You are on page 1of 16

YORUBA LANGAUGE SCHEME OF WORK

BASIC 7 SAA KEJI

OSE AKOONU ISE

1. Agbeyewo Awon eko Ise Taamu To Koja


2. Silebu ati ihun re.
3. Awon ohun ti a le ri ninu ile iwe
4. Awon ise abinibi tabi isenbaye.
5. Ayoka kukuru(Ewi)
6. Isori oro Yoruba.
7. Isinmi ranpe(Mid term break)
8. Oro oruko: oruko awon eranko.
9. Awon orin keekeekee ati ere idaraya omode.
10. ATUNYEWO si awon koko ise fun saa yii.
11. IDANWO.

WEEK ONE (Ò̩ SÈ̩ KIN-IN-NI)


Agbeyewo Awon eko Ise Taamu To Koja
WEEK TWO (Ò̩ SÈ̩ KEJÌ)
TOPIC: SILEBU ATI IHUN RE.
Silebu ni ege oro ti o kere julo ti a le fi ohun gbejade leekan soso.
Silebu ni a maa n lo lati gba ami ohun(tone mark) ninu ede Yoruba. Iye
silebu ti o ba wa ninu oro kan ni iye ami ohun ti iru oro bee yoo ni.
(Syllable is the unit of pronounciation consisting of a vowel alone or a
vowel with one or more consonants)
Awon oro oni-silebu kan(KF)(monosyllabic words)
1.ba=to meet
2.ja= to fight
3.je= to eat
4.ka=to count
5.fa= to draw
6.sun=to sleep
7.dan=to shine
8.rin=to walk
9.fun=to give or to squeeze
10.yan=to roast
Awon oro oni-silebu meji(words with two syllables)
1.ada (a/da)=cutlass
2.owo(o/wo)=money
3.ona(o/na)=road
4.ewe(e/we)=leaf
5.baba(ba/ba)=father
6.dodo(do/do)=fried plantain
7.sibi(si/bi)=spoon
8.ewa(e/wa)=beans
9.keke(ke/ke)=bicycle
10.omi(o/mi)=water
Awon oro oni-silebu meta(words with three syllables)
1.obinrin(o/bin/rin)=female
2.adaba(a/da/ba)=dove
3.egungun(e/gun/gun)=bone
4.sokoto(so/ko/to)=trouser
5.okuta(o/ku/ta)=stone
6.ijapa(i/ja/pa)=tortoise
7.akisa(a/ki/sa)=rags
8.egusi(e/gu/si)=melon
9.oluko(o/lu/ko)=teacher
10.tabili(ta/bi/li)=table
Awon oro oni-silebu merin(words with four syllables)
1.gbalegbale(gba/le/gba/le)=sweeper
2.kabiyesi(ka/bi/ye/si)=salutation to king
3.labalaba(la/ba/la/ba)=butterfly
4.olopaa(o/lo/pa/a)=policeman
5.peteesi(pe/te/e/si)=storey house
Awon oro oni-silebu marun-un (words with five syllables)
1.afenifere(a/fe/ni/fe/re)=well-wisher
2.agadagodo(a/ga/da/go/do)=padlock
3.abogibope(a/bo/gi/bo/pe)=an idolater
4.adanilekun(a/da/ni/le/kun)=a prohibitor
5.alaafia(a/la/a/fi/a)=peace
Igbelewon
Pin awon oro isale wonyi si silebu ti o ye.(split these words into their
syllables)
1.akekoo=
2.ijakadi=
3.ade=
4.osan=
5.osupa=
Ise Amurele
Silebu meloo ni o wa ninu awon oro wonyi(How many syllables are
there in following words)
1.olopaa(policeman)=
2.maluu(cow)=
3.Dare(name)=
4.agbalagba(aged people)=
5.labalaba(butterfly)=

Ò̩ SÈ̩ KÉ̩ TÁ (WEEK THREE)


