You are on page 1of 2

Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,

Ilẹ̀ mo pè o,

Ẹgúngún o

Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,

Ẹgúngún o

(Bobô mònríwo)

Ẹgúngún a yè, kíì Xẹ́ bọ ọ̀run

Mo júbà rẹ̀ Ẹgúngún mònríwo

Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,

Ẹgúngún o

A kíì dé wa ó, a kíì ẹ́ Ẹgúngún

Won bobo ará asíwájú awo

Won bobo aráalé asíwájú mi

Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,

Ẹgúngún o

Mo pẹ̀ gbogbo ẹ̀nyin

Si fún mi ààbò àti ìrònlọ́wọ́

Agó, kìì ngbọ́ ekún ọmọ rẹ̀

Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,

Ẹgúngún o

Ki o ma ta etí wéré

Bàbá awa ọmọ rẹ ni a npẹ̀ o

Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ẹgúngún o

Ki o sare wá jẹ́ wa o
Ki o gbọ́ ìwùre wá

Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,

Ẹgúngún o

Má jẹ̀ a ríkú èwe


Má jẹ̀ a ríjà Èsú
Má jẹ̀ a ríjà Ògún
Má jẹ̀ a rija omi
Má jẹ̀ a rija Soponná

Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,

Ẹgúngún o
Motumbá Bàbá Egungun

Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,

Ẹgúngún o

You might also like