• Eo wa alangba tako tabo, eo gbe eyin abo le isale ape eo ko sugar oni koro meje si eo wa da aya ako yen de ti abo yen pelu sugar mesan mii, ao wa po mo ose, ose yen ni ao ma fi fo nkan omokunrin wa kato ba obinrin lopo, to ba je obinrin ni ako alangba yen lo maa wa ni isale