You are on page 1of 5

[13:07, 7/17/2018] Abese Awo: IWE SIGIDI ALARA

[13:07, 7/17/2018] Abese Awo: 1 SIGIDI AKOKO TI EUN WO AWORAN RE YI NI AUN PE NI


SIGIDI IROKO ABIJA WARA WARA
Sise sigidi eo lowa igi iroko kan won ma bayin gbe ni ere eyi keyi too baje wipe ere okunrin ni
wongbe eo Mon peni baba eo fun ni oruko kan too baje wipe ere obinrin ni wongbe iya ni eo
monpe eo lo bamin si idi alade Igbo waale eo bamin gun kun noo daada pelu awon ewe yi ewe ino
mejeji ewe esisi mejeji ewe oloyin pelu ewe sawere pepe abamoda ewe ogbo

Leyin tia gun kun noo daada ao po Mon yepe yen ao pa odidi erankan ao gba ejere oun lao fise
omin tao fipo ao Mon oun ni ijoko fun SIGIDI IROKO YEN ao wa gbe sigidi yi le lori yio joko
daada

Leyin too ba gbe ao mun awo eronja yi bakon noo ao gbo lomin

Ewe ino mejeji ewe oloyin ewe airagba ewe esisi mejeji pelu ewe imun ewe ogbo ao fi Mon gbo
SIGIDI YI Lara bi igba taun we ao Mon je ki omin yen kio Mon gbe mon ijoko yen laara titi tao fi
setan tia ba ti setan baun leyin ojo keta ao pa akuko adie fun

Ao Mon fi epo pupa bo pelu iyo ati akuko adie fun isure
Tia ba fe ranse ao Mon fi ekuru dudu boo pelu adi eyan ao karabsun kio Loja ao wawa awon ako
ewe mererin ao gun Mon iru ao fifi turare nidire pe eniyen lo dano Mon laara kin se awooo
[13:07, 7/17/2018] Abese Awo: 2 ESU AJAKALE
[13:08, 7/17/2018] Abese Awo: Esu ti eun wo aworan re yi laun peni AJAKALE esuyi daa ta baun
bo OSI maun mun unkan wa daada akin ranse aburu amaun ran ni daada bi kia ni ko boni laaairi

Sise esuyi ao lowa awon ako okuta towa ninu odo tounsan ao kowon sinu ikoko unla kan ao lowa
ewe esisi ati ewe abamoda lopolopo ao gunwon papo daada ao kowon sori okuta yi ao lora eyele
akala toje ejigbele ao pa eyele yi ao ro ejere le Lori ao da obi abata alawe merin meta le Lori
orogbo meta atare odidi meta oun lao kole Lori ao wa da ino sinu aro kaale ao gbe unkan yi le ino
noo ao bu omin ojo tio konle le Lori yio GBA OJO mesan ni ori ino leyin OJO kesan kia to GBE
wole ao bere si ao Mon iru unkan tio gba letutu too ba tiso ao se etutu noo ao GBE lo si orita meta
pelu esuyi too bati di ni idaji kutu hai ao logbe esiyi wole pada awo tia fi gbe ipese no ao GBE
wole pada oun lao Mon fitan fitila tia ba tife ranse aje

Tia ba fe se inowo tia sife kio bowa lasiri ao Mon fitan inore ao fi #1000 tele abono pelu ase oloun
yio je iseno funwa daada ao si ri anu GBA

Bibo esuyi ao Mon fun NI omin iyo epo pupa pelu EYELE akala awon unkan ta fiun boo nuu

Akiyesi
Ema ranse aburu ooo esi Mon je ki eni to loyun de idi oosa yiooo

Tori oolewu otete maun gbeyan nioooo


[13:08, 7/17/2018] Abese Awo: 3 ESU LAALU ABILU
[13:08, 7/17/2018] Abese Awo: Sise esuyi ebaun wa yongi inu omin ti omiun GBA orire koja
daada

EWA bamin wa awon ewe wonyi

Ewe inoo mejeji ewe esisi mejeji ewe labelabe ewe oloyin ewe akere jupon ewe airagba omin. Iwe
oku awon unkan yi leo bamin wa

