You are on page 1of 12

ORIN OWURO

1C.M.S. 1 H.C. 2, L.M. (FE 19) 3. Oluwa mo tun eje je,


Tu ese ka b'iri oro;
"Emi tikara mi yio ji ni kutukutu"
- Ps 108:2 So akoronu mi oni
1. Ji, okan mi, ba orun ji Si f‘Emi Re kun inu mi.
Mura si ise oojo
4. Oro at'ise mi oni
re; Mase ilora, ji kutu, Ki nwon le re bi eko Re;
K’o san gbese ebo ooro. K'emi si f‘ipa mi gbogbo,
Sise rere fun Ogo Re.
2. mp Ro gbogb’ ojo t‘o fi sofo; AMIN
Bere si rere ‘se loni,
Kiyes' irin re laiye yi;
K'o si mura d‘ojo nla ni.
3. mf Gba ninu imole orun,
3 C.M.S.2 t.S. 634, CM (FE 20)
"Emi dubule, mo si su, mo si ji
Si tan ‘mole na f'elomi, Nitori Oluwa ti mi Iehin" - Ps. 3:5
Jeki ogo Olorun re,
Han n’nu wa ati ise re. 1. mf Ninu gbogbo ewu oru,
4. Ji, gbon‘ra nu ‘ wo okan mi Oluwa l‘o so mi;
Yan ipo re larin Awa si tun ri' mole yi
Angel, A tun te ekun ba.
Awon ti nwon nkorin iyin
Ni gbogbo oru s’Oba wa. 2. Oluwa, pa wa mo l'oni,
AMIN Fi apa Re so wa;
Kiki awon ti ‘Wo pamo
L‘o nyo ninu ewu.
2C.M.S. 1 H.C. 2, L.M. (FE 19) 3. K’oro wa, ati iwa wa
1. Mo ji, Mo ji, Ogun orun, Wi pe, Tire l'awa,
K'emi l'agbara bi ti nyin; Tobe t'imole otito
K'emi ba le lo ojo mi. Le tan l‘oju aiye.
Fun iyin Olugbala mi.
4. Ma je k’a pada lodo Re,
2. Mf Ogo fun Eni‘ o so mi Olugbala owon;
To tu mi lara loju orun Titi a o f’oju wa ri,
Oluwa ijo mo ba ku Oju Re ni opin
AMIN
26
ORIN ALE
Kunle k'a gbadura;
f Adura ni opa Kristiani,
Lati b'Olorun rin.
4 C.M.S 5, H.C 17, L.M (FE 21)
2.mf Losan, wole labe
“Nigbawo ni iwo o to mi wa?"
- Ps 101:2 Apat' aiyeraiye;
f Itura ojiji Re dun,
1. mf WA s‘odo mi, Oluwa mi Nigbat' orun ba mu.
Ni kutukutu owuro
Mu k'ero rere so jade, 3. mf Je ki gbogbo ile,
Lat'inu mi soke orun Wa gbadura l'ale
Ki ile wa di t'Olorun,
2. Wa soda mi, Oluwa mi, di Ati 'bode orun.
Ni wakati osan gangan;
Ki ‘yonu ma ba se mi mo, 4. p Nigbati od'oganjo
Won a si s’osan mi d'oru Jek'a wi l'emi, pe
Mo sun, sugbon okan mi ji
3. mp Wa sodo mi, Oluwa mi, Lati ba O sona.
Nigbati ale ba nle lo, AMIN
Bi okan mi ba n sako lo,
Mu pada; f'oju ‘re wo mi.
6 C.M.S 4, H.C. 16, L.M (FE 23)
“Ma rin niwaju mi, ki iwo si pe"
4. Wa sodo mi, Oluwa mi, - Gen. 17:1
Ni oru, nigbati orun
Ko woju mi; je k’okan mi 1. mf OLUWA mi, mo njade lo,
Ri simi jenli aya Re. Lati se ise ojo mi,
lwo nikan l'emi o mo,
5. Wa s’odo mi, Oluwa mi, L'oro l’ero, ati n'ise.
Ni gbogbo ojo aye mi;
Nigbati emi mi ba pin, 2. Ise t’o yan mi l'anu RE
Ki n le n'ibugbe lodo Re. Jeki nle se tayotayo;
AMIN Ki nroju Re ni ise mi
K‘emi si le f’ife Re han.
5 C.M.S 7, H.C. t.H.C 258 3. Dabobo mi mi lowo ‘danwo
S.M.
K'o pa okan mi mo kuro,
"Lale loro ati losan li emi o ma
gbadura" Ps. 55:7 L'owo aniyan aiye yi,
Ati gbogbo ifekufe.
1. mf WA s'adura oro, 4. lwo t'oju Re r’okan mi,
ORIN OWURO

