You are on page 1of 2

Mo Fe Ibitimo lo

Corus: Mo fe mo ibitimo mbo, mo fe mo ibitimo de


Olorun mi o Mo fe mo ibiti mo unlo O tini mimo si
mi loju eini.

Bi Un o bam o ibitimo mbo, tiun tun mo ibitimode, ti


uno tun mo ibiti mo unlo, emi oyato si afoju
aririnajo, to si tun diti, ireti woni iba wa fun mi o
emi mimo wa si mi loju emi.

Igbagbo tidi kara, kata, ojulowo omo olorun sowon


won tifi ipile rere sile to satani lehin, o wa nje inira
fun won lati lo sin olorun, Angeli okunkun wa
parade di ti imole, Oba aiye won rin, Won ti gbagbe
bi won ti koko gba, won orun ibiti won ti mbo, kan
motile so ibi tiwon de, ireti wo ni yio wa fun won o
emi mimo wa ba aiye won pade dakun

BIBLE READING: HEB 11:13, john 14:6


ORO KIKOJO
Opolopo lokorojo lai ti o lo won gbeyin; Opolopo lo saralogbe bee laimo
pe ikan ni yio njee won; iku apa eni ti anpe kotowa pada pe enitope ni;
Jaiye moni wono kose jeje iwo onigbagbo ese.
Araye gbona odi korojo, won ko mo pe baba le binu; kini afani omo
eniyan tolo gba ona odi korojo; bi iu bade lojiji amu won lo; oro adi ti
eni-eni; to ba lo tan o kosi we yin wo; akitiyan tole se laiye losi mo iwo
onigbagbo ese.

Toba nje tan; to mu tan laiye, ko ma se gbagbe oloro kan; Koma se


gbagbe oloro kan; to je tan;
Tomu tan lojokan, tolo sinu oko re toni; tori Gbagbo dukai re jare; bayi
lo bokan re pininu pe okan mi mayo ma simi wahala kan, kosi fun o
mo(Olorun) Olorun kosi latisanmo olorun kosi latisanmo pe iwo asiwere
oloro, Ani-Ioni-Ioni-Ioni-Ioni la ogba emi re lowore

Iyakoto iya la fi ada pa ikun; ikun ti salo ada junu iyakoto iya la fadapa
ikun; ikun ti salo ada sonu kini wahala re lai bee orun /2x
Tioba loro ti oko ile; bi oba loro ti olowo kini wahala re labee orun; kini
wahala re labee orun

You might also like