BEO SE SE

Ao gun awon ewe yi papo daada ao wa pomon omin iwe oku yi ao fi fo okuta yangi yi daada ao
tun fi oti gboo ao tun fiwe

Leyin eyi ao ko gbogbo sakitire sinu koko kan abi inu ile logangan ibi tia fe gbesi ao gbe okuta no
le loori ebamin wa arorin kan si idire

Tia ba fe danwo ebamin fi eran le ori esuyi kie wa fi aja kaale kio lo gbe eran noo unkan tio ba
sele si ajano Leo fimon gboya odaju daada

BIBO ESUYI eo Mon fun ni abo adie dudu pelu iyo epo pupa

Akiyesi

Ti ebaun we lowo eo mon ki ni mesan mewa loruko ti ounje niooo teo fi setan
[13:08, 7/17/2018] Abese Awo: 4 SIGIDI OLUGBOUN
[13:08, 7/17/2018] Abese Awo: Ebamin wa opolo mefa 6 konko 6 akeke 6 ori oka ori ere eyin
ororo iyepe ile alakan iyepe idi ODO iyepe konga tiwon ko jade eo gun gbogbo awon unkan yi
poo Mon gbogbo eronjayi ewe ino ewe esisi ewe oloyin pelu egbo igi osusun ewe osunsun oti lao
fise omin re ao fi Mon sigidi ale fun loju ale fun lenu ara too ba wuwa lale fi sigidi no daa kia sa ti
mon NI eni tio bawa mon sigidi yi gbodo je arugbo tio bimon mon raara nio bawa booo
Amara yaa lao fipo lai fi omin kan laara

Ao fi eyin ororo kan le loori tia ba tife suure ao mun eyin ororo yi kuro ao sure nibe leyin eyi ao
fun loti

Ipiun

Ao ba olugboun nooo piun pe afe kio mon gboro tia ba yoo eyin orire ki gbogbo oro tia ba solo
lasiko nooo kio mon se tia ba wa da eyin yii paada si orire kio mon gbo oro eni kankan mo.

Ofore

Kankan*3 wara wara lomode ti OKO esisi boo ile kogba ode kogba loun se ewe airagba ojo ti
omode bawo Igbo oloyin ipon oun eeje Lounbo gbogbo iwure emin lagbaja OMO lagbaja ti mo
wuu loni kio bere sini see tori ase oka awon iyamin aje loni ase eere awon iyamin aje loni wonwa
pa gbogbo re poo wonko senu emin lagbaja OMO lagbaja loni won ni gbogbo oun ti mobasooo
lonni ase tigun

Olugbohun ooo ! Olugbohun oooo !! Olugbohun ooooooo !!! Wa gboun enu min saseoooo tori
bagbe bake nigbo ire olugboun maun gbanioo baluko bake lodan ire olugboun maungba niooo oya
wa Tara sasa kio gboun enumin saseoooo

Ao wa seri oti si Lara otan emase aburu pelueoooo


[13:08, 7/17/2018] Abese Awo: 5 ESU EBITA ALATUPA
[13:08, 7/17/2018] Abese Awo: Ebamin wa iyepe ogan eletutu iyepe ibi ti ewure ba bimon si iyepe
ibi ti aguntan ba bimon si iyepe ile Alaskan iyepe orita meta aagokan oru lao bu iyepe orita yi

SISERE
aopo awon yepe yi papo ao wa lo saa okuta emere 201 lao da sinu yepe yi ao wa gbo ewe labelabe
pelu omudun ewe igba awon ewe yi lao pomon eronja wonyi ao fi omin tiwo fi we oku po ao wa
mon ki leyin eyi ao mun owo ero 16 ao to mon laara ao wa logbe si orita metameta fun OJO meta
meta yio wa je ojo mesan leyin ojo kesan yi ao gbe wole ao wa fitila oloju kan ao mon fi tan Inore
pelu adua
[13:08, 7/17/2018] Abese Awo: Riran si oota kia kia Lori unkan tia ba fe kio se fun ota niooo yio
se kiakia
[13:08, 7/17/2018] Abese Awo: Eo mis epo mon adi dudu Leo fi mon tan inore adi Leo fimo booo
tie ba feran si oota pelu ekuru dudu ni eo fimon bo