Ma wa low'otun mi titi;
Ki n ma sise lo lase Re, Si ma ghona l‘okan wa,
Ki n f'ise mi gbogbo fun O. K'o si mu wa l'ara ya,
K'a le ma fayo sin O,
5. Je ki n r'eru Re t'o fuye, L‘aiye wa.
Ki n ma sora nigbagbogbo;
4. Amona, lreti wa,
Ki n ma f'oju si nkan t‘orun
Ma fi wa sile titi,
Ki n si mura d‘ojo ogo.
Fi wa sabe iso Re,
Titi opin emi wa,
6. Ohunkohun t'o fi fun mi, Sin wa la ajo wa ja
Jeki nle lo fun ago Re, S‘ile wa.
Ki nf'ayo sure ije mi,
Ki mba O rin titi d'orun. 5. Pa wa mo n'nu ife Re,
Amin Lojo aiye wa gbogbo,
Si mu wa bori iku,
Mu wa de'le ayo na,
cr K'a le b‘awon mimo gba
7C.M.S 97s 3. (FE 24) p Isin mi. Amin
“Oluwa, ohun mi ni iwo o
gbo ni owuro" - Ps. 5:3
8C.M.S 596, t.H.C. 552, L.M. (FE 25)
"Orun ododo yio la fun enyin t'o beru
1. f JESU, oorun ododo, oruko mi" - Mal 4:2.
Iwo Imole ife
Gbat' imole owuro
Ba n t'ila orun tan wa, 1. ORUN Ododo, jowo la,
Tan’mole ododo Re Ma ran jeje lori Sioni
Yi wa ka. Tu okunkun oju wa ka
Je k'okan wa ko ji si ye.
2. mp Gege bi in ti nse,
Son eweko gbogbo, 2. Jek'ore ofe ba le wa,
K‘Emi ore‘ofe Re B‘iri orun, b’opo ojo;
So okan wa 'di otun; K'a le mo p'On l‘Ore wa san,
Ro ojo ibuknn Re
p Sori wa. Ka le pe 'gbala ni tiwa.

3. B‘imole orun ti nran


K‘imole ife Tire,

28
ORIN ALE

‘Wo ti ri danwo bi awa


'Wo si ti mo ailera wa.

7. Agbar‘owo Re wa sibe
9C.M.S17,H.C25,L.M.(FE26) Ore Re si ni Agbara,
"Nigba ti o si di asale, ti orun wo, p Gbo adura ale wa yi,
nwon ko gbogbo awon olokunrun cr Ni aanu, wo gbogbo wa san.
to o wa" - Marku 1:32
Amin

1. mf L'OJU ale, ‘gbat’ orun wo, 10C.M.S 18, H.C 24, t.H.C 99
Nwon gbe abirun w'odo Re; 10s. (FE 27)
Oniruru ni aisan won, "N o dide, n o to Baba mi lo" -
f Sugbon nwon f‘ayo lo le won. Luku 15:18

