You are on page 1of 2

Ife tribute to Moremi

Yorùbá

Mọrèmi Àjàṣorò!, ọlọ́wọ́ arẹmọ,


Abọ̀jẹ̀ pọ̀ọ̀pọ̀, a ó mú ọ jọba
Ẹ̀ rẹ̀kún-ẹwẹlẹ.
Ayaba Mọrèmi Àjàṣorò
Ìyàwó Ọ̀rànmíyàn.

Gbangá dẹkùn, kederé bẹ̀ ẹ́ wò.


Obìnrin bí ọkùnrin
Ta lééyàn tó ní ò sỌ́loun
Ééyàn lásán-làsàn
Ó jẹun, ó yó tán,
Ó ní ò sỌ́loun

Ọmọ Ìyá Olúrónbí


Ìyè Oluorogbo
Ọmọ ọlọ́fà mọjọ̀
Ere ká relé mi ò, ajé ọjàafẹ̀ẹ̀
Awọ tó kájú ìlú, olùdáǹdè wàá.

Àṣẹ!

English

Moremi, the great warrior, honored mother,


With our blood, we shall make you - king,
Let's all dance to the victorious tune,
Queen Moremi, the great warrior,
Wife to Oranmiyan.

You've opened our eyes, you've shown us the truth,


A woman like a man,
Who claims there is no God,
An ordinary person,
He ate to his fill,
And claimed there is no God.

Daughter of mother Oluronbi,


Mother to Oluorogbo,
With her ancestry rooted in offa,
Let's accompany you home,
A leather that covers the drum,
Our savior!

Ashe!

You might also like