You are on page 1of 1

A O JUBA RE

Chorus:- Ha o wole, a o juba re, oba taiye


ati orun nbo, la o fiyin fun.

1. Ki gbogbo aiye ho, iho ayo/2ce


kajumo gbee ga o ki aiye gbo
2. ki gbogbo eniyan shape lati fiyin/2ce
kajumo korin ogo re ki aye gbo
3. Jeka gbohun wa soke kaforin mimo yin/2ce
kajumo korin iyinre ki aye gbo.

GBOGBO OGO TIRE NI

Prelude: Tire ma lope/niyin, tire losana /3ce


Olorun iyanu,
Chorus: Gbogbo ogo, Olorun tire ni, gbogbo ope olorun tire ni, gbogbo
iyin, olorun tire ni /2ce.
1. Iwo lodawasi tiletile/tomotomo/tayatoko, a ko weni Kankan ti ninu ebi
wa, fun pe a ri o ni o ogo ni foluwa/2ce.

2. Esu gbogun titi lori aye wa/lori ise wa lori ebi wa, o tun gbogun titi lori ijo
olorun, oba imo esu je olorun iyanu wa.

All: Eni ba more re koba wa gbega eni ba more re koba wag be Jesu laruge
emi more baba, ma yin o nitemi.

All: Fun pe ari oni o ogo ni foluwa.

You might also like