You are on page 1of 2

IGBAGBO WUNMI YEYE Key: C

Solo 1:Igbagbo wunmi yeye igbagba lere


All: Owu mi yeye igbagbo lere 2ce
Solo: Kalowo lowo lou gun se igbagbo lere
All: Owu mi yeye igbagbo lere o
Solo: Ka kole mole lai gun igbagbo lere o
All: Owu mi yeye igbagbo lere

Solo 2:Igbagbo dara yeye o dara pupo


All: Odara yeye odara pupo 2ce
Solo: Katun wa bimo lemo odara pupo
All: Odara yeye odara pupo
Solo: Latun wa lalafia odata pupo
All: Odara yeye odara pupo
Solo: Igbagbo dara yeye o dara pupo

Solo 3:Ere pupo nbe ninu igbagbo yio


All: Ere nbe ninu igbagbo yio 2ce
Solo: Ayo nla ti ko lopin nbe ninu re
All: Ere nbe ninu igbagbo yio
Solo: Anfani tun be fun wa lati bolorun soro
All: Ere nbe ninu igbagbo yio
Solo: Ere pupo nbe ninu igbagbo yio
All: Ere nbe ninu igbagbo yio

Solo 4:Ade ologo nbe foni gbagbo o


All: Ade pupo nbe fun wa lorun o 2ce
Solo: Eni to ba si segun ni yio gbade ye
All: Ade pupo nbe fun wa lorun o
Solo: Onigbagbo omuna kele gbondelye
All: Ade pupo nbe fun wa lorun o
Solo: Tere dara pomo wa lowo ore mi
All: Ade pupo nbe fun wa lorun o
ASIWERE ENIYAN
1. Asiwere eniyan wipe olorun kosi (2ce)
Sugbon lesekese mo ro do ti san mo ri eja
Tin luwe won fohun kan korin wipe olorun nbe.

2. Asiwere eniyan wipe olorun kosi (2ce)


Sugbon lofurufu gbogbo awon eye, pelu
Awon oko won fohun kan korin olorun nbe. (Interlude)

3. Asiwere eniyan wipe olorun kosi (2ce)


Sugbon ki atoso mo rododo kan, peluwon
Kokoro won fohun kan korin olorun nbe. (Interlude)

4. Asiwere eniyan wipe olorun kosi (2ce)


Sugbon ki atoso awon igbi okun ati igi
Oko won nke lohun rara olorun nbe. (Interlude)

5. Asiwere eniyan wipe olorun kosi (2ce)


Sugbon lawon san mo gbogbo awon rawo,
Orun atosupa won ke lohun rara olorun nbe. (Interlude)

6. Asiwere eniyan wipe olorun kosi (2ce)


Sugbon minu ile golu ati leke, epo ati kusa,
Won nke lohun rara olorun nbe. (Interlude)

7. Asiwere eniyan wipe olorun kosi (2ce)


Sugbon mbi gbogbo lotoke de ile ohun
Gbogbo njeri lohun rara wipe olorun nbe. (Interlude)

You might also like