Eo wa karan sunoo pe lagbaja loni kin gbe ino ruooo moni yio joo oni ise kilounse moni omaun se
ise waala fun idamun ai rino airilo aibegbepe oni iro ni oni olese mowa fe kio lo jewo arare fun
lagbaja OMO lagbaja kio fi asiri bio Tito han lati wakati yi looo unkan tie fe kio sele si enino EBA
piun
[13:08, 7/17/2018] Abese Awo: 7 ESU AWODE AGBODE
[13:08, 7/17/2018] Abese Awo: ESU AWODE AGBODE

ESU ELEYI AMOUN FI SURE NIOO BE AMOUN FIUN TORO OORE TI UNKAN BADA
DIE

SISE ESU AWODE

AO lo toju igba ipese ti won fi diru egbe tiwon gbe si ori akitan ao lo tojue ao lo bu iyepe ooja
tokun daasa iyepe ori akitan toun gba ile daada omin isa ewe ejinrin ako ewe mererin ewe rere
mejeji awon unkan yi lao gunpo pelu amon funfun eje monlu eje abo ewure dudu lao fipo unkan yi
ao to owo eyo yika gbogbo arare ao fi unkankan yika gbogbo arare

Bi ao se mon ao mon bi alade Igbo amon aketere koni tobi kotopo ni akete re yio ri yio ni iho
ninu tao gbe olugboun re booo nibi akete nooo leyin tia ti pari mimon re ao je kio GBE die ao wa
lo gbe bo ile ni orita meta toun gba ebo daada ao fi esu yi bole nibe ao mon gbe eyi keyi ipese lo si
idire logangan ibi tia gbebo ao se bee fun 21days leyin eyi ao lowa irun ori asun mon dide ao lo
pelu egbo akere jupon yio kun noo ao wa fi omin tangiri po lose ao ko sinu Iwo etu ao fi sinu iho
too wa laara esuyi ao de pada ao mon sure nidie fun oni baara wa pelu

04 yi

Boku Baku tekun keje niwon fiun dawo oku okan soso tangiri igba awo loun wu ojo akere jupon
ba tale ojono loun kan ilepa eyin isiku orun oya gboun enumin sase
Ao mon toro unkan nibe

Bibo sigidi yi ao mon fun ni epo pupa nikan soo pelu asua
Ao mon fun ni eje ewure kekan laarin osukan abi metaoo ireooo
[13:08, 7/17/2018] Abese Awo: 8 ALARA GBAIDA IRANSE IKU
[13:10, 7/17/2018] Abese Awo: Humm Moro gbogbo Iwo tio ba fe se sigidiyi dakun kio to ran
nise ranti OMO eni ti Iwo hunse

Ebamin tooju awon eronja yi eo lo bamin wu ile ika eyi tie ba tiba OBA kan pelu oun Leo bu
yepere wale pelu oba ikan yepe alade Igbo yepe oja ilu meje tokun daada yepe idi igi taara sanpa
aso oluwo awon yepeyi Leo baa min gunpo mon ako ewe mererin eo bamin mon aso ooluwo yi eo
bamin Jo pelu ako ewe mererin pelu okan aja okan oloungbo okan alaungba awon okan tie joyi ao
pelu aso oluwo yi ao fi ewe apada kun ao wa gbe si igba aya aigidi yi ao ni de lenu raara bi ao se
GBE sinu aya sigidi no niyen ao lo bo mon ori akitan fun ojo meta kio tope ojo meta eo lowa
awon tiwo maun gbe ilu won ma bayin fi igi iroko gbe ilu kekere kan bi gangan leyin ojo keta eo
tise ase kaale daada eo pe awon eyan eo mun akuko adie meji dani tie ba tide ori akitan yen eo pa
akuko adie kan won yio mon lu ilu lodoro eo fi eje akuko yen ra owo mejeji eo wa wu sigidi yen
leyin eeyi eo mon GBE loo ile kie to GBE de enu ONA adugbo yin won ma pa akuko kan yio Ku
eo te ejere monle kie to GBE woole
[13:10, 7/17/2018] Abese Awo: Eo tun lo bee kunmon akoko oun Leo munle lowo fun jija leyin
eyi lobata

