Professional Documents
Culture Documents
Yoruba Content 12
Yoruba Content 12
Arrangement: 9
Recap:
Gbolohun is also know sentence in English.
Gbolohun ni akojopo oro lati fun wa ni itumo kikun.
Now, Read after me
Omo aja mi
Ti mo sese ra
O sare fo titi
Tatapupu gba a
O ke hao! Hao!
Mo toju re
O si gbadun
Lojo ojo kan
Mo mu u lo soko
Aja mi roya
O si le pa
Mo reran fi jeun
Bemii ba wa
Ireti n be
English translation
ISE SISE:
Dahun awon ibeere yii pelu akaye yii
Bi emi ba wa, n be.
Kin ni aja mi ri ni oko? (a) igi. (b) obo. (c) oya
Ibo ni mo mu aja mi lo? (a) oko. (b) odo. (c) ile
Kin ni o gba aja mi? (a) moto. (b) keke (d) tatapupu
Aja ni ese (a) meji. (b) meta. (d) merin
Chapter Summary:
Ni bayii, ati wa fi opin si eko tonii. This means, we have come to the end of
today’s lesson. Lonii, a ko nipa oro oruko. Ki a tun ma pade ninu eko to n bo,
odaboo.