You are on page 1of 3

HYMN 48 HYMN 63 HYMN 112

“Inu mi dun nigba ti won wi fun mi pe, “Oluwa gbo, Oluwa d’ariji- Dan 9:19 ‘Gba a gbo’-Job. 5:27
e je ka losi lle oluwa”-Ps. 122:1
1.“mf GB’ADURA wa, Oba aye, 1.mf JESU, mo wa sodo re,
1. f Bi mo ti yo lati gb’oro, ‘Gba t’a wole fun O, Je ki n le ma to O leyin,
Lenu awon ore, f Gbogbo wa n kigbe n’irele, Bi ‘ni mi gbogbo segbe,
di A mbebe fun anu
Pe, “Ni Sion ni k’a pe si, Ti ero mi gbogbo si pin.
Tiwa l’ebi, tire l’aanu,
K’a p’ojo mimo mo.” Mase le wa pada, Egbe: E yin logo, eyin Mimo,
Sugbon gbo’gbe wa n’ita Re, E f’ope fun Baba loke,
2. f Mo f’ona’ta at’ekun re, Ran adura wa lowo. Da wa si nu ‘jo Serafu,
lle t’a se loso, Ni ‘kehin gba okan wa la.
lle t’a ko fun Olorun,
2. p Ese awon baba wa po,
Lati fi anu han. 2. mf Keferi, Imale, e wa,
Tiwa ko si kere,
Onigbagbo, ma kalo,
Sugbon lati irandiran,
3. S’agbala ile ayo naa, K’a le d’ade ni ‘kehin.
Lo ti f’ore Re han,
Leya mimo si lo,
Nigba ewu, b’omi jija,
Omo Dafid wa lor’ite, Egbe: E yin logo ….
Yi ilu wa yi ka,
O n da ejo nibe.
Iwo la n wo ta si n ke pe,
3.mf A dupe lowo Olorun,
K’a ma r’riranwo Re.
4. O gbo iyin at’igbe wa, T’o fi jesu Kristi fun wa,
Bi ohun eru re, Lati ra araye pada,
3.p L’ohun kan gbogbo wa wole,
mpTi n ya elese sib’egbe, Lowo ese at’esu.
L’abe iyonu Re,
a n yo ni wariri.
A n gbawe fun ‘le wa,
F’oju anu nwo aini wa,
5. K’ibukun pelu ibe na,
Bi a ti n ke pe o,
Ayo nigbakugba,
Ma fi’dajo Re ba wa wi,
K’a fi ore ati oore,
Da wa si laanu Re.
F’awon ti n sin nibe.

Amin
6. Okan mi bebe fun sion,
Nigba ti emi wa,
f Nibe n’ibatan at’ore,
At’ Olugbala wa.

Amin
HYMN 481 HYMN 473 HYMN 421
‘A fi ipile re sole lori apata’ Matt. 7:25 “Bi eyin ko tile ri nisinsin yi, sugbon ‘Emi ti fe ofin Re’- Ps . 119:97
1. Igbagbo mi duro lori, eyin n gba a gbo.” – 1 Pet. 1:8
1. mf BIBELI mimo t’orun,
Eje atododo Jesu, 1. f AIGBAGBO, bila! Temi owo isurs t’emi!
di Nko je gbekele ohun I”Oluwa , ‘wo ti n wi ri bi mo ti ri,
kan, Oun o si dide fun igbala mi, ‘wo ti n so bi mo ti wa.
cr Leyin oruko n’la Jesu, Ki n sa ma gbadura, Oun o se
ranwo, 2. p’ Wo n o mi bi mo sin a,
ff Mo duro le Krist’ Apata Gba Krist’ wa lodo mi, ifoya cr’ Won fi ife oluwa han,
ile miran, Iyanrin ni. ko si. mf ‘Won I’o si n to ese mi,
‘Wo n lo n dare, at’ebi.
2. mf B’ ire-ije gun 2. B’ona mi ba su, Oun I’o sa n
Or’Ofe R ko yipada, to mi, 3. f’ Won n’ima t wa ninu,
B’o tiwu k’iji na le to, Ki n sa gboran sa, Oun o si Ninu wahala aye,
Idakoro mi ko ni ye, pese, cr’ Won n ko ni, nipa ‘gbagbo,
Bi iranlowo eda gbogbo saki, Pe, a le segun iku.
ff Moduro le Krist’ Apata Oro t’enu Re so y’o bori,
Ile mran, iyanrin ni. dandan. 4. ‘Wo l’o n so t’ayo ti mbo,
At’ iparun elese,
3. f Majemu ati eje Re, 3. Ife t’o n fi hank o je ki n ro pe, Bibeli mimo t’orun,
l’em’o ro b’ikun mi de, Y’ o fi mi sile niu wahala, Owon isura t’emi.
Gba ko s’alati lehin mo, Iranwo ti mo si n ri lojojumo,
f o je ireti nla fun mi, O n ki mi laye pe, emi o la ja. Amin

ff Moduro le Krist’ Apata 4. pEmi o se kun tori iponju,


Ile miran, iyanrin ni. tabi irora? O ti so tele!
Mo mo’ro Re p’awon ajogun
4. f ‘Gbat’pe kehin ba si dun, ‘gbala,
mp A! mba le wa ninu Jesu,
cr Ki now ododo Re nikan,
ki duro ni ‘waju ite,

ff Moduro le Krist’ Apata


Ile miran, iyanrin ni.

Amin
HYMN 851

‘Oluwa Olorun awon Omo-Ogun, gbo


adura mi’-Ps. 84:8

1. mf Ago RE wonni ti ni )
Ewa to, Oluwa, )
Okan mi fa si’le orun )
Tor’awon eyeorun ) 2ce
Won nile lor’igi )
Alanpadede won te ite o

cr Egbe: Sugbon ibukun ni


f’ awon Ijo Serafu,
aw anile, ile ayo , lodo Oluwa,
ibukun o, halleluya, ibukun
o,ibukun o, halleluya, ibukun
o.

2. mf Okan mi n fa nitoto sile


o )
s’agbala Oba mimo o )
n o ma lo lat’ipa de’pa )
titi o, )
N o fi gunle s’ebute Ogo )
cr Egbe: Sugbon ibukun ni …..
Etc

3. mf Ojo kan ninu agbala


Oluwa,
Osan ju egberun ojo lo ) 2ce
Ore- Ofe pelu ibukun je t’
Olorun,
Ibukun ni fun eni to sin.
cr Egbe: Sugbon ibukun ni …..
Etc

4. Mimo, Pipe I’ Obaluwaye )


Mimo o, )
Angeli e wa ka jumo sin o )
Eni ba sin” Erintunde titi
d’opin ) 2ce
Yoo gba ade iye )
I’ebute Ogo )
cr Egbe: Sugbon ibukun ni …..
Etc

You might also like