Professional Documents
Culture Documents
Odù Ògùndá
ÒGÚNDÁ 1
Ogunda mon sa
Ijarain mo sojo
Ijarain ni se obinrin ogun
A difa fun opolo oun ikonko ogun
Lojo ti awon mejeeji n lo gbori omo lodo
Ebo lawo ni ki won o se
Won si gbebo nibe won rubo
Won gberu won tu
Nje ki ni n be lodo tii gbori omo
Opolo o oun ikonko nii n be lodo tii n gbori omo
Compilation made by Ibuowo Sangodiran Adebayo
Ile Ase Olukoso Temple (+234 810 763 4033)
Translation:
Ogunda mon sa
Ijarain mo sojo
Ijarain ni se obinrin ogun
Divine for rtoad and frog
When they want to rescue the children in river
The priests ask them to do ebo
Both of them comply
What are in river that rescue the children
Its toad and frog that live in river to rescue the children
Ẹbọ: Egberun meta lona meta, eyele meta, akuko meta, epo, omi tutu,
ito (saliva).
ÒGÚNDÁ 2
Translation:
Edun nii gori igi kere kere
Ekun nii pa silo silo wogbe
Cast for Owakawaka
The father of crocodile who own the big river
When they want to collect it from him
The priest ask him to do ebo and he comply
Do who wants to collect the deep river from crocodile?
Owakawaka the father of crocodile is the owner of of the river
Who wants to collect the river from crocodile?
Ẹbọ: egberun meta lona meta, oruko kan, akuko kan, eyele kan, egbebo
kan, igba eru kan, epo pupa, omi tutu. Offer ekuru and white pigeons to
olokun and dog and gin to Ogun.
ÒGÚNDÁ 3
Agongo sígolo
Agòngò sígòlò
A difa fun ogunda
ti o tẹ́yìndé, ti o borí ogbè mọlẹ̀
nje ìgbà ògúndá tẹ́yìn dé o ló borí ogbè mọlẹ̀
Orí rere níí tìrère
Compilation made by Ibuowo Sangodiran Adebayo
Ile Ase Olukoso Temple (+234 810 763 4033)
Translation:
Agongo sigolo
Agongo sigolo
Cast for Ogunda that came last and became the senior for ogbe
So when ogunda came last and overcome ogbe
The good fortune is for irere (turtle)
Ẹbọ: Ireke, aadun, egberun metala, abodie, eyele kan, akuko kan,
eeru igi ako, oyin (honey).
ÒGÚNDÁ 4
Translation:
Ogbologbo aparun abidi sakasiki
Cast for head of chief in farm
They ask him to do sacrifice and he comply
Compilation made by Ibuowo Sangodiran Adebayo
Ile Ase Olukoso Temple (+234 810 763 4033)
Ẹbọ: Three pigeon, three cocks, three thousand times three, omi
tutu, epo pupa.
ÒGÚNDÁ 5
Translation:
Opa eluju abidi ranje ranje
Divide for mokanjuola
Who is the son of elerinsaje
Ehn he cries for sufferness
Compilation made by Ibuowo Sangodiran Adebayo
Ile Ase Olukoso Temple (+234 810 763 4033)
Ẹbọ: A lot of maze, 33000 naira, three cocks, three hens, a pigeon,
water and palm oil. That person must offer to ogun by asking what ogun
wants.
ÒGÚNDÁ 6
Abẹ́mọlẹ̀ eèkàn abojú règun règun
Adifa fun oòrì
Òòrì n sunkun omo rode ipo
Ó n sunkun omo rode ọfà
Ebo lawo ni ko se
O si gbebo o rubo
O gberu o tu
Wọ́n ní koori ó rógún, oori rogun
Wọ́n ní kóòrì ó rọ́gbọ̀ n, oori rogbon
Ẹ̀yin ò mọ̀ pógún ọmọ ò tó oòrì
Translation:
Abemole eekan aboju regun regun
Divine for oori when she cry for children
The priest asked her to do the sacrifice
Compilation made by Ibuowo Sangodiran Adebayo
Ile Ase Olukoso Temple (+234 810 763 4033)
Ẹbọ: Eku, eja, egberun meta lona meta, agbebo adie meta, oyin.
This person need to offer koori with food and gin.
ÒGÚNDÁ 7
Translation:
Aparun singin the priest of olomo
Cast for olomo that he seat and eat thirty baskets of colanut and be
wealth
They told him to do the sacrifice and he comply
Later he became famous and popular
Ẹbọ: Three hens, Naira 33000, pigeon, epo pupa, cold water and
beads. For the person to have children.
Compilation made by Ibuowo Sangodiran Adebayo
Ile Ase Olukoso Temple (+234 810 763 4033)
ÒGÚNDÁ 8
Translation:
Otu kuku yi biri
Cast for Ogun
That was going do Regbomejeesegi
They told him to do ebo for victory
After he did it, he had victory
Ẹbọ: Epo isu, ewe odan, ewe eeran, Naira 30000, epo pupa, omi tutu,
ewa, isu sisun. Offer a dog to Ogun.
ÒGÚNDÁ 9
Oju o kan mi
Emi o kanju
A difa fun eera
Compilation made by Ibuowo Sangodiran Adebayo
Ile Ase Olukoso Temple (+234 810 763 4033)
Translation:
Oju o kan mi
Emi o kanju
Cast for ant who is bossom friend of land
The priest ask him to do the sacrifice and he comply
He was victory all his enemies
ÒGÚNDÁ 10
Igbo rere ni mo wa
Ni mogbo ohun odo
Oke rere ni mo wa
Ni mo gbo ohun ẹdun
Omo odo loje omu o yo tan o n mi silasila
A difa fun Orisanku
Eyi to somokunrin Ogun
Compilation made by Ibuowo Sangodiran Adebayo
Ile Ase Olukoso Temple (+234 810 763 4033)
Translation:
Igbo rere ni mo wa
Ni mogbo ohun odo
Oke rere ni mo wa
Ni mo gbo ohun ẹdun
Omo odo loje omu o yo tan o n mi silasila
Cast for Orisanku
Who is son of Ogun
Divine for ori ilemere
The son of ija
Cast for afuwape who is the last born of all of them
When they are coming from heaven to this earth
The priest asked them to do sacrifice
Only afuwape comply
When they arrive to the earth
Orisanku die untimely
Ori ilemere die untimely
Only afuwape is living comfortably live.
Ẹbọ: Ewe eeran you, ebe isu, opolopo owo, akuko meji, agbebo
adie meji, iloko amo meji, aso funfun to po.