You are on page 1of 4

CK{ ìîô

Z*V{RZN MOSE ATI IKU AARONI


CSC AK{SORI: “OLUWA si s[ fun Mose ati Aaroni pe, “Nitori t7 2yin k0 vz Mi v=, lati
ya Mi s7 m7m- loju aw[n [m[ Isracli, nitori nqz 2yin ki y90 m5 ij[ aw[n eniyan y7 l[ si
ilc nqz ti Mo fi fun w[n” <Numeri Äî:ìÄ>.
IBI KIKA: Numeri ìò:ì]Äò
Aini suuru Isracli pclu Mose ati {l[run xe okunfa oniruuru ajalu. {p[ iva ni o maa n
fa ijiya ti o xe3 ycra fun ti o si maa n fi w[n le aw[n [ta l[w[. Lati inu ibi kika wa, a ri
iwa ive]aye tabi imunibinu aw[n eniyan w[nyi, eyi ti o mu ki Mose vave ara rc ti o si
fi ibinu s[r[ si aw[n eniyan {l[run <Orin Dafidi ìîÆ:ÅÅ>. O lu apata naa dipo ki o ba a
s[r[ lati mu omi jade gcgc bi {l[run ti pa q ni axc. Bi o tilc jc pe omi tu jade latinu
apata naa, xuv[n oun ati Aaroni fa ibinu {l[run wa si ori ara w[n. W[n kuna n7 g1r1 ti
w[n ti f1r2 de ilc ileri. Dipo vive [w[ ikaarc Mose ati Aaroni soke, Isracli ti aw[n adari
w[n sinu ewu, w[n ko si jc ki w[n w[ ilc Kenaani. Eyi ni oxu ikinni ogoji [dun ti w[n
jade kuro ni ilc Egipti. Ibi ti o kan bayi ni Oke Hori nibi ti Aaroni ti ku ni oxu karun]un
ogoji {dun naa <Numeri ÅÅ:Åö>. C wo pzk5t3 ibi ti 2x2 dc silc\ Pclu bi ifc {l[run si iran
eniyan ti ga to, sibc a v[d[ x[ra ni [na ti a fi n ba A lo.
{kunrin [l[kan tutu jul[ ko ni suuru t9 lati lee kiyesi axc {l[run, nipa bayii, o mu
ibinu R2 ati iku wa sori Aaroni ni akoko yii. Lcyin iku Aaroni, Eliasari [m[ rc va ipo rc
gcgc bi olori Alufaa. Ibi kika wa pclu xe afihan bi Isracli ti ra [w[ cbc si Edomu lati va
ilc w[n k[ja, xuv[n t7 w[n k0 vz. Ck[ yii jc 8x7t7 fun aw[n eniyan mim[ isinsinyi lati
maa fi iva vovo xe iv[ran si {l[run ni ibamu pclu [r[ ati axc Rc.

K&K^N ATI D&DOJ% *JZ K{ AW{N ADARI <Numeri Äî:ì]Æ; CksoduìÉ:ìì;ìæ:ÄÉ; ìÆ:Ä;
ìô:ì]Æ; Numeri ìì:ì; Filipi É:Æ; ìPeteru æ:ô; Heberu Å:ìÄ,ìò; É:Æ; ìì:Æ>

