Professional Documents
Culture Documents
site-name .wikidot.com Share on Join this site Edit History Tags Source Explore »
Expert tip #5: Click 'Help' in the menu to learn more about Wikidot syntax Create account or Sign in
spiders discuss edit this page view source history other tools
OCEANOGRAPHY
pages The oceans also have a major influence on the weather and changes in the oceans can drive or moderate climate change.
Àwọn òkun sì ní ọpọlọpọ ipa ti wọn nkó lórí ojú-ọjọ́. Àwọn ìparadà tó nṣẹlẹ nínú àwọn okun lè fa ìrúkèrúdò tàbí kí wọn tilẹ mú
new page àyípadà dé bá sáà ojú-ọjọ́.
Oceanographers work to develop the ocean as a resource and protect it from human impact.
- applied curriculum
delete-this-page research Àwọn onímọ-jinlẹ ẹ̀kọ́ òkun nṣiṣẹ́ láti wá ìlò wọn fún ìpèsè ọrọ àti láti dáàbò bo wọn lọwọ ìlòkúlò ọmọ aráyé.
s yoruba The goal is to utilize the oceans while minimizing the effects of our actions.
Ìyànjú wa ni wípé ki a lè lo àwọn òkun kí a má sì jẹ́ kí ìṣèwàhù wa ní ipa lórí wọn.
watchers
Mz Shetzy Ocean: Body of salt water that covers much of the earth’s surface
Dr Abayomi Òkun: àgbágbúù omi oníyọ tó bojú ọpọlọpọ ojú ayé
Ferreira
Diipo Fagunwa Tides: the rise and fall of sea levels caused by the combined effects of the gravitational forces exerted by the moon and the sun and the
Kayode Afolabi rotation of the Earth.
bayo_rep Ìyọ àti ìṣa omi (Ìyọ: flood tide; Ìṣa: ebb tide): Ìlọsókè àti ìsọkalẹ omi òkun tó jẹ́ òkùnfà àpapọ ipá òòfà òṣùpá àti ti oòrùn pẹ̀lú bí ayé
nellista ṣe nyí kiri
ifayemi
Jesus Rodriguez Waves: moving ridge on the surface of a liquid
Alabi Taofeek Ìjì-omi: Àwọn nkan bí ebè-gbọọrọ tó má nkọjá lọ lójú àwọn aṣọn (omi)
Owolabi
Prince_Analyst Beaches: areas of loose sediment (sand, gravel, cobbles) controlled by ocean processes.
Oyekunle Bebe-okun: Àwọn ibi ti ó kun fun oniruru isile (yanri, taara, okuta-wẹ́wẹ́) tó jẹ́ pe iṣesi okun ló nṣe òkùnfà wọn
Ridwan
balogun Ecosystem: Natural community of plants, animals and the environment associated with them
oafak Ètò ọjọ̀-ẹ̀dá: Ijọ ayébáyé àwọn ọgbin, ẹran (ẹranko àti ènìyàn) àti ibi tí a so wọn l’ọjọ̀ sí.
Olamide Olobi
herziz
Vincent
ogoubiyi
Kunnuji
Ridwane Ade
Seggylee
Watch: site | category |
page
_e
page revision: 2, last edited: 15 Oct 2017, 23:52 (969 days ago)
Edit Tags History Files Print Site tools + Options
1 of 2 11/06/2020, 20:26
Ẹ̀ KỌ́ NIPA AWỌN OKUN AIYE - OCEANOGRAPHY - yoruba scienc... http://yoruba-scipedia.wikidot.com/wiki:e-ko-nipa-aw-n-okun-aiye-ocea...
Unless otherwise stated, the content of this page is licensed under Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 License
2 of 2 11/06/2020, 20:26