You are on page 1of 2

Owonrin sogbe

Olu kinndirin
Asa kinndirin
Adifafun Owonrin
Ti n sawo lo apa Okun
O nloo gbgn Okun
O nloo gbgn Ide
O nloo gbgn aso Ologiningin daso Irada wale
Ebo ni ko waa se
Ogbebo orubo
Olu kinndirin
Esu Owonrinsogbe paya wa
Olu kinndirin
Esu Owonrinsogbe paje wa
Olu kinndirin
Esu Owonrinsogbe pomo wa
Olu kinndirin
Esu Owonrinsogbe pogbo wa
Olu kinndirin
Esu Owonrinsogbe pre gbogbo wa

Owonrin sogbe
Bnrahun Awo Ode
Ope gorongobi awo ijesa
Erigi dudu awo imosakun
Adifafun Olofin obelenje

Ti nba ibi i sun


Ti nba ibi i ji
Ebo lori wase
Ogbebo orubo
Oni ki ibi di
Ibi a o mo yaa lo
Igba lewe Olowaransasan oko
Ka si ko rebi eluju
A kore soju Awo
Alubi a si da epeyin da
Edu gbaleo
Edu gbona
Edu gba irunbi gbogbo da sosa

You might also like