You are on page 1of 2

ìô/îò/ÄîÄÅ

J&J! OLUBORI TI IFC {L{RUN NINU {KZN


ì K[rinti ìÅ:ì]Å
*f1 {l[run ninu [kzn aw[n onigbagb[ j1 olubori ju ixc]isin, ififun]ni, talcnti, [gb-n ati aw[n ohun t7 2k-
eniyan l4 gb3xe l[. (un ni 9 maa n n7 ipq t7 9 s8 n xzk9so ohun gbogbo ti w[n bq n xe. Lcyin igbala ati
wiwc onigbagb[ m-, {l[run maa n gbin ir5 8f1 at[runwq kan sinu [kzn wa t7 9 maa n wq nipa ixc]abc ti
oore][fc, k8 7 xe 8f1 ti eniyan, 8f1 fun 8xek56xe tabi 8f1 zw6j[. N7n7 8f1 t7 9 n tinu [kzn {l[run wq y87 l3r4 9
s8 xznfzn7 niwaju R2. Ip0 olubori r2 j1 ninu ohun gbogbo, ohun t7 z n fiyesi ninu aye wa k87 kzn]qn xe
k8k8 ipq t7 a n7, xugb[n ti ir5 8f1 ti {l[run t7 z n fihan. Lz8s7 8f1, asqn ni ix1]8s8n y09w6 t7 a le maa xe fun
Oluwa yoo j1.
ì. J&J! OLUBORI IF!: *F! TI {L{RUN NINU {KZN
ì K[rinti ìÅ:ì
“B7 mo til2 n f[ on7r5ur5 4d4 zti ti ang1l8, t7 4mi k0 s8 n7 8f1; 4mi dzb7 idc ti n d5n, tzb7 b7i k7nbql8
ol9h6n]goro”. ( jc 2k- p3 k87 xe k8k8 aw[n ara K[rinti nikan ni iwaasu Aposteli Paulu lori 8f1 naa n
dojuk[ k7 0 wa y[ ara r2 s1gb21 kan. Kzkz bcc, 9 s[r[ latinu agbeycwo ti ara]cni, b7 9 t7 n xzpccrc 8f1
{l[run ninu [kzn. A gb[d[ xzy2w0 [kzn wa k7 a s8 r7 i daju pe a fi 8f1 s7p0 olubor7 ninu aw[n 8xes7 ati
igbesi]aye wa.
<i> Gbigba *f1: *f1 ti {l[run ninu {kzn Funfun
ì Timotiu ì:æ; Ä Timotiu Ä:ÄÄ; ì Peteru ì:ÄÄ; Orin Dafidi ÄÉ:Å,É
*f1 t7 Oluwa n tcnum- maa n wq “lati [kzn m7m-”. If1 t7 a n fihan latinu [kzn mim[ wq k8 7 xe ifckuf21 t7
ara t7 aw[n eniyan ninu aye n xzfihzn r2 ati lori eyi t7 gbogbo 8bqni]k1d6n w[n dq l3 lori. A n7 lati “Mqa
sq f5n 8f1k5f21 4we; s8 mqa l3pa 0dodo, 8gbzgb-, 8f1, zlzqf7z, p2l5 zw[n t7 n k3 pe Ol5wa lqti in5 [kzn
funfun wq.”
K0 s7 8f1 lq8s7 8gb[ran. B7 a bq fcran {l[run, a 9 gb-rzn s7 otit[ t7 ( ti fi k- wa nipasc Kristi. Bakan naa ni
a 9 fcran aw[n arq l-nz t7 9 t- t7 9 s8 l3r4. Lati k5n fun ifc k7 a s8 maa fi ifc {l[run hzn, olukuluku n7 lati
n7 [kzn t7 9 m- gaara. K8k8 lcyin iriri igbala ati ti is[dimim[ pqtqpqtq nikan ni a fi l4 r7 i gbz, 4y7 t7 9 n77
xe pclu h7h5 2dq Adqm6 ati 2dq 8m[tara]cni]nikan ninu eniyan kuro.