TOPIC: AWON OHUN TI A LE RI NINU ILE IWE(THINGS THAT
CAN BE FOUND INSIDE AND OUTSIDE SCHOOL
ENVIRONMENT)
1. O̩ gbà ilé ìwé = School compound
E̩ fun- ìkò̩ wé/s̩ ó̩ ò̩ kì = Chalk
Yàrá ìkò̩ wé = Class room
Ò̩ gá ilé ìwé = Principal
Olùko̩ = Teacher
Aké̩ kò̩ ó̩ = Student
Gege = pen
Iwe = book
Tabili =table
Apo iwe =school bag
Faanu =fan
Ina monamona =electricity
Patako ikowe =chalkbaord
Aga =chair
Ori papa = field
Ile-iwosan = Health bay
2. DIE NINU AWORAN AWON NNKAN TI A LE RI NI ÀYÍKÁ
ILÉ- ÌWÉ.

Ìwé ( Book) Bírò / Gègé (pen)

Pátákó- ìkò̩ wé ( chalkboard) Bó̩ ò̩ lù (Ball)

Bó̩ ò̩ sì ilé-ìwé (school bus) Tábìlì (Table)


Àga(chair) Aago (clock)

Rúlà (Ruler) Agogo (bell)

IS̩ É̩ S̩ ÍS̩ E ( WORK TO DO)

Write the Yoruba names of the following objects

(i) Tree (ii) school bus (iii) book (iv) school bag(v) electricity

Iwe itokasi:Agboola Ayandiran(2003:27-30)Essentials of


Yoruba L2.Rasmed publications limited Lagos.

Ò̩ S̩ E̩ KÉ̩ RIN (WEEK FOUR)


TOPIC:AWON ISE ABINIBI TABI ISENBAYE(Yoruba traditional
occupations

YORUBA ENGLISH NAMES OF


PROFESSIONALS
ISE ISENBAYE TRADITIONAL
OCCUPATIONS
Ise Àgbè̩ Farming Àgbè̩

Ise O̩ de̩ Hunting O̩ de̩ (hunter)

Ise ilu lilu Druming Ayan/onilu(drummer)

Ise awo Divination Awo(diviner)

Ise Onísègùn Herbalism Onísègùn(herbalist)

Ise Onkola Surgery Onkola(surgeon)

Ise Onidiri Hairdressing Onidiri(hairdresser)

Ise Onigbajamo Barbering Onigbajamo(barber)

Ise Ako̩ pe̩ Palm wine tapping Ako̩ pe̩ (palm wine
tapper)

Ise Gbe̩ nagbe̩ na Carpentery Gbe̩ nagbe̩ na(carpenter

Ise O̩ mo̩ le Bricklaying O̩ mo̩ le(bricklayer)

Ise Alapata Butchering Alapata(butcher)

Ise Ahunso̩ Weaver Ahunso̩ (weaver)

Owo sise Trading Onisowo(trader)

Ise Alagbe̩ de̩ Blacksmithing Alagbe̩ de̩ (Blacksmith)

Ise aro dida Tie and dye Alaro(dyer)

Ise oko wiwa Driving Awako(driver)

Ise amokoko Pottering Amokoko(potter)


ISE ILU LILU(DRUMMING)

Àgbè̩ ( Farmer)

IS̩ É̩ S̩ ÍS̩ E (WOOK TO DO)

(1) What are the following words in Yoruba ?

(i) herbalist (ii) carpenter (iii) hunter (iv) farmer (v) driver
ISE ASETILEWA

(2) Daruko ise isenbaye marun-un ti o mo.

IWE ITOKASI:Oluyemi Aya Adebowale ati awon akegbe re(2014:79-


83)Eko ede Yoruba titun iwe kin-in-ni.Ibadan,University P.L.C.
Ò̩ SÈ̩ KÁRÙN ÚN
TOPIC: AYOKA KUKURU
EWI APILEKO – MURA SI ISE (lati owo J.F. Odunjo)

