You are on page 1of 11

ILE-EKO GIGA TI KIRISITI ARANIPADA

(CHRIST THE REDEEMER SECONDARY SCHOOL)


AGBEGBE J1, OPOPONA GBOORO ELEKEJE, NI ILU FESITAAKI, NI IPINLE EKO
IDANWO IGBARADI FUN IDANWO ASEKAGBA (MOCK EXAMINATION)
TI ODUN 2022
_______________________________________________________________  
EKA-EKO: EDE YORUBA AKOKO:WAKATI MEJI GBAKO KILAASI: J.S.S 3

DAHUN GBOGBO AWON IBEERE EWO-NIDAHUN YII.

PAPER 1
SECTION ( IPIN KIN-IN-NI)

AKAYE KIN-IN-NI A. Agbado


Ko awon ayoka isale yii ki o si dahun awon B Amala
ibeere ti o tele won C Ewura
D Iyan
Opolopo ounje ni o wa ni ile YorubaO
ounje dabi oba ni ile Yoruba. Apeere awon
ounje ni ile Yoruba ni isu.Ounje ti a maa fi isu 2. Awon agbegbe wo ni o gbadun iyan
se ju ni iyan, a si tun le e je isu ni sise. julo?
A. Ekiti
Orisiirisii isu ni o wa. Isu bi efuru, odo olo, a- B. Ijebu
reyin-gba kumo, olobe ku asenu, petisan ati C. Ondo
bee bee lo. D. .Oyo
Pupo ninu awon isu wonyii ni o dara
lati je bi i iyan, awon bee ni isu odo, arehin-
gba kumo. Efuru, gambari aro ati bee bee lo. 3. Oba ounje ni ile Yoruba ni
Bi a se n gun won ni won yoo maa gba omi ti A. Isu
won yoo si maa wa fuu. Awon isu miran wa ti B. Iyan
o je wi pe ko se e fi je isu tabi sise ni asaro C. Iresi
awon isu bee ni olobe ku asenu. Petisan. olo. D. Ogede
ewura ati esuru. Igba miran a le fi ajeku isu se
elubo ii a o si maa ro o je bi amala.
4. Ounje ti a maa fi isu je ju ni
Ti a ba maa soro nipa awon agbegbe ti A. Amala isu
o n je iyan bi-o-tile je pe gbogbo ile Yoruba ni B. asaro
o n je e sugbon oto ni ti awon Ekiti ati Ijesa. C. Iyan
Awon ti won wa ni agbegbe Oyo feran amala D. isu
isu lopolopo.

Awon Ijebu feran ikokore ti won fi 5. Gbogbo isu wonyi ni o dara fun jije
ewura se, a tun ri awon ounje miran bii iyan ayafi
agbado, gbaaguda, ogede, iresi, oka baba ati A. aro
beebee lo. B. areyin-gba-kumo
C. efuru
Yato si awon ounje wonyi, awon D. ewura
Yoruba feran obe pupo nitori obe ni a fi je
opolopo awon ounje ti a menuba saaju wonyii.
6. iru ojune wo ni a le fi ajeku isu se?
Dahun awon ibeere wonyi
A. Asaro
1. Iru ounje wo ni awon Oyo feran? B. Elubo
C. Ikokore
D. Iyan Akanbi: Kolade aburo mi ni o to ojo meta ti
iba ti mu un mole

7. Awon ijebu feran ikokore ti a fi Banji: Kin ni o wa ti n lo?


_______ se
A. agbado Akanbi: A ra tabiileeti iba ati ara riro fun un
B. ewura sugbon ko si iyipada. Nitori re ni won fi ni ki
C. gbaguda n. . . mu un lo si laabu jenera
D. ogedi fun ayewo.

Banji: Se won wa ko oogun miran fun un?


8. Ewo tun ni Yoruba feran yato si awon Akanbi: Bee ni. koda o gba abere meji.
ounje ti onkowe menuba.
A. Akan Banji: E ku itoju re. O se Pataki lati toju
B. Ede ayika wa ki o mo tonitoni. Ki o da awon
C. Eja adagun omi
D. Obe
to ba wa ni ayika ile yii nu ki o si ri
I pe gota yin naa mo. Awon ibi ti
9. Akole wo ni o ba akaye yii mu julo? yanmuyanmu

to n fa iba maa n gbe ni iwonyi.