Riran nise ao kigbe ibosiooo lagbaja OMO lagbaja loni kin gbeo waooo oni ibi too wayi kinse
aiyere oni inu orun ni kin gbeo si oni Ibe laiye re ao mun foto enino lewo ao wa gbe sinu orun ao
fi ori le loori ki ori no bafiyo loori sigidi yi kosi unkan meji teo gbo leyinre iku niooo kosi bi enino
sele ni agbara too kai yio dagbere fun aiye komon ereooo

Leyin too bajise tan eo lu iluno eo tun fun NI eje akuko adie kie to tungbe woole
[13:10, 7/17/2018] Abese Awo: Lai sebe yio mon da ile lamun niooo koda ole seku paniooo
[13:10, 7/17/2018] Abese Awo: 9 SIGIDI TAFIUN RAN NI LAAJO TABI YONI KURO
LAARIN EGBE
[13:10, 7/17/2018] Abese Awo: Elo bamin mun awon eronja yiii

Iyepe kanga too tigbe tio si omin ninu remon Iyepe oodo toti gbe iyepe ile alakan ti alakan re tiku
iyepe ile alapa oun lao gun mon awon ako ewe mererin ao fi adopo oun lao fise omin ree leyin eyi
lao mon nisigidi bia timon yen elo wa alagemon meta oje iroko oje oro agogo oje oro adete ao
pomon eje alagemon meta ao da le osa yi loori ao tun wa mun alagemon yooku ao ko si labe

Leyin eyi ao GBE lonu Agbo ogede Ibe ni yio mongbe kin bani gbe inu ile oooo tori OJO jumon
inu ilenoo koni tooro

Tia ba feranse siyan ao mon karan sun ao wa mon da ino mon laara titi pelu oruko eninoo pe oun
loni kia mon se oooo kio yira pada kio di enino gbogbo inira ti orisa no yio monri enino NI kio
mon rii

Ikiloo gbogbo awa tia ba sa ifayi agbudo mon se etutu daada lorire kio mon ba han awa noo
leumon
[13:10, 7/17/2018] Abese Awo: 10 SIGIDI IROKO TA MAUN RANSE
[13:10, 7/17/2018] Abese Awo: Ebamin gbe igi iroko ni eere yio noo owo bi enipe ofe mun unkan
tabi GBA unkan sigidi yi yio NI itise daada tio fi idi munle leyin eyi ao lowa ogan eletutu pelu
alade Igbo ao powonpo ao fimon alade Igbo yen pada yio NI ihoo ibi tia fi pankere si leyin eyi
awon eronja ako ewe mererin pelu omi isa omi isa yi lao fi gbo awon ewe noo mon ara sigidi yi
oun no lao fipo eyi tia mon lalade Igbo un nooo bakan noo ao fi atorin si ori alade Igbo noo sigidi
yi yio se bi eni femun atorin no ao ko gbogbo sakiti yen sobi ti alade Igbo noo waa
[13:10, 7/17/2018] Abese Awo: Ao wa ni kiwon bawa da obi nidie ao le unkan ti orisa no yio mon
gba NI bibo
[13:10, 7/17/2018] Abese Awo: Ati unkan tio gbodo de idire ni bibo awon Unkan yi lao mon lo
[13:10, 7/17/2018] Abese Awo: Lati fi ran nise ati lati fi pa ero fun orisa yi daaju daada osi yaara
jise daada oti di eyan meji si meta toti Dan orisa yowo kin NI apare akoko teo ri nibe yio mon kun
daada eo simon gbo oun ese bi igba ti eyan baun ri igbamiran ele mon gbo ariwo from no wear
Orissa yi daaju daada mio ti se ni eo fi ri aworan re
[15:18, 7/17/2018] Abese Awo: Hummm

Okan oka oojo okan alaugba oojo okan alagemon oojo okan opolo oojo ewe ino ewe oyin ewe
sawere pepe oojo NI awon ewe yioo ewe olojoungbodu eo joo mon odidi atare kan eo waro sinu
aado ijamon odi min min

Gbogbo igba tie bafe loo eo mon fi owo alafia GBA idodo lemeta eo wa mon so gbogbo oun tie fe
kosele abi adua abi eepe

You might also like