“Aw[n [m[ Isracli si wq, ani vovo ij[, si aginju Sini ni ox6 kinni: aw[n eniyan nqz
si j9k09 ni Kadexi; Miriamu si ku nib2” <Numeri Äî:ì>. Miriamu jc [m[binrin Amiramu
ati Jokebedi, arabinrin Mose ati Aaroni. A v[ oruk[ Rc fun iva ak[k[ lcyin iva ti
Isracli re okun pupa k[ja. O fi ilu ati orin 4v4 dari aw[n obinrin lati yin {l[run fun ixc
avayanu Rc. Cni ti a t[ka si gcgc bi “arabinrin Aaroni”, ipo pataki ni o wa ninu ij[, o si
tun jc ohun]elo ti o wulo pup[ fun Isracli. Alebu ara rc ni iwa ow5 r2 si ipo ivega Mose.
@t2 k[lu u nivooxe, eyi ti o mu idaduro ba itcsiwaju vovo ij[. Mose vadura fun un, a
si mu un larada. O va akiyesi pe a ko v[ ohunkohun nipa ive]aye iwa]bi][l[run rc
8vz kan r7 m- titi de ori yii ti a fi n ka nipa ak[silc iku rc.
Iku Miriamu ni Kadexi jc k9k9 kan ti o xe pataki ninu irin]ajo lati Egipti l[ si
Kenaani. Iku rc xe afihan r2 pe vovo [m[ adqr7hurun ni yoo t[ iku wo ni [j[ kan.
Gbovo wa ni o v[d[ ni ero yii l[kan ki a si maa xe imurasilc iva vovo lati pade
Oluwa. Amuyc lati w[ [run ni a xe alaye rc yekeyeke ninu Iwe]Mim[. “C mqa lepa
alaafia pclu eniyan vovo, ati iwa m7m-, ni aisi eyii]ni k0 si cni ti y90 ri Oluwa”
<Heberu ìÄ:ìÉ>.
“Omi k0 si s7 fun ij[: w[n si k9 ara w[n j[ p[ si Mose ati si Aaroni” <Numeri Äî:Ä>. O ti
di baraku fun aw[n [m[ Isracli lati maa kun ki w[n si maa rahun nivakuuva ti w[n
ba xe alaini ohunkohun, pclu bi {l[run ti xe oniruuru ixc]iyanu ti o ni avara laarin
w[n to <Cksodu ìÉ:ìì; ìæ:ÄÉ; ìÆ:Ä;ìô:Å; Numeri ìì:ì>. Nihin]in ni w[n tun bcrc sii kun
si Mose ati Aaroni nitori aini omi dipo ki w[n vckcle {l[run fun ipese w[n. O xe bcc ni
Refidimu <Cksodu ìô:Ä]ô>. Xuv[n ihuwasi w[n si aini yii maa n kun fun aivav[,
k7k6n ati awawi, eyi si maa n mu ki w[n s[ [r[ k0bq]k6nv3 si Mose ati {l[run. W[n
maa n xiyemeji aw[n ileri {l[run lojukooju, eyi ti o s[ pe Oun y90 mu w[n de ilc ileri,
w[n si tun maa n beere eredi ti a fi daw[n nide kuro ninu ivekun aw[n ara Egipti eyi ti
{l[run xe pclu [p[l[p[ ixc avara, ixc]ami ati ixc]iyanu nla.
Gcgc bi aw[n [m[ Isracli ti nilo omi, aw[n onivav[ v[d[ m[ wi pe niw[n iva ti a
ba xi wa ni odikeji ayeraye nihin]in, ipenija aye yii jc ohun ti a ko lee ycri fun. W[n le wa
nipa aitete ri cnikeji fun iveyawo, eso ti inu, iwosan, airixc xe, tabi ipese ojoojum[ fun
cbi wa. Aw[n ipenija w[nyii kii xe fun iparun wa; bcc ni ko tum[ si wi pe iwa]laaye
{l[run ko si pclu aw[n eniyan R2 m-. {l[run maa n fi aaye va w[n niva miiran lati jc
ki a le ni ivav[ ninu Oun lati ba vovo aini aye wa pade. Iru ipenija yoowu ki a maa
la k[ja, k7k6n, aroye xixe ati aivav[ ko v[d[ jc ihuwasi awa cni mim[ ti n l[ si [run
rere. Aw[n [m[ {l[run ko v[d[ “..Mq xe aniyzn ohunkohun; xuv[n ninu ohun
vovo, nipa adura ati cbc pclu idupc, c mqz fi ib34re y7n hzn fun {l[run.... nitori Oun
funra Rc ti wi pe, “Emi k0 jc fi [ silc, b12 ni, $mi k0 jc k[ - silc” <Filipi É:Æ; Heberu ìÅ:æ>.
Niw[n iva ti Mose ati Aaroni ti m[ wi pe inu {l[run ko ni dun si iwa aivav[ aw[n
[m[ Isracli, w[n jade kuro laarin awuj[ lati l[ wa oju Oluwa. “Mose ati Aaroni si l[ kuro
niwaju ij[ si cnu]=nz zg- aj[, w[n si doju w[n bolc: ogo OLUWA, si hzn si w[n” <Numeri
Äî:Æ>. Aw[n olux[]aguntan ati aw[n adari ij[ v[d[ wa oju {l[run ninu adura lati ba
aini nipa ti cmi ati nipa ti ara aw[n ti o fi si ikaw[ w[n pade.

