You are on page 1of 1

Nooti Ikeeko fún Kíláàsì Olodun Kini Sekondiri Kékeré fún Ose Karun

Kíláàsì: Olodun Kini Sekondiri Kékeré


Ìṣe: Yoruba
Orí Ọ̀rọ̀: Àmì Ohùn
Kókó Ọ̀rọ̀: Ami Ohun lori oro onisilebu meji
Déètì: 4th - 8th September, 2023.
Ìwé Itokasi:

Ìjíròrò:
i ba – ta(shoe) (dd) – kf – kf
ii E - we(leaf) (rd) – f – kf
iii A– ja(dog) (rm) – f – kf
iv Ba – ba (father)(dm) – kf – kf
v Ti – ti(a name of a person) (mm) – kf – kf

AMI OHUN LORI KONSONANTI ARAMUPE


Ninu ede Yoruba konsonati aramupe asesilebu ti a ni ni “N” konsonanti yii le jeyo ninu oro bi eyo silebu
kan nitori o le gba ami ohun lori. apeere,
i n lo –(mr) –k –kf
ii n sun – (md) – k-kf
iii o –ro –n –bo (drdm)-kf-k-kf
iv ba-n-te (ddm)-kf-k-kf
v ko-n-ko (ddd)-kf-k-kf abbl

IGBELEWON:
- Ko oro onisilebu marun-un ki o si fi ami ohun ti o ye si i
ISE SISE: ko oro oni konsonanti aranmupe marun-un pelu ami ohun to dangajia.

You might also like