMU NI SIBIKOKAN.

GBERE STROCK:-- EGUNGUN KINIRUN, EGUNGUN EKUN AOLO PAPO AOFI SIN GBERE
MEJEMEJE NI GBOGBO ORIKE .

EHIN DIDUN :-- ORI IJAPA ATI ESE RE MERERIN, ATARE EYO OGORUN (100) AOJO PAPO
GBERE KAN ATANPAKO ESE OTUN, GBERE META NI IBARA IDI. �

*Asina agbekole

omi agbara ojo

Ifun ako adie

Ifun abo adie

Ewe arunpale

Akeregbe kekere

Sisere

Ao ro omi agbara sinu akeregbe, ao wako ifun adie mejeji sinu re ao wafi ewe arunpale di enu akeregbe
yen ao soko si enu ona ile tabi office wa, odaju far
*Asiribibo) eko elewe kan ogede agbagba topon Dada odidi atare kan ao gba aso Lara eko yi ao ti atare
ye bo inun eko yi ao fi ewe eko yi pon pada ao gbesi inun ape pleu ogbede odi jiji ao po mon ose dudu ao
mafi we confirm ni�

*Ogun_iko_todaju

a o pa epo igi isin die, okuta ni a o fipa epo yi, ti aba npa epo yi lowo eyi toba jabo sile a ko gbodo mu mo
a o te aso kan sile tabi ki a tewo si abe re iwonba die ni, ao sa(dry) ki o gbe toba gbetan a o lo pelu sugar
oni koro meta a o mafi epo pupa laa die die mofi olorun bura ogun gidi

*AROBI PADA SI ORI OTA

ti ota bapo fune lo gbiyanju arobiyi kio man fi oju awan ota re han enman

Ori oka toni ase

Ijalo ti awan peni eerun

Epo igi apa

Epo igi iroko

Epo igi araba

Egun osusu

Aoko awan epo igiyi tele ikoko,ati ori oka,aofi atare le,ao man jo tio bati fe jotan.ao da ijalo si kio jo
papo,aolo kunan dada aopo lose,dd

Ao ko sinu igba tabi ike,

Aoman fi we,tabi kia man fi fo ori.nikan

Enikan ki gun ori oka.ko pete oka pa oka.enikan ki gori eerun kio pete ijakadi,enikan ki gun ori egun
osusu ko pete erinrin,

Bi omode ba dari so apa apa apa,bi omode badari so iroko iro iroko ako,bi omode badriso araba,araba
apa pata pata,igbe rara laran nke wole,igbe rara,

Okunrin ni porimi nibi igbe rara laran ke wole igbe rara,obinrin ni pe orimi nibi igbe rara lara nke wole
igbe raraaaaaa�

* ORUKA MALOYUN TIO DAJU (PREGNANCY PREVENTION RING): ao lo EWE AFUA TUTU
loju olo, ao wa AKO ALANGBA (adanripon) kan,ao la ni aya ao ye IFUN alangba yen si egbeegbe,ao
wa ko afua ti a ti lo yen si IGBAYA re,ao ko ORUKA iye ti o bawu wa si ewe yen lori,ao tun wa fi ewe
afua yen bo oruka lori,ao wa gbe sinu AGBADA,ao jo, Ao yo awon oruka yen kuro ninu re bi o ba ti jo
tan, OBINRIN YIO MA KI ORUKA YEN BO OWO TI O BA TI FE SE ERE IBALOPO, IKILO:EBU
TI O KU NINU AGBADA NI OBINRIN TI KO BA FE BI OMO MO LAILAI YIO FI OMI LO TABI
KI O FI FO EKO MU, ejowo mo fi Aseda ti o ni emi onikaluku beyin 'oruka ni ki e lo e ma lo ebu o, �
* OGUN AWURE OWO TODAJU GIDI.. EWE BOMBOM. ERU. EPO OBO. EGUN GUN ORI AJA
DIE AO WA LO GBOGBO E PAPO AO GUN MO OSE DUDU AO MA FI WE LARARO TABI KI
AMA FI FOWO WA. AO MA PE OHUN YI SI PE BOMBOM LONI KI TOKUNRIN TOBINRIN
BOMI TOWO TOWO. OBO LONI KI TOKUNRIN TOBINRIN MA BO LODO MI TOWOTOWO
OWO WON. ERU O O O WALO RU TAKO TABO WA FUN EMI LAGBAJA. TORI WAGBA
WAGBA NI A UN PE AJA. AO SE ADURA SI OTAN WALAI TALAI ENIKENI TIO BA UN LO ISE
YI YI O GBA PE EGUN JU EGUN LO ORISHA JU ORISHA LO TENU KO DANWO �

*OSE EYONU TO DAJU

Omisnmisn Eyikeyi Ewe Lapalapa Ff ( 16 ) Ati Lapalapa Pp ( 16 ) Oyin Gidi .Ao Ko Gbogbo Ewe Yen
Sinu Odo Ao Gun Dada Ao Wa Ko Ose Si Ao Tun Gun Tia Ba Ko Ose Si Tia Gun Ao Ma Fi Oyin Gidi
Si Ao Fima Gun Aba Gun Tan Tia Tiri Pe Oyin Yen Dun Dada Ao Wa Ko Ose Naa Sinu Igba Olomori
Ao Te Ifa Ejiogbe Lelori Ao Jeki Owowa Ote Ose Naa Ki Iho Lewa Ni Oju Odu Yen Ao Wa Fi Epo
Pupa Ati Adin Ati Ori Si Oju Awon Odu Yen Ao Wa Gbe Sinu Orun Ti Ori Ati Epo Ati Adin Yen Bati
Yoo Ao Fi Omorin Igba Na De Ao Fi Owu Dd Ati Ff We Dada Ao Lo Gbe Pamon Fu Ojo 7 Leyin Ojo 7
Ao Lo Gbe Odi Wiwe Laro Laro Pe Lu Kanikani Tuntun .Akiyesi . Ibi Ti Aba Gbe Pamon Si Oju Mi
Ko Gbodo Ri O �

* ASEJE TIA FIN RI OWO,

ofe kia fi asejeyi wa owo awe romodon kale nio

Eresile itanan tananan gbowo 9

Omo atare 9

Iyere 9

Igbin apinu kan

Aolo gbogbo ernja yi papo,aoge igbin si 9

Aofi seje lepo niyo

Odaju

*EBE AGBA.........

Eso laha pupa aoja ti yiopo dada, aotoju epo obo tofe die, padi atare kan (1) , aojo papo aolo sinu igo
kan tobajotan Aomu die nibe aopomon ose dudu, aopo die mon Ori, aomala eyiti oni ori, aomafi toni osé
dudu we....... Iba agba oo......

TURARE...........

Eku afe kan(1) epo obo, adi eyan gidi, eku asin, alubosa elewe, iyo (salt) aogun eru ati eku afe tiyiokuna,
aoko gbogbore sinu odo kan aogun dada epo pupa ati adi gidi yen aofi po monrawon, aoma busina die
die....... Moseba

agba ooooo......
OSOLE TODAJU.......

Ewe ekuya tutu, okete aye kan(1) owo tuntun #1000 tabi owo nla ilu, aodu okete na lori owo ninu
Isaasun, aowa mu owo kuro aogbe okete na télé sinu agbada aofi owo na lelori aowa ko opolopo ewe
ekuya Pupo lelori aojo papo aolo, aoma fi....... Lo tabi eko

OSOLE......

eyele funfun kan egun ori esin egun ori ajiyo die aofi egun ajiyo lapa otun egun ori esin lapa osi aofi padi
atare kan sini igba aya aowa we lowu dudu ati funfun aojo papo aolo aofi eje alujonu lo Lekan........ Iba
agba ooo

OSOLE.........

ori aguntan kan, aofi owo nla kan we ewe ola aogbe Si ori aguntan na lenu aogbe sinu agbada pelu padi
atare kan (1) aowa KO Ewe tanaposo tiyiopo lelori ninu agbada aojo gbogbore papo aolo aomafi eje
alujonu lo tabi eko fifo mun....... Iba agba oooo

OSOLE TODAJU.......

odidi eyele kan aola laya aofi ori oka kan si lapa otun ori alangba ako kan si lapa osi padi atare kan na
Si aoko opolopo ewe ola lelori aojo papo aolo aoro sinu seere aomafi eje alujonu loni ago kan Oru......
Iba agba ooo

*TURARE ARISIKI........

