OF Holding @ FUNTUA BAPTIST First Baptist Church Funtua
ASSOCIATION 7th – 8th of April 2023
BIBLE STUDY /EKO BIBELI THEME: LOVE AND UNITY: A TRUE IDENTITY OF CHRIST DISCIPLES Text: John 13: 31 – 35 ORI ORO: IFE ATI ISOKAN: AMI IDANIMO AWON OMO LEHIN KRISTI TOOTO Johanu 13: 31 – 35 Prepared and presented By GOD’S SERVANT JAMES O. ADEMOLA Pastor of First Baptist Dandume INTRODUCTION/IFARA A farewell speech is one of life's most essential and challenging speeches. It usually contains past achievements, instructions for the future, and warnings. Oro ikehin je eyi ti o lagbara ju ti o si tu ma n nira. O ma n kun fun awon aseyori atehinwa, itoni ati ikilo fun ojo iwaju INTRODUCTION/IFARA Like Jacob, Moses, Joshua, David, and many others, Jesus' words in John 13 – 17 were his farewell speech to the disciples. Gege bi Jakobu, Mose, Josua, Dafidi ati awon opolopo, awon oro Jesu ninu Johanu 13 – 17 je oro ikehin jesu fun awon omolehin Re. His words were filled with prayers, encouragement, warning, and preparing the apostles for the task ahead. Oro Jesu kun fun adura, igbaniniyanju, ikilo, ati pipese awon aposteli sile fun ise ti o wa niwaju won. INTRODUCTION/IFARA In John 1 – 12, the word love is mentioned 8 times, and 31 times in chapters 13 – 17. This morning, Holy Spirit is drawing our attention to 'LOVE AND UNITY: A TRUE IDENTITY OF CHRIST'S DISCIPLES as we study the text above. Ninu Johanu 1 – 12, ife farahan ni eyo igba 8, o si farahan ni igba 31 ninu ori 13 – 17. Ni awuro yi, Emi Mimo n pe akiyesi wa si ijiroro lori ‘Ife ati Isokan gege bi ami idanimo awon omolehin kristi tooto’ bi a se n wo ese bibeli ti o wa loke yi THE NEED TO LOVE AND UNITE AMONG THE DISCIPLES (31 – 33) IDI FUN IFE ATI ISOKAN LARIN AWON APOSTELI Now Christ is glorified: The word “NOW" has many implications for the next command Christ will give. Now the reality is going to be done on the disciples. Nisisinyi a o yin Kristi logo: Oro Ni Niisisyi ni ise pelu ase ti Jesu yio fi lele fun awon Omoehin Re. Bayi gbangba yio dekun, kedere yio bewo fun awon Omoehin Jesu. THE NEED TO LOVE AND UNITE AMONG THE DISCIPLES (31 – 33) IDI FUN IFE ATI ISOKAN LARIN AWON APOSTELI
Now the pollution among the
disciples had left. Can we talk as one family? Nisisinyi Kanda ti kuro larin awon omoehin. Se a lee soro gege bi ebi kan naa? THE NEED TO LOVE AND UNITE AMONG THE DISCIPLES (31 – 33) IDI FUN IFE ATI ISOKAN LARIN AWON APOSTELI
Now I have shown you who will be the
greatest by way of love and humility. Nisisinyi mo ti fi hanyin eni ti yio je olori larin yin nipa irele mi ati ife. Now that all of you have been washed completely. Nisisinyi ti gogbo yin ti we mo da shasha. CONT…. Now Judas has left the place of light to darkness. Nisisinyi Judasi ti kuro ninu imole lo si inu okukun. Now that I am going to be glorified by doing the will of the heavenly father. Nisisinyi ti a o yin mi logo nipa sise ife baba mi ti nbe Lorun. CONT… Now that God will be glorified in me by showing the greatest love through the greatest suffering for you and the world. Nisisinyi ti a o yin Olorun logo nipase mi nipa ife ti o ga julo ninu ijiya ti o ga julo ni aye. Now I am about to depart, and you cannot follow me to where I am going now. If there is a question, ask. If there is a need, request. If there is an issue you want us to discuss or clear, let us do it now because a little while you will not see me. Nisisinyi Emi n lo kuro lodoyin, eko lee tele mi lo si ibi ti emi nlo nisisinyi. Ti ibere ba wa e bere, ti e ba nilo ohun kan, e bere. Ti o ba ni ohun ti o ru yin loju tabi ti ko ye yin to ti e fe ka jo so ye ara wa, akoko ni yi fun iru nkan be. Nitori laipe eyin ki yio ri mi mo. Now that I am about to be glorified let me give you a new command. Nisisinyi ti a yin Olorun logo, e je ki n fun yin ni ofin titun kan. THE NEW COMMAND TO LOVE AND UNITE (34 -35) ASE LATI FE