mole 1, ao wa ewe sawerepepe Ewe rekureku Photo client Yan Aolo gbo gbo repo Pelu iyere aofi se Eja aro Tutu kan Tobajina ao so Ori Osuka kan aowa Daoruko client Yan Si temeta aotun so Inkan tiafe si aowa je odaju gbo gbo inkan tiafe ni yio mase fun wa
2, aowa photo client Yan aowa
itan na owu akese iru woro Aowa afokun digi Tosin oju soke to arihe lona ata ijosin Ao lo gbo gbo re lototo aowase dapo Aowa fise igbin topinu kan je lepo ni yo aleni aose asejeyi tobajina ao so si Ori osuka kan aofikale di ojo keji Aodajin je ni idajin Laitisoro si eni Kan Ao dani yan ohun ti afesi aowa je
3, aowa passport client yan aolo
ge gilas ni dede passport yan Ao wa ewe sikimini Sisere Ao sin oju gilas soke aoko eweyan lelori ao doju photo yan de eweyan ao wa lokun na dada Lilore Aoda sinu awo fun fun ao bu oyin gidi si aofi ika arin ropo Ao ma la laro laro Ika arin lao mafi la
*IWULO IYO SALT*
(A)ONFA OBINRIN=ao lo ra iyo
didi ni oja bi meji toba di ago kan oru aoda iyo yii sinu paper funfun kan. Aote eji ogbe silori pelu atare meje lenu gbolohun yii(OFORE =ina jo titi ina jo won nu igbo,orun ran titi orun lowo leyin odan,ado metta ni ado eyin iyami eleye okan foo okan sonu okan toku niwon fii damo nidagiri koru ,ki ewa bami koda lagbaja omo lagbaja nidagiri loru oni koma le sun koma le wo oro emi lagbaja omo lagbaja ni koma fii salala.AO WA GBE ISE YII SI ABE PILLOW WA AO SUN TII ILE BATIMO AO LO FE ISE YII DANU SII ITA .ejekii asa ise yii fun ojo metta le arawon.
( B )IFERAN ARAYE = taba fe lo
si ode tasi fe ki won feranwa nibe - ao bu epo pupa si atelewo ,omi,iyo aowa pe gbolohun yii si( OFORE=omo pon loruko ti anpe epo,omodun ni oruko ti ape iyo ,awolu matte laruko anpe omi ti emi lagbaja omo lagbaja ba de ibi ti mo un loyii ki won ma yo momi pelu adura ife aowa fi pa oju wa ati gbogbo arawa .
(D)AWURE ARISIKI= ao ja ewe
ewuro ati iyo ti won dii pelu ori (shea butter) aogun mo ose dudu ao ma fi fo owo wa laraaro.
(E)AROBI( BACK TO SENDER)=
iyo didi, eru oju aro ,epo obo aogunmo ose dudu aoma fi we ni ekookan pelu omi tiloowooroo.
EJE KII AMA GBIYANJU ATI MA
DA IYO DIDI SINU OMI IWE WA LOOREKORE WALLAHI ONA WA YOO MA SI SOWO ,SI OLA (amin)