2. mi Jesu a de loj’ ale yi, 1.mf Baba, a tun pade l'oko


A sunmo O t’awa t'arun wa,
Bi a ko tile le ri O, Jesu,
Sugbon a mo p’O sunmo wa A si wa teriba lab‘ese Re;
A tun fe gb‘ohun wa soke
3. mf Olugbala, wo osi wa, si O,
Omii ko san, ‘mi banuje
Omii ko ni ife si O, Lati wa anu Iati korin 'yin.
Ife elomii si tutu.
2.f A yin O fun itoju ‘gba
4. Omii mo pe asan l'aye
Beni nwon ko f'aiye sile Gbogbo,
Omi l'ore ti ko se ‘re Ojojumo l'a ma rohin se
Beni nwon ko fi O s‘ore. Re,
Wiwa laye wa, anu Re ha
5. Ko s’okan ninu wa t'o pe ko?
Gbogbpo wa si ni elese Apa Re ki O fi gba ni mora?
Awon t’o si nsin O toto
Mo ara won ni alaipe. 3. p O se! a ko ye fun ife nla Re,
A sako kuro Iodo Re poju
6. mf Sugbon Jesu Olugbala mf Sugbon kikankikan ni O si
Eni bi awa ni Iwo ‘se
npe;
ORIN OWURO

Nje, a de, a pada wa ‘le, Ti ofa nfo wa koja


Baba.
Awon Angeli yi wa ka,

4. Nipa oko t‘o bor‘ohun gbogbo Awa o wa l‘ailewu.

Nipa ife t'o ta 'fe gbogbo yo,


4. Sugbon b’iku ba ji wa pa,
Nipa eje ti a ta fun ese,
Ti busun wa di iboji
Silekun anu, si gbani s'ile.
Amin Je k’ ile mo wa sodo Re,

HYMN 11 L’ ayo at’ alafia.


C.M.S 21, H.C 29, t.S 370,
8s7s (FE 28)
"Eniti npa o mo ki itogbe" - Ps 5. N’irele awa f’ara wa,
121:4
Sabe abo Re, Baba

1. K’A to sun, Olugbala wa, Jesu, ‘Wo t’osun bi awa

Fun wa n’ibukun ale, Se orun wa bi Tire.

A jewo ese fun O,


6. Emi Mimo rado bo wa,
Iwo lo le gba wa la.
Tan 'mole s’okunkun wa,

2. B’ile tile ti su dudu Tit’awa o fi ri ojo

Okun ko le se wa mo Imole aiyeraiye. Amin

Iwo eniti ki sare, HYMN 12


C.M.S 22, H.C 6.8s (FE 29)
Nso awon enia Re. “Oluwa yio je imole ainipekun
fun O" - Isa 60:20

3. B’iparun tile yi wa ka,


30
ORIN ALE
1. JESU, bukun wa k’a to lo
Egbe: Nigba iye ati...
Gbin oro Re si okan wa;

K’o si mu k’ife gbigbona 5. A mbe O f'awon alaini,

Kun okan ilowowo wa, F'elese at' awon t'a fe,

Egbe: Nigba iye at’iku wa Je ki anu Re mu wa yo,

Jesu, jare se’ mole wa. 'Wo Jesu, l‘ohun gbogbo wa,

Egbe: Nigba iye ati...


2. Ile ti su, orunti wo,

'Wo si ti siro iwa wa 6. Jesu, bukun wa, - ile su;

Die n'isegun wa loni Tikalare wa ba wa gbe

Isubu wa lo papoju Angeli rere nso ile wa;

Egbe: Nigba iye ati... A tun f'ojo kan sunmo O

Egbe: Nigba iye ati... Amin


3. Jesu dariji wa: fun wa
HYMN 13
L‘ayo ati eru mimo C.M.S 120, t.H.C 224, 7s (FE
30)
At‘okan ti ko l'abawon “Iwo ti ngbo adura, si odo re
ni
K'a ba le jo O l’ajotan: gbogbo enia mbo" - Ps.65:2

Egbe: Nigba iye ati...


1. A GBOJU soke si O,

4. Lala dun ‘tri lwo se ri At'owo ati okan,

Aniyan fere, O se ri: Tewo gba adura wa,

Ma je k'a gbo t'ara nikan B'o tile se ailera.

K‘a ma bo sinu idanwo,


ORIN OWURO

2. Oluwa, je k'a mo O
Nibi t'Olugbala ngbe
Je k'a mo oruko Re;
Ni won nko t'osan
Je k‘awa si ife Re, t'orun

Bi nwon ti nse Ii orun.


