You are on page 1of 31

IWE AKONI OODUA

LATI OWO ALAGBA OPA FITILA (OPEYEMIDANIEL)


TEL-07080271083

ORO AKOSO
Mo juba akoda aye, mo juba aseda aye, mo juba Olorun ton be ki aye toma be, mo juba
Olorun ti yio si mawa nigbati aye koni simo

Mo juba gbogbo ajunilo


Mo juba gbogbo awon tiwon nbo leyin

Mo se akojopo iwe akoni odua yi fun iwulo gbogbo eda patapata, yala musulumi,
chriteni,tabi elesin abalaye, AGBARA IGBAANI eyi ti o fi ara han fun awon eda kan ti o si
faraapamo fun awon eda kan gbangba.
Ni sise iwe yi mo Juba Iya Mi Ti o Se Oloko Mi Wasi Aye
Eniti o funmi ni opolopo alaye nipa awon ohun ijinle ti o wa ninu iwe yii
Gbogbo awon ohun ijinle ti awon agba ijohun finse agbara ti o dabi wipe oti di igbagbe,
ni atu jade ninu iwe yi, ki olukuluku ki o gbiyanju kio lo ni tire ni tire Gbogbo awon ise inu
iwe yi lo daju sakasaka. Ejowo gbogbo eda ti o ba fe dawole ise inu iwe akoni oodua e
je kia se pelu atubotan

Lagbara Olorun ao nise aseti laye


(AMIN).

Lati owo
ALAGBA OPA FITILA (Opeyemi Daniel Kilani)
OLOTU
AGBARA IGBAANI SOCIAL GROUP
ADMIN IMO QURAN ATI HANTU

PAGE 1

ANASARE
AO LORA ORUKA KAN,AO MA SO AJA TOFE YAGBE AO MA SOO AKO AJA TOFE YAGBE
AO PARIWO MO AJA NA TI IGBE NA BATI FE JABO NINU IGBE NA TO BA JASILE AO FI
NKAN KO AO LOJO PAPO AO DASI INU EPO PUPA INU EPO PUPA LAMA TIMA MU
ORUKA NA.

PAGE 2

OGUN IJAKADI
Ose dudu, alubosa elewe , irun eyin olongbo dudu, tiko ni awo kankan ju dudu lo oruka
ogun meji 2, koro atare meje, ao wa gun po ao wasu rugudu ao fi oruka na bo ni arin, ao
wa fi aso akisa di ao lofi ha palapolo iganna (ogiri alapa tio la enu sile) fun ojo meje , ao
lo mu odi lilo.

PAGE 3

IFERAN GBOGBO ENIA TODAJU


Ewe Awerepepe, ewe Taba ibile, Igbo mimun, ori ijapa, ao gun kuna daadaa, ao da sinu
lofinda eyikeyi ao maa fi paa oju tabi gbogbo ara. Awon Enia yio maa ni ife waa pupo

PAGE 4

ORORO IPARA ANU TODAJU


Ao gun ewe imunle die, ewe lapalapa funfun die, ata ijosi meta, epo obo die pelu epo igi
nla die kuna daadaa, ao daa sinu Olive oil ao da lofinda orisi meta si die die, ao maa fi
para, Odaju samu

PAGE 5
OLUGBOHUN RIRISE TODAJU
Ako ewe mereerin (ewe ina ewe esisi ewe aragba ati ewe oloyin) aogun po mose dudu
aofi emu aila pelu oguro aila po papo pelu oti schinap po Papo dada aofi oga aye ati eja
ojiji aye kan tele iho malu yan aowa ko ose yan lelori aofi aso pupa bo lori ao we mo
lara aomasin aso pupa yan loju re ti abafelo ao kan ma se hahaha lemeta si ni aose
adura ikan ti abafesi

PAGE 6

ILEKE ADODUN
Ao jo ori oka toni ase lenu kan pelu ewe ominsinminsin gogoro ati pelebe ati atare odidi
kan, ao wa agbon kan totobi dada toni omi ninu, ao wa fi omo inu agbo ye gbo ewe
mejeji ye again, ao wa da ebu ye sinu egbon ye, ao ki eleke bo, ao wa da omi agbon ye
si ninu, ao gbe pamo fun ojo meje, lehin ojo keje odi lilo sidi fun obinrin

PAGE 7

IWE EPE DANU


Efun die, Osun die, Edu Die, ewe awerepepe ojo, ao koko gun Efun loto, Osun Loto, edu
loto, ao waa gun Ewe awerepepe pelu ose dudu, ao fi owo mun Ogun ina si ao gun po,
ao waa da osun si ao po po daadaa, ao tun Efun si ao po po daadaa, ao waa da edu si
ao po mo ar won daadaa, ao ko sinu ike kan ao gbodo gbe si inu ile o, eyinkule ni ao ma
gbe si, ti aba fe lo, ao bu die ni ibe lo si odo, ao ko eyin si ibi ti odo ti nsan bo ao koju si
ibiti omi naa nsan lo, ao maa we.

Ao fi iyere Osun te ifa Ejiogbe ao waa pe ohun si bayi,

Ohun re
Para Pahun 3x
Oju Orun o lenini
Adifa fun Orunmila nigbati o nti ikole orun bo wa si ikole aiye, Won ni ile aiye ti o nlo yi,
awon Elepe nbe nibe, Awon alasasi nbe nibe, Awon Alasan nbe nibe awon Alfa, woli
Babalawo ika nbe nibe etc oni toba se bi ise temi Lagbaja omo Lagbaaja ni oni
Efun ni nba aiye osun je
Osun ni nba aiye efun je
Ati efun ati osun Edu ni ba ye won je
Gbogbo epe won lori emi lagbaja Omo Lagbaja ati efun ati osun edu ni nba aiye won je,
ki gbogbo epe ori mi asasi ori mi, asan, epe idile baba, epe idile iya etc Ati efun ati osun
edu ni nba aiye won je.  Toripe enikan ki se ina koma le joni, Awerepepe ooo, Epe idile
baba epe idile iya, Epe ota lori emi lagbaja omo lagbaja ki o waa pe gbogbo e danu lori
mi lati oni lo, odo ki san kobu oju wo eyin... Adua, ao waa daa mo ose eyiti abu ti afe lo
wa yen, ao lo we.

IKILO
ti aba fe lo we aso ti awolo ao gbodo wo pada wale mo, ao si gbodo wo eyin titi ao fi
dele, Ojo meta lao we ose yi lera lera, Odaju

PAGE 8

PENIS ENLARGEMENT  (KI OKO LE GUN DAADAA)

Ao lo be Ogede Agbagba ti koti ni omo lori, Ao beni arin, Eyiti o baa tun nyo ni arin re ti a
ti ge (Abeyo) re, ao jeki o yo de dede size unkan omo kunrin ti a nfe, ao tun lo ge sonso
mariwo ope ni nize ti ogede ti a ge yen, ao gun won kuna daadaa ao fi odo irin gun ko
kuna daadaa, toba wuwa ale sa si orun ko gbe daadaa ki a tun tun gun daadaa, ti o baa
si wuwa ale gun ki a lo beyen naa, ao fo eyin ororo kan si, ao fi po ori ao ma fi wo Oko
naa lati Oke wa sile, ao gbodo fi wo lati isale waa si oke o.

