You are on page 1of 2

1, Elarowa i Elarowa ii Elarowa iii

Akinsala, akinsala, akinsala,


Abeni ade, abeni ade, abeni ade,
If mo p, ifa mo pe o, ifa mo pe,
Orunmila mo pe o, orunmila mo pe o, orunmila mo pe o,
Tti were ni tekute ile,
Asun parade ni ti igi aja,
A biamo ki gbo ekun omo re ko mo tati were, ogbo loni ki ogbo ogba loni, ki ogba iba
baba oro to kete baba ileso ni ile gbo, iba baba, iba yeye, iba oluwo, iba ojugbona, iba
ara. Mo n aa ti ko omo ni ifa oju ala aju ba, ki iba ose.
CANCION
Adupe lowo olorun
Adupe lowo olorun
Orun ti asun to jiwa saye
Adupe lowo ori wa
Adupe lowo ori wa
Orun ti asun to jiwa saye
Ojumo mo ho oye le ho
Ojumo mo ho oye le ho
Aji awa gbo ore ore owuro ho
Aji awa gbo ore ore Oruro ho
2, EMPISAR
Subu lade ojire, iyeloko ojire, ojikutu, lawofun ojire, ifa aji aluk loni, afeyin ti igi
akoko, awa debi ti y ogbe ko gege, tako tabo ewa, bawa ni ijoko ho, onakona ti oba san
mo omikun ona kona bi omi ba san mono mi osa, emi oye emi oye lan ke mo ojo , bojo
ba yo ni iwonran gbogbo aye lori, ekorere wa sin wa o, akoko eruju ekorere wa o,
akoko eruju igba owa lo di fa fun awa, owa oko gi gbedu, omo oko yeye won ni ti owo
ji ki ofi ori ba le ki omo ki bara apetu, owani tori kinni, owan tori k oba se ku, owa
owo okumo, igbo tfa aji afori bale kion, igbo won ni tio ba ji ki ho fio ri bale ki ho, owa
n tori ki ni owa ni tori ko l ba ni ire gbogbo owaji owa ni ire gbogbo
3, I DUPE. GRACIAS
Orunmila ni kaso pe, ifa ni kaso pe, oni ti omo eku ba ji ko sop lowo Eledumare, oba
adani wa ye oni ohun yo fi ona aiku han orunmila ni ka sop, ifa ni ka sop , oni ti omo
eku baji ki osope lowo ohun Eledumare, Eledumare, ni kutukutu owuro koso lowo
eledumare oni ohun yo fi ona aiku han idin owonrin rosun asope, elawori asope
orunmila asope lowore adupe ni pa ase orunmila, bara agboni regun. Ase Edumare.
4, I DARINGIN ESSE. PERDON
Oni toki lawo ode egba, ol obu iyepe sese lawo ode ijesa okete abori bobo adi fa fun
odun ela omo larogun ti o sese kanra kan ti o se ara du e ri,bara petu ni ka wa be ho,
bara petu mon ti gbe be ije be de lawo olugbebe ti a bati rawo re be ni aje bebe ni igbin
de omo oni ipere akoko ifa yo poro si awo ni ile yo poro si awo lona a ti oni ka lu ku
wa ho. Ase
5, IRIN AJO
Apalan ba atisa, adi fa fun ade, ti se yeye onilu, oni ibi o sun won lomo ohun loni, ade
loni ki ode obobo loni ki opada bo ni irin ajo, ewo orisa eye keye ki fo ko fi orisoa i, bi
na ba ko odi owo eni tin f ina, borun kobaranmo odi pwp olodumare, adi fa fun aina ka
tin se awo lo si ilumokun won ni bi ise tohoun ayan ko ni yan, era koni rin, eni ayan
bayan nikuso si inu igbo eni era barin ni kuso si a luju ona, ifa ni a lore abo re a ni sije.
AES EDUMARE

6, I JUBA
Ajirawo lawo ajirawo, ajirase rase lawo, aijrase, ajirawo rase, lo di fa fun ajiraworase
moyin ho, ajirawo rase awo rere, ti a ba ji ki eledumare kawe owo e ni fini, kawe esse e
ni fini, kawe gbogbo ara e ni ko fin ninini, tori ara e ni edumare gbe ibi okun kun
edumare ki gbe ibi eri edumare ki gbe ibi egbin orunmila eri gi alo, je ki ona re ko la fun
wa O. ase
7, IPABI
Aji mo bi kan ile lo di fa fun Ala moye awon, agba to ba ji to fio bi kan l ori awon
adarugbo ke lese obarisa, kanna jangbon ori e abeso jingbini a di fa fun olomo, i ti
jogun etan, abufun olomo i ti jogun obi, kato fie yin ti kato jogun obi, kato fie yin to
jogun etan, ire gbogbo ni towo e ni igbin de omo oni ipere a koko ifa opor osawo ni l
ifa ho poro sawo lona, kato feyeyin ti ka to jogun iregbogbo, ire gbogbo ni towo eni
moto ki lawo moto ki moto yin lawo motoyin, motoyin bunban bolori, adi fa fun kowe
oya, omo adabo oke ti n b ora kinrakin, orunmila lo de erro opo erro ofa eyan to ba fun
ikin lo bi ara je so hun rere erin ke erin sese adi fa fun kowe, ti yo pa bi lafin, koko re ni,
adi fa fun lan ta kun,tin lore raye eleru, baduro bawure ire awa ko sai gba, bi abere ti
awure ire awa ko saigbo, bi ayoko bi awure ire wa ko saigba, alaba lasa, alamun lasa, a
di fa fun orunmila tin lo re gbe kolobo ni iyawo, ba laye amon laye kolobo fie nu ara re
wure, kolobo ba ni ire gbogbo amo ni ire gbogbo kolobo fenu arare wure kolobo ire kan
eji kan ti aba su loni ki eledumare ba wa mun ile ase.
ASE EDUMARE
8,
1. IFA ITANIJE LEYIN IGBANA
2. IWURE LATI ENU OKUNRIN
3. IWURE LATI ENU OBINRIN
9, ORIN IPARI
Awure tan anre l baba Edumare mon ba w alo
Awure tan anre l baba Gbogbo irunmole mo ba wa alo
,,
,,
,,
,,
Ejiogbe mo ba w alo
,,
,, ,,
,,
Oyekumeji mo ba w alo
,,
,,
,,
,,
Iwori meji mo ba wa lo
,,
,, ,,
,,
Odi meji mo ba wa lo
,,
,, ,,
,,
Irosun meji moba wa lo
,,
,, ,,
,,
Ownrn meji mo ba wa lo
,,
,, ,,
,,
Obara meji mo ba wa lo
,,
,, ,,
,,
Oknrn meji mo ba wa lo
,,
,, ,,
,,
Ogunda meji mo ba wa lo
,,
,, ,,
,,
Osa meji mo ba wa lo
,,
,, ,,
,,
Ika meji mo ba wa lo
,,
,, ,,
,,
Ologbon meji mo ba wa lo
,,
,, ,,
,,
Otura meji mo ba wa lo
,,
,, ,,
,,
Irete meji mo ba wa lo
,,
,, ,,
,,
Ose meji mo ba wa lo
,,
,, ,,
,,
Ofun meji mo ba wa lo
Awure tan anre le baba Ose eleru mo ba wa lo
Awure tan anre le baba Gbogbo irun mo ba wa lo
Awure tan anre le baba Gbogbo odu mo ba wa lo
Awure tan anre le baba Eleumare mo ba wa lo.3

You might also like