Professional Documents
Culture Documents
Arrangement: 13
Recap:
kinni a n pe ni Eso? What is Eso?
The word Eso is called Fruit in English language. Eso ni a n pe ni Fruit ni ede
geesi.
Orisirisi awon eso ni a maa n ri ni agbegbe wa.
E je ki a ko nipa orisirisi eso ile. Let’s learn about the different types of Eso.
Bi a se ni oruko fun eso ni ede geesi, naa ni a ni oruko ti a n pe won ni ede Yoruba
bakan-naa. What this means is that as we have names for the domestic animals
in English language, so do we have names for them in Yoruba language likewise.
ESO FRUIT
ibepe pawpaw
Ogede Banana
Eso pia pear
iyeye plum
Awon eso yii a ma se ara ni ore pupo pupo. A maa mu ara dan pelu.
ISE SISE:
Daruko orisi eso marun’un.
Kinni awon oro wonyi ni ede Yoruba? (what are the following words in
Yoruba?)
orange
peach
apple