Ora maalu epo Pandoro eru alamo aogun papo ninu odo, aoma busina, aomafi aragba efinre

* EYONU TIA FIN NI CONNECTION gidi pelu owo

Olongbo tio ti ya were

Ako alangba 7

Abo alangba 7

Eiye ega ako 7

Eiye ega abo 7

Eyin ororo 7

Atare nla 7

Ewe abamoda tutu

Ewe ominsinminsin oojo


Sisere:Ao di awan alangbaye man arawan ati ako ati abo aofi owu funfun we wanpo dada ,ao gbe kale

Ao pa olongbo,ao ko ifunre ao bomanle,ao gbe alangba ye sinu re,ao ao ran pada,aogbe sinu koko
tuntun,

Ao ko eyin si ninu koko aoko awan eiye ega si,ao da atare le

Aofi awan ewe bo manle

Aojo,aolo aoro sinu igo ff,

Ao man fi,oti lo laro

Eyan meta lopoju fun iseyi koo man ju meta lo

*OGUN INTERVIEW EYONU

a o wa ewe ominsiminsi pelebe tutu , a o gun mo ose Iwe ekan pere , a o temo ara kainkain tutun kan , a
o lo gbe si ori ibikan lale moju aro , laiti soro si enikokan , a o lo mu nibe , a o lo fi we

* AWURE TO MUN OWO ATI ALEJO GIDI WAA

Iye agbe kan iye aluko kan iye odidere kan oga gbigbe kan itun opa kan ifa opa kan abere aogun papo
mose dudu ao wapa eyele funfun kan ao la laya aoko nkan inu e kuro ao gbe ose yen sinu eyele na ao
wada eje eyele naa le ose naa lori ao ma fi we Odaju

*OSO OWO TO DAJU TO BIYA GBOGBO BUKATA

Ori olongbo dudu kan ewe orijin tutu aofi #1000 tuntun kan tele ape tuntun aogbe ori olongbo naa le
aoda ewe orijin bo ao ta epo pupa round aro naa

Ago kan oru laojo ise yii aso funfun lao wo abi kalo aso funfun mon idi oru na lao loo kuna ao wafi
#1000 kan sinu lord aoda gbogbo ebu naa si aogbesi igun ile ao malo laro kato soro seni keni

Note.. Aogbodo loo ni thursday

Aogbodo loo taba sunmo obinrin

Aomase sara fun ni thursday thursday

Osise gan

*ALUWO TO DAJU TORI TABA NWA OWO KAMAWA AGBARA

Ewe ina adigbonaku ewe esisi ewe aluro obi abata oloju meta kan oruka kusanri iye tafe odidi atare kan
igbin apinu kan

Ao ko gbogbo nkan yi soju igbin ao lori mon oju aro fun ojo meje ao loko aomafi sowo

Note.. Ojo ko gbodo ro larin ojo meje tare oruka naa obaje niyen oo
*TURARI_AWURE_TODAJU

Awo ewure, awo ijimere, odidi atare kan, ao gun gbogbo re papo, ao mafin ni turari laraaro pelu pipe
ofore, ao ma gba efin re sara dada

#_OFORE :- Ile onile ni ewure ti njeun, oko oloko ni ijimere ti njeun ti nfi nto omo re dagba, atare loni
kie ma tami lore ki ema ko owo mi wa fun mi loni odaju