<ii> J7j1 Olubori ti *f1 {l[run ninu {kzn t7 9 n7 $te
Deuteronomi ìî:ìÄ; Matiu ÄÄ:Åô]Éî
Oluwa m[ aw[n ixes7 wa nigba t7 8f1 ati 4te t7 n fi 0go fun {l[run bq n m5 wa xe 3. X7xe ohun gbogbo
pclu 8f1 at[runwq ninu [kzn n m5 wa n7 8m=lqra nipa ohun t7 “OLUWA {l[run rc n beere l[w[ rc” t7 a 9
s8 m0ye 8farahzn ati ohun t7 Jesu n f1. Aw[n t7 w[n bq n h6wz lq8s7 8f1 {l[run ti d1x2 nlq zk-k- nitori
w[n k0 gb[ran s7 “4k7nn7 ati 0fin nlq.” Zw[n 4r4 y09w6 t7 aw[n ixes7 wa l4 m5 wq, lq8 maa pa 0fin lati f1
Oluwa pclu gbogbo zyz, [kzn ati in5 m- n s[ aw[n 4r4 naa di alq8w5l0. “$kej8 s8 dzb7i r2, Iw[ f1
[m[nikej8 rc b7 ara rc”. Gbogbo ohun t7 a kz lati Gcncsisi titi d3 Malaki ni a t5m= l9r7 8p8l2 8f1 s7 {l[run
ati 8f1 s7 eniyan.
<iii> N7n7 )ye *f1: *f1 ti {l[run ninu {kzn t7 9 n7 Zlzqf7z
Kolose Å:ìÉ,ìæ; Filipi É:ô,ò
A gb[d[ “gb3 8f1 w=” l3k4 [gb-n, 8m=, ipq lati gb3 nnkan xe, ix1, aw[n xixeexe ati ohun gbogbo t7 a bq n
xe. Lati gb3 8f1 w= ni lati lati s[ 8f1 {l[run ninu [kzn wa di 4y7 t7 9 xe3 foj5r7. Zn7 gcgc b7 aw[n eniyan ti
maa n ri ax[ t7 z w=, w-n gb[d[ r7 8f1 ninu 8xes7, ibani]s=r=, 8f=r=]w3r=, ati ibaxep[ wa pclu w[n. Yzt= s7
8w=ny7, a gb[d[ “j1 k7 zlzqf7z {l[run k7 9 mqa xe zk9so [kzn <wa>”, nitori {l[run 8f1 k87 gb3 ninu [kzn
on7jz b7 k0 xe [kzn t7 a ti dqlqre nipa igbagb[, t7 9 ni alaafia pclu {l[run, alaafia ninu ara r2 ati alaafia
pclu aw[n clomiran. {kzn 8gb2san k8 7 xe ti Kristi. N7n7 [kzn pclu alaafia {l[run “t7 9 ju 8m= gbogbo l[”
ni 2r7 oore][fc kan ninu [kzn wa. Nigba t7 “zlzqf7z {l[run” bq wz pclu wa, zlzqf7z {l[run naa yoo maa
xzk9so ohun gbogbo ninu ay3 wa.
Ä. Z*JQM_ NKANKAN TI CBUN LAISI IFC NINU {KAN
ì K[rinti ìÅ:ì,Ä
Cbun n t[ka si aw[n cbun ti Cmi. Cbun ko jam[ ohunkohun niva ti ifc ko ba si ninu [kan. Xiwaju
v7va aw[n cbun ti Cmi, [p[l[p[ eniyan maa n jc onirclc, onifcc, cni ti n wa alaafia ati cni ti o r[r6n lati
bq v3. Xuv[n n7 k3t3 ti w[n ba ti va aw[n cbun w[nyi tqn, iveraga a ve w[n w= bi 2w6. Nipa bcc,
w[n a “dabi idc ti n dun, tabi bii kimbali olohun gooro”. Aw[n cbun w[nyi ko jam[ ohunkohun fun aw[n
ti w[n xi n fi aaye va ctaanu ninu [kan w[n. Nitori naa, lati ni il[siwaju ninu ive]aye ati ixc]iranxc awa
funra wa, ki a si va 4r4 l[d[ {l[run, ifc v[d[ jc olubori xiwaju ifisojuxe aw[n cbun ti cmi wa.
