You are on page 1of 6

GBÀDÚRÀ TI OBÀLUWÀIYÉ

(JUNTOS)

BÍ A SÁPADÀ, BÍ A SÁPADÀ.
DÀGÒLÓÒNÒN É, Ó Ó ONÍ YÈ.
E NJÍ ÈDÁ
MO DÁRA ÀGÒLÓÒNÒN É.

ADURÁ OBÀLÚWÀIYÉ

ORISA JINGBINNI
ORISA TII MU OMO ATI IYA
BI O BA MU NWON TAN
O TUN LE PADA WA MU BABA
ORISA BI AJE
O MO ILE OSO, O MO ILE AJE.
O GBA OSO LOJU
OSO KU FINRINFINRIN
O SO AJE LERUKALE
ORISA JINGBINNI
A MOMO OHUN
O POMO-OLOMO KU FINRINFINRIN
O FOJU OMO OLOMO GBEDORO
JOWO MA SE MI

ORÌSÀ JÌNGBÌNÌ ABÀTÀ,


ARÚ BÍ EWÈ AJÓ ORISÁ TÍ NMÚ OMO MÚ ÌYÁ BÍ
OBALUAYÊ BÁ MÚ WON TÚN O TÚN LÈ SÁRÉ LO BÁBÁ
ORÌSÀ BÍ ÀJÉ OBALUAYÊ MO ILÉ OSÓ,
Ó MO ILÉ ÀJÉ O GBÁ OSÓ L’ÓJÚ,
OSÓ KÚN FÍNRÍNFÍNRÍN O PA ÀJÉ KU ÌKAN SOSO
ORÌSÀ JÌNGBÌNÌ OBALUAYÊ
A MÚ NI TOÙN TOÙN
OBALUAYÊ SSÍ ODÙ RE HÀN MÍ KÍ NDI OLÓWÓ
KÍ NDI OLOMO
ORIKI SOPONA
ENIKENI AWA PE LI AGBA
BABANIJE ALAJOGUN IYALAYEWU AJOGUN APAKE
AWA KO FO ENI KI OMÓ PA ENI JE
ROJU NLO NI ELE MIRAN
IRAWE OJU OMI WELE NI SE WELE
OKOYIKO O GBA ODE ELERAN KI MO UM ERAN
ARIKO OJE KI NRO KO
AGEGE IDE KI KO OPE
AWON TI OBU OKO ENI LI ONA OKO
AWA RU OKU E DE BOLI
IPO KOSI ENU KO SUN
SAKA SIKI GBA OJU ONA
ONI WOWO WDO
GBA OMÓ LI OGUN DANU

ORIKI OBALUWAYE

ILE MO PE O
OBALUWAYE
OBALUWAYE ODUN RE NI AWA SE
MA JE KI A RI IKU
MA JE KI A RI ARUN
AGAN TI KO RI EJA RE O
MA JE KI A RI IGBONA
JE KI A LEKE
OBALUWAYE A JE IGBA OGUN MA KU
OTA ILE, OTA ODE
OSO ILE ATI AJE ILE
OTA OKUNRIN, OTA OBINRIN
OTA OMODE, OTA AGBA
OBALUWAYE BA WA PA GBOGBO WON RU PATAPATA
FARI ORO, ONI WOWO ADO
ORUMO LOGUN DANU
OBALUWAYE SANU IYAWO
O PA OKO RE TAN
O FI ORI RE JO OGUN
SANU FUN GBOGBO WA O
GBOGBO ENI BA NPE ORI WA NI IBI
OFO LOMI, EFO NSE
OFO NI KI GBOGBO WON O SE KALE AYE WON
ORISA JINGBINI
ABATA, ARU BI EWE AJO
ORISA TI NMU OMO UM IYA,
BI OBALUWAYE BA UM WON TAN,
O TUN LE SARE LO UM BABA,
ORISA BI AJE
OBALUWAYE MO ILE OSO, O MO ILE AJE
O GBA OSO L’OJU,
OSO KUN FINRINFINRIN
O PA AJE KU IKAN SOSO
ORISA JINGBINI
OBALUWAYE A UM NI TOUN TOUN
OBALUWAYE SI ODU RE HAN MI
KI NDI OLOWO
KI NDI OLOMO
OMO EBEDU
EDU ILARA
OMO ALASE OJU OMI
OMO AFEPE WE
OMO AFIJA BA WON DA BUDO
OMO ARORO KO WON LOJU OGUN
ELEGBEE BORISA BOGIBOGI
BABA OKE
BABA KIJIPA ASO TI BEMII DIJE
OMO AGORI ODO JIYAN
A FAYA GBOMO PON KADUN TORI IKU NI
ORUN IRE OO
ADURA OBALUWAYE

ERU MOWO
OLORI OLOOLO
KINIUN ARA IGBO INA-ESA
ERU TI NBA ERU NINU JE
ARUWE KO SE OGUN AGBEDE TOUN PELU EYO
TAPA MAA FI OGO OWO TONU
MAA FI EJI OKO TELE NI MOBA
OGAA ARA KATA KA NI OWO
OGAAA ARA ILU OSINGIN
IDE LO NFE MI NILE BI KO SI ENI
ADIGO JA
OHUN MO BA WA O JU TI ORI ENI LO
OGARA WON KI JE IRU
OGARA WON KI JE OGIRI
KO GBODO JE YANRIN
NITORI YANRIN NI IYA EEGUN
OMO ENI JE OGUMO ATI ODO
BI ONI KOLE NI-WARIN
ASE ABE ROKOSO BI OJO YO
OGA TI NMI MAA MI SOKE BI EKURO
ABIDAYO BABA MI OMO AGBALAJA BI ESAN
OGARA OMO ONILE REFUREFU
OGARA OMO ONILE REFUREFU
NIBI TI A RI EYE TI A KO RI OKO FI PA EYE

OFO - ADURA PARA ASSENTAMENTO DE OBALUWAYE

OBALUWAYE
ERU MO IYI OWO
BABA AWON ALABE
EKUN INU IGBO
ERU TI NPA ERU LEKUN
ATUWE O SE OGUN EYO
TAPA, MA MOWO RA OUN GBOGBO
ONILE OWO
OLONA OLA
ONILE IYI
MO GBE E JOKO BABA
MO NI O KI NJE IRU
BENI O KI NJE OGIRI
GBUGBURU NI OUN BABA
GUDUGUDU NI ILU RE
BABA A JI JE PETEKI TOUN ODO
BI A BA WURE
WA GBO IWURE WA
OBALUWAYE TENREN BI EKURO
OBA NINU IGBO,
NIBI TI A RI ERAN
TI A KO RI OUN FI PA
OBALUWAYE IBA
SOPONA IBA
ENYIN ELEYE TI E NI AYE
TOUN ILE, IBA
OSANYIN, KI O JE EWE, O JE
OSANYIN, KI O JE ORISA, O JE O

You might also like