Professional Documents
Culture Documents
6. Jo Oluwa l'onakona,
Sa se emi wa ye fun orun:
Laipe awa na yio mo
B'o ti dun to lati de 'be.
Amin.
Amen.
3. Awosanma dide,
Gbogbo ero mi pin;
Bi adaba Noa, mo nfo
Larin iji lile
Sugbon sanma kuro,
Iji si rekoja
Ayo ati alafia
Si gba okan mi kan.
Amen.
Ibi ayo!
Nigbawo ni
Un o r'oju Re
Olorun mi?
3. Patriark igbani,
Par'ayo won nibe
Awon woli, won nwo,
Omo Alade won!
4. Nibe ni mo le ri
Awon Aposteli;
At'awon akorin
Ti nlu harpu wura
5. Ni agbala wonni,
Ni awon Martir wa;
Won wo aso ala,
Ogo bo ogbe won.
6. T'emi yi sa su mi,
Ti mo ngb'ago Kedar;
Ko si 'ru yi loke,
Nibe ni mo fe lo
Amin.