Professional Documents
Culture Documents
Agbara Igbaani Apa Iketa (Part 3) Pelu Akojopo Asiri Ona Abayo
Agbara Igbaani Apa Iketa (Part 3) Pelu Akojopo Asiri Ona Abayo
WEBSITE- AGBARAIGBAANI.BLOGSPOT.COM
(1)
ORO AKOSO
Mo juba akoda aye, mo juba aseda aye, mo juba Olorun ton be ki
aye toma be, mo juba Olorun ti yio si mawa nigbati aye koni simo
Ejowo gbogbo eda ti o ba fe dawole ise inu iwe agbra igbaani yii
ejo e je kia se ni mimo, pelu okan kan soso,
(2)
AKIYESI
2. Gbogbo ogun ti aba nse ema jeko mawa ninu iyara ti atin ba obiri ni
ajosepo
3.Ka jina si biba obirin lajo sepo lati eyin tabi ki obirin wani oke
6.Leyin ojo keta ti aba lajosepo tan aye wa funwa lati fowo kan ogun
7.Efi ojo meta tabi merin sile teba se ogun tan kie to sunmo obirin
8.Ki obirin oni isun eje, mase fowo kan ise wa tabi wo ibi ti anko ogun si
9.Olo ti abafinlo nkan eje ki ama fi ewe rinrin ati ewe safara pelu epin fo oju
olo na nu
10. Ti aba njo any ise lowo ki ama so kio maba foo tio bati fo koni sise mo
13.Ti aba nlo ise lowo ao gbodo mafi omo olo si lori ni igbati aba dawo
duro
14. Kia ato dawo le ise kankan e je kia ma se aluwala, tabi kia ya omi si
mimo ki afi san oju ati ese pelu owo wa.
15. Omi ti aba fi fo aso ao gbodo fi fo bata ese wa kokin jeki ise dahun
94- LORA ASO OPA FUNFUN KOFI SE ITORE ANU NITORI EWU WA
8- AYO, IDUNNU,ATI ORIRE NI IWAJU ATI IGBEYIN
12- KOTO SE OHUNKOHUN ESE IWADI DAADA
16- OLE ATI OLOSA WANI ITOSI RE SORA
11- OTA WA NI IWAJU ATI EYIN
13- KOSI ABURU KANKAN
4- JOKO SILE RE
18- ONA DARA PUPO FUN OO
9- IGESE RE YORI SI RERE LAI SI ANIANI
21- ITORE ANU FUN AFOJU KIOTO GBE IGESE
(SPIRITUAL ZONE)
WON
AWO FUNFUN – WHITE – FUN (IYASIMIMO)
GOLD- ORIRE
IFERAN
16 DAYS LAMA FISE ISE YI AO TAN ABELA PUPA PELU FUNFUN 3 AO FI
ORORO OLIVE PA LARA AO KA PSALM 33 LEMETA AO MA PE ORUKO ENI
TI ANFE KIONI IFE WA SI NIGBA 9 ATUN LEFI PHOTO RE SILE NIBE AO
GBADURA ATI OKN WA SI.
ASEYORI
AO SE EYI FUN ODIDI 8DAYS AO TAN ABELA AWO PINK PELU ABELA
FUNFUN META AO FI ORORO OLIVE PA LARA AO FI TURARI PELU AO
GBADURA ATI OKAN WA
OJURERE ELOMIRAN
ISE ISEGUN
ISE IRIRAN
M.I.L.O.N
I.R.A.O.O
L.A.M.A.L
O.G.A.R.I
M.O.L.I.M
Q.E.B.H.I.B
E.R.A.I.S.A
B.A.Q.O.L.I
H.I.O.I.I.A
I.S.L.I.A.G
B.A.I.A.G.A
LILO- AO MA FISI INU APO TABI PURSE OMO ILE IWE, ONISE OWO,ONISE
IJOBA E.T.C OJO MONDAY LAGOGO MEFA IDAJI LA SE ISEYI AO DI PELU
OWU YELLOW AOKA PSALM 23 LATI FI YASI MIMO
osan wewe, oti schnap ati bara, bi a o sese re...... ao fi bara yen ra
ina ti o ma ro ao wa fun omi re, ao fun omi osan wewe na, dede
omi bara na ni osan wewe na ati oti na, gbogbo re ma (equal), ao
po gbogbore papo ao ka psalm 24 si lekan, ao ma mu sibi kan
laro ati lale for five day, Note: ki eni naa to lo iseyi kori pe ohun se
ayewo boya ohun ti loyun ko to lo nitori yo ba oyun je osi le mu ki
nkan osun kowa ki gbogbo idoti ba igbe ati nkan osun jade ki
olorun si gbadura eni na leyin ti eba ti lo tan
ELI-FIRANUMANU
Jasimi igo kan, bintu igo meji, mariamo igo kan, taniya igo kan, petrol die,
adin agbon igo kan, oyin igo kan, kafura,omi odo sisan, a o pa gbogbo re po
pelu psam 3, 10 and 29 pelu iya si mimo alaboyun na yio maa mu diedie
S.A.T.O.R
A.R.E.P.O
T.E.N.E.T
O.P.E.R.A
R.O.T.A.S
IKILO: Aso yi ti di aso agbara,a ko gbudo fi sere o, tabi fi
sepe, bee ti a ban i ibalopo, owo wa ko gbudo kan yii. A le
ma fi aso yi bora sun tabi ki o ma wa labe irori wa.