AIV{RAN MOSE SI AXC {L{RUN <Numeri Äî:ô]ìÅ; ì Samucli ìæ:ÄÄ; Orin Dafidi
ìîÆ:ÅÄ,ÅÅ; ì Aw[n {ba ìì:ìì; Jeremiah ìö:ò,ìî; Ä Peteru Ä:Äî]ÄÄ; Romu Ä:ìì>

L[gan ni {l[run dahun si ixoro aisi omi ti aw[n [m[ Isracli n s[ nipa rc. “OLUWA si
s[ fun Mose pe, M5 [pq n8, ki o si pe ij[ aw[n eniyan j[, 8w[ ati Aaroni arakunrin rc, ki
c s=r= si apata n8 ni oj5 w[n, y90 si t5 omi r2 jade; iw[ yoo si m5 omi lati inu apata nqz
jade fun w[n wq: iw[ o si fi fun ij[ ati fun cran w[n mu” <Numeri Äî:ô,ö>. Gbanva
xzn]qn ni {l[run s[ fun Mose lati mu [pa ki o si s[r[ si apata ni oju aw[n eniyan naa.
Xiwaju akoko yii ni Refidimu, {l[run s[ fun un wi pe ki o lu apata, omi yoo si jade
<Cksodu ìô:Æ>. Nihin]in, o v[d[ s[r[ si apata naa pclu [pa ni [w[ rc. {pa yii duro gcgc
bi ami axc lati [d[ {l[run. {w[ {l[run ni ipinnu [na abay[ kuro ninu ixoro wa. Kii xe
Cni ti a lee maa dari si ibi ti o ba w6 wa. Oluwa le4 pinnu lati yanju ixoro ti o j[ ara w[n
ni [na ti o yat[ sira w[n.
Ohun ti {l[run n beere l[w[ aw[n iranxc Rc ni iv[ran kankan si axc Rc. “Samucli si
wi p3, OLUWA ha ni inu]didun si [rc sisun ati cb[ bii pe ki a vz oh6n OLUWA v[?
kiyes7 i, iv[ran szn j6 cb[ l[, ifetisil2 si san ju =rz zv0 l[“ <ì Samucli ìæ:ÄÄ>. Mose
bcrc si i xe ohun naa gan]an ti Oluwa paxc fun un lati xe. Ascyinwa, ascyinb[, o wa xe
ohun ti {l[run ko ran an lati xe: o fi ibinu ati aib[la funni ba aw[n [m[ Isracli s[r[
<Orin Dafidi ìîÆ:ÅÄ,ÅÅ>. O pe aw[n eniyan {l[run ni aw[n [l[tc. O fi iwa ix[tc w[n k-
Oluwa l[run. “....ki awa ki o ha m5 omi lati inu apatq y87 fun y7n wq b7?” <Numeri Äî ìî>.
Dipo ki o s[r[, o fi [pa rc lu apata lccmeji.
Oluwa ki yoo ve oju fo axe]tinu]cni [m[lcyin Kristi ti o m[][n]m[ l[ sinu cxc ti o si
fidi pava sinu aiv[ran. Bcc gcgc, Oun ko ni maa gbojufo iranxc, oniwaasu tabi
olux[]aguntan yowu ti o ba n dcxc. Yoo fi iya jc cxc nibikibi ti o ba ti ri i. “Bi a tilc fi [w[
so [w[, eniyan buburu ki yoo l[ laijiya, xuv[n iru][m[ olododo ni a o va la” <Owe ìì:
Äì>. Bi o tilc jc pe {l[run dariji Mose, o si de [run nikcyin <Matiu ìô:ì]Å>, xuv[n o
padanu ay[ ti wiw[ ilc ileri ninu aye.
Bi Mose tilc xe aiv[ran, {l[run si tun pese l[p[l[p[ fun aw[n eniyan naa. Eyi n k[
wa pe ifc {l[run si aw[n eniyan Rc jc alailcgbc. Sibcsibc, niti pe O n lo cnikan kii xe ami
idaniloju wi pe O tcw[gba igbe]aye cni naa. Aw[n onigbagb[, paapaa jul[ aw[n adari
Kristicni gb[d[ maa xcx[[ lori aye w[n, ki o maa baa jc wi pe lcyin ti w[n ba ti waasu
fun aw[n clomiran, aw[n naa yoo di cni itanu <ì K[rinti ò:Äô>. {l[run yoo ba Mose wi,
xugb[n aw[n eniyan w[nyii nilo omi, a si pese rc fun w[n. Mose ti le maa lero wi pe
ohun ti oun xe dara, aw[n eniyan w[nyi pclu tilc lee maa ro bcc, nitori o dabi cni wi pe
ohun ti o xe xix1, xuv[n ohun ti o xe ti o xix1 kii saba jc odiw[n ohun ti o t[ niwaju
{l[run. “Ma xe halc; ma jc ki iveraga ki o ti cnu yin jade: nitori pe {l[run Olum[ ni
OLUWA, lati [d[ R2 wa ni ati 7w[n iwa <ìSamucli Ä:Å>.