Ise ni oogun ise

Mura si ise ore mi

Ise la fi i deni giga

Bi a ko ba reni fehinti

Bi ole laa ri

Bi a ko ba reni gbekele

A tera mo ise eni

Iya re le lowo lowo

Baba re si le lesin leekan

Bi o ba gboju le won

O te tan ni mo so fun o

Ohun ti a ko ba jiya fun

Se ki i le tojo

Ohun ti a ba fara sise fun

Ni i pe lowo eni

Apa lara, igunpa niye kan

Bi aye n fe o loni

Bi o ba lowo lowo

Won a ma fe o lola
Tabi bi o wa nipo atata

Aye a ye o si terin terin

Je ki o deni n raago

Ki o ri bi aye ti n yinmu si o

Eko si tun n soni doga

Mura ki o ko o daradara,

Bi o ri opo eniyan ti won n feko serin rin

Sora ki o maa fara we won,

Iya n bo fomo ti ko gbon

Ekun n be fomo ti n sa kiri

Ma fowuro sere ore mi

Mura si ise ojo n lo

Igbelewon

1. Se alaye gbolohun yii bi o ti ye o si ‘Ise ni oogun ise’

2. Ki ni itumo oro yii ‘raago’?

3. Ipenija wo ni o ri gba ninu ewi yii?

Ise Amurele

1.Ta ni o ko ewi ‘mura si ise ore mi’?

2.Kini oogun ise?

Ò̩ SÈ̩ KE̩ FA (WEEK SIX)


TOPIC: ISORI ORO YORUBA
ISORI-ORO NINU GBOLOHUN

Isori oro ni owo ti a pin awon oro inu ede kan si. Opolopo
akitiyan ni awon onimo girama Yoruba ode-oni ti se lati pin
awon oro inu gbolohun si isori. Isori oro mejo ni a ni ninu ede
Yoruba lowolowo bayii. Awon naa ni;

(i) Oro-oruko ( Noun)

(ii) Oro-aropo oruko (pronouns)

(iii) Oro-ise (verb)

(iv) Oro-aponle (Adverb)

(v) Oro-apejuwe ( Adjective)

(vi) Oro-atokun (Preposition)

(vii) Oro-asopo ( Conjunction)

(viii)Oro aropo afarajoruko(pronominals)

Oro oruko.

Oro oruko ni oro ti o le duro bi oruko eniyan,eranko,ibikan,ohun


ti o lemi,ohun ti ko lemi,ohun ti a foju ri,ohun ti a ko le foju
ri,ohun ti a le ka,ohun ti a ko le ka.Gbogbo ohun ti a ba ti le pe
ni oruko ni a n pe ni oro oruko.Bi apeere;Bola,Kola,Adewale,
aja,ewure,Eko,Osogbo,aga, tabili,okuta,ategun abbl.
Oro-Ise

Oro-ise ni oro ti o n fi isele inu gbolohun han. O je opomulero fun


gbolohun ede Yoruba. O maa n fun gbolohun ni itumo̩ . Bi apeere: lo, sun,
sare, jeun,se, wa, ri, han, ropo, duro, jo, rerin-in, dide, korin, sunkun, wo,
ro, ka, pade, to, to, abbl.
Oro-Aponle

Oro ti a fi n pon oro-ise tabi apola-ise ninu gbolohun. Bi apeere: kiakia,


foo, werewere, taarata, fee, gbangba, regi, nini, booli, jaburata, rekete,
abbl.

Oro Apejuwe

Isori oro ti a fin se apejuwe ohun tabi eni kan. Bi apeere: pupa,
fuye, dudu, funfun, tobi, nla, kekere, kukuru, giga, sisanra, titin-in-ni,
pipon, dide, abbl.

Oro-Atokun

Oro ti o n fi ibasepo laarin awon akopa ninu gbolohun han. Bi


apeere: si, ni, fi ati ti.

Oro aropo oruko.

Eyi ni awon oro ti a n lo dipo oro oruko ninu gbolohun.Bi


apeere;mo,o,a,e,won abbl.

Oro asopo.

Eyi ni awon oro ti a fi n so oro tabi gbolohun meji po.Bi


apeere;ati,sugbon,tabi,abi,amo abbl

Oro aropo afarajoruko.