2. Ero at‘alejo t‘aiye

3. Nigbati a sun l’oru A ngb‘arin awon ota!

So wa, k‘O duro ti wa Yo wa, at‘ile wa l‘ewu

Nigbati ile si mo L’apa Re ni ka sun si;

K‘a ji, k'a fi iyin fun O. N'ijo iyonu aiye pin,


Amin
Ka le simi l'odo Re.
HYMN 14
C.M.S 140, t.HC 120, D. 8s Egbe: Halleluyah,
7s (FE 31) Halleluyah... Amin
"Eniti npa o mo, ki yioo togbe"
- Ps. 121:3 HYMN 15
C.M.S 20, H.C 22, 10s 4s (FE
32)
1. lFE Re da wa wa si loni, “Li osan pelu o fi awo sanma
se amona won,
L'are a si dubule; ati loru gbogbo pelu imole
ino" - Ps. 78:14
Ma so wa ni dake oru

K'ota ma yo wa lenu; 1. 'WO Imole! larin okun


aiye,
Jesu, se Olutoju wa,
Ma sin mi lo,
lwo l'o dun gbekele.
Okunkun su, mo si jina
Egbe: Hulleluyah, Halleluyah s'ile

Ni won nko t'osan t'oru Ma sin mi lo,


32
ORIN ALE

To ‘sise mi: ohun ehin ola Ma sin mi lo, Jesu


Olugbala
Emi ko bere, ‘sise Kan to
fun mi. S’ile Baba

Ki nle simi lehin ija aiye


2. Nigbakan ri, emi ko be O,
pe Ninu imole ti ko nipekun.
Amin
Ma sin mi lo,
HYMN 16
Beni nko fe O, sugbon P.B. C.M.S 23, 9s 8s (FE33)
nigbayi, "Ise won ni lati duro lororo lati
dupe, ati lati yin Oluwa, ati be
Ma sin mi lo, gege Ii asale” - 1 Kron. 23:30

Afe aiye ni mo ti nto lehin,


1. OLUWA, ojo t'o fun wa pin
Sugbon Jesu, ma ranti
igbani. Okunkun si de l‘ase Re,

‘Wo l'a korin owuro wa si,


3. lpa Re l'o ti ndi mi mu y‘o
si lyin Re y'o m'ale wa dun.

Ma sin mi lo,
2. A dupe ti Ijo Re ko nsun,
Ninu ere ati yangi aiye,
B’aiye ti nyi lo s'imole
Ma sin mi lo,
O si nsona ti gbogbo aiye
Titi em‘o fi ri awon won ni,
Ko simi tosan-toru.
Ti mo fe, ti nwon ti f'aiye
sile.
3. B'ile si ti mo lojujumo

4. K'o to di ‘gba na, l'ona aiye Ni orile at'ekusu


yi
Ohun adura ko dake ri,
T’iwo ti rin
ORIN OWURO

Be l’orin iyin ko dekun.


Mo sunm‘okan Kristi

4. Orun t‘o wo fun wa, si ti la Mo sumo ‘le Baba

S‘awon eda iwo-orun Nibiti 'bugbe pupo wa.

Nigbakugba li enu si nso


3. Mo sunmo 'te nla ni,
lse ‘yanu Re di mimo.
T'a so e ru kale

5. Be, Oluwa, lai n’ijoba Re, T‘a gb'agbele bu si le

Ko dabi aiye T'a si be re gb'ade.

O duro, o si nse akoso


4. Lagbedemeji eyi,
Tit' eda Re o juba Re.
Amin Ni ‘san‐omi dudu

HYMN 17 Ti a o la koja dandan


C.M.S 19, H.C 35, S.M. (FE
34) K‘a to de ‘mole na.
"Nisisiyi ni igbala wa sunmole
ju
lgbati awa ti gbagbo lo" - 5. Jesu, jo se mi pe
Rom. 13:11
So ‘gba gbo mi di lile

1. ERO di dun kan nso Je ki n mo p'O sunmo mi

S'okan mi fi ri fi ri, Leti bebe iku.