<i>. Ah-n laisi Ifc ti o m[ gaara
ì K[rinti ìÅ:ì; Jak[bu Å:ì,æ,Æ
“B7 mo til2 n f[ on7r5ur5 4d4 zti ti ang1l8, t7 4mi k0 s8 n7 8f1; 4mi dzb8 idc ti n d5n, tzb7 b7 i k7nbql8
ol9h6n]goro”. {p[l[p[ eniyan maa n fede f= xuv[n ko si ifc ti o m[ gaara ninu w[n si aw[n clomiran.
W[n maa n lzkzkz lati fi aw[n cbun w[n sojuxe pclu 8jz ati 8faga]vqga, xuv[n w[n ko le fi ifc {l[run
hzn. W[n maa n fi ah-n w[n ba aw[n clomiran jc, w[n si maa n lo o lati fi ba cbi w[n jc. Bi a o ba jc cni
ti o wulo ninu Ij[ba {l[run, a v[d[ fi aaye va oore][fc {l[run lati xe 8t6l9j5, is[d[tun ati lati mu ki
ah-n wa fi ifc ti o m[ gaara hzn.
<ii>. Ikede Alas[tclc laisi Ifc ti n Daabo boni
ì K[rinti ìÅ:Ä; Numeri ÄÉ:ìæ]ìò; Ifihan Ä:ìÉ; Matiu ô:Äì]ÄÅ
{l[run n fc ki a ni ifc ti o maa n daabo bo aw[n clomiran kuro ninu ewu. “B7 mo s8 n7 2b6n 8s[t1l1, ...t7
4mi k0 s8 n7 8f1; 4mi k0 j1 nnkan”. Pclu vovo cbun is[tclc w[n, aw[n eniyan kan ko le daabo bo ohun
rere, ive]aye, im[lara ati il[siwaju aw[n clomiran. Balaamu ni as[tclc nla xuv[n ko ni ifc Oluwa. O
va Balaki nim[ran lati mu ki aw[n [m[ Isracli xc si {l[run. Kristi ni aw[n [j[ R2, xe afihan iyalcnu R2
lori iru aw[n eniyan bcc ti w[n n bc laarin ij[ aw[n olododo ti w[n n k[ni, n7 ipq, ru aw[n clomiran
soke, ti w[n si n va clomiran nim[ran lati dcxc. W[n le jc cni ti o munadoko pclu cbun w[n, ki w[n ni
ipq ixakoso lori aw[n clomiran, bi w[n ko ba ni ifc ti n daabo bo aw[n clomiran lati ma dcxc, w[n yoo
xeve bii Balaamu.
<iii>. Ivav[ ti n xi Oke nidi laisi Ifc Oluwa
ì K[rinti ìÅ:Ä; Johanu ìÉ:ìæ,ÄÅ,ÄÉ
“B7 mo ...s8 n7 gbogbo 8gbzgb-, to b12 t7 mo le x7 zw[n 0k4 nlq n7p0, t7 4mi k0 s8 n7 8f1; 4mi k0 j1 nnkan”.
{p[ aw[n onivav[ ni w[n ni ivav[ ti n xi oke nidi xuv[n ti w[n ko ni ifc Oluwa. W[n n lzkzkz fun
iru ivav[ ti n xi oke nidi, ti n muni]larada, ti n le cmi exu jade, ti si n dani nide, dipo ti w[n i ba fi ni
afojusun sii lori bi ifc Kristi i ba ti maa j[ba ninu [kan w[n. Iru cbun bcc laisi ifc ko jam[ ohunkohun
niwaju {l[run. Ohun yowu ti ayidayida wa l4 j1, a v[d[ k[ bi a ti n “pa [r[ <Kristi> m[”, gcgc bi cri ifc
wa fun Un. Bi a ba n jcw[ pe a m[ {n, a v[d[ fi ifc wa han fun Un niva naa nipa sisin In.