#_AWURE_TODAJU

Obi ifin alawe meta 3, obi ipa alawe meta 3, odidi atare meta 3, #20 tabi #10 tabi #5 naira tuntun meta,
owu alantakun, ao ge obi ifin sona 200, ao ge obi ipa sona 200, ao jo gbogbo re papo, ao lo kuna dada, ao
mafi etu yi je ekuru funfun ninu awo funfun odaju gan

e gbiyanju e wo

#_AWURE_OWO

Afara oyin, omo irula to tutu mini dada, eyin adie ibile meta 3, ewe omisinmisin pelebe, ori aparo kan,
ao jo papo, ao lo kuna papo ma sugar onikoro, ao ma to la laraaro

e gbiyanju e wo

gbogbo ise timo bamu wa confirm ni

*Afose todaju, ahon okete,ahon OGA,ekolo ao gunwon papo pelu ose dd,awakosinu Iwo etu,awafi oko
oka gun Lori 04 re, oro tokete babaleso nilemongbo,abati alagemo bada lorisa okengba, bi ekolo bajuba
ile ile alanufun,ile lanufun oromi loni oromidase gbogbo ntimowibayi komase, ( akiyesi fun awa ologbon
inu ile yi, enikeni too bafegbiyanju side iseyi latise tabi latikosile,lai jubaa lowo babami Awoseyin
Aremu, okan fowosofoni, itoriwipe bimobafegbiyanju ise ninu odumosun babami Awoseyin momanjuba
kintolese isekan nibe tinutinu nimofifisile fun gbogbo ile latije anfanire ,iba, iba,iba olorun iba agba
emajekohunmi ejekojumise �

*EYONU AWON AGBA TODAJU COMFIRM

Eyin adie ibile meta,

Orogbo meta

Obi abata olojumeta meta

Atare meta

ao ko gbogbo e sinu ape tuntun awa ko ewe dagunro pipo bo mole, ao jopo ao lokuna daada awa toju
fitila oloju kan ao ma bu ebu yi die sinu re lale ao da epo pupa ogere le lori ao ma fi ika oba arin tola.
Ako gbodo jade sita mon di ojo keji.

pelu ogo olorun iwo toba riseyi se wa yin olorun.

AWON APERE TO MA RI

wa mon la awon ala toda. Otun bawon lala jakujaku mon awan agba ma yonu sio. Ona si ma si, o ma la.

KEFUN MI LABO ogun gidi ni walahi.

ire o!

* AWON ISE IWOSAN TI ALE LO OYIN GIDI FUN__OYIN WULO NINU IRIN AJO AYE OMO
EDA.

1,BELU BELU:-AO LO ESO ABERE EKUNWO KAN KUN NA DAADAA AO POMO OYIN
GIDI ,AO MALO SIBI KAN NI WAKATI KO KAN TITI TI YIO FI RA.

2,ARAN INU :-AO LO ESO IBEPE PIPON, ARA FUN OMI ARA IBEPE YI, PELU OYIN GIDI AO
DA GBOGBO RE PAPO, AO MALO SIBI MEJI NI EMARUN LOJUMO .

3,APORO MAJELE:-AO LO OROGBO GBIGBE KUNNA DAADAA ATI ESO ABERE DIE,AO DA
OYIN SIBI MERIN ATI EPO PUPA DIE MO,AO WA PONO AGOLO MILK KAN, ENINA YIO MU
LESEKESE.

4,ALESE DEEDEE OKUNRIN LODO OBINRIN:-AO SE ALUBOSA ONISU FUNFUN META TI YIO
RO DAADAA, AO FUN OMI RE, AO SE, AO DA DEEDEE OYIN RE PAPO MO OMI ALUBOSA YI,
AO GBE KANA AO SE FUN ISEJU MARUN, AO MALO EMEJI LOJUMO.

5,ORA INU ARA:- AO PO OYIN GIDI MO OMI OSAN WEWE DEDE IYE IWON KAN NA, AO FII
OMI DIE SI, AO MA MU IDAJI CUP LEMETA LOJUMO FUN OSE KAN AO SI MA SE EXERCISE,

6,ATO SISAN:-AO LO OPOLOPO ESO OGBOLO KUNNA DAADAA , AO RE SINU OMI FUN OJO
KAN, AO MA BU IDAJI GLASS CUP PELU SIBI OYIN GIDI MEJI SI AO MA MU LEKAN
LOJUMO.