Akiyesi ni wipe, ti o ba jepe asa egboigi yen ni, ti aba ti fe fi po ori ao fo eyin kan si ao fi
po pelu ori, Odaju 

PAGEE 9

OLUGBOHUN ADURA TODAJU
Ao wa iwo malu kan, oga oye kan, eyo ataare mesan, ewe esisi funfun, ewe aragba, ao g
un ewe mejeji papo mo ose dudu, ao ki oga oye yen bo inu iwo malu naa ti yio yo ori sok
e, ao koko ko eyo ataare mesan si inu iwo yen ki ato ki oga yen si, ao ko ose ten fi bo lor
i, ao maa fi kan enu fi se adua lorisirisi. Koda ti abani Enia ni ilu ibo miran ti
o baa nri awon walah kan, ki afi se adua fun, lagbara Olohun won yio maa ri gbigba adu
a naa ni kiakia

PAGE 10

AGADAGODO FUN OMO YAHOO ATI ENIKENI


Agadagodo eyikeyi ao ha gbogbo oda ara re kuro akara elepo pupa ao yo funfun inu e
ao pomo epo oparun ti afa lati isale losi oke ao wa kosi inu owu etutu ao ao dini owu
dudu ati funfun ao dimo ara padlock na ao sese weni owu pupa ati dudu

Ao mu iwo etu ao ko ose dudu ti ati lomo oko oka sinu iwo na ao dimo ara agadagodo
na ao fi owu etutu pupa di loju

Lilo ao ma fi ahon kan afima soro sinu padlock na.

Ao tipa alefi tin nkan bi mewa papo odaju.

EPE TODAJU
Iwo eran agbo ibile ti won pa lojo odun ileya, eyokan, ojo ti aba fe se ise yii lao lo ja ewe
ewuro ojo, ao lo ra orogbo lojo naa orogbo kan ni o, ao gun mo ose dudu ao kosi inu iwo
eran yen. Ao fi aso pupa bo lori ao ma pe ohun si bayi

OHUN RE
ojojumo ni ikoro nba ewuro, ojojumo ni ikoro nba orogbo, ojo odun ni ikoro nba Eran
Agbo ki ori bayi bayi fun lagbaja omo lagbaja ao fi enu kan so ohun ti abaa fe so. Ti a
baa lo epe yii fun odun kan, koda bi ao baa gbe epe yii lowo mo ti abaa fi enu se epe ni
kia kia ni yio maa se

PAGE 11

ASIRI TI OUNJE KONI FI MA WON WAA NINU ILE

Ao han Suratul Nasir  Eyo kan pere ao  ti abati de ibi Afuwajan yen ao para ibe ni igba
101 ao waa pari Surah yen dele, ao wa ijesi adie to kun daadaa, ibiti adie maa nje ounje
si ni orun re, ao jo pelu ewe awerepepe die  ao lo kuna ao fi se gari tira yii, ao waa iwe
akuko adie to tin nko daadaa, ao ki tira yi si ninu ao di lowu funfun ao fi ko enu ona waa
ao si maa saa Surah yen ni igba 1000 lojojumo tabi 313, won yio maa gbe ounje fun wa
lona kona.

Akiyesi
Adie ti alo iwe re naa lao lo ajesi re, ogbodo je akuko nla toti gbo daadaa, ti a baa fe la
iwe yen ao gbodo ko idoti ibe kuro, ao ki tira yen bo be ao di lowu funfun, owu funun
naa lao fi i tira yen. Odaju

PAGE 12

ASETA TOBURU TODAJU

Ao han SAFI ti yio pe daadaa, ao waa ako alangba kan ti afi egba pa, ao fi tele koko
isasun dudu kan, ao ja ewe akoko ojo, ewe ajeobale ojo, ao da sori Ako Alangba yen, Ao
fi omi topo daadaa fifo Safi ta han yen, ao daa sori awon egbo igi yen, ao fi se ko jina
daadaa, ao yo omi yen si ibi kan, ko fi tutu die.

OSE RE
Ao han Safi kan, Ewe Ajeobale to jabo fun ara re to siju si oke, epo Obo die, ao gun po,
omi hantu yen lao fi po papo, ao ko ose yi sinu igba oni koko, ao fi Orogbo kan gun lori,
ao bu die ni ibe fi we agbo yen. Ti aba fe se fun enia ao se agbo yen ose yen lao ma bu
fun won fi we ni Ale ki ato sun.

PAGE 13

OGUN AMUDO TODAJU GAN

Panumabo 7, panumoabafe 7, ewe emu 7, ewe amunimuye7,eyo atare meje, oruka ede
7, ao fa irun epon wa, ao jo po gbogbore po, ao fi ebuna re sin gbere meje si orukayemi
ni owo osi, ao mati oruka bo o ti a ba fe lo.
Ofore: Abegan loruko ti anpe oko,ebefere loruko anpe iwo obo,okan ganganran tinse
omo yeye oju loruko tianpe omu,ebefere turasile kio wa je oko, oko lonje re, ao fi di mu
ni orun owo

PAGE 14
OGUN KI ONDE TABI ORUKA MA RANWA :

a o wa igba eyo atare, igba eso ido, igba werenjeje, a o jo po, a o lo kuna, gbere yika
orun owo wa mejeji

OGUN AJEGUN

a o wa egbo tude , erunrun ide , a o gun mo ose dudu iwe ekan , a o wa gbo ewe lapa
mejeji , ewe ewuro tutu , sinu omi , a o da sakiti re nu , a o wa fi ose yi we omi yi , a o fi
epo para ki ato we , ekan lodun ni iwe yi o 

OGUN AWEBI DANU / TUDE

a o wa ojele ewe bomubomu kan , ose Iwe ekan , a o gun po , a o wa se lona meta , a o
fi we ni ojo meta lale , pelu koinkoin ototo , Iwe akoko , a o fi epo para , ikeji Oyin gidi ,
Iwe eleketa eru aro

OGUN ISOYE

a o wa isawuru 9 ewe oniyemeye, ewe amunimuye, ewe iyeye, Odidi atare kan, a o Jo
po, a o lo kuna, a o da sinu oyin gidi, a o ma la.

OGUN FUN ENITI OTE NKAN MOLE

a o wa eso laa pupa topo , odidi atare kan , a o Jo po , a o bu die sinu epo pupa , a o ma
fi pa ese towu , eniti oba njeun loju orun yi o mala

OGUN IFERAN

a o wa oju oro, osibata, ewe amunimuye, a o lo po pelu die Lara omo olo, ati iya olo, ti a
fi lo, to ba kun na a o fi te ojiogbe soju si ori olo, awa pe gbolohun si, a o fi ose ko loju
olo, ama fi ose yi we, a o ma rin sibi ti obinrin na yi o ti mariwa. gbolohun re: tipa tipa
loju oro fi nsoko omi, tipa tipa losibata fi nsoko odo, omo olo ni nsoko iya olo ,
amunimuye bami muye lagbaja OMO lagbaja ko ma nife emi lagbaja OMO lagbaja
PAGE 15

AFOSE MAYEHUN TODAJU

egbo akerejupon meta di papo ao fi eyo atare mesan si enu kio je, ki awa maje bi enipe
anri paako lenu kio wa ma so ohun ti aba fe lowo enitohun ki yio yi ohun re pada..

PAGE 16

OGUN AGANDANGODO TI AFI GBA NKAN

a o wa die lara igiti oku sori iduro , die lara ope ( palm tree) toku sori iduro , iyepe ebe ti
adie fi ese tuka die , iyepe ti alakan wa seyin , awo obo die , odidi atare kan , a o Jo po, a
o di mo agadangodo , a o fi awo obo ran , a o pe gbolohun si , a o ti pa , agadangodo
atijo ni a o lo . gbolohun re : inu bi igi oku tewe tewe , inu bi ope , oku tegbo tegbo , inu
bi alakan , o gba iyepe sodo , ofe fi mo ile , inu bi adie , ofi ese ko ebe , otu tuka , inu bi
obo won so okun mo nidi , Iwo ,,,,,,,,,,,,,,, omo ,,,,,,,,,,,,, ki inu bi iwo lagbaja loni , gbogbo
nkan ti mo ba bere , ki o binu ko

PAGE 17

SIGIDI IRANSE TALE RAN NI OHUN KOHUN

ILE IKAN ALADE .ILE ODE .YEPE AMO DIE AOGUN PO AO WA TOJU OTI BABA OTI
OGOGORO LAOFI PO ERUPE NA AO WA MO NI SIGIDI OLOWO MEJI ELETI MEJI ELESE
MEJI AO WA IKOTI IRIN SOKIBO EJIKA RE MEJEJI AOKI IKOTI OJE ATI IKOTI BABA
IKOTI IDE AOKIBO GBOGBO ERIKERIKE ARA SIGIDI NA .AOGBE SINU ABO SOBI .AO WA
LO EWE INA EWE ESINSIN .EWE ARAGBA.EWE OLOYIN ITO IDAJIN WA LAOFI PO EWE
NA AO WA PIN SI ONA MEJI ..AOKO IDA KAN SINU IDODO RE AOFI AMO MO PADA .
AOLO IDAKEJI PELU EYO ATARE DIE AOKO SINU SEERE ......

