Professional Documents
Culture Documents
Òtúrúpõn Òdí
Babaláwo erin ló d’ífa fún erin
Òtúrúpõn ‘Dí, eye sí
Erin mo díè lé’rí
Òtúrúpõn ‘Di, eye bà
Erin nròde Àlo
Òtúrúpõn ‘Di, eye sí, eye ò sí
Ìtàkùn tó bá ní kí erin má dèe Àlo,
Òtúrúpõn ‘Di, eye bà, eye ò bà
t’òhun t’erín ní nlo
Òtúrúpõn ‘Di, eye ni ò ta kánkán, kó gun’gi
Erin, “Ni ìgbàwo lo di òkè?”
Ad’ífá fun Õrúnmìlà
Ìsinsìnyí ni a rí erin
Ní’jó àwôn eleye ilé ìyá rê rán’ni wá pèé
Erin, “Ni ìgbàwo lo di òke?”
Àjë ilé, osó ilé, e m’owùn mi
Erin g’òkè Àlo
Eleye kìí bá eleye wíjö
Àgùnfon, erin mà ti g’òkè Àlo
Osá-L`Ogbé Eyan tó bá ní kí ebo má nşeda
t’òhun t’ebo ní nlo
Ágbonrín ígbóró kó yólé é té
Kó´má baá derán Igún “Òsì ni abiyamô nda ômô rê sí”
Kó´má baá derán Ájé Ókánrán-ÁdÍsá (Ókánrán-Ósá)
Kó´má baá derán Íyá mi
Díá fún Ájágbé
(Mano Derecha) Ötún Pèlé, Awo won óde Àbá
Ti won mú re igbodú ló té ní fá
Bábáláwo kíí rùkú ógbèrí Día fún won lóde Àbá
Ògbèrí kíì wó igbódú láì té ní fá Won ji, Ekún Ajé, Ekún aya,
Ifá ló wá di Óbírí Ekún iré gbogbo ni wón n Sun
Mo ló wá di ewé àpadase Wón ní kí wón sákáale, ebo. ní síse
Wón gbébo, wón rubó
Óferegége Kó pé kó jínná
Ájàgbé á dide ò Ire gbogbo wá ya dé tútúru
Óferegége
Bí ewúré bi `mo lóòjó a díde (Mano Izq) Osí pélé. Awo won óde Ábose
Oferegége Día fún won lóde Ábose
Ájágbé á dide ó
Won ji, Ekún iré gbogbo ni wón n sun
Óferegége
Bi àgùntàn bí`mo lóòjó a dide Ebo ni wón ní kí wón wá sé
Óferegége Wón gbébo wón rubó
Ájágbé á dide ó Kó pé kó jínná
Óferegége Ire gbogbo wá ya dé tùtúru
Bí ádíe ókókó bí´mo lóòjó a dide
Óferegége Átotún, at Osi kíí sebo áífin
Ájágbé á dide ó Átotún, at Osi kíí sebo áímádá
Óferegége
Bí ikú ´n bó Áséwélé ni wón difá fún
Jókòó tèé Omo okúnrín dépénú
Bí ófó ´n bó
Ó di dépénú dépénú
Jókòó tèé
Á bá dégún. Dépé I´Áwó lóri
Níjó´ajé ´n bò nílé elébo Kó lé já láídáláí
Níjó aya ´n bò nílé elébo Áséwélé o dé ó. omokúnrin dépénú
Níjó omo ´n bò nílé elébo
Níjó ire gbogbo ´n bò nílé elébo
Kí gbé ìdí kí jé kí ó tó owó elébo
Bí árún ´n bó
Jókòó tèé
Òkín ningín-ningín Áwo Olókun
Ókánrán-ÁdÍsá (Ókánrán-Ósá) Díá fún Olókun
Nijó omi òkun ó tóóbù bójú
Álúkó dòdòòdó awo Olósá
Orí adé níí se bín Opón Díá fún Olósá
Awón Òdelé níí rín ihòhò sosín sorà Nijó omi Osa ó tóóbú sin`sé
Idànndán níí fi ara re se afárá olúkoyin Ódideré abírín esé kerewé- kerewé
Díá fún Olú-iwó `Modú Obá
Díá fún akówó-rarí Omo atórun lá, gbegbá ajé karí wáyé
Ifá somo Àjàníwàrun Ò túká ó dà ká
Akówó-rarí kíì kú Erigi lawo Ágbasá
Díá fún won ni Isése-Ägéré
Èèyán tó kówó rarí Nijó ti wón kó Ohun ebo silè
Elédáá ré á báa tálé Ti wón nwá Bábáláwo ó loro
A rò´hun ebo lónìì, a rò´hun ebo
Erigi lawo Ágbasá
Ifá a róhun ebo
Ogbe-Odi Harina________Éko tó nbe níle yíí `nkó
Ohun ebo níí se
Erigí lawo Ágbasá
Gbamí igbó lawo gbamí igbó
Ifá a róhun ebo
Gbamí òdán lawo gbamí òdán Agua_________Omi to ´nbe nilè yìí nkó
Gbamí hènhen níí sawo gbamí Ohun ebo níí `nse
hènhen Erigí lawo Ágbasá
Ifá a róhun ebo
Ifá ti o bá yò mí ní ibi tó dí gágáágá Corojo________Epo tó `nbé nílé yíí `nkó
Bí mo bá dé ibi tósunwon Ohun ebo níí se
Màá san oore é re fún o Erigí lawo Ágbasá
Ifá a róhun ebo
Díá fún Orúnmilá Erígí tí `nbé nílé yíí `nkó