ADURA ISEGUN
Psalm 109, 118, 25, 119, 27, 71, 120, 91, 30 7, 68, 14, 55,
140, 9, 13, 35, 144, 10 ati 38
8, 4, 81, 23, 16, 20, 32, 133, 52, 57, 121, 131, 1, 126
Fun awon eto adura miiran, e ma kan si OLORUNLOGBON
la be aso, A ki juba afogun sinu ku, eleyi ti a ban i ni ikawo, a
o fi sowo si wa.
E seun pupo fun ifowosowo po yin
WIWA ISE
PSALM 30 LEMEJE, SINU OMI PSALM 126 LEMEJE SINU OMI FI OMI OKUN
ATI OMI AGBON SI PE ORUKO YI
ELIAFARAIMU
KI OFA IRE WA FUN O AO MAMU OMI NA AO FI NINU E WE.
Irawo iyepe gbodo je kie sara sise mo awon laraju ki won ma fon nkan eyo
Bi agbado,okababa ati biki won tun ma we osedudu atiaseje eleyidara
Pupo funwon.
(3) IRAWOAFEFE
Irawo afefe gbodo mase adura nigba gbogbo tabiki won tun ma be awon
Alfa ki won maba won se adura tabi awon woli nitoripe ti aye eniyanba
Daru tabi egun idile tiwon bari alfa tabi woli gidi tiwon sumo olorun dada
Gbogbo nkanburuku yini wonoba fi adura gbodanu ati bi sara sise bi
Nkan pupa,10naira ,obipupa, epopupa ,okababa pupa ,ki won sima tan
turari
Adura tabi turari awon agba tabi aseje ati ose wiwe ati ebu lilo awon nkan
yi
Tete man sese lara won nigbati won ko bati fi adura sise sile
(4) IRAWOOMI
Irawo omi gbodo malo nkan ti won ba fi omi seta biti won fi omi pelo
Re bihantu mimu pupo opejularin ose kan tabi kiwon bawonya
Omisi mimo abi aseje lekokan sugbon ebu jijo kin saba sise lara won aya
fin kan tiko baje mo nkan eran osese kio sise larare
Sugbon tio basepe bi ewe ati egbo nio lesise larare ose funfun
Lodara pupo lati ma fi sise fun irawo omi sara won ni nkan funfun bi
Pure water ,owo funfun,agbado funfun,oka baba funfun,sugar obi
Funfun ati bebelo
Opo obi loti da igbesi aye omo won ru nipa pe dandan ise bayi nio gbodo
se
Koolukuluku eda ni olorun tifi ni ise tiyio mase laye sugbon latari agidi ti
Awon omo adamo nikojeki ani ifura oro olorun ko leye omugo eda sugbon
Ologbon eni ani oye opo ti oye kio lose ise bricklayer sugbon alakiyesi koje
Kio tete yan ise orire
Layo eda tio baje omilaye tioban sise ina kole ni aluyo eda ton sise ina ti
Olose ise omiko leni ilosiwaju layeni ofiye ki eda ni igbesi aye tio legbe
Ohun tioye ki ama se ati ohun tikoye kia mase eda ti olorun da lati ara
omi tio wa lo nsise ni ile bread kin see pe rara kole ni aluyo laye tia bati bi
omo eje kia ma gbiyanju kia to awon toni imo lo nipa irawo wiwo ki won
Se alaye lori iru irawo tio mo na gbewa si aye iru ise ti o le se esu koni da
gbogbo irin ajo waru mowa lowo laye (amin).