7,AISAN ENU RIRUN:-AO PO OYIN GIDI ATI OMI OSAN WEWE DEDE IYE IWON KAN
PAPO,AO MA FIFO ENU WA LEMETA LOJUMO.

8,ULCER:-OYIN IGO KAN ,ADIN EYAN IGO KAN, AO DA MEJEJI PAPO MO ARA WON ,AO
GBE PAMO DI OJO META , LEYIN OJO KETA AO MALO SIBI MEJI LARARO ATI LALALE
LEYIN OUNJE.

9,AISAN ARA TI ENIYAN BA NI IDA DURO OMO:-TAGIRI META AO RO EPO ARA RE BI RE NI


RO OSAN AO WA FI BLADE GE SI WEWE ,ADI EYAN IGO KAN, ALUBOSA ELEWE IDI MERIN
AO AO FI BLADE GE SI WEWE, AO WA GBE ADI NA KANA, AO WA DA TAGIRI TI A GE SI
PELU ALUBOSA ELEWE TI YIO GBE (DRY) DADA ,AO WA SO KA LE KO TUTU TO BA TI
TUTU AO WA SI ASERE GBA SI NU IKE (PLATE) KAN , AO LO KAUN BILIALIA MO ,AO WA
DA MO OYIN ILAJI IGO ODI MUMU NIBI META NI ARO ATI ALE....
10,EDA OBINRIN:-OROGBO GBIGBE 9,EWE PATAN MO ABO,EWE IYEYE,EGBO AKA,EWE
IROKO PELU EGBO RE,EWE TUDU PELU EGBO RE,EGBO AKO IBEPE ODO ASUWON DIE BI
AGOLO KAN, ISAWURU KAN,OBI ABATA OLOJU MERIN KAN,PELU ATARE AJA KAN, AO JO
GBOGBO RE PAPO AO DA SINU OMI OSAN WEWE

* OSOLE OWO OLOJO META TI YIO SI BERE ISE AMA RI ISE NLA GBA WON SI MA FI OWO
NLA WA WA RI SUGBON KOLE DAHUN FUN AWON TIKO NISE TIWON NSE TABI TI IWA
BURUKU KUN OWO WON...

*ISE NA RE__EYELE FUNFUN KAN, AO LA INU RE AO KO GBOGBO OWO NIGERIA SI NINU


YATO SI #5,#10,#20 BERE LATI #50 TITI DE 1000, AO KO SI NINU AO DE ESO ABERE SI NINU
AOFI OGA GBIGBE SI NINU PELU AO WA DINI OWO DUDU ATI FUNFUN, AO GBE SINU APE,
AO KO EWE SAWEREPEPE TUTU BO MOLE TI YIO PO DAADAA, PELU ODIDI ATARE KAN,
AO JO PAPO AO PIN SI MEJI AO PO APA KAN MO OSE DUDU, AO KO SINU IGBA AJE KAN,
SUGBON OMI INU IGO NI AO FIPO, AO MAFI WE LARARO,AO DA APA KAN TOKU INU OTI
LORD ,AO MAMU LEYIN WIWE OSE RE..

GBOLOHUN RE___SAWEREPEPE SARE TETE KIO LO BAMI PE OWO OLOWO NLANLA WA


KIWON WA FOWO OWO WON DAMILOLA , ABERE MI JEKI AWON OLOWO NLANLA FOWO
OWO WON BERE MI, ATARE KIDI ERU TIRE KODI KU LABO, KIE DI OWO NLANLA WA FUN
EMI LOMO L LONI, NITORI EYELE ONI JADE KOMA KORE WOLE TOTUN TOSI EYELE NIFI
NKORE TIE WOLE, KIN KORE OWO NLANLA WOLE MI WA LONI ,OSISE FUN AWON OLOJA
DAADAA AWON WOLI ATI ALFA ,PELU AWON TIO BA NISE GIDI LOWO......