IXC TI A RAN SI {BA EDOMU ATI IKU AARONI <Numeri Äî:ìÉ]Äò; ì Peteru Ä:ìÅ; Romu
ìÄ:ìô]Äì; ì Peteru Ä:Äî]ÄÅ; Heberu É:ìÉ]ìÆ; Ixe É:ìÄ; Johanu ìÉ:Æ>

Ni bayii aw[n [m[ Isracli wa ni Kadexi, w[n si n fc la ilc Edomu k[ja. “Mose si ran
onixc lati Kadexi si [ba Edomu, wi pe, Bayii ni Isracli arakunrin rc wi, Jc ki awa ki o la
ilc rc k[ja l[; awa bc [, awa ki yoo la inu oko rc tabi inu [va]ajara rc k[ja, bcc ni awa
ki yoo mu ninu omi Kanga, [na opopo [ba ni awa o va, awa ki o ya si [w[ [tun tabi si
0s8; titi awa o fi k[ja ipinlc rc” <Numeri Äî:ìÉ,ìô>. Edomu k[ ibeere on7r2l2 yii. Abay[ri
eyi ni pe, Isracli ni lati dari va ibomiran. C jc ki a ranti pe aw[n ara Edomu jc idile
Esau niva ti aw[n [m[ Isracli jc iran Jak[bu, aw[n mejeeji si jc [m[ Isaaki. A le t[
ipasc aini ibad[rc Edomu yi pada si ix[tc [l[dun v[[r[ laarin Esau ]baba nla aw[n
[m[ Edomu ati Jak[bu baba nla aw[n [m[ Isracli <Gcncsisi ÅÆ:ö,ò;ÅÄ:ìì>. Ija
emi]ju][]iw[]oju]mi yi ti wa di axeju. Eyi fihan pe aw[n [m[ Esau xi ni ikunsinu si
aw[n [m[ Isracli.
Gbogbo ohun ti Mose n tipasc aw[n [m[ Isracli beere ni if[w[si w[n lati rek[ja. W[n
ko reti ipese kankan lati [d[ aw[n ara Edomu, nitori w[n vckcle {l[run fun ipese
aw[n aini w[n. Aw[n [m[ Edomu ko fi aaye va Isracli lati k[ja. “Edomu si wi fun un pe
“iw[ ki yoo k[ja l[d[ mi, ki emi ki o mq baq jade si [ ti emi ti idz” <Numeri Äî:ìö>. K7k= ti
w[n k[ yi mu 8dqlqgara ati ewu ti o lavara ba irin]ajo aw[n [m[ Isracli <Numeri Äì:É,æ>.
Pclu ihuwasi yii, sibc, a si tun paxc fun Isracli lati ba aw[n ara Edomu lo gcgc bi
arakunrin <Deuteronomi ÄÅ:ô>.
Ck[ ti a ri k[ lati inu ixesi Mose yi ni wi pe, gcgc bii onivav[, a v[d[ maa lepa
alaafia pclu aw[n ti o yi wa ka niva vovo nipa viva axc l[w[ w[n ki a to lo nnkan
w[n. Lati yago fun wahala ti ko wulo a v[d[ va iwe axc ti o t[ lati [d[ aw[n axoju ij[ba
ki a to k[ aw[n ile ij[sin wa. “Bi o le xe, bi o ti wa ni ipa tiyin, c maa wa ni alaafia pclu
vovo eniyan” <Romu ìÄ:ìö>. Nihin]in ni {l[run ti n k[ Isracli ni bi w[n xe lee fi idaj[
aw[n ti o ba pa w[n lara le Oluwa l[w[, ki w[n si fi ifc han si aw[n ti o n xe bii [ta si
w[n <Romu ìÄ:ìô]Äì>. Lati wz ni alaafia, w[n xcri gba ibomiran.
Iku Aaroni jc ohun mani]vave ninu itan ive]aye Isracli. Oun ni Olori Alufaa
ak[k[ fun orilc]ede naa, sibc ko m[rib[ labc ibawi {l[run. “A o ko Aaroni j[ pclu aw[n