COLOUR- Red
NUMBER- 9
DAY- Tuesday
LOVE- Libra, leo
WORK- enterpreneur agent, healer, professor, stunt person
hairdresser, sales person.
(ISESE ZONE)
(A)
ASINA
Ao wa ewe agogo igun tutu, eru Alamo, ao gun pomo ose
dudu ao fi iyere-osun te ifa ika meji ao pe gbolohun resi
ao dasi ose na ao po dada ao gbesi ile nle ni igun ilea o pe
ohun re si ao so fun ose na pe (iwo ose yi aini owo lowo ni
mofi koe si ile nle tio ba mu owo wa funmi inu igba golu
ati fadaka ni ma koe si ao mafiwe laro.
AYA DIDUN
EEWO / PETELE
EO LOWA EWE TOMATO, KANUN, EWA DIE AO LO WON
PAPO AO SIMA FISI OJU AO LO WON PAPO AO SI MO FISI
OJU.
OGA GBIGBE KAN, EKU ASIN KAN EYO OBE KAN, ATA
IJOSI, AO GUN PO MO OSE AO MAFIWE.
IKIYA
AWURE NLA
EWE ISAJU, SAWEREPEPE, EWE SEFUSEFU, AO GUNPO
AO FI PO OSE FUN WIWE.
TI ONA BADI GAGA
EWE TAGIRI, PELU ESO RE AO LA TAGIRI YEN SI ONA
MERIN PELU OSE RE
ADODUN
OGUN WARAPA
AWURE
AJESARA
ADARIN
EESAN, PELU OSE DUDU AO LOPO AO JO AO POMO OSE
NA AO MAFIWE.
ABUSARI AWORO
200 THOUSAND
AO WA 200 NAIRA TUNTUN, AO YI ODOO META META
SIBI TI WON KO 200 SI LARA OWO NA AO WA MU ERAN
RASU TUTU AO FI SINU 200 NAIRA NA PELU IRUN ABE
OBIRIN AO FI SINU E AO RA ROBOROBO AO KI SINU
OPOLO AIYE AO JO PELU ATARE ODIDI KAN AO LOO
KUNNA AO DASI ENU NI ORU AO FI HOT LOO EKAN NA
LAMA LO GBOGBO RE.
AJEGUN ASIINA
TURARI OWORO
EWE EGELE, PELU ORI AO GUNPO MO ARA WON AO MAFI
FIN TURARI BI ABA SE NFI NI ERO YIO MA WA.
OGUN EDA
ODIDI IGBIN KAN, AO JOMO OKO ATARE KAN AO POMO
OSE DUDU OKO ATI IYAWO YIO FIMA WE.
BIG PENIS
OGUN ANASARE
ORUKA IDE
EWE INA
EYO ATARE KAN
ETU IBON
AO LO GBOGBO RE PAPO AO KOSI INU ALANGBA AO LO
RIMOLE FUN OJO MEJE AO LO WUNI OJO KEJE ODI LILO
ALEEBA
IROMI OJU OMI EYOKAN
AO LO PAPO MO EYO ATARE KAN AO LO TI YIO KUNNA
DAADA AO WAFI SIN GBERE EYO KAN SI IPAKO WA.
ORUKA IJA
IFERAN OBIRIN
AWISE MAYEHUN
AJERA
AKOYA
OWO IBON
ORUKA SUBUSERE
AFOSE
AYETA
BABA IJEBU
IYE AGBE 7
IYE ALUKO 7
ODIDI ATARE 7
EWE IYALODE OMUNU PUPA 7
AO WA PAPER FUNFUN KAN
AO KO NUMBER 1 T0 80 SI AO JOPO MO AWON
EROJA NA AO WA DASINU OMI AGBON NLA
ISORA
OGA AYE 7
EWE ABAMODA 7
ATARE ODIDI 7
AO JOPO AO PIN SI ONA MEJI AO FI IKAN SIN
GBERE YIPO APA OSI WA EBU TIO KU AO DA SINU
AWO EKUN AO RAN NI ONDE AO MAWE MO OJU
GBERE NA
IDAN SARADIJE
3 SI EJIKA OTUN
3 SI EJIKA OSI
3 SI ORUN OWO OTUN
3 SI ORUN OWO OSI
3 SI ATANPAKO OTUN
3 SI ATANPAKO OSI
3 SI ORUKUN OSI
3 SI ORUKUN OTUN
3 SI ORUN ESE OSI
3 SI ORUN ESE OTUN