OFORE..

ASURE GANRAA 3* ARINA GERERE 3* OBURINBURIN DURO SIDUN 3* ONI OHUN ONI
ANU ENIYAN LOJU WON NI KINNI ODURO SI DUN FUN.IKOTI IDE KISUN KOSUN OJU.
IKOTI BABA KI SUN KOSUN OJU .IKOTI OJE KISUN KOSUN OJU IKOTI IRIN KISUN
KOSUN OJU.KANKAN LEWE INA JONI.WARAWARA LOMODE TOKO ESI BO.ILE OGBA
ONA OGBA NITI ARAGBA .KILE MAGBA L OMO L TEKUN TEJE NI ESINSIN ODE FIMO ILE
TIRE.ENIKAN KIFI ITO SAARA KODURO .AOMA MI SEERE YEN ENIKAN YIO TIRU ADIE
LORI OOO AO WA MASOPE EJE ADIE NI MOFUN KISE EJE EYAN OOOO ..ADIE NA YIO
KU

AKIYESI TABA GBAGBE LATI SO PE ADIE ..TI ENI NA BASUBU AOFUN NI EPO PUPA MU
OO

PAGE 18

IMULE ELEYE TI AOMA BAWON SORO LOJU KOROJU

EYE EGA AYE AOLO LORUN PA EMA JEKI EJERE DA SILE OOOO EDE MAJEKI EJE JADE
RARA OOOO AOKI IKOIDE BO LENU AOKO SINU APE TUNTUN PELU ODIDI ATARE KAN
TABAJOTAN AOFI TE EJIOGBE AOPE OFORE SI.. AO WA OLE ELEPO META AKARA
ELEPO META EKURU FUNFUN META AOKO SINU AWO IPESE .AOTIRO EBU YEN SINU
ADO IJAMO AONIDE LENU AOWA GBE ADO NA SORI IPESE YI AOGBE SEYIN KULE
TOBA DI ARO OJO KEJI AOLO GBE AJEKU AOJO PELU ADO NA AORO SINU ADO
MIRAN AO MA FI FOKO MU LALARA OOO OJO META META. .FUN OJO KAN GBAKO
AODE BODO SU OBINRIN
OFORE.
EMI L OMO L TIBBA EYIN ELEYE FUNFUN MULE LONI KEWA JAWO LARA KE WA MA
BAMI SORO LOJUKOROJU KEWA FI ILE MI SE GBUGBE TI OHUN KOHUN BAFE SELE
KEWA MA SO FUN MI
PAGE 19

IBANTE AGBARA TABA FI OJU HAN ENIYAN WON YIO SUBU

AOKO YEPE AGO ORU SINU ISASUN AOJU EYO ATARE KAN SI AOKO ORI IKUN KAN ORI
OKETE KAN .EWE OWO TUTU 16 EWE ABAMODA 16 EWE EWON ILE PELU EDUN ARA SI
AO WA DA YEPE AGO KAN OSAN SI PELU EYO ATARE KAN NA AOJO TABA JOTAN
AOLO EBU RE AOMO AONI LO EDUN ARA OOOO AODA SINU EFE OWU AODINIKOBERE
PELU OWU DUDU ATI FUNFUN .AO RAN ASO IDASA NI IBANTE AOJU IKOBERE YEN
SININU AORAN MO LARIN LATINU AO WA RAN SEKESEKES 16 ATI OWO EYO TIKOLU
16 ATI EMU 16 PELU ORUKA IRIN MO LARA AOFI OPELE ABI IFA BEERE ETUTU OHUN
YIO GBA BI AKUKO ADIE ABI MALU ABI EWURE . EJE NKAN NA LAOFI YI DADA AO WA
SA KOGBE . AOMA KUNLE WO IBANTE .AOSI MA KUNLE BO ENI TABA SI IBANTE NA
HAN YIO SUBU
ERO.AOTA OTIN SHRINPA SORI IBANTE NA AOFI KAN ENI NA LEYIN YIO DIDE

PAGE 20

ADO ATONA INU AWO FUNFUN

ADO IJAMO KAN AORE SINU IGI EMI FUN 3 DAYS LEHIN AOYO JADE AOLO ORI
ALABUN ATI YEPE ORI SARE ATI TITI ATI ATAN NA AO WA DA SASEROS POWDER ATI
JADE POWDER SI AORO SINU ADO YI AOFI ASO PUPA WE LORI .AO PA ADIE AKUKO
KAN FUN AODA EJE RE LE AOFISILE FUN OJO META ODILILO NIYEN
LILORE.
AODA BU RE SINU AWO AOJU AWON AGBA AOSOPE TOBA JE LAGBA OMO LAGBA
LOSE NKAN BAYI BAYI OJA IWO ADO OYA DIDE JOKO
EWO RE ... IRU ISEBE OBUDO KAN LARA OOOO

PAGE 21

OLUGBOHUN IBEJI

ERE IBEJI AOKO SINU APOTI IGI IROKO AOKO EWE ABAMODA LE ATI EWE OGBO ATI
EWE EMILE ATI ODIDI ATARE KAN ATI OPOLO AYW KAN OGA AYE KAN ALAGBA AYE
KAN .ALAKAN AYE KAN .EJA OJIJI AYE KAN .AO WA KAN OJE EMI SI ATI OJE IGI
APAKU .AODE APOTI NA PA .AO WA FI ASO FUNFUN WE AORIMOLE FUN OJO MESAN
LEHIN AO WU AOFI ADIE AKUKO YIKA AO PA ADIE NA SI LORI ..LOBATAN
OSU META META LAOFI MABO
AOSOPE .ORISHA IBEJI OYA LO BAMI SE NKAN BAI BAI ..AORAN NISE

SIGIDI ESU ODARA

AO LO WA AMO YEPE AOFI EPO ATI ADIN PO AOFI MO ERE TIKO LESE AOFI ASO PUPA
WE ERE NA AOLORIMO ORI OGAN OKO FUN 7 DAYS LEHIN NA AO WA LOWA OJE IGI
APETE AORO SI LORI DADA AOFI SILE NIBE FUN OJO META .AOBEERE LILO RE NI OJO
KEJI KATO LO EFI AKUKO ADIE YIKA LEEMETA KEWA PA SIWAJU RE ... KEFI ADIE NA
SE SAARE
LILORE.. AOFI OORE NA LEEMETA AO WA RAN NISE

ASO IWOSE NLA

AO WA ASO FUNFUN ILAJI OPA .SILE


AO WA SCOTI POWDER ATI SPIRIT POWDER AO DA SINU OMI IWE OKU AOPO PO DADA
OMO TIKOTI BALAGA YIO KI OWO BO OMI NA FI PA OJU RE YIO WA RANJU MO ASO
NA YIO SOPE .EYIN ALUJONU ORUN EPARA PO KEWA BA EMI OMO OLODEDE AYE
NIGBOLOHUN

