You are on page 1of 1

Owariri tororo

Owariri gbororo
Adifa fun ojomoda
Tnise aremo olodumare
Omo anteni legelege fori sapeji omi
Ojo timoda koope iman won kolejo
Atori manse belenje atori
Atori laye ,to ba lo si waju
Atun lo seyin ni
Erigi Alo ,mo ti di Aremo Olodumare bayi ooo ,ki ri ba tise ,
Ki Rona gbe gba
Orunmila AJANA , mo ti di omo irunmole, ki GBOGBO irunmole o ba mi gberu mi dori
Ela iwori. Mo ti di omo orisa, ki gbogbo orisa OTI mi le yin
Ifa olokun asoro dayo ,o ba soro Awo ire DAYO bayi lotun isalaye
Ase

You might also like