You are on page 1of 1

Ogo F’Olorun Loke key E Mimo Mimo key D

s s m m f m r:-- d d d d:-- d d:--


m m d d r d t:-- d d d d:-- l s
Chorus: Ogo f’olorun Loke, Ogo Chorus: - twice
(twice) Mimo Mimo
Mimo ni O!
For each line
ssmmfmrf msmss
1. Ogo ni f’olorun baba mmdd
Laye alafia fe da mmrd
To nse fe olorun baba Adani waye Oba oke
Afi bukun f’oru ko re mimo ni O
A dupe aforibale
F’olorun kan to da awa
1. Apa nla to so aiyero
2. Ogo fun Jesu omo olorun Mimo ni O
Kristi, Jesu awa sope Orun ataye n yin O logo
Odo agutan omo baba Mimo ni O
To nko gbogbo ese eda
Iwo nikan lo je mimo 2. Ibukun ni fe ni
Kristi eni to gaju lo To n bowa
Olorun aye atorun Mimo ni O
Gbogbo eda yio ma yin O L’oruko olorun alaye

3. Ewa kayin olorun emi


To ba wa gbe titi d’oni
Olorun kan pelu baba
Ninu ogo Kristi Jesu
Meta Lokan awa sope
Afe O, awa ma sin O
Titi aye gbogbo eda
Yio ma korin Alleluia
Hossana f’olorun orun O

You might also like