WON YIO SOSI YIO SI MA BAWA BEERE IBEERE

PAGE 22

SIGIDI IWOSAN
AO FI OMI OSUN MO SIGIDI AOPOMO EFUN ATI OSUN MO KATO FIMO ERE TOLE GBA
AWO FUNFFUN SORI .. AOFISILE FUN OJO MEJE ...LEHIN EO WA EGBO IFON, EGBO
IPETA, OJULOWO ETU-IBO OYINBO,,ISETA,EGBO AWOGBA-ARUN,, EO GUN WON PAPO
MO ARA WON..EO RO SINU OTI ABALAYE..AOKO SINU AWO EO GBE SORI ERE NA
SUGBON IDI RE KO GBODO KANLE OOOOOO KATO GBESI OO
LILO RE- ENIKENI TI OTA BATA NI OFA, TABI ENITI O BATE OGUN BURUKU MOLE - EO
MA BU FUN ENI NA MU NI GAS KAN LARO GAS KAN LALE LEHIN TIO BA JENU TAN..
O DA JU.. BOTINU KI AGBARA OFA NA LAGBARA TO - OLORUN YIO KAPA RE KIAKIA
NIPA LILO ISE YI..

PAGE 23

OPA AGBARA NLA

AO WA IGI IROKO GBE OPA AOKIBO ITI OGERE AOFI ASO PUPA WE AOLORIMO
ORISARE FUN OJO MESAN LEHIN AOYO KURO AOKI OPA NA BO INU OBO AO WA FI
ASO PUPA WE AOLORIMO ORI ATAN FUN OJO MESAN AOYO OPA AO PO OJE IGI
APETE PO ORI AOFI PA OPA NA LARA .AORAN LAWO DUDU ABI PUPA AOFI OWO EYO
SE DISGN SI LARA

AOMA MU DANI LO OJU OGUN ENI TABA FINA YIO WO LULE KOLERO OOOOO TOBA
NBE LOWO WA IBON ADA .AKE OFA KONI HAN WA

PAGE 24

IMULE ELEYE TOSISE OSO OWO

EO WA EYE KOWE DUDU AIYE NI OOO,OGA GBIGBE META,ASIRI GBIGBE META,ORI ERE
META TONI ASE LENU META,ORI OKA TONI ASE LENU META,OPOLO IJOKUN GBIGBE
META,EWE OMISIMISIN GOGORO,EWE IGI AYE OOJO LEO KOBO WON MOLE ELEYI TIKO
DALU,.
APE TUNTUN LEO FIJO ISE YI..EO FI EPO PUPA YIKA IDI ARO TI EO FIJO ISE YEN KA..EO
SI BU OMI TUTU SINU IGBAA KAN EO GBE SIWAJU ARO TIE FI NJO ISE YI..TIO BA
JOTAN EO LO..EO RO SINU ADO TABI IGO FUNFUN BALAU KAN..EO PA ADIE KAN FISE
SAARA SIWAJU LILO ISE YI..
LILO RE..NI OJO TI EO BA BERE LILO ISE YI..EO GBO EWE EWURO MU NI ARO KUTU,.EO
TUN GBO EWE EFINRIN MU NI ASALE..TIO BAWA DINI DEDE AGO MEJILA ORU-LEO
BORA SI IHOHO TI EO BU DIE NINU ISE YI SI O WO YIN OSI EO FITE ODU IFA OSA-LOGBE
-EO WAPE AYAJO ISALE YI SI..EO FI MOHU LO..
O4- IBA- 3X - OSA LOGBE 3X IWO NI EMI L OMO L GBE ISE TEMI RAN LONI KIO WA
YAARA WALO RE MU ISE TEMI JE LODE ISALA AIYE TIMO WAYI OSA KIO YARA BAMI
LORE SAA ORE AJE AISIKI OWO TEMI WA OGBE KIO BAMI LORE GBE IRE AJE AISIKI
OWO TI NBE LODO OMO ARAYE WA FUN MI- NITORI OJUKAN ERE LO NSAN ERE OJU
KAN TI OKA BAKA SI NA LO NSAN OKA - NIDI ISE TABI OJA TI EMI L OMO L NSE YI KIO
SAN MI KI NBERE SINI RI OWO NLA NLA- KI ONA MASE DI MO MI NITO IGBAA EKU
WON KI NDENA DE ASINRIN,BIA BAMU OPOLO TIKO JO KOMUKO NSE LA NJU LE
ANAMU BAI NITI OGA(EO WA DANIYAH GEGEBI E BASE NFE) ODI IMULE ODI ASE.
AKIYESI_PATAKI_ KOSI KOSI IDI MEJI TIO MUMI JU ASIRI ISE YI SITA NIPE MO FE KIA
FIWA OWO KIA LERI OWO FIGBO AWON BUKATA TIO BA NBE NIWAJU WA LASIKO YI
TIA BA NFE BIYAA MAJEMU ISE YI NI PE - GBOGBO ENIKENI TIO BASE ISE YI OWO TIE
BARI NIGBATI E SE ISE YI-

PAGE 25

OLUGBOHUN EDAN

AO GET EDAN TAKO TABO TIO JE EYITI O TOBI ONIKUMO TABI ALADE, . EO WA AWON
EWE IFA YI - EWE OLOGBOKIYAN, EWE INA FF, EWE AIRAGBA OOJO,,EWE OLOYIN,,EWE
ESINSIN,,EWE OWU-AKESE OOJO,EWE ABAMODA,,EWE ODUNDUN,,EWE ESO,, EWE
TETE ABALAYE ,,EWE WORO,, GBOGBO AWON EWE YI LEO WA WON SI GBODO JE TUTU
TABI TOOJO,,EO WA LO ODINDI ESTATE KAN EO DA SINU BASIA NLA KAN PELU AWON
EWE YEN,,EO WA DA OGIDI EMU-AIRAN SI PELU OMI AGBON, PELU OTI SCHNAPPS
KAN, EO WA FIWE AWON EDAN TAKO TABO NA, TIA BATI NWE AWON EDAN YEN
LOWO EO MA JE OBI PELU OROGBO LENU EO MA TU SINU OOGUN ATI SARA AWON
EDAN YEN.. TIE BATI WA WE AWON EDAN YEN TAN..EO SI KOWON PAPO SINU APOTI
TIA FI IGI IROKO KAN, EO TE ASO FUNFUN BALAU TELE INU APOTI YEN, EO WA RU
EKURU FUNFUN SAARA AWON EDAN YEN NINU APOTI NA- EO SI FI AKUKO ADIE KAN
NU ARA AWON EDAN YEN.. EO SI MA WI BAI PE- EDAN TAKO TABO OOOOOOO BIE BA
NBE NILE MOFE KIE BERE SINI GBOHUN EMI OJOGBON AGBOMOLA 3X BIE BA NBE
LOKO KIE BERE SINI GBOHUN ENU MI NITORI PE BI AKUKO BAKO LAAYE DANDAN NI KI
EGBE RE GBOHUN RE LORUN GBOGBO OHUN TI EMI L OMO L BATI NWI FUN EYIN
EDAN TAKO TABO YI LATI ONI LO ONU NIKI E MA MUSE) EO WA LOPA AKUKO ADIE
YEN SITA GBANGBA NIWAJU ILE.. EO WA GBE APOTI YEN SI IGUN INU IYARA KAN..FUN
OJO MEJE..NI OJO KEJE EO WA DIFA LORI AWON EDAN YI LATI BERE NUKAN ETUTU TI
EO MA FUN WON-...
WALAHI TALAHI MOFI OLORUN JERI SI-ASIRI GIDI NI..
AKIYESI ASIRI YI KI NSE ISE TI TAJATERAN LESE OOOO AWON AGBALAGBA ALASIRI
TIWON DA NKAN MO NUKAN NI ISE YI WULO FUN - ENITI KOBA TINI ILE HOUSE) TIRE
KOLE SE ISE YI OOOO NITORI PE A KI NBA AWON EDAN YI GBE INU IYARA OOOOOOO..
ODINDI IYARA KAN LA MA FI NJI ISE YI..