ATI LATI WA NI ISOKAN It is impossible to love and not unite, but it is possible to unite and not love. Discuss. Jiroro lori gbolohun yi: ko sese lati ni ife ki a ma wa ni isokan sugbon o sese ki a wa ni isokan ki a maa ni ife. The command to love one another is divine 1John 3: 16 – 18, 4: 12, 17. Ase lati ni ife wa lati Orun The command to love is not new in the Bible, Leviticus 19: 18. Christ says it is a new command. But why Jesus says is new here? Ase lati ife omoenikeji ko je titun ninu bibeli Lefitiku 19: 18. Kristi so wipe tuntun ni. Ki ni idi re? IT IS NEW BECAUSE OF THE FOLLOWING: It is a new command because it is a command to the disciple alone – love one another It is a new command because it is as Christ love – as I love you It is a new command because it is a witnessing love - by this, all shall know that you are my disciple. WHAT IS CHRIST'S LOVE? KINI IFE KRISTI?
Christ's love is unchanging – John 13: 1. Ife
Kiristi kii yipada Christ's love is divine - John 15: 9. Ife Kiristi je ati oke wa/mimo Christ's love is sacrificing – John 15: 13. Ife Kiristi maa n fi lele fun awon elomiran CHRIST LOVE IS … Christ's love is inseparable – Romans 8: 35. Ife Kiristi kii ni pinya Christ's love is sacrificial - Gal. 2: 20, Eph. 5: 2. Ife Kiristi irubo ni Christ's love constrains – 2 Cor. 5: 14. Ife Kiristi maa n ro wa Christ's love manifested in His death 1John 3: 10. Ife Kiristi farahan ninui ku re WHAT ARE THE IMPLICATIONS OF CHRIST'S LOVE AMONG THE DISCIPLES? KI ni Awon atunbotan ife kristi fun awon omoehin re? CONT. … This is a new command because it is particular to the Disciples of Christ. Ase yi tuntun nitori o wa fun awo aposteli gangan. Love among the disciples is like a wall. Ife larin awon omolehin kristi dabi odi. It will prevent the enemies from penetrating their fellowship. Ko ni jeki ota ri aye wo arin agbo won Now the shepherd will be striked and the sheep will scatter, nothing could keep the disciples together except the Love of Christ among them. Nisinsiyi ti a o lu oluso aguntan ti awon aguntan yio si tuka, aya fi bi awon omolehin ba ni ife won ko lee wa ni isokan. Christ's love and unity among the disciples is proof that they have been with Christ and have His nature in them. Ife ati Isokan larin awon aposteli yio fi han pe won ti wa pelu Jesu. Love and unity among the disciples will help them to treat one another as Christ will treat them. Ife ati isokan ni yio jeki won se si ara won bi Kiristi yio ti se si won Love and unity among the disciples is a emblem they wear. Ife ati isokan larin awon aposteli ni ami idanimo fun aye. Love and unity prove they have dealt with the flesh of pride, jealousy, and struggle among the disciple. The question of who will be the greatest will not arise again. Ife ati isokan ni yio so pe eran ara ti di wiwo pale CONT. … Love and unity among the disciples will help them to stay and pray together. Ife ati isokan larin awon aposteli ni yio je ki won gadura papo Love and unity among the disciples are true marks that they are Christ's disciples. Ife ati isokan je ami awon omolehin Kristi tooto CONCLUSION. NI IPARI By the grace of God, we have discussed the reality that requires the command to love and unite. The new command to love and unite, and the peculiarity of the command to Christ's disciples. It is evident through this study we have discovered that a community of Christ's disciples is a loving community. How do we live and relate as an association, church, organization, and family? Do our relationship reflect the love of God? Let us consider these things and amend our ways before the Lord as we pray together. WISDOM A COMMUNITY WITHOUT UNITY WILL LOOSE OPPORTUNITY AMONG THEM AWOJU TI KO BA NI ISOKAN YIO MAA PADANU AWON AN FANI TI O WA LAARIN WON.
Thank You for listening
James O. Ademola God’s commissioned servant To: teach, preach and pray