Professional Documents
Culture Documents
Arrangement: 11
Recap:
Ni ede Yoruba, “ARA” ni a n pe ni “BODY” ni ede geesi. Orisirisi eya ara si ni o wa
ti won si ni ise otooto ti won se. this means “ BODY” is called “ARA” in Yoruba
language. And there are different parts of the body.
So, before, we proceed, can you sing this rhyme with me?
HEAD - ORI
TONGUE - AWON
EYE - OJU
EAR – ETI
MOUTH – ENU
HAND – OWO
NOSE – IMU
NECK – ORUN
LEG – ESE
ISE SISE:
Ko eya ara marun-un to o w ani ori.(write five parts on the head).
Chapter Summary:
Ni bayii, ati wa fi opin si eko tonii. This means, we have come to the end of
todays lesson. Lonii, a ko nipa awon eya ara. E ma gbagbe pe orisirisi eya ni o wa
ni ara wa ti won si ni ise otooto ti won se. Today, we learnt about parts of the
body. Do not forget that there are different parts of the body that perform
different functions. Ki a tun ma pade ninu eko to n bo, odaboo.