You are on page 1of 7

Cantigas de Osala

IGBIN

1. Asó dudu go iya pi

 Asó funfun t’Orisalá

A e Ajálê o

Asó funfun t’Orisalá    (alá)

2. Ajale mo ri mo yó Forikan          (bis)

E ajo o firiri

3. Opere kete

Opere kete baba

Ibi ala do injena                                                 

Opere kete baba

4. Baba baba ebo baba ekó m’okan        

Baba baba oge baba eko m’okan o

Sire olo ore baba oge

Baba ekó m’okan kare le

Baba eko m’okan kare le

5. Baba oje o eru nhe


Ajale baba oje eru nhe e kun ni kun ni
Baba oje eru nhe oje b’awa oyo
6. Ken sen k’ewa b’awa o
Obatala k’ewa b’awa o
7. Egbo Baba egbo un alá                  (bis)

 Orisá nla t’alá b’ori o

Egbo baba egbo un alá

8. A ira ala gba mi la l’okan (bís)

Kere lú

Ki padê sire

Babá epá

Sire o re re

Babá epá

9. Epa e nu are o

 Ata k’ori ko

Baba epa

Iru wa

Ata k’ori ko baba

10. Baba efun durode ajale

Babá durode

 Babá durode

Ajale

Baba durode

11. E abuke k’ewa já


 Baba oje

Obere iko k’ewa ja

Baba oje o

12. Dide dide dide na                       (bis)

 Baba forikan dide na

Dide dide dide na

13. Ago ala  Ala osu

 Osu kekere ile

 Ago ala  Ala osu

 Baba durode

14. Dide dide toke jo joko (bís)

Orisa pajo man isin ae

Man isin

Omi saba jo man isin ae

Man isin

15. Akete oba ese oni e (bís)

Baba oko odara oba ala w’ese oba ala w’ese

Baba fun mi l’aiye

16. Omo’dara bíy omo’dara bíy ile (bís)

Eledumare bíy

Omo’dara orisa oko


17. Igi w’era ebo baba ebo

Igi w’era ebo obatala t’ode

18. Burukan burukan

Baba burukan lehin

Baba burukan e iyawo

Baba burukan sen ken sen

Sen ken sen sen ken sen

Baba burukan sen ken sen

19. A inako inako baba r’ebo

Sar’ewa ile m’oyo

A inako baba epe gi

Sar’ewa ile m’oyo

AGUERE

20. T’awa un obi igbin je je

Orisa giyan s’ewa o

Jagun ajagunan

Erun obatala wa o

Olorun obe modupe


Olorun obatala wa o

21. Oro k’oro k’ode

Baba oge

22. Ewa kanse ewa kanse

Baba ipê ewa kanse ( baba)

23. O fururu ore re o

 Aila alá babá ken en Elejigbo

Ile ifon omo ti wá babá

Ejigbo re re omo ti gba o

Oluwaye

E ma ó e ma ó

Ala w’ese

E ma o l’ese kan baba (oju kan)

E ma o e ma o ala w’ese

24. Ilerio ilerio

E m’awo ile baba b’ere ki o

25. A indaro omo d’igbin o

Mojuba mi baba okunle

Baba gba k’ose wo

Mojuba mi baba okunle


IJESÁ

26. Alá un alá oro alá

A iku p’ara ada

27. Ala ‘la la e e e

Babá la we se

28. O d’wure        (bis)

 Ailalá

 E maman jô

 Osogiyan

 E maman jô

 Osogiyan

 E maman jô

 Osolufon

29. Baba oke

Epeja epeja l’odo

30. O fi ‘la la e o

 Le l’ewá

 Osalá la e o

 Lê l’ewá
31. A’wure a’wure Babá

32. Odure adagba kun f’ere eja

Awa sire adagba kun f’ere min

T’ogun a merin

Afofo m’ale

Baba f’aya f’aya

Ara aiye aro g’odo g’odo

Orisa iki kun baba omo tin saworo

Baba omo tin saworo

Baba omo tin saworo

33. A igi w’ere irunmole lario

Esu ebo r’ewo (OGUN, OSOSSI,...)

34. Oro Baba ni soro

Ero ni Babá koja de

NLÓ

(IJESÁ)

35. Babá mi a un ló

 Babá orisá sire lode

You might also like