OPE NI FUN OLOHUN OBA TO NI GBOGBO AIYE ATI ORUn

*AYETA_IBON_TODAJU

Ao wa itanna sawerepepe 21, eyo atare 21, ao lo papo, ao fi singbere yipo orun owo wa mejeji

ao nije ki gbere yen koja po o, ao ma singbere na ti space yio ma wa larin wan nio

ao wa oju eiyele 16, omo inu irula 16, eyo atare 16, ati ota inu iroko niwanba, ao lo gbogbo re papo, ao fi
singbere 16 si apa wa mejeji

ti wan ba yin ibon lu wa koni ba wa pelu ogo olohun ayeta todaju gan ni

e gbiyanju e wo

*Ose awon agba,

Ewe arunpale eepo obo eedu ao lo lototo ao wadapo ao pomon ose dudu, ao kosinu igba ao wate ifa
ejiogbe si lori,
Ofore

Aji daago3* arin madaago3* ogboju monja osere tin daso gooro bora wa loruko tanpe eyin iyami
osoronga iku kije ose arun kije eedu eyin iyami ekinje igi orungo emi L omo L tidi igi oorungo loni o eo
gbodo pami eo gbodo jemi eo gbodo fi aburu semi mon lati onilo, oseyi daju Far walahi

*MADARIKAN TODAJU 100%

awo ejo eyikeyi ti koja rara pelu adidi atare kan ao jo po ni ihoho eni kan kogbodo bawa ni be o.ao po
mo ose dudu.ao ma fi we in gbakigba to bawuwa.odapupo

*AWURE_TODAJU

Egungun erin, egungun efon, awo ijimere, ewe ogo 201, ao jo wan papo akoni jo ewe ogo yen ma wan o,
ao wa po etu yen ma ose dudu, ao wa gun ewe ogo yen papo ma ose na, ao fi ori owawa tele inu igba
olomori tuntun kan, ao wako ose yen le lori, ao te ni ejiogbe, ao wape ofore le lori, ao mafi we laraaro
pelu pipe ofore

#_OFORE :- Inu igbo ni abi erin si koto gba ola lowo omo eranko, kekere labi efon kotofi atelewo re gba
iyi lowo omo eranko, igi ogo de elewu iji oo, enikan soso ni mope, igba eni ni koma jemi, bi eranko bape
igba lori ite ohun owawa ni yio bori wan male, emi ni kin gba yi kan lowo lowo, ki nmari eyan ti okunrin
ati obinrin ati omode ati agba ki wan ma bami roja

ise nla gidi ni

* Asiribibo #1000 tuntun ao fi sinu isasun ao fi ori olongbo lelori ao wa ko eso Lara si pelu atare kan ao
jopo ao ma fi milk lo lararo �

*ASETA TODAJU,TI RUOMILA FI SEGUN AWON OTARE)ogede omini to pon (16),eye adan
kan(1),alakan(1),ewe raforafo,odidi atare (1),aojo papo aolo kuna dada,aote ni ifa irete meji,aope
gboloun resi leyin gbolounre aomo fifo eko tutu mu,ofore,oba oni warewasewa tinba ifa sota oju opon
loku si,oba oriwori wosewi toba ifa sota oju opon loku si,orunmila ni ota ti tan,ifa moni otaku,orunmila
ni taloku moni oku baba alawo to gbo ifa yanran yanran ti fi ifa pa baba alawo egbere je,orunmila ni
kole kole pami,oni to bani oun yio oami,atare ni yio pa,ni tori ti raforafo pa pon omi sinu tan,inu atare
ni pon si,orunmila ni ota titan,ifa nmoni otaku,orunmila ni taloku moni oku onisegun to mo ewe ati egbo
yanran yanran ti fi ewe ati egbo pa eni segun egbere je,orumila ni kole pami,oni to bani oun yio
pami,atare ni yio pa,ti alakan pa da ewu ti ko suwan tan orun arare ni gbe wo,orunmila ni ota moti
tan,ifa ni otaku,orunmila ni taloku,moni oku alufa tomo tira yanran yanran tifi tira pa alufa egbere
je,orunmila ni kole pami oni toba ni oun yio pami omo ztare ni yio pa,ni tori ti ogede ba pon tan ti nure
adi omini ominu to ba pon sikun nani mu ogede ra,omi inure na ni yio pa,orunmila ni ota tan,ifa moni
otaku,moniorunmila ni tale ni to tunku,moni oku,oso ile aje ile,oso ode aje ode,emere,woli,alaroka,
orunmula ni wan kole pami koda di gbogbo wan ba dari jo,nitori ti adan ba pete pero tan,oro idori kodo
ni ba,ori idori kodo nisi kusi,oro idori kodo ni yio ba gbogbo awon otami loni,ori idori kodo yi ni wan
yio si kusi,irete meje te ori awon ota mi mole ki won oku,kin raye se ni temi.aose adura si lopolopo ao
mo fi foko tutu mu..O daju