PAGE 26
AKO OLUGBOLOHUN NLA

EO LO JA OJUDA EWE ABAMODA ONIGA MARUN EO JA MERINDILOGUN,PELU EWE


OGBO OOJO MERINDILOGUN EO WA GUNWON POMO OSE AGANYIN DUDU EJE
ALUJONU LEO FI PO OSE YEN NI IWONBA DIE, EO KAN OJE ORO-ADETE DIE PELU
ORO-AGOGO DIE SARA OSE YEN DAA DA,, EO WA IWO..MALU EO KO EYO ATARE 16
TELE RE, EO WA JU AKO ALAAMU AYE KAN SI,EJA OJIJI YIO TELE,ALAKAN AYE YIO
TELE, ALAGEMO IBILE AIYE KAN NA YIO TELE EO KO ENU RE SOKE EO WA SARE KO
OSE YEN BO OJU IWO YEN, EO FI O WO TE OSE YEN BO INU IWO YEN DAA DA, EO FI
OKO-OKA KAN GUN ORI ISE YI,E O WA FI OWO EYO AILUJU TE ODU IFA OSE-NTURA LE
LORI, EO LORI OLUGBOHUN YI MOLE SIDI OGEDE OMINI GBAA OJU MESAN..NI OJO
KESAN LEO LO HU..
EO GBE SIBITI OJU MEJI META KOTI LE MARI.. EO DI LETI NITORI KIO MABA MA GBAA
OHUN TI GBOGBO AWON ENIYAN BASO NI AYIKA IBITI E BA GBESI.. AYAFI OHUN TIYIN
NUKAN NIYIO MA GBA.

PAGE 27

SHO AGBAYE 2m

odidi card bolu to pe daa da kan.ewure tio ti bimo ri kan.eodu sinu ape eo fi 1k tuntun
kan si eo gbe card bolu si legbe.eoko odidi atare 10 si eru awonka tio po eojowon papo
tio bajo tan eolo yio kuna .eo waro sinu akerengbe eo wa fi idi akerengbe yen yi o eje tio
wa lara orun eran ewure yen. Eo wa gbe jo. Ni kete bie base lotan ni ori olo keo te ni ifa
ogundabede eo pe gbolohun re si kie to ba ro sinu akerengbe yen
Ofore. Ifa be sode 3x .orunmila besi idale adia fun ajeteluwa.ifa mi o bateluwa kiakia.
obatedalewa sasawara.ifa mi o bawa wa owo nla nla lotun o bawa owo nla nla losi kio
gbe won komi ki nri muse ohun rere laye mi. Ifa moni o to gege kio wa silekun ola temi
funmi. Nitori pe orun akerengbe finsilekun ola fun onile. Ori ni ewure fin ru eru ola fun
oloko bi asiri alajobi aye ko babo. Alajobi orun ni nbo eyin isinku orun oo 3x e sure tete.
Kie lo bami mu owo nla nla wa lodo tokunrin tibinrin omo araye. Ogundabede ole 3x wa
lo bami dagara owo nla nla temi wa fun mi loni ni kia kia ni weresesa
Eo ma fi otin lo ni aro. Pelu gboLohun

PAGE 28

IMULE ARAYE TO SISE EBE AGBA NA

Awó Ewure dudu tibile, aolowa egusi itoro kan aopani pansa, aofi eyin adie ororo
boninu aofi awo Ewure yen lelori aodepa aokoni ikobere aolorimo oju aro aodana lelori
funbi Wakati, meji tabi jubelo titi eyin yen yiofija, aoyo eyin yen aoje, aowa mun awo
Ewure dudu aojopo pelu odindi atare kan aofi singbere 21 si oriwa

PAGE 29

DINGI IWOSE TIMONLO TOSI DAJU DADA

AOLORA EJA ARO KAN AOJU SINU APE TUNTUN AOKO EWE OSEPOTU SI ATI EWE
SAWEREPEPE OOJO NI EWE MEJEJI YI BODO JE OOOO AOLO AWON EWE NA NI OOO
AOKO LE AODA COTIN POWDER SI AO WA SE LEPO NIYO PELU ODIDI ATARE AOYIN SI
AO WA FI SE
NI AGO KAN OSAN AOJE ASEJE YI NINU YARA KOBUDO SI EYAN NIBE AOTI LEKUN
MORI NI OOOOO AOJE TAN AO WA SA EGUNGUN EJA NA SIBI KAN AOJO EGUNGUN
NA PELU ODIDI ATARE KAN AODA SINU OWU ETUTU AODINIKOBERE AOSE NI IKORUN,
AO WA LO WA DINGI NLA KAN AOYO IGI ARARE KURO PATAPATA . AO WA LO PON
OMI ODO LARO KUTU KUTU AOTI PON OMI GONDA NA .AO WA OMI OJO OFURUFU TI
AOGBA FUNFUN RAWA TIKO KISE ELETOMA GBA ORI PANU ABI SILI WONU ..OMI OJO
OFURUFURU TI AOGBE IKE SILE TI YIO ROSI .. AODA OMI METATE YI PO AO WA FO
IKOKO ASEJE YEN AOKO SINU IKOKO MIRAN AOJO AOLO EBU RE AODA SINU OMI YI
AO WA RE GLASS NA SIBE FUN OJO META LEHIN AOSA SIBI TI KOTINIRI ORUN RARA
ATI RARA

LILORE ... AOTE ASO FF SILE AOGBE GLASS LE AO WA GBE IKOBERE YEN KORUN

#AYAJO_RE_
AOJUBA AWON AGBA KOKO NA AO WA AOPE
ALUJONU OMI 3*
EYIN ALUJONU METETA NI MOPE KEWA PARAPO BAYI
KEWA JE EMI LAGBA OMO LAGBA LOHUN BAYI NIBI KIBI TEBA WA . KI OSELE SI
LAGBAJA OMO LAGBAJA ..TI NKAN BAYI SE SELE (ISORO RE ) KEWA FIHAN EMI L
OMO L .ITORI BI EJA NLA BASO AORI ILE ODO KEDERE AO WA TEJU MO DINGI NA
DADA .AORI AWORAN EYAN BI TIWA YIO MA BAWA SORO ..

EWORE
TABA FEWO DINGI YI .AOBUDO GBE IKOBERE KORUN ITORI OLEWU
BEE NI AOBUDO DE FILA EJEKI ORI WA NI SISI SILE OOOOOO
AOBUDO WO DINGI LAGO KAN OOOOOO

PAGE 30

AKEESU ADAJO TODAJU GIDI ONI #2000 PERE TIMONLO TOSI DAMILOJU PA

ado ide kan.ao fi oti fo inu ati eyin ado naa.ao wa pa oga ooye kan sinu ado na.ao tun
pa eku lili kan sinu ado ati ako alangba..ao ro eje awon nkan meteta yi sinu ado ide naa.
ao wa ko ifun awon nkan meteta naa ao jo pelu odindi atare kan ao da sinu ado ide naa.
ao tun jo awon nkan meteta na pelu odindi atare kan ao po mon ose dudu ao le ose na
mon egbe kan lara ado ide na lati oke de le.ao wa gbe ado na sinu awo tanganran ffun.
ao wa kan apoti iroko ao gbe awo na si..ao ni de ado yen oo ati awo naa ooo.ao wa ko
owo paper meji si egbe ibi ti kosi ose legbe ado na...ao ma ko owo nibe lojojumo....
Akiyesi ti ko ba mu owo wa ni ijo keji ki afi sile fun ijo meta...nitoripe igba ti mo dan ise
na wo leyin ijo keta loto mu owo wa...ki a de gbiyanju lati se etutu fun awon agba ki a
de se nkan awenu toda ki ato se ise naa ooo.

