You are on page 1of 2

Awon nkan to wa ni ayika. Things in your surroundings.

Awon nkan to wa ni ayika naa ni awon ohun ti a maa n ri ni ayika wa. Ayika ni a n
pe ni surroundings ni ede geesi.

Niyiii ni awon nkan to w ani ayika wa pelu oruko ti won je ni ede Yoruba ati ede
gessi.
Ede Yoruba Ede geesi

boolu Ball

Moto/oko ayokele Car

Aga Chair
Tabili Table

Ero amohunmuaworan/telifisonu telvision

Keke Bicycle

You might also like