*OSO OWO TO DAJU OMO YAHOO NAA LELO


Ori agutan kan ogba gbigbe ibile mefa ori sebe mefa atare mefa aojo papo ao aoro sinu sere aoran
asunwon funfun aogbe sere naa sinu e aogbeko sinu ile

Aomafi peak milk loo ni ago kan oru ni ihoho omoluabi...Tested and trusted

* OGUN ONFA OBINRIN

Ao bu epo pupa si atelewo, iyo isebe, ati Omi, meteta Ni yio Wa Ni atelewo Wa ao Wa po papo.

Gbolohun re

Aponroro loruko ti anpe epo, ajefunfun yinyin loruko ti anpe Iwo iyo, awolu maate Ni oruko ti anpe
Omi, emi L omo L ti di eyin meteta loni. Ti L omo L bati je epo, oro mi ni ki o ma ro, ti o ba ti je iyo oro
mi ni ki o ma ro, ti o ba ti mu Omi oro emi L omo L Ni ki oma ro. Ao Wa fi ahon la o pari.Iba agbagba

*AWORO OSHOLE TI AWON ENIYAN NLANLA MAFI NWA LATI ILU OKEERE

Ao wa igba totobi die, ao ju owo ilu okeere sinu re, ao gbe ori eiye agbigbo lelori, ao bu iru tikoni iyo
lelori, ao wa gbe ori olongbo kan si, ao wafi owu dudu ati funfun we igba naa, ao fi aso tia gba lara oku
tiwon ti sin, ao fi su osuka, ao gbe sinu agbada, ao wa gbe igba yen lori osuka naa, akogbodo siwo titi yio
fijotan tobajotan ao lo kunna, ao mafi oti lord loo ni ojo meta meta, pelu ogo olohun ero làti ilu okeere
wọn yio ma gbe ire wa.

*OGUN ASIRI BIBO(TO SEE MONEY)

ewe orijin,ewe tonagbowo,ewe rinrin,A o gun po mo ose aganyin A o ma fi wee laro..O daju

* Ogun iferan(Love charm)

Ewe sikirimidin,Ewe omisimisi gogoro,A o gun pelu ose aganyin(Ghana soap) ati Ori(Shea butter).A o
ma fi wee laro kutukutu�

* OGUN OKIGBE

Eja Aro Kan,A o ki owo eyo Kan ti koluju si lenu,A o wa Jo pelu odindi atare Kan.A o wa fi sin gbere
metaa si gboro orikiriki ara wa..A o wa lo eyitoku pelu oti..�

*Ogun Eyonu aiye

Egbo tude,Epo obo,ewe orijin a o gun pelu ose dudu,A o ma fi wee Lori odo..�

*Ogun Eyonu

Ewe ajeobale a o gun pelu epo obo ati ose dudu,A o ma fi wee�

*OGUN INU RIRUN

Ororo malu a o gbo pelu ewe tabaa,A o wa mu.

You might also like