Ifá ó yó omo ré nínú irunbi Ifá a rohun ebo
Owó ò mi wá ba ewé olóbýóboyo témi Ginebra_______Otí ti `nbé nílé yíí `nkó
Okòsòkósó Ohun ebo níí se
Erigí lawo Ágbasá
Nifá ó yo ´mo ré kúròú ibi Ifá a rohun ebo
Okòsòkòsò Gallo_________Ákúko ti `nbé nílé yíí `nkó
Ohun ebo níí `nse
Erigí lawo Ágbasá
Ifá a rohun ebo
Ifa mo ní kóo gbérú kébo fin Nues de Cola__Obí áti Orógbó tí `nbe nílé yíí `nkó
Ifá mo ní´ kóo gbérú kébo ó dá Ohun ebo níí `nse
Ifa mo ni kóo gbérú kébo dé áládé órun Erigí lawo Ágbasá
wón níóná wo lo gbá tóo fi njé béé Ifá a rohun ebo
A rohun ebo
mo béé náá lóó jé ifá K ´èbo náà ó fín
Erigí lawo Ágbasá
Ifá a rohun ebo
A rohun ebo
Otúrá-Túkáá K ´èbo náà ó dá
Erigí lawo Ágbasá
Ifá a rohun ebo
Bíebi bá n’ pa inú Egúngùn Akoda, Egúngùn édídááré
Ákásású banba làá fií beé Erigí lawo Ágbasá
Díá fún Téyíngbíwá Ifá a rohun ebo
Bólótíbá pon otí tán
Ti yóó san`wó ípín lórun Édídá a dáá
Mo san ’wò ípín mo ní ísinmi Erigí lawo Ágbasá
Ifá a rohun ebo
Téyíngbíwá Dáá-dáà níìs`adie ába
Mo san`wó ípín lorun Erigí lawo Ágbasá
Téyìngbìwá Ifá a rohun ebo
Dánidáni lasiwéré ´n rìn
Erigí lawo Ágbasá
Ifá a rohun ebo
Eni bá pé kébo má dá
Kásáí máa b`ébo lo o
Erigí lawo Ágbasá
Ifá a rohun ebo
ÓWÓNRÍN-ÓGÚNDÁ Òtúrá Òsá (Òtúrá gàsá)
Ókánrán Ádísá
Àsá ó lápá
Ó fenu s ´oró
Áwódí ò lápá
Ó fesé jalé
Díá fún Ohún awo fowó bá
Tíí dí ebo
Ebo kóó fín o
Ásání ájá
Ókánrán Ádísá Odu consulta
Oyeku Meji
Odi Meji
iká-Méjí
2- Kéngbé ni ó pa gburu w`amu
Ká gbáa nibuú Díá fún Odi
Ká gbá-a lóoró A bú fún Yárá
Díá fún Áásé Iwá Odi n sé
Ti nIo ogun llurin Iwá Odi n bajé
Ebo n wón níkó wáá se o Atéwe, átágbá
Ó gbébo, ó rúbo E wá lo reé tún `wa Odi se o
Táasé bá lu'rin tán
Ara a ré a si le kokooko
3- Aagba fáá níhìn-ín
ijóku fáá Ióhún-ún
Ejó ni ó kómo léyin yooyóóyo
Díá fún Walami
Kó máa aje ká ko Tí nlo reé bá won tún iwà Okó se
Díá fún Kérénnasí Bókó bá rókun rósá
Tí yóó gbógbóógbó EIébúúté níí forí í fún
Tí yóó gbé egbéédógún odún láyé Nílé Oba won nílé Eyó-maró
Má ma jokó ó dá
Ki má í kú 'kú oeówó
Walami
Sasara Má ma jokó ó dá
Kíí kú orówó Walami
Sasara
Akàràkàrà ojùu Kangara ni O seé gbá mú
Okánjúwa tó wóké rádárádá
Ni n wó rosoroso
Íreté-Méji
Ofun Meji
1- Eérún-ún yán ni ifofó kété
Je n gede
Díá fún Atóka
Je n gede
Tíí se ikari Ólódúmaré Je n gede
Mo di Ílarí Íkin Babalawo Aye lodifafun aye
Emi ó r'oko Aye n jaye inira koko bi ike
Atóka di Ílárí Ólódúmaré Aye wa jogede tan
Mo di Ílárí Íkin Aye n tutu bo
Je n gede
Emi ó r'oko
Je n gede
Atóka di Ílárí Ólódúmaré Je n gede
2- Oko ré
Aya ré
Díá fún Ókéké jégbé
Tí yóó fé' binrin Ikú tán
Ti yóó fobi méfa tan
Ero Ípo, éró Ófa
E wá bá ni lárúúsé ogun
Agbágbé nifá ó gbá láya
Ókánrán-Ádísá (Ókánrán-Osá)
Kiki Epo
Ká mú gégé lu gégé
Gúrugúru gúégúé Awo ilé Alákóókó
Díá fún Epo Ígbin ótara iná yíyá
Tííí se omo íyá Ebo Awódí ni ó pa sáá gb’ádie rá
Epo gori i ré ó d' Ebo Olúwo méta, irúkéré méfá
Guruguru gúégúé Ogun tí a fi ésin sí
Epo gori i ré ó d' Ebo Ti a ó leé sí
Guruguru gúégúé Ogun ti a fi ókó já
Tí a ó leé já
Ótúrá-Íreté Kínni Edú fi tú'mó o ré
Írúkéré I’ Edú fi tú'mó o ré
Ótúrá lalému
Íreté lalera Tú'mò lkú
Diá fún Áránisán Tú'mò Árún
Tí yóó mutí kan ámulówó Tú'mò Ejó
Otí olá lawo mu Tú'mò Ófó
Ọsà Di