You are on page 1of 2

Sub-topics Elements:

Ori oro (Chapter Title): ONKA YORUBA (YORUBA NUMERALS)


Arrangement: 2
Recap:
Ninu eko tonii, a o ma tesiwaju ninu eko onka Yoruba. A o bere lati ori ogorun-un
de igba. In this lesson, we shall continue our lesson on Yoruba numerals, onka,
from aadota, which is fifty to ogorun- un which is one- hundred.

Mo lero pe e ranti ilana iropo ati ayokuro lati fi mo onka ti o kan ti a ko ni eko ti
a ko kojo, a o maa se amulo re ninu eko toni naa.
Oya, e maa tele mi kalo. So, let’s get started!

Remember the key term we learnt that are used in the formation of these
numerals in an earlier lesson? let’s start by learning the ending numbers first. e
je ki a koko bere pelu kiko nomba ti o pari naa.
100 – ogorun-un
110 – aadofa
120 – ogofa
130 – aadoje
140 – ogoje
150 – aadojo
160 – ogojo
170 – aadosan
180 – ogosan-an
190 – igba-din-mewaa
200 – igba

ni bayyi, e je ki a lo ilana ‘o le’ iyen (aropo) tabi ‘o din’ (ayokuro) lati se onka aarin
won. this means, now, let’s use the method of subtracting and adding to learn
the middle numbers.
we make use of
 ‘laa’ which means surpasses
 ‘din’ which means less
 ‘le’ which means more.
Please, take note of these keywords, as they are often used in creating Yoruba
numerals.
Now, note that once you get to a mid-point number such as 15, 25, 35,45 and so
on, Yoruba numerals take up the subtraction method, up on to you reach an
ending number.
Ookan-le-logorun-un = 101
Eji- le-logorun-un = 102
Eta- le-logorun-un = 103
Erin- le-logorun-un =104
Aarun-din- laaadofa = 105
Erin-din- laaadofa = 106
Eta-din- laaadofa = 107
Eji-din- laaadofa = 108
Okan-din- laaadofa = 109
aadofa = 110

bayii ni a se maa siro onka aarin won titi ti a fi maa de ori igba. this is how you do
the calculation for the remaining middle number.

ISE SISE:
Yi awon onka wonyii si yala onka Yoruba tabi ti oyinbo.
1. 51 ……………
2. 69……………
3. Eerindinlaaadota ……………
4. Ookanlelaaadota ………………
5. Ogorin ………………
E je ki a ko ko orin yii
Chapter Summary:
Ni bayii, ati wa fi opin si eko tonii. This means, we have come to the end of
today’s lesson. Lonii, a ko nipa oonka Yoruba. E ma gbagbe ilana aropo ati ayokuro.
Today, we learnt about the Yoruba numerals. Do not forget the use of addition
and subtraction to get the next numerals. Ki a tun ma pade ninu eko to n bo,
odaboo.

Oro to ye lati mo (Key Concepts/vocabulary): oonka – number, iropo –


addition, ayokuro – subtraction.

You might also like