Å. B&B{LQ FUN DIDABII KRISTI PCLU IFC NINU {KAN WA
ì K[rinti ìÅ:Å
L7law- ati jijc onitara fun 2s8n laisi ifc “ko ni 4r4 kan...”. A v[d[ maa pounvc lati dabii Kristi niva
vovo. Kristi ati aw[n [m[ Ij[ ak[k[ xe ohun vovo ninu ifc. Sibcsibc, k0 t9 lati maa xe awok[xe 8xe
aw[n clomiran; a v[d[ k[ bi a ti n fi ifc hzn. Ki i xe ti 8xe bi ko xe cdun][kan ti o wa lcyin r2 ni o xe
pataki. Bi a ba dabii Kristi, ohunkohun ti a ba n xe ninu aye ati ninu ixc]iranxc yoo maa jc f7fi ifc hzn.
<i>. Aito *fif5nni pclu Ifara]cni]rub[ laisi Oore][fc ti n Gbani la
Ä Aw[n {ba ìî:ìÆ,Åì; Matiu æ:Äî
Ififunni pclu ifara]cni]rub[ laisi oore][fc ti n vani la ti 9 yc k0 t9. Bi o tilc jc pe Jehu jc onitara, ti o si fi
opin si s7sin Baali ni ilc naa, oun “k0 xe ak7y4s7 lqti mqa fi vovo [kzn r2 r8n n7n5 0fin OLUWA {l-run
Isracli”. Gcgc bii tirc, [p[l[p[ maa n jalankato pe aw[n ni ero rere sibc w[n n xe irek[ja <dcxc>. Niva ti
ifc ba wa ninu ete aw[n ixe wa nikan ni a to le va ojurere ati iboriyin ti [run.
<ii>. Ewu S7sun ara wa fun @s8n laisi Ibi Tuntun nipasc Irapada
Johanu Å:Å,æ

{p[l[p[ aw[n eniyan ni w[n dara ninu r7ran eniyan l[w[ ati lati ba w[n yanju ixoro w[n, ti o s8 k9 aye
w[n sinu ewu ninu xixe bcc. O bani]ninu jc pe w[n ko i tii ni iriri ibi tuntun nipasc irapada. O xeexe ki
w[n kun fun ojuxe xuv[n ifc {l[run ko si ninu [kan w[n. Iru aw[n eniyan bcc “ko le w[ ij[ba {l[run”
bcc ni ixc]8s8n w[n yoo si jasi asqn.
<iii>. Koxee]mani Jijc Oloore][fc At[kan]wa pclu Aw[n Cbun ti Cmi
ì K[rinti ìÅ:Å; ì Peteru É:ìî,ìì; Efesu É:ô,ìì]ìÅ; ì K[rinti ìÆ:ìÅ,ìÉ
Jijc oloore][fc t[kant[kan pclu xixe afihan aw[n cbun ti cmi jc koxee]mani. Xiwaju fifi aw[n cbun wa
hzn, a v[d[ jc oloore][fc, oloot[, ki a si pa ibaxep[ ti o dqn]m-rqn m- pclu aw[n clomiran. Iru jijc
oloore][fc bcc v[d[ tzn de [d[ aw[n [m[, alailera, cni ilcclc ati aw[n ti a n tc m[lc, ki o si maa jc jade
ninu 4d4, 8r7s7 ati ixe wa. O ko v[d[ maa k6]g8r8 lati xe afihan cbun rc ninu ij[ bi ive]aye rc ko ba ni
oore][fc, ifc, irclc ati didabii Kristi. Niva ti ifc ba farahan ninu jijc oloore][fc ati ijoloot[ wa si aw[n
clomiran, niva naa nikan ni a to le xe afihan aw[n cbun ti Oluwa ti fi fun wa. Niva naa nikan ni a to le
ni il[siwaju ninu aye wa, ti a o si ni ireti ti o duro v[in]in fun [run]rere.

Aw[n Orin Ajum[k[: ìÄÅ, ììì ati Äîì

You might also like