A. Agbegbe ti o feran ounje ju lo
B Awon ounje ile Yoruba. Akanbi: Ooto ni dokita naa so pe ki n ge
C Isu loba gbogbo koriko to ba yi wa ka ki a si gbiyanju
D Isu ni ile Yoruba lati ra

Neeti efon ki a maa ta a si ori


10. Ewo ni o dara fun iyan jije lara awon ibusun wa.
isu wonyii?
Banji: Awon oogun wo ni won tun ko fun
A. Aro e?
B. Ewura
C Esuru Akanbi: Awon naa niyii parasitamoo, toniki
D Olo eje ati antibaotiki.

Banji: Osoosu ni mama mi maa n ki agbo


iba fun gbogbo wa. Ko si si eni to gburoo iba

SECTION 2 (IPIN KEJI) lati ibere odun yii.


AKAYE KEJI
Akanbi: E e en Sugbon agbo a maa koro
Ka itakuroso yii ki o si dahun ibeere ti o tele
lenu
e.
Banji: Bee ni bi o se koro to naa lo dara
Akanbi: Kaaaro o Banji
to ni ara wa. Maa ki yin wa leyin ti aburo re
Banji: O o Akanbi. o ma tojo meta
ba pari gbogbo oogun re.
Akanbi: Ojo kan pelu Nibo lo ti n bo?
Akanbi: O daa ore maa maa reti re o dabo.
Banji: Mama mi ran mi ni ewe ti a o fi
Dahun awon ibeere wonyi
ki agbo iba ma ni. Nibo ni iwo naa ti n bo?
11. Banji ji _____ Akanbi
Akanbi: Lati jenera osibitu ni
A. akekoo
Banji: Ta lo siiki? B. alabagbe
C. ebi B. Banji
D. ore
C. Dokita
12. Orisii oogun meloo ni Banji ri lowo
Akanbi D. Kolade
A. Meji
B. Meta
C. Merin 19. Asiko wo ni Akanbi ati Banji pade?
D Marun-un
A. Ale

13. Kin ni o n fa aisan iba gege bi o se han B. Aaro


nina itakuroso yii?
C. Idaji
A. Aayan
B. Esinsin D. Irole
C. Oorun
D. Yanmuyanmu

14. Bawo ni kolade se je si Akanbi? 20. Ta ni o ran Banji nise?


A. Aburo
B. Baba A. Aburo re
C. Dokita
B. Baba re
D. Egbon
C. Egbon re
15. Nibo ni Akanbi ti n bo nigba ti o pade D. Mama re
Banji
A. Hosipitu
B. Oofisi
C. Oja SECTION 3 (IPIN KETA ) ONKA
D. Papa isere 21. Ogun je

A. 10
16. Okan lara awon imoran to dokita gba
Akanbi ni pe ki o B. 20
A. dekun mimu omi tutu
B. ge koriko to wa ni ayika won C. 40
C. gba orisii oogun mefa
D. mu agbo iba D. 50

17. Iru aisan wo jo ko lu omo naa Aisan

A. akandun 22. Isu mewaa ni mo ta me waa is


B. ebola A. 9
C. iba B. 10
D. iko E. inu rirun. C. 15
18. Ta ni aisan n se ninu itakuroso yii? D. 20
A. Akanbi
23. 100 Is C. good luck

A. ogun D. welcome .

B. ogoji 28. How are you means

C. ogota A. Bawo ni?

D. ogorun-un B. Iwo da?

C. Nibo lo n lo?

24. 64 ni a pe ni D. Se o ti jeun?

A. aarundinlogota

B. aarunlelogota 29. Ade is eating tumo si Ade n

C. eerindinlogota A. jeun

D. eerinlelogota B. jo

C. korin

D. rin

AAYAN OGBUFO

25. Wa mu omi means come and drink

A. water 30. Welcome tumo si

B. malt A. kaabo

C. milk B. kaale

D. tea C. kaaaro

D. kaasan

26. This is my mother _______ mi niyi.

A. mama

B. mami IRO EDE

C. moda 31. Iro keta (3rd) ninu alifabeeti Yoruba ni

D. momi A. d

B. f

C