PAGE 31

Ogun Aya Jija


Orogbo Gbigbe Kan,ao Lo Pelu Ewe Owo Eyo 3,ao Ma Fi Ojere Epo Pupa La Die Die
PAGE 32

ORUKA ALUPOYI

Egbo ako ibepe, oruka elelo, ao ko atare eyo pupo die si inu egbo na pelu oruka na fun
ojo meje.

PAGE 33

SEE THE ANSWER FUN OMO ILE IWE

Ao pa alanbere kan, odidi atare kana o fi ikode kan ha lenu apadi toti fo ao jopo ao ma
pomo atike funfun ao ma kun soju ni ojo examination

PAGE 34

ARUNKI

Eja ojiji kan, oruka dudu meta, bara tutu, ao ko oruka yen si eja na lenu ao wag be sinu
bara na fun ojo meje

ERO- ki a to mu ao fi epo pupa, pa owo ati ki a to kibo ika wa ti a ba filu eniyan ti o ba


subu ao bu epos i lenu yio dide.

PAGE 35
APAJI

Igbin apinnu kan, imi oru, ao lo yio kunna ao wada si oju igbin na ao da oju igbin na dele
ao fi apere bomole ti o bati ran jade ao wa mu igbin na ao ge si iyekiye ti abafe, tio ba
jinna tan ao sokale si ori osuka kana o koje ni gbigbona.

PAGE 36

OGUN TEAR-GAS

Etu ibon gidi, ao teni eji ogbe ao fi ina si ao fi oju gba efin re, ao fi ogede omini ko eru
reje.

PAGE 37

AWORO ITAJA

Iruu, ogiri ijebu, alubosa elewe, ao gun won papo moo se dudu, ao kosi inu bata aloku ti
a make sure wipe awa lawo titi o fi gbo, ao ma buwe.

PAGE 38

AYETA ALASO PUPA ENU IBON

Orogbo kan, ao gbemi tobadi ojo keji si ojo keta ao yamo igbe ao yo kuro ao sati yio gbe
dada, ao fi aso pupa we orogbo na pelu atare odidi kana o jopo gbere mesan si igba
aya (meje fun Obirin)

PAGE 39

OKIGE ADA, OBE,

Pepe aka 3, ako okuta 2, ao file arawon ao dini owu ff/dd ao mafi si ara

PAGE 40

IMULE EYONU AWON AGBALAGBA TIWONTUNMAAPENI (EYE DUDU ORI AGBON)

Olongbo nla 1, Opolo ijokun 3 Eku asin 3 Oga gbigbe 3 Opolopo ESO idoo Opolopo ESO
werenjeje Ataare odidi 3 Aopa musu yen ti eje kankan koniiyo laraare.....ao ju sinu
agbada...aowako awon eroja yoku sii bi aseti so si oke yen.......leyin nan Eepo obo aopa
pepepe......aodabo gbogbore lorii ninu ape tikonii han sitamo Igo oti 1 Igo epo pupa 1
Aomaa tasi ileele tabanjolowo diedie.....taba jotan...Aoro sinu seere 1...

Liloore...Aobu die sinu awo ipese tuntun kekere kan....aotenifa orangun meji...Aope
ofoore sii.... leyin nan aomaafi epo pupa la lalaale
OFOORE.....Ifarowa 3x, Elarowa 3x, ojuponmi kankan kintooma ifaada, mosalo salo
kintoomo ogbedi..Aajo nimose kintooko erun miloreba olofin, titoro nitoro, odi oluyoro
nyoro, eyin onan onan, atoboseje, tedafafunwon nilu ogege, nibiti wontin dajo eesu,
eesu tiwondanibe omowon niwon finko, wonpa OMO alaraje, wonpa OMO ajero jee,
wonwani orangu meji kini oun kanhoo, orangun meji nikokanmi, wonni tori kinni..?
onitoripe ijeti aje eran gbogbo enikan kiije oga bee, ijeti aje eran gbogbo enikan kiije eku
asin bee, bi asenje eran gbogbo akogbodo je ologinni bee.......ijeti aje ohun gbogbo
enikan kiije werenjeje bee, ijeti anje oun gbogbo enikan kiije ESO idoo bee, ijeti anje oun
gbogbo enikan kiije ataare bee, wonni baba ofo lemanpayii.....

Adura.onikiise ofo, oni oso ileyii, shebi imule yin nimonse, aje ileyii shebi imule yin
nimonshe, akiibanimule katunpani, akiibanimule kadinilowo. akiibanimule katun da oro
eniru.....EYE DUDU ORI AGBON OOO 3x, shebi eye iletiwa leyin she....adura .opari....

Aoto epo pupa si oju awon ODU yen ao fi dongoyaro arin ropapo. Ao LA,ni alaale.

PAGE 41

 AFEERI

Ewe Alupaida Pupa Odidi Atare Kan Ao jopo Ao Rosinu Ado Ijamo Kan Ao Loran Lawo
Dudu Ao Magbe Korun Confirm Akoko Wole Miniyi Egba Afeeri Yi ...Ewe Alupaida Pupa
Odidi Atare Kan Ao jopo Ao Rosinu Ado Ijamo Kan Ao Loran Lawo Dudu Ao Magbe
Korun .
PAGE 42

OGUN FUN PROMISE AND FALL


Oga gbigbe 1, efun ado, osun buke,imi ojo, ikumu ojia, ewe areyin kosun, odidi atare ao
jo papo ao fi omi agbon pomo ose dudu ao kosinu fitila oloju kan ao wa te ifa ogbe fun
(ogbe ofun) si ori ose na lori
NB inu fitila oloju kan lama ko ose yi si lao sese Wa te ifa yi si lori ao mafi we odaju
Promise and fail yio da gbere ninu aye enina....

PAGE 43

AGADAGODO YAHOO TODAJU

Irun ori Oodi, Iyan ana, Ori Alabahun, Eepa igbe totigbe, ewe Amunimuye, obi alawe
meta, awo ewiri alagbede, odidi atare kan, Ao jo gbogbore po, Ao bu ebu ogun yi die
sinu efe owu’Ao dini ikobere,Ao fi owu dudu ati funfun dimo ara agadagodo, Ao ran
Awo ijimere mo Agadagodo na lara, GBOLOHUN RE,,,,, Aki pejo je Ahun, Aki pejo lu ewiri,
Agbagba mefa ki pejo je ewu iyan ana, hunhunhun lodi nwijo, oro ti lagbaja bafeso loni
ki amunimuye mun iye re’ ko ma lemo ohun ti ohun se, Oro ti oba tiwo Agadagodo ki
jade mo, Ao ti Agadagodo na pa, Ao bere Ohun ti abafe lowo otitohun ‘ esekese ni yio
se funwa.

PAGE 44
OGUN FOBON OLOJO META PERE

Gbogbo eyo atare, ewe ogbe ori akuko meje pelu Akara elepo kan(beads cake). Ao ko
gbogbo re sinu akara elepo(beads cake) naa, ao waa jee. ¤NB¤:- Ogun yi maa sise fun
ojo meta Pere.

PAGE 45

OGUN AROBOKU OKUNRIN TI KOLE BA OBINRIN SUN

AO toju egbo Ajara,ao ge wewe sinu igo kan,ao jo eyin adie ibile 7 si,ao da opolopo omi
agbon si,lehin OJO keta ao ma Mu

PAGE 46

OGUN AJAGBILE FUN ENITI WON FE GBA ILE RE.