eniyan rc, nitori pe oun ki yoo w[ inu ilc naa ti mo fi fun aw[n [m[ Isracli, nitori ti cyin
x[tc si axc mi bi omi ni Mcriba” <Numeri Äî:ÄÉ>. Aaroni ku gcgc bi adari nla ti {l[run lo
ni [na ti o ni avara gcgc bi am5vql2v1 fun Mose <Cksodu É:Äô]Åì> lati ve oye alufaa
kalc <Lefitiku ö> ati lati ba Mose jircbc fun aw[n eniyan naa <Numeri ìÆ:Äî]ÄÄ>. Xuv[n
ko xe alaini aw[n ailera tirc; Oun ni avatcru vive ere wura kalc fun aw[n eniyan lati
maa sin <Cksodu ÅÄ:ì]É>, ati ni akoko ti oun ati Miriamu arabinrin rc pe axc Mose nija
<Numeri ìÄ:ì]Ä>. Lara aw[n ohun ti a tun ri ninu aye Aaroni ni wi pe ipo xe pataki ju
onipo l[. Aaroni, gcgc bi eniyan, ko yc ni cni ti a ba maa fi iva vovo bu [la fun,
xuv[n Aaroni gcgc bi Olori alufaa yc fun [la ati =w= iva vovo.
{l[run fun w[n ni akanxe it[ni nipa iku Aaroni, nitori naa, ixipo]pada lee waye ni
[na ti o t[ pclu oore][fc lati fa oye alufaa le Eliasari [m[ Aaroni ti o wa laaye l[w[.
{kunrin naa ti a pe ni Aaroni ku, xuv[n oye alufaa n tcsiwaju. Ko si ibaxep[ cnikcni
pclu {l[run ni Isracli ti o gb[d[ gbckcle Aaroni bi ko xe lori olori alufaa. {l[run ri i daju
wi pe Olori alufaa kan yoo wa ti a o maa t[ wa ti i xe Jesu. Ki i xe gcgc bii Olori alufaa ti
o ti wa xiwaju R2 ti iku n fi opin si, Kristi ti ni oye Alufaa ti ko lee yipada <Heberu ô:ÄÉ>.
”N jc bi a ti ni Olori Alufaa nla kan, ti o ti la aw[n [run k[ja l[, Jesu {m[ {l[run, c jc ki
a di ijcw[ wa mu xinxin” <Heberu É:ìÉ>. A ko nilo lati vckcle cnikcni fun ivala ati
ibaxep[ wa pclu {l[run.
Iku Aaroni n ran wa leti wi pe dandan ni iku fun vovo [m[ adarihurun <Heberu
ò:Äô>. Eyi n pe akiyesi wa si arojinlc ati imurasilc wa niva vovo. Aw[n onivav[
v[d[ murasilc fun [j[ ipade ati jijihin ixc]iranxc ti Oluwa ti fi le w[n l[w[.

Aw[n ibeere fun aveycwo:


ì. Ck[ wo ni aw[n eniyan mim[ ode]oni lee ri k[ lati inu iwa aiv[ran Mose?
Ä. Kin ni o yc ki o jc ihuwasi onivav[ si aw[n iyiriwo aye?
Å. Kin ni cxc Mose ati pclu ck[ wo ni a le ri k[ ni [na ti {l[run fi da si i?
É. Kin ni o yc ki o jc ihuwasi aw[n onivav[ si aw[n ti o s[ ara w[n di [ta wa?
æ. Ck[ wo ni aw[n onivav[ le ri k[ lati inu iku Aaroni ati itcsiwaju ixc oye Alufaa?
Æ. Kin ni idi ti oye Alufaa Kristi fi yat[ si ti Aaroni?
ô. Iru ihuwasi wo ni aw[n onivav[ fi v[d[ varadi pclu otit[ ti wi pe iku daju fun
vovo iran eniyan?

You might also like