Mo sunmo ‘le mi lo ni
6. Ki nmo p'O sunmo mi
Ju bi mo ti sunmo ri.
Gba mba njin si koto;

2. Mo sunmo ‘te nla ni, O le je pe mo nsumole,


34
ORIN ALE
Oluwa, sise oro Re
Sunmo ju bi mo ti ro.
Amin Ma jek'o sun ninu ese

HYMN 18
C.M.S 16, H.C 21, L.M (FE 5. Bukun fun awon alaisan
35)
“Emi o dubule Ii alafia" - Ps. Pese fun awon talaka
4:8
K‘orun alawe l'ale yi

1. IWO imole okan mi, Dabi orun omo titun.

Li odo Re oru ko si
6. Sure fun wa nighat’ aji,
Ki kuku aiye ma bo o,
K'a to m’ohun aiye yi se,
Kuro I'oju iranse Re.
Titi awa o de bite

2. Nigba t'orun ale didun T'a o si de ijoba Re. Amin

Ba npa ipenpeju mi de HYMN 19


(FE 36)
K‘ero mi je lati simi C.M.S 15, H.C 20, 10s
"Ba wa duro, nitori o di oju
Lai l’aiya Olugbala mi. ale"
- Luku 24:29

3. Ba mi gbe l'oro tit'ale


1. WA ba mi gbe Ale fere le
Laisi Re emi ko le wa, tan,

Ba mi gbe gbat’ile ba nsu Okunkun nsu, Oluwa ba


mi gbe
Laisi Re, emi ko le ku
Bi oluranlowo miran ba ye

4. Bi otosi omo Re kan, lranwo alaini, wa ba mi


gbe!
Ba tapa s'oro Re loni
ORIN OWURO

2. Ojo aiye mi nsare lo s’opin lbi ko wuwo, ekun ko koro

Ayo aiye nkun, ogo re nwo Oro iku da? ‘segun isa da
mi,
Ngo segun sibe, b'lwo ba
Ayida at’ibaje ni mo nri mi gbe.

Wo ti ki yipada, wa ba mi
gbe. 6. Wa ba mi gbe ni wakati
iku

3. Ma wa l'eru b‘Oba awon Se 'mole mi, si toka si


Oba, orun

Sugbon ki O ma bo B'aiye ti nkoja, k'ile orun


b‘oninu re mo

Ki o si ma kanu fun egbe Ni yiye, ni kiku, wa ba wa


mi gbe. Amin

Wa, ore elese, wa ba mi HYMN 20


gbe! (FE 37)
E.O. 16, C.M.S 488 6. 6 7. 6.
7. 6.
4. Mo nfe O ri, ni wakati "Ojo keje li Ijo isimi Oluwa
gbogbo Olorun re" - Eks 20:10

Kil'o le segun Esu b‘ore


Re? 1. OSE, Ose rere,

Tal‘o le se amona mi bi lwo ojo simi;


Re?
O ye k’a fi ojo kna,
N'nu 'banuje at' ayo ba mi
gbe! Fun Olorun rere,

B‘ojo mi ba m’ekun wa,


5. Pelu 'bukun Re, eru ko ba
mi lwo n’oju wa nu;

36
ORIN ALE
Iwo ti s'ojo ayo,
Ojo orun ni ‘wo se
Emi fe dide re.
‘Wo apere orun

2. Ose, Ose, rere Oluwa, je ki njogun

A ki o sise loni ‘Simi lehin iku

A o f'ise wa gbogbo Ki nle ma sin O titi,

Fun aisimi ola, Pelu enia Re. Amin

Dldan l'oju re ma dan

‘Wo arewa ojo

Ojo mi nso ti lala,

Iwo nso Ii ‘simi.

3. Ose. Ose, rere

Ago tile nwipe

F'Eleda re l’ojo kan,

T'O fun wa n’ljo mefa

A o fi ‘se wa sile

Lati lo sin nibe

Awa ati ore we,

Ao lo sile adua.

4. Ose, Ose, rere

Wakati re wu mi,

You might also like