Eyi ni awon oro ti o fi ara jo oro oruko.Mefa pere ni won, awon


naa niyi;emi,iwo,oun,awa,eyin & awon.
IGBELEWON

Daruko awon isori oro to wa ninu ede Yoruba.

Ise Amurele

Fala si awon oro oruko ti o wa ninu awon gbolohun isale yii.

1.Olu je dodo.

2.Bayo na aburo re.


3.Ojo wo ile.

4.Ade de ade.

5.Mo je eba.

Ò̩ SÈ̩ KÉJE (WEEK SEVEN)


ISINMI RANPE(MID TERM BREAK)
Ò̩ SÈ̩ KÉ̩ JO̩ (WEEK EIGHT)

TOPIC: ORUKO AWON ERANKO

ORISI ERANKO TI O WA

1. Eranko ile (domestic animal) Awon wonyi ni eranko ti won n gbe


ile ti won ki n dede pani lara bi ko ba nidi. Apeere iru awon eranko
bee ni ologbo, aja, ekute, obo, ewure abbl.

Ologbo Maluu Aja

Ewure Elede

2. Eranko igbo (wild animal): Awon wonyi ni eranko ti won n gbe


inu igbo paapa inu igbo kijikiji ti won si le se eniyan ni jamba.
Apeere iru awon eranko bee ni ejo, kiniun, erin, efon, elede igan,
ikooko, kolokolo, inaki, ijimere, abbl.
Inaki Erin Kiniun

Amotekun Agunfon Egbin

3. Eranko – omi(Aquatic animals): Awon eranko kan wa ti won n


gbe inu omi. Apeere iru awon eranko bee ni eja, oni, ijapa inu omi,
erinmi, akan,ede abbl.

Eja Oni Akan

Erinmi Irere(turtle) Ede

4.Eye ile(domestic birds).

Eyi awon eye ti o n gbe inu ile pelu awon eniyan,won ki pani lara,bee ni

Je ounje fun eniyan.Bi apeere;adiye,pepeye,tolotolo,eyele,okin abbl.


Adiye Tolotolo Okin

IGBELEWON

Daruko (a)Eranko igbo marun-un (b)Eye ile marun-un (c)


Eranko omi marun-un
ISE AMURELE

Ya aworan eranko marun-un.


Ò̩ SÈ̩ KÉ̩ SÀN ÁN (WEEK NINE)
TOPIC: AWON ORIN KEEKEEKEE ATI ERE IDARAYA
OMODE(Children’s Songs and plays)

ORIN O̩ MO̩ DE (Children song)

Ojò ń rò̩ (it is raining) It is raining

S̩ ere ninu ile Play inside the house

Ma wo̩ ‘nu òjò Don’t enter rain

Kí as̩ o̩ re̩ So that your cloth

Ma baa tutu Would not wet

Ki otutu So that cold

Ma ba mu o̩ o̩ Would not catch you.

Bata re̩ a dun ko! Ko!! Ka!!!


Bata re̩ a dun ko! Ko!! Ka!!!
Bi o ba kawe re̩ ,

Bata re̩ a dun ko! Ko!! Ka!!!


ERE IDARAYA OMODE
(1) Lile Ckun mcran 2. Ta lo wa nu [va nqz
Eve M23 [m[ kekere kan ni
Lile O ko ri b[vo Xe ki n wa woo,
Ma wa woo,
Eve M12 8w[ lo pqz abbl.
Lile O k[run b[va 3. Bojuboju o
Eve M12 oloro n b[
Lile O fc l[ xe ki n xi abbl
Eve M12 abbl.
*velew[n : Ki aw[n ak1k-= ko orin erem[de meji.
Ise amurele.
Eko wo ni a le ri ko ninu orin‘ojo n ro sere ninu ile’?

Ò̩ SÈ̩ KÉ̩ WÀÁ (WEEK TEN)

ATUNYEWO AWON KOKO ISE TAAMU YII ( Revision)

Ò̩ SÈ̩ KÓ̩ kànlàá (WEEK ELEVEN)

IDANWO (Examination)

You might also like