You are on page 1of 2

Eko idaraya je ona ti awon omode maa n gba dun ara won ninu.

Awon omode ni won


maa n se ere yii, kii se fun agbalagba rara. Leyin ti awon Yoruba ba ti se gbogbo
ise ti o ye ki won se ni won maa n se ere idaraya. Idi niyii ti o saba maa n je irole
ni won maa n se ere naa.

Eko idaraya is the Yoruba term for GAME in the English language. Just as there
are various types of games in English, there are also diverse forms of games in
Yoruba culture. These games are predominantly enjoyed by children.

Wonyii ni apeere awon ere idaraya ti a ni ni ede Yoruba.


 Bojuboju
 Ayo tita
 Ekun meeran
 Boko boko
 Kini newu

Now, let’s look at advantages of ere idaraya: E je ki awon anfaani sise ere
idaraya
Akoko, o n maa n muni ronu jinle, it helps one to think deep
Ekeji, o maa n mu ajosepo to danmoran wa laarin omode: it builds a loving
relationship between children.

Ni bayyi, e je ki a se apeere ere idaraya laarin ara wa. Ere idaraya bojuboju.
(Follow the description)

Awon to fe se ere yii yoo yan eyan kan ti yoo bo elomiiran loju. O le fi owo tabi
aso di loju. Ni kete ti o ba ti boo loju ni awon eyan to ku yoo lo fi ara pamo si
ibikan. Eni ti won bo loju yoo maa korin nigba ti awon ti won lo sapamo yoo ma gbe
bayii:
Lile : bojuboju
Egbe : OOOOOOO
Lile : oloro n bo
Egbe: oooooo
Lile: e para mo
Egbe: ooo
Lile: se kin si
Egbe: si si si si
Lile : e ni toloro bamu, a paje
Egbe: paje paje
Kete ti gbogbo won ba to farapamo ni yoo bere si ni wa won kiri. Bi owo re ba te
okan ninu won, onitoun ni yoo di oloro ti yoo ma wa awon to ku kiri.

You might also like