You are on page 1of 1

OSE IFERAN, ODARA FUN RIRI OWO

ISENA RE:-

Ao wa kafura Pelebe 3

Igbo Mimu die (Tanpe Ni Ewe Ola)

Ose

SISE RE:-

Ao lo gbogbo re kuna, Ao po papo mo ose

Dudu, ao wa ko sinu awo funfun, ao Ki abela funfun bo lori.

LILO RE:- Ao ma we ni araro ti yio fi tan. Ao tan ina si, ki ato buwe, ti aba ti we tan ao wa pa ina na. (Ise
sele ni oo odaju)

Odara gan fun gbogbo eyan lati ma lo. (ASINA NI) (ANU NI) (IFERAN NI) (EYONU NI) (ASIRI BIBO OWO NI)
(OSEGUN PROMISE AND FAIL) (OSEGUN ALAKALA) BEBELO......

You might also like