Ori ikun kan, ewe alukerese, ewe epa, odidi atare kan, ao jo papo, ao dasi kolobo lona
merin, ao lo ri si ori ile na lona mererin, ki atori ao pa akuko adie kan si kolobo mererin,
ao fi ejere die naa sinu won.
OFORE:- Ojo tikun × 3,
Iletepa ×3.
akiba alukerese du ile baba re ×3, kiwon gbagbe ile yi funmi, nitoripe akiiba alukerese
du ile babare.
Lenin naa, ao wa se adura ti abafesi, ao lori mo origun mererin ile naa

PAGE 47
Ogun Afeeri

Ologbo dudu kan, irun abia Ewure, irun abia aguntan, eyin abie ti OBA bimo kan, ao pa
ologbo yen, ao ko gbogbore sinu alati funfun kan.
Asiko ti kobasi Osupa, ao wa pa awon nkan yi, ao Jo ninu okunkun ni ale, ao da si ninu
ado kekere kan, ao gbe ado yen fun awon onisona ,won ao ranni Awo dudu.
Ti abafe lo, ao fi korun, ao yisi eyin, oju merin ko gbodo ri ado naa, inu ikankan lao gbesi
ti ao se mo,7 ao mafi si ibi ipamo ti aba lotan..

Ofore –
Bi Oru bio Oru niise Ologbo dudu, Ologbo dudu kiigbe inu iyare riran, aguntan kiigbe inu
iyare riran, ewure kiigbe inu iyare riran, oromo adie kiigbe inu eyin kio ri iyare.
Ki Omo Eniyan mari emi loni.

PAGE 48

OGUN FUN ENITI O WA OKO TABI IYAWO :

ori adaripon (fun Obinrin) tabi Alangba àbo oojo fun okunrin, eso werenjeje mesan fun
okunrin, meje fun obinrin. Ao gunpo mo ose lux iwe eekan pere

PAGE 49

OGUN TI IBALE OBINRIN FI NPADA SIBE

Ewe ege were, owu Elena, lilopo, ao fipa ara eyin adie, ao fi owu Elena yi eyin adie na, ao
fi aso osu ti obinrin na lo lowolowo we lawetan, ao mulo sinu okiti ogan, ti okiti ogan yi
babo, ibale(virginity) yio padabo Sibe

PAGE 50
OLUGBOHUN NLA

Egun efon iha egbe osi meta afi ika arin won igi abo lona meta, edun ara gidi kan,egbo
iroko, egbo akshe, egbo orogbo, egbo akerejupo, ao diwon po mo edun ara naa, pelu
owu dd ati ff.
Epo ara egbo iroko, egbo orogbo, egbo akerejupo, egbo akshe, ewe oloyin, ewe ina
pupa gidi, ewe esisi ff, ewe aragba, alake ojuna 9, ibi omo tuntun ojo, ao gun papo mose
dudu, ao wa san MO ara eyi ti adi lakoko yen, ao wa pa ako Aja kan, ao la laya, ao wa
gbe ogun naa sinu Aja naa, ao da etu IBON gidi milik kan si ao fi ina si leyin ti Oba gba
tan ao fi aso ff no gbogbo ara Aja naa ao gbele, abo Aja naa mole fun ojo mesan, ao wa
lowu lojo kesan ti orun bati wo tan, ao fi emu gbe ogun yi jade, ao gbe sinu awo SOBI ti
ole gba ogun naa, ao wapa obuko nla kan fun iseyi, ao fi ro ejere si ori ogun yi, ninu awo
sobi naa, ao wa gbe sinu aori iroko, ao koko fi aso ff tele apoti yi ki ato gbe awo sobi
yen sibe, awa ba pin hun wipe

Ofore
Iwo olugbohun yi gbogbo igba kigba ti ami l omo l bati pe o miki oma dami lohun,
gbogbo ise kise ti moba ti ran o niki omadami lohun, ki omalo si gbogbo ibi kibi ti
mobaran o, onakona ti mobaran o, niki omalo, nitori kan kan lewe ina jomo, wara wara
lomode too esisi bowa, ile ogba ona ogba nise ewe aragba, ewe oloyin kin pahun
obarise daa, bi oko ara ba bo tigbo tiju niko monamana re, gbogbo ohun ti mobaso nidi
re niki omaa ri bee oo, bose oso, Aje, emere, alujannu, alufa, babalawo, onisegun,
adahunse, lokunrin lobinrin, lomode ati agba, atoba, ati ijoye, ati bebelo, ni moba ran e
si, ni ki oma gbo o, ki ise emi l omo l omalo dede o, gbogbo awon ire owo, omo, motor,
mecca lilo, ilu oyinbo gidi lilo, ile kiko, ile ise nla nla, lorisirisi, alafia, emigigun, Alanu
lokunrin lobinrin timo ba hun pe won ki won o may wa bami ni pelu owo lan lan lomo
won, ki gbogbe re wama ribee, lagbara olohun, amin ase, nitori pe ogangan ona ni alake
no gbogbo ohun ti moba so kama ri bee ni ooo.

PAGE 51

OGUN TI AFI NSEGUN PROMISE AND FAIL

Aso ff opa kan,epo pupa,ataare kan,eko kan,akara kan,moin moin kan,a o lo sinu Igbo,a
o te aso ff naa sile,a o ta epo le lori,a o so wipe,ijo toba baje fun aje,ijonan ni baje fun
oko re,epo pupa ni baye aso ff je,akara ati moin moin ni baye eko je,oun naa ni kii je ki
ebi o pa okanran,ki ebi owo ma pa emi lagbaja omo lagbaja.A o fi akara yi epo naa ti a
ta sori aso ff yen,a o je,a o fi moin moin yi bakanna,ao je,a o fi eko yi,a o je,a o wa sope
ewe nii basiri eko,a o mu ataare,a o so wipe abotan ni orisala nbo ataare,a o fi ataare
naa yi epo,a o fi sile ninu aso funfun,a o mu orogbo a o so wipe ‘Areyin kosun,oya kowa
kosun,ekeji a o fi yi epo naa,a o dipo mo ewe eko ni isale,ewe moin moin loke,a o dipo,a
o gbe koto,a o gbe aso ff yen le lori, a o ri mole,a o so wipe gbogbo eniyan ti e se
adehun fun mi ni mo rimole yi o ,lati oni ke wa ma mu gbogbo adehun yin se fun mi,ti a
ba dele,a o fowo fole wa,a o lo sun tabi ki a lo wakati meji ki a to jade.
O dara fun awon omo yahoo,

PAGE 52

AMUDO TO NJE BII IDAN


Ewe amunimuye
Oruka irin
Itakun isirigun
Ewe aluro
A o lo won papo, ao koo si inu eyikeyi iwe adie
tutu, aofi aso waji we daada, aolo boo mo idi amun ti
omi kiitan ninure, fun Odidi ojo 9, ao lo ko o, ti
abafelo, aofisowo, alefidimu, sugbon eyi
ti o maa n tete sise ni wipe ki a maa fi romance obinrin naa. ,Ko ni pe iseju meji ti ido re
yoo fi maa dide.,

PAGE 53

OSE IYONU OMO ARAIYE

ORO AGOGO , ERU ALAMO , ODIDI ATARE KAN , EPO OBO , EWE ALUPAIDA , EWE
PATANMO ,OGA GBIGBE META AO GUN PAPO DADA PELU OSE DUDU , AWA FI OMIN
AGBON POPO , AKO SINU IGBA AGBON , INU IGBA AGBON YI LATI MAN BU OSEYI WE ,
PAGE 54

ASEJE OWO NLANLA LAARIN OSU KAN PERE

Ewe dandan , ewe atewogba, iyere, epo, iyo, a o fi se Igbin agbonu meji meji je ni emeta
laarin ojo meje

PAGE 55

OGUN TI AFIYA TOKO TAYA

Okun meji toba lomo arawon, ao je atare mesan lenu, ao tu siwon lara, ao daruko oko
ati aya naa peki won di ota lati eni lo. Ao fi igi ja okun naa, ao wa di oju mejeeji, ao mu
eyi ikan ninu okun yi, ao so sinu igbo.  

PAGE 56

OGUN ANOBO
Opolopo ijalo, oga tutu kan, oruka irin kan, ao la ikun oga yen, ao ko ijalo ati oruka yen si
inu re, ao wa ri no ile fun Ojo meje, ao wa lo hu, ao wa Jo, ao wa ko etu yen sinu apo
kan, ao mafi owo sinu re… Ao fi oruka nasi aarin owo na fun Ojo keji, leyin na, ao maa na
owo… Bi Aba se nna ni yio ma pada wale pelu opolopo owo koda koje owo bank.

PAGE 57
 

OOGUN ATIKE TI OKUNRIN FI N FERAN OBINRIN

Obinrin na yio mu orogbo kan si abe re moju, a o gba ni ojo keji, a o gun orogbo na pelu
epo bodunbawo ti o wo sile funrare ati ifo ejo die, a o lo kunna dada, a o po mo atike,
obirin na yio ma
PAGE 58

Ogun Akammole Obinrin

Epa tutu, ewe amunimuye, ewe alupaida, ewe panumo abo, irun abe okunrin, irun
ipenpeju okunrin, ekanna owo ati ese pelu odidi atare aja kan, ao jo po, ao fun obinrin na
je

PAGE 59

OFO AMUDO

Amuka oruko ti anpe Oko, ore midede loruko ti a npe obo, Agbari sole mare oo. Lagbaja
mofe do e

PAGE 60

OWO NLA LAARIN OSE KAN PERE¤

Eja Aro meji(2), ede pupa 16, ewe awere pepe(iyekiye), ao fi iru ati iyere se laseje 

PAGE 61

OGUN TIDIYO IBON TODAJU GAN

Ao mu eso bomubomu, ao fi eyin si inu re, ao wa see, toba ti jina, ao wa maa je ti aba
tin ya igbe lowo. ako gbodo yo eyin naa kuro ninu eso bomubomu na o, ao je papo nio. 

PAGE 62

ATIKE ANU
ITUN, IFA, ESO EWE OLA, ABEERE, EWE AJEOBALE, LILO KUNA DAADA, MIX PELU
ATIKE, KIKUN SOJU

PAGE 63

OGUN TI A FI NGBA NKAN LOWO ENIYAN

Ewe omisinmisin, a o fi sugar die, a o lo papo pelu suga, ewe omisinmisin gbigbe ni, a o
ma la, a o sima fi beere nkan lowo enia.

PAGE 64

OGUN ALUWO
ewe ina pupa, adigbonaku kan ao wa lo papo ao wa isu ogiri sako ao ri bonu ao wa bu
ogun ti a lo yen ao bu die tele ninu ogiri sako yen ao wa ko oruka meta si ao wa bu ogun
to ku si ao wa pa oga ao wa da eje re le lori ao wa lo fi pamo di ojo meje otan
e
ERORE KIATO MU =ori lao fi pa owo

PAGE 65

OGUN ONMO IWOSE

Ori Ikun Kan Alelo Gbigbe Amo Tutu Lodaju Ao Fi Tele Ape Aowa Ko Ewe Epa Tutu Bo
Mole Pelu Odidi Atare Kan Ao Jopo Ao Lokun Na Aoda Sinu Oti Ao Mamu Ni Gbogbo
Igba Ti Aba Fefimo Nkan Tosele Si Eyan Ti Enina Bawa Niwaju Wa Aodiju Wa Pelu Ogo
Olorun Gbogbo Nkan Tose Eni Na Lama Mo Odaju O Ona Tafinlo Po Dada Edan Wo

PAGE 66

ORUKA AWAMARIDI
TI IYAWO WA BA NJADE TABA FI ORUKA YI GBA NIDI HAAAAAAAA...
INA NI KOMO OJU ENI DA OOO
...... .....
ABI KOJE OMO WA OBINRIN LAFI GBA NIDI NIGBA TO HUNLO ..
TI WON BA FE SUMO OKUNRIN KO KUNRIN ..WALAHI TALAHI MOFI ISE YI BURA GIDI
GAN..
....
...NKAN OMO KUNRIN NA KONI GBERI RARA OOOO
AMO TI OKUNRIN BAFE SUMO OBINRIN OKO RE YIO GBERI AMO IYAWO WA ABI OMO
WA TI ADE TIFI ORUKA NA GBAWON ...HMMM
OKO OKUNRIN KONI GBERI RARA ...OOO
.....
#EROJA_ISE_NA_
EWE AMUNIMUYE
EWE INA
EWA KAKURE DIE
ORUKA OJE KAN
...
.....
#SISERE_
AOLO AWON NKAN YI PAPO ..AOKO SINU IKARAHUN IGBIN KAN ABI INU IKE KAN
AORE ORUKA NA SINU RE FUN OJO MEJE GBAKO LEHIN OJO KEJE AOYO AOSA SIBI TI
KONIRIN ORUN RARA ...

.....
#LILORE_
AOKIBOWO FI GBA OBINRIN NA NIDI
MAFI SEKA OOOOO
OLORUN NBE OOOO
...USE IT TO PROTECT YOUR SELF WITH YOUR OWN WIFE OR DAUGHTER ...
......
#ERO_RE_
ITORI TI ABA SE LO ERO RE ..HAAAA
OKO TIWA NA KONI GBERI LATI BA ENI NA SUN OOO
PAGE 67

AFUNJE CUSTOMER/OBIRIN

AOYA IGBE SINU FILA NI ARO KUTU KUTU LAITI FOHUN RARA ATI RARA AOKI ORI
APARO KAN SINU IGBE NA AO WA GBE PAPO FUN OJO MEJE LEYIN OJO KEJI AOGBE
SINU APE IJOGUN TUNTUN PELU FILA NA..AOJO TOBA JOTAN... TI ONIBARA BADE
AOFUN NI DIE KOFI OTIN LO.

ERO RE ..___ ITORI TI ABA LOFUN OBINRIN AOFUN NI EBU NA LOO LEEKEJI... YIO DA
KOJU RE... IKILO... ONIBARA OBUDO LO LEEMEJI OOOOO OJO KAN PERE NI LILO ..... TI
OBA LO LEEMEJI OBAJE NIYEN OOO

PAGE 68

OGUN ORUKA FONYEPE

Ao fi ori ( silbutter ) ra owo wa mejeji Ao wa bu iyo die si ile salamo Ao ko oruka dudu
mesan sinu re ati eyo atare mesan Ao gun bu iyo lelori Ao fikale fun ojo mesan leyin ojo
kesan Ao lo koo kato ko ao fi ori ra owo wa mejeji sugbon meta pere lama banibe leyi
naa Ao ma fi bu iyepe lu ota wa, Ero re yio dide Larin iseju marum yio dide tabi lie fi epo
si lenu odaju emafise ika o

PAGE 69

KI A MAA LU MAGUN LARA OBINRIN

Ao waa Okun (Millipeas) eyiti o baa fe daa oju ona koja, ti o baa ti waa ni arin ona ki o
to ki ori bo inu igbo ao jaa ewe kewe ti o waa ni owo otun ao so wipe EYITI A JAA
LOTUN OTUN NI NGBE, Ao tun jaa ti owo osi ao tun so wipe EYITI A BAA JA LOSI OSI NI
NGBE, ao waa fi ewe yen ko Okun yen po ao jo pelu odindin ataare kan ao fi sin gbere yii
ibadi ka... Opo enia le lo

PAGE 70

TOILET INFECTION
Epo Aganwo ati ewe eti Erin, ao ge kekeke sinu omi ao fi Alomu die si ao maa mun ni
gasi kan aro ati ale

You might also like