You are on page 1of 44

SACRED DOOR

ORIKIS

SPECIAL THANKS TO CENTRO YORUBA


Table of Contents
1. Egungun Pg. 4
2. Ori Pg. 6
3. Eshu Pg. 8
4. Orunmila Pg. 10
5. Oriki Iyami Osooronga Pg. 12
6. Oshun Pg. 16
7. Yemaya Pg. 18
8. Oya Pg. 20
9. Orisha Aye Pg. 24
10. Orisha Oko Pg. 26
11. Ogun Pg. 28
12. Ochosi Pg. 30
13. Shango Pg. 32
14. Olokun Pg. 36
15. Obatala Pg. 38
16. Olodumare Pg. 40

pg. 1
Always remember…This one sacred truth.

You will never find me outside of yourself… If


you do not first find me within yourself.
pg. 2
The Sacred Door

Welcomes you.

pg. 3
Egungun 1
Ìbà se Ose - Oyeku. E nle oo rami oo
Eiye dudu baro Babalawo la npe ri Eiye dudu baro Babalawo ma ni o
Igba kerìndínlogun a dana igbo Ose O digba kerìndínlogun a dana igbo Ose 'na oo rami
o O jo geregere si owoko otun O gba rere si tosi o Ora merìndínlogun ni won ima dana
Ifa si. Emi o mona kan eyi ti nba gba r'elejogun o. Ase.

We respect the sacred Odu Ose-Oyeku that guides our communication with the
ancestors. We salute our friends and brethren salute black bird uttered the names of the
first Babalawos salute the black blackbird uttered the name of the first Babalawos salute
the fifteenth Odù in which ignites the sacred fire of Ose
Thanks to the 16 sacred fires of Odù not hurt us
Roaring fire burning right roaring, fire burning on the left. I love the 16 places Odù fire
forge the wisdom and the wisdom of Ifa.
Always I remember that when I did not know which way to go, I should follow the
destination.
So be it.
pg. 4
Egungun 2
Egúngún gún ani o gún. Akala ka ani oka lekeleke foso.
Ani ofun fun a difa fun. Òrúnmìlà Baba n'on ko lase lenu mo.
Woni kolo pe Baba pe lode Òrún. Tani Baba Òrúnmìlà, morere ni Baba Òrúnmìlà
Mije morere no o. To ase si ni lenu morere mi o. Ase.

The spirit of the Ancients mediums rides softly, as the vulture flies over the ceremony
like a snake. Feathered bird clean white flashes of light. Òrúnmìlà the wisdom of the
Spirit of Destiny, it emits its light flashes. Wisdom comes from the Queen in Heaven,
the kingdom of the Ancients. Òrúnmìlà look to the Spirit of Destiny, who has the good
fortune. The seven rays radiate their power over us. The seven rays of light represent
the spiritual powers that come to us. So be it.

Egungun 3
Ègúngún kiki Ègúngún.
Ègúngúnikú ranran fe awo ku opipi.
Oda so bo fun le wo.
Ègúngún ikú bata bango Ègúngún de.
Bi aba f'atori na le Ègúngún a se de.
Asè

I praise all the Ancients


The ancestors who have preserved the mystery of flight
In the words of reverence and power
A drums announcing their arrival
Because on the mat they spread their presence and power.
So be it

pg. 5
Ori 1
Bi o ba maa lowo, Beere lowo orii re, Bi o ba maa sowo,
Beere Lowo ori re wo, Bi o ba maa kole o, Beere lowo orii re,
Bi o ba maa laya o, Beere lowo orii re wo, Ori mase pekun de,
Lodo re ni mi mbo, Wa sayee fun awon omo mi di rere,
Ase.

If you want money, ask your head,


If you want to start trading,
Consult your head, If you want to build a house,
Consult your head,
If you want a relationship,
Consult first with your head,
Please do not close your spirit inside the door,
It is to you I address myself, come and make my prosperous life, so be it.

pg. 6
Ori 2
A t'aná alé Ilè mó roro
Iná kú pi Okùnkùn kùn bataku D'ifá fún Eyi-orí-wáá-se Tíí s'omo oba l'álède Oyó
Nje, Eyi-orí-wáá-se
Orí ko gba alái lo'ayé pé

When the light was lit at night


It was unclear when the light went out
There was total darkness, darkness enveloped all
You guessed for Eyioríwááse
A princess in the village of Oyo
contemplate Eyioríwááse
Orí not support someone dies as a young man

Ori 3
Èmi mà jí lónì o, o, Mo f’orí balè f’Olorún.
Ire gbogbo maa’ wa’ba’ me, Orí mi da’mi da’iye.
Ngò kú mó. Ire gbogbo ni t’èmí. Imole ni ti Àmakìsì. Ase.

Now I just get up, I present my respects to the realm of the ancestors. Let all good
things come to me. The Inner Spirit gives me life. I never die. Let all good things come
to me. The spirits of light belong to Àmakìsì. Make it so.

Ori 4
Orí san mi. Orí san mi. Orí san igede. Orí san igede.
Orí me apoya. Orí otan san mi ki nni owo lowo. Orí tan san mi ki nbimo le mio. Orí oto
san mi ki nni aya. Orí oto san mi ki nkole mole. Orí san mi o. Orí san mi o. Orí san mi o.
Oloma ajiki, ìwá ni mope. Ase.

The Inner Spirit guide me. Ori guide me. The Inner Spirit supports me. Inner Spirit, give
support to my abundance. Ori, give support to my future children. Inner Spirit, give
support to my relationship. Ori protect my house. The Inner Spirit guide me. Ori guide
me. Ori guide me. Protector of children, my inner character is grateful. Make it so.

pg. 7
Esu 1
Esu, Esu Odara, Esu lanlu ogirioko. Okunrin ori ita, A jo langa langa lalu.
A rin lanja lanja lalu. Ode ibi ija de mole. Ija ni otaru ba d'ele ife. To fi de omo won.
Oro Esu to to to akoni. Ao fi ida re lale. Esu ma se mi o. Esu ma se mi o. Esu ma se mi
o. Omo elomiran ni ko lo se. Pa ado asubi da. No ado asure si wa. Ase.

Divine messenger. Divine Messenger of Change, Divine Messenger talk to power.


The man of the crossroads, Dance in the drum. Tickling the tip of the battery. Exceeds
the fighting.The struggle is against the spirit of heaven.
Une unsafe babies feet. The word of God's messenger always respected.
We will use his sword to touch the Earth. Divine messenger, do not confuse me. Divine
messenger, do not confuse me. Divine messenger, do not confuse me. Let it be one
who is confused. Change the suffering around me. Give me the blessing of the
pumpkin. So be it.

pg. 8
Esu 2
Ogundá l'awo alagbá. Iwori l'awo alupese
Ogun ti a l'ahlu pese si, Ogun kuró d'ogon ayoda
Ogun d'ogun l'owó oba, A d'ifá fún omokunrin
Dudí ita, E duro e kí esu, Esu duro e kí esu
Esu ni yo o tún tiwon se, E duró, e ki esu

Ogunda is the guesser for water drum (Barrel)


Iwori is the guesser to drum Ipese (Sacred Drum Ifa)
Ogudu Gbada is a reference to the sound of the waves
Immediate war is announced with a drum barrel Ipesé
It is no more a secret war
The war has come by the King
Divinity for the black man outside
Esu stop and greet
Esu look out for their welfares
Stand and greet Esu

pg. 9
Orunmila 1
Òrúnmìlà, ajomisanra, Agbonniregun, ibi keji Olodumare,
Elerin-ipin, Omo ope kan ti nsoro dogi dogi, Ara Ado, ara Ewi, ara Igbajo, ara Iresi, ara
Ikole, ara Igeti, ara oke Itase, Ara iwonran ibi ojumo ti nmo waiye, akoko Olokun, oro
ajo epo ma pon, Olago lagi okunrin ti nmu ara ogidan le, o ba iku ja gba omo e si le,
Odudu ti ndu ori emere, o tun ori ti ko sunwon se,
Òrúnmìlà ajiki, Òrúnmìlà ajike, Òrúnmìlà aji fi oro rere l o. Ase.

Spirit of Destiny, dew and eternal source of life, word and exultant strength, located
next to the Creator. Witness of Creation, offspring of eternal palm tree that radiates
strength. Ado native, native EWI native Igbajo, Iresi native, native Ikole, Igeti native,
native Itase Hill, Eastern Native generator sea pure mystical, is the most powerful who
gives vitality youth, who rescues children from the wrath of death. The Great Savior who
saves youth, he saves the lost, Orunmila is worth pleas in the morning, Orunmila is
worthy of praise in the morning, Orunmila is worthy of prayers for the good things in
life. So be it.

pg. 10
Orunmila 2
Orunmila, ajomisanra, ibi keji Olodumare,
Eleri Ipin, Omo ope kan ti nsoro dogi dogi,
Ara Ado, Ewi, ara Igbajo, ara Iresi, ara Ikole, ara Igeti, ara oke Itase,
Ara iwonran ibi ojumo ti nmo waiye akoko Olokun, oro ajo epo ma pon,
Olago lagi okunrin ti nmu ara ogidan le, o ba iku ja gba omo e sile,
Odudu ti ndu ori emere, o tun ori ti ko sunwon se,
Orunmila ajike, Orunmila ajike, Orunmila aji fi oro rere lo. Ase.

Spirit of fate, dew and eternal source of life, word and exultant force, which is next to
Olodumare, Witness the creation descendant palm tree spark eternal force. Ado native,
native EWI native Igbajo, Iresi native, native Ikole, Igeti native, native Itase Hill, This
native generator sea pure mystical, The most powerful youthful vitality giver, who
rescues children from the wrath of death. The great savior who saves youth, he saves
the lost, Orunmila is worth pleas in the morning, Orunmila is worthy of praise in the
morning, Orunmila is worthy of prayers for the good things in life. Ase.

Orunmila 3
Ìbà Orunmila, Elérì ìpín, Ikú dúdú àtéwó Òró tó sí gbógbó òná
Ìbà awo Akódá Ìbà awo Àsèdá

Tribute to the spirit of fate, saw the creation which avoids death The power of the word
that opens all roads Tribute to guess Akoda call (the first student Òrúnmìlà)

pg. 11
Iyami Osooronga 1
Iba eyin Iyami Osoroona, Iba eyin Iyami Osoroona, Iba eyin Iyami Osoroona
Eyin la japa jori, Eyin la ti fun joronro obantala, Ori eiye ni e gba mama kin jefun
Isinku orun won kin jefun, Isinku orun won kin jedudu
Isinku orun won kin josun, Isinku orun e pehin da
Ajogun orun e dehin lehin awa o, Ajogun orun e pehin da

I greet the Iyami Osoronga, I greet the Osoronga Iyami


I greet the Iyami Osooronga
You eating whole head
Bowel you eating honey
Tap the bird's head
and touch the head of (name of person)
Spirit of death eat efun
Spirit of death eat osun
Spirit of death, coma loin abiripolo
Glue to the back of abiripolo
Spirit of death behind (Name of person).

pg. 12
Iyami Osooronga 2
Iya mi osooringa.
Afin'jú eye.
A pa má wa a igún.
Onníwowó adó.
Orú mo l'óogun danu
Olçogbo dçudçu oro
Olçokiki orun
A jé do tutú má bi
Obinrin dúdú regi régi, eyí ti i lo nigba oja ba tu
Da'se d'epenu ti í gbe ni mi bí kalokalo
Ojiji firí
Afé gégé niyeé,
A ró igba aso má ba'le
Eléyin'jú egé, eye ní more
a-je-apa-je-orí, j'ebo-j ohun, a ti inú orooro je'fun
O we nínu omi saló saló
Ode t'apó y' oró, arinimoja t'apó yoogun
Eyin ebiti ká wo s'eyin s'oro
A ba l'ori igi iróko má ye
Oró gogoro l¡oko olóko
Oníbanté pelejá ti í bá ni ja lái fowo kan ni
Ológbo dúdú etí oja
Ese a b'irun golo gilo ,
Ají ká igboro, a rin ka igboro
Ejí ní kutu f'omi ogboro bó ju
Ti a bá pe'ri okoni, aá fi ida na'le
Iba tó tó tó

pg. 13
My mother Osoronga
The immaculate bird
She ruthlessly killing animals for vulture and consumes the shell
Owner of medicinal güiras
She provides charms and spells
Black cat at night,
She does not suffer from nausea eating raw liver
The beautiful black woman is always the last person to leave the market
She curses providing ASE and impotence while treating people like machines,
Flash shadow
The feathered bird slightly
The 200 pieces of clothing that surround and are never long enough for her
The Beautiful bird More
Eating her head via the arm, throat liver and intestines from the gallbladder
She bathes in blood like a fish
Jacket venom that brings the enchanted backpack; Medical staff that brings powerful
charms pocket
Wreck havoc cold
She that sits comfortably in the iroko tree
Fearful mystique strikingly positioned either on the farm
The unseen war fight
Black cat on the edge of the market
The cat with a long tail
The marauding village
She begins to wander the streets early in the morning
It is with great fear that the bold moves
My humble respect.

pg. 14
pg. 15
Oshun 1
Òsun mo pé ó o!
Mo pé ó sí níní owo. Mo pé ó sí níní Omo. Mo pé ó sí níní àláfià. Mo pé ó si òrò.
Kí àwa má ríjà omi o, Kí ilé má jò wá. Kí ònà má nà wá o.
Pèsè àse fún wá o. Kí àwa má ri Ogun idilé.

Oshun call you, I call you to give us money.


I call you to give us children. I call for you to give us health.
I call for you to give us a peaceful life.
Oshun, protect us so that there are no problems between us, your children.
So you always have peace in our homes.
That our objectives will not turn against us.
Give us a blessing! That there is no problem in our family.

pg. 16
Oshun 2
A tun eri eni ti o sunwon se. Alase tun se kí nla oro bomi.
Ipen obinrin a jo eni ma re. Óşún ma je mo aiye o jó le li eri.
Ala agbo ofe a bi omo mu oyin. Otiti li owó adun ba soro po. O ni ra mo ide
O ro wanwas jó wa. O o lubu ola eregede. Alede obirin sowon. Afinju obirin ti ko a ide
Óşún olu ibú ola, Olo kiki eko. Ide fi ojú ta iná Omi ro wanranwanran waran omi ro. Afi
ide si omo li owo. Ase

The witness ecstasy of a person reborn. It is once again in charge of things, she greets
the most important matter from the water. The most powerful woman can burn a
person, Osun not allow the evil of the world dancing in my head. We care without
charge, heals us, it gives the child sweet water. She is wealth. He speaks softly into the
crowd. He bought all the secrets of copper. Here comes dancing and makes her
bracelets jingled as forest stream. He is dancing with the riches of the deep underwater.
My mother has sunk something outside in the sand. The woman crowned is very
elegant in its way of handling money. Osun, owner of wealth from the depths, owner of
the countless parrot feathers. Brass Flare is present in the fire in his eyes. Murmuring
water on the stones is the Spirit River with their dancing brass jewelry jingling rings.
Only children have such coppery Osun bracelets on her arms. So be it.

pg. 17
Yemaya 1
Yemonja Olodo Obalufe Yemonja Olodo. Yemonja Olodo Obalufe Yemonja Olodo.
Didun lobe Yemonja lògerègerège. Okéré, 'mo de o Báròyé ò, Báròyé ò Okéré, ayádòó
rà, Yemoja ayádòó rà, Obalufe ayádòó rà é, Yemoja ayádòó rà è
Pàròyín o, Pàròyín o. M' Okéré me dé, Omídína. Ase.

The spirit of the river, Yemanja. Guardian of Ife, Spirit River. Yemonja
The spirit of the river, Yemonja. Guardian of Ife, Spirit River. Yemonja
The sweetness of the soup prepared by Yemonja flows smoothly.
Okere comes and brings fortune to children. Inside his word born children born within its
word children. Okere is who buys The Secret of the Magic Gourd. Yemonja buy The
Secret of the Magic Gourd, fishing mother buy The Secret of the Magic Gourd. And
exposes the riddle solves itself, and exposes the riddle solves itself. Okere arrives and
pretends a magical representation, the torrent of water that blocks the way. So be it.

pg. 18
Yemaya 2
Ayaba ti gbe ibu omi, Yemoja a so igbe di oju ona
Yemoja on je oti pagogo oju akagba
A gbo ni se oba ma kase
Yemoja a lobi iji wo´lu
A pekoro yi ilu kaa
Awoyo, Awoyo je´le je l´odo
Iya olo oyon oruba
O ni run abe osiki
Abi obo fun ni orun bi egbe isu
Okun onilaiye a san enia bi
Arugbo olokun
Fere obirin aji fon ni lara oba
Obirin pepe li gba eni gbe ilekile
Ko je dahun ni ile
Oju omi ni je ni koro

The Queen lives in deep water


Iemanja softens path surfaces
Yemonja leans over the edge of the pumpkin, taking effervescence
Wait sitting, even in the presence of a king.
Yemonja rises, it is swirl. When a tornado comes into the country;
It moves around the city
Awoyo, Yemoja eat at home and in the river
She tearful mother breasts grew a forest of private business
And it's hard as dried yam
Deep and swollen, Queen of the World, healthy as a medicine;
Elderly woman who owned the sea
Female flute, who plays for the awakening of the kings
Woman gently carries the swimmer to rest somewhere
She does not want to answer on the ground
She did it quickly on the surface of the water.

pg. 19
pg. 20
Oya 1
Oya Opéré làlàóyàn. A gbé ogbòn obì siwaju oko, O ni ìl ós ìn Oya rúmú bi eni gbé ike
oya òpèrè, 'wa gbà je, kò dé inú, Oya l'o L'Ósin, ki Olónje máa há onje rè Oya péré bi
ewé bó! Oya fúfú lèlè bí iná là l'okè Oya péré má mà dá igi l'ékùlé mi
Oya a ri iná bo ara bí aso! Bi e ba nwá Oya bí e kò bá rí
Oya ki e wá Oya de isò kòlá, nibi ti Oya gbé ndá kéwù sí enu
Ki e wá Oya de isò osùn, nibi ti Oya gbé nf ó búké si ara.
Ki e wá Oya de isò bàtá, nibi ti Oya gbé nla igó móra
Iya, iya mo ni ng ó mà je ìgbé Oya, nwon, ni kí n'ma se je igbe Oya.
Mo ní kíni kí n'wa se? Nwon ní ki n'sare sésé ki n'ún Oya l'aso
Ki n'fi àtàmpàràkò la obì n'iyàn. Oya nwon nwon fune ni idà o kò pa eran
Iya sáàn nwon fun e ni idà o kò bé rí. O ní kini o yio fi idàdídà se!.
Oya a-riná bora bí aso, Efùfù lèlè ti ndá igi lókèlokè
Ojèlóìké a-ní-iyì l'ójè. Iya mi pòrò bí omú sé l'aíyá
Òjè l'o ni oketè Se. Oya l'ó ni Egun. Ase..

Complete Wind Spirit, walking with full confidence and importance. She gets a basket of
kola nuts to offer it to her husband.
Owner of the place of worship. Oya deep in thought, shaping out the concepts. Full spirit
of the wind, come and receive their offerings without offense.
Oya is the owner of the place of worship, may those who have prepared begin to serve
good food. Oya causes the leaves tremble! Oya, strong wind that gave birth to the fire
as he crossed the mountain. Wind Spirit, please do not lie tree in my backyard.
Wind Spirit, we saw the fire covering her body as a canvas. If you are looking to find
wind spirit Oya. Perhaps the you find in the place of the kola nut where Oya enjoys
pulling small pieces in his mouth. Perhaps you find Oya Ranked Carpenter, where he
likes to rub her body as a red energy. You may find Oya in the position of the drums,
which moves his body in a frenzied dance. Mother, Mother, I always answer the call
Oya, they warned me not to answer his call. Where I can go, what I can do? I was told
that I should offer small pieces of fabric Oya. They said I should offer kola nut and
pounded yam ancestor. He was given a sword Oya but she does not usually kill animals.
A sword must submit to the mother that is not used to kill animals. They should give a
sword used to behead people. The spirit of fire used fire to cover his body, like a fabric.
Strong wind hits under the trees of the forest. The ancestors deserve good treatment
and respect for ancestral community members. Mother, pour into me from her breasts,
Mother of the world. Devout ancestor, owner bush rat, Oya is the owner of the Egun
society. So be it.

pg. 21
Oya 2
Ajalaiyé, ajalorin, Funeral mi ira. IBA Oya AJALAIYE AJALORUN, FUN MI Gbogbo IRE
IBA Yansan. Ajalaiye, ajalorun wi Wini Bueno ma Yansan
ASE!

The winds of the Earth and the sky give me good luck. I am the son of the nine. The
winds of the Earth and the sky give me good luck. I applaud the spirit of wind. The
winds of the Earth and the sky are wonderful. She will always be the mother of nine,
ASE!

Oya 3
Ajalaiye, ajal òrun, fun mi ire. Iba Yansan. Ajalaiye, ajal òrun, fun mi alafia. Iba Oya.
Ajalaiye, Ajal òrun winiwini. Mbe mbe ma Yansan. Asé.

The winds of the Earth and the sky bring me good fortune. I commend the mother
of the nine main ancestors. The winds of the Earth and the sky bring me good health. I
commend Oya. The winds of the Earth and the sky are wonderful.
There is the mother of the nine main ancestors. Ase.

Oya 4
Obinrin tó torí ogun dá irun agbón sí. Efufulele ti í dá igi l'óke A sú ojo má ro
Orisa merindinlogún ti mbe l'ódo Sangó, ni bí i ká sán apá, ní bí i ká yan, ni oya fi gba
oko l'owo o won Oya a r'iná bo'ra bi aso

The woman who grows a beard because of the war. The strong wind tearing trees from
the top. She threatens to rain and cloudy weather never rains. Out of the 16
goddesses rivals have competed for Sango as a husband; Oya won Sango as a husband
by virtue of the charm of his personality, his grace and his graceful movement. Oya is
covered with fire, as if it were a dress.

pg. 22
pg. 23
Orisa Aje 1
Oro tere awo inu igbo
adifa fun aje omo olusikiti sikiti
nijo ti un lo re fi ile ejiogbe se ibudo
woni o kara nile ebo ni kio wa se,o gbebo nibe o rubo
aje mo de o niso,o ba fo so sile awo,aje mo de oniso
o ba mo fiso si ile mi,aje oniso

Gold tere Awo Ifa inu Igbo guessed for wealth daughter Olusikiti Sikiti
the day he was to make the house a purple Ejiogbe
are asked to make ebo, she turned
Aje (wealth) has arrived, the shop owner and the earth, please make the dwelling of
awo, look for me to make my house a permanent address.

pg. 24
Orisa Aje 2
Aje iwo lobi Ogun ilu
Aje iwo lobi Olufa
Aje iwo lobi onipasan owere
Oyale asin win oso asin win dolowo
Oyale asi were oso asi were di aniyan-pataki
Aje pe le o a kin lOrisas
Agede ni wo Ajenje lotu Ife ti o fi njo koo ti ni
Aje dakun wa jo koo temi ki o ma se kuro lodo mi

Aje gave birth to the war the city


Aje gave light to boa
Aje gave light to Onipasan Owere
It was a mad house and made him rich
It was a mad house and made him a character
Aje, I salute you, the last one came between Orisas
Aje, eat banana fruit des Ifa for one
Aje please come to me, stay with me and not let me.

Orisa Aje 3
Ogunda funfun
Orun e funfun
Adifa fun aje ti I somo Olokun
Atewe atagba are aje la n sa kiri

Ogunda is immaculate
While its sky is white
Cast divination for Aje the offspring of Olokun.
All the sundry are searching for money.

pg. 25
Orisaoko
Òrìşà Oko baba Iroko
Imorisa baba igbo ewele
E ku odun oni o, Bodun ba dundun iroko
A mawo funfun bowaye
Aboyon ilu abimo yee o
Agan ti o bi o towo e bosun o
Gbogbo wa lao fehin
Pomo ire, Guluaso ninu mi
Abiamo feehin so o Guluaso
Iroko Imorisa e maa se un
Imo pele o o, Igi Agon yee o,
Imo pele o, Igi ire o

pg. 26
Òrìşàoko living in the bush with Iroko
I give a party for you today
The festival brings happiness
The festival brings wealth
Severities birth bring happiness
People will be working in children
All have happiness
The bellies of women will enlarge with raising
Thanks Orìşaoko
Thanks Orìşaoko
Orìşaoko brings blessing to me.

Orisha Oko 2
Eléní à te ká.
O rí ajé, O pá ni l pá ika.
Òrìsà Oko, a tó gbangba sùn nínú oyé.
A rí owó èyó se èsó.
Orí ògún èyó sensen.
O rí ìbon gbé re ojú ogun.
Òrìsà ti ó torí.
Akàsù iyán,
O fun won ní ogún omo.
O torí àgbébò adie,
O fún ení nwá aya,
Ní ogórun aya.
O tú fún en i nwá oko,
Ní ogórun oko.
Òrìsà oko ò ò ò
Baba o, Baba o.
Ení kúrú,
O ntiro.
Ení gùn,
O nbèrè.
pg. 27
Bèrè owó,
Bèrè olá ní òdò mi o,
Iwo lorí iyán.
Ti o njó bèmbé,
Iwo lo tún rí iyán,
Ti o nkan sáárá.
Òrìsà oko gulutu nlé.
Igbá funfun báláuuú.
Alágbára tí nlo fòse.
Òrìsà Oko gbè mi o,
Òrìsà oko tu mi o,
Jé ng ní nínú àse re o.

One that has a trail of kindness,


I saw the witch and killed her in the worst possible way.
Ò Orisha Oko, who can sleep in the cold.
He who uses shells to decorate.
He who see the war rejoices.
He who has a rifle for use in war.
The Orisha, which due a large portion of iván,
He gave his devout twenty children.
He who by a large chicken,
He gave to that woman he wanted to marry.
One hundred offers of marriage.
And he gave to that man you were looking husband.
One hundred offers of marriage. O Orisha Oko!
The father! The father! Who's down put up on tiptoe to get louder.
Who is high ducked. Bring on the money. Bring on prosperity for me.
You saw that the Iyan and began to dance bembé.
You saw that the Iyan and praised him.
Orisha Oko, the great on earth. You are the white gourd.
Powerful using afoxé. Orisha Oko, support me!
Orisha Oko, support me! Have I have part of his ax.

pg. 28
Ogun 1
Ogun awo. Olumaki, alase a juba
Ogun ni jo ti ma lana lati ode
Ogun onaire, onile kangun-dangun ode orun egbe l ehin
pa san bo pon ao lana to remove
imo kimo bora egbe lehin a nle a benge ologbe. Ase

Spirit Mystery of iron, the head of the force


Iron spirit dancing outside to open the way
iron spirit, owner of good fortune, landlord of man in heaven helps those who travel
removing obstacles from our path
wisdom of the warrior spirit, guide us through our spiritual journey with strength
So be it.

pg. 29
Ogun 2
K'o se kére o. Kó se kére, e gbóhùn mi o. Ibà o. Ibà èsí ng bá jú o? Ibà èsí ng bá hàn kó
jú? Ibà Ògún Onírè Odo. Awénné, Eji Olúmakin o Ògún l'ó sá mì ní kéké ojú npélenpéle,
Ògún l'o sá bù mí ní abaja èké. Ògún náà l'ó d'atoto ìdí mí tí mo fí nsoge. Òrìşà o
I'yo bá wi p'erí t'Ògún ò sí, A f''erun hó'su je. Ooooo

And a perfect silence, There is perfect silence and I listen.


my tribute, Who do I give tribute? Who do I give homage first? I give tribute to you
Ògún Onírè Odo. AWENNE, or Olúmakin Eji Ògún ago Pele mark (three vertical lines) on
my face. Ògún does abaja mark (three horizontal lines) in my cheeks.
Ògún cut the foreskin of my penis that I use to deter. The God Who looks down on
Ògún. You use your mouth to peel yams cooked.

pg. 30
pg. 31
Ochosi 1
Ìbà Ochosi. Ìbà olog'arare, Ìbà Onibebe. Ìbà Osolikere.
Ode ata matase, Agbani nijo to buru, Oni ode gan fi di ja, A juba.
Asé.

I praise the Spirit of the Tracker. I praise the love of it. I praise the owner of the river
bank. I praise the forest wizard. Hunter never strange, Wise spirit that offers many
blessings, The parrot owner who guides me overcome fear,
I salute him. So be it.

Ochosi 2
Oshoosi 're 're-ooo (Oshoosi is great in good fortune)
Odede (owner of the ownside and open frontier places),
Ode de (The hunter arrives).
Oshoosi Odede (Oshoosi arrives standing tall).
Oshoosi ode mata (Oshoosi do not shoot).
Oshoosi Ode mata sele (Oshoosi,the shooting hunter does not miss).
Ode ata matase Onibebe (The owner of the riverbank where he hunts and associates
with Oshun and Erinle). Osholokere (The forest magician or wizard)
Oluwo igbo (The king of the forest) Olog'arare (Master of Himself)
Oshoosi Alaketu (Oshoosi,the king of Ketu (Benin) Africa, and king of the Ketu "nation"
in Brasil) "Enibumbu, Olodo-Odo, Olomi-omi lbase..." "I praise all you pools (or "roads,"
"types," or "caminos" or "ona" of Oshoosi) and all of your rivers!,All you waters, I
salute!" (see section on Abatan, below). Ode olorore (Hunter of abundance).

pg. 32
pg. 33
Sango 1
Alaafin, ekun bu, a sa Eleyinju ogunna
Olukoso lalu A ri igba ota, segun, Eyi ti o fi alapa segun ota re 4
Kabiyesi o. Ase

Alaafin, (the king of Oyo) roars like a leopard and people flee
He whose eyes glow like coal. Olukoso, the famous city
Which uses hundreds of rounds for victory in war
One who uses remains of broken walls to defeat their enemies
We honor you. So be it.

Sango 2
Ogbe níí bo Àrìrà mólè. Àrìrà níí bolè. Níí bogi oko. Díá fún Olúkòso-làlú. Jénrólá, omo
arígba-ota ségun. Igbà ti nbe láàrin òtá.

Ogbe is covering the thunder storm. Lightning is the one that covers the Earth.
And covers trees from the farm. You guessed Ifa for Sàngó.
Sàngó, which used 200 pebbles to overcome adversaries.
When I was in the midst of enemies.

Sango 3
Şàngó. Kábíyèsí şàngó káwó silé, olúfiná o lù ekò, ó lù sìn ó saan
a ká tàn ilé, eepà şàngó oşé eere ré, ada şe.

Greetings to King Sango, you send in the house, who holds the candle, the effect hits,
the hits to master, loud, who finishes in the house shining, greetings (welcome) Sango,
his stick is short and idol acting sword.

pg. 34
Sango 4
Oko ibeji eletimo, oju eri eri o la orun garara. O sa ogiri eke nigbeigbe Egun toto bitan li
awa yi ofo fun.
Omi lei eba ina li arin Orun, Olowo mi edun kan soso li o fi pa enia mefa,
Ori Ose li o gun lo, afi enia ti Soponnon eleran ekun to o gbopa.
Ekun Baba timi, Orun funfun bi aje.,
Oni laba jinijini ala a li ase atata bi okunrin a dugbe ekun oke.,
Agbangba li oju agada ina wo ile eke.,
Shere Ajase Ose Orobondo.
Ki ñ oju bo orule ki o duro iná wonu ekun, nitori ayibamo e je ki awa jo se. .
Oba tete li o ale bi osu pa - eni, pa - eni, ni li ale. Ase.

Father and guardian of the Ibeyis. Love of knowledge and courage. Intelligent Eye,
brash and ruthless warrior. You., Is crossing the heavens to fight the sea to sail Olorun.
Father of musical sounds. Òrìsà dance and Bembe. Fire burning souls. Owner throne,
the pylon and mortar. The watering his fire across the sky. Evil spirit that destroys with
fire, stone and thunder. The Ose riding on his head and launched as the powerful
spotted in pursuit of their enemies leopard. Leopard Father, head of Ede. White and
purple sky, a sign of spiritual wealth. Pattern of thunder and lightning. Owner power.
Tireless, relentless and indestructible warrior. Ose victorious. Cutting knife edge
adversity and obstacles. The leading fire on his head. Orisa that fell to Earth through the
beam sent by Olorun to impose justice against the enemies of creation. Flare Eye of the
Leopard. Sky fire that devours evil. King fast on the sky as the sun in the afternoon. I
Orisa powerful entertainment, admire you, respect you and implore you. So be it.

pg. 35
pg. 36
Olokun 1
Awa ntoro ilosiwaju lowo Olokun
Obirin takun takun ti ngbe inu Omi

We seek prosperity from Olokun


Our bountiful lady of the Ocean
pg. 37
Olokun 2
Agbe ni igbe're k' Olókun Seniade, Aluko ni igbe're k'olosa ibikeji odo.
Ogbo odidere ni igbe're k' Oniwo. Omo at'Orun gbe gbe Aje ka 'ri w'aiye.
Olugbe-rere ko, Olugbe-rere ko, Olugbe-rere ko,Gbe rere ko ni Olu-gbe-rere. Ase.

The bird is Agbe taking Seniade good fortune, the Spirit of the Ocean. It is the aluko
bird is the good fortune that takes the spirit of the Albufera which is the Spirit of the
Ocean assistant. The parrot is the good fortune leads him to the head of Iwo. The child
who brought a load of good things from heaven to Earth. The largest is the one that
gives good things, the greatest is the one who gives good things, the greatest is the one
who gives good things. Give me great things. So be it.

Olokun 3
Malókun bu owo wa, jími tètè núwà o. Oba omí ju Oba òkè.
Malókun ni mo bá dá jími tètè núwà o. Oba omi ju Oba òkè. Ase.

Spirit of the Ocean, please give me abundance so that I may become wealthy
quickly. The Spirit of the Ocean is greater than the chief of the land.
It is the Spirit of the Ocean that I turn to for abundance. The Spirit of the Ocean is
greater than the chief of the land.

Olokun 4
Iba Olokun fe mi lo're Iba Olokun omo re wa se fun oyi o
Olokun nu ni o si o ki e lu re ye toray. B'omi ta 'afi B'emi ta'afi Olokun ni 'ka le
Mo juba Ase.

Praised the spirit of the vast ocean. Praise the Spirit of the Ocean is beyond
comprehension. Ocean Spirit, I adore you as much as there is water in the sea
Let there be peace in the ocean. Let there be peace in my soul. Spirit of the Ocean, The
Eternal. So I give it my respect.

pg. 38
Obatala 1
Obanla o rin n'eru ojikutu s'eru
Oba n'ile Ifon alabalase oba patapatan'ile iranje
O yo kelekele o ta mi l'ore. O gba a giri l'owo osika.
O fi l'emi asoto l'owo. Oba igbo oluwaiye re e o ke bi owu la
O yi 'ala Osun l'ala o fi koko ala rumo Oba igbo. Ase

Owner of the white cloth that does not fear the arrival of death
Heavenly Father always rules for all generations
Gently dissolves loads of my friends
Exposes the mystery of plenty
So I became as white cloth
White fabric protector, I salute
Father of the Sacred Grove
Thus it

pg. 39
Obatala 2
Iba Òrìşà Nlá osere igbo, iku ike oro
Ababa je'gbin, a s'omo nike agbara, a wuwo bi erin, Oba pata pata ti nba won gb' ode
iranje. Ase.

Respect the spirit of the White Light, the messenger who brings goodness to the forest
and power overcomes death.
Immortal father who eats snails, the oldest son, who brought the mystery of the
mystical vision, head of all things that exist in the world. So it

Obatala 3
A dake sirisiri da eni li ejo. Oba bi ojo gbogbo bi odun
Ala, ala. Niki, niki omi panpe ode orun
O duro lehin oso tito, Oro oko abuke
Osagiyan jagun o fi irungbon se pepe enu, A ji igba asa
Ti te opa osoro, Ori sa Olu Ifon
Lasiko fun ni li ala mun mi ala mu so ko
O se ohun gbogbo ni fun fun ni funfun. Pirlodi aka ti oke
Ajaguna wa gba mi, O ajaguna. Ti nte oje. Ase.

Spirit, Mighty King of Ejigbo. Silence at trial, judge calm.


The king whose day becomes a party, owner of the bright white cloth.
Owner of the chain of the court, he is placed behind the people who tell the truth.
Producer Empire warrior Osagiyan a stylish beard.
He wakes to create 200 customs to civilize,
King of iFon.
Osa NLA gives me a white cloth off my property.
White spirit that makes things. High as a barn, high as a hill.
I delivered Ajaguna. The king leaning on a cane white metal. So be it.

pg. 40
Olodumare
Ìbà Olodumare, Oba Akiji ajigbe. Ogege Agbakiyegun. Okitibiri Oba ti nap ojo ike da.
Atere k'aiye, Awusikatu, Oba a joko birikikale, Alaburkuke Ajimukutuwe, Ogiribajigbo,
Oba ti o fi imole se aso bora, Oludare ati Oluforigi, Adimula, Olofin aiye ati Orun. A fun
wen ake wen, Owenwen ake bi ala.
Alate ajipa Olofa oro Oba a dake dajo.
Awosu sekan. Oba ajuwape alaba alase Olri ahun gbogbo.
Araba nla ti nmi igbo kijikiji.
Oyigiyigi Oba akiku ati Oba nigbo, Oba atenile forigbrji, Awanmaridi Olugbhun mimo to
Orun. Ela funfun o Oba toto bi aro, pamupamu digijigi ekun awon aseke.Awimayehun
Olu ipa Oba Airi. Arinu rode Olumoran okan. Awobo gbogbogbo ti yo omo re. Ninu ogin
aiye ati Orun. Iba to-to-to Ase.

pg. 41
We respect the womb of creation; the monarch of the first messengers; senior father of
the ancestors; the ruler who never faces death; the spirit of the Earth. The praise praise
your name.
You. Modeling light to create all things, the mystery of nature owner, whose words are
law and the creation, owner of the mysteries of the unknown. The source of all heads of
creation.
Divine light that always will be praised in the sacred grove.
The king of all forms of consciousness on Earth. First among the immortals of heaven.
The Spirit of demonstrations and king of all kings.
. You are the very creation; this is his work, and therefore receives the praises of their
children. Is he who gives you blessings in heaven and on earth.
Heavenly Father, we offer our full respect, so be it.

pg. 42
Stay blessed… Stay Clean.

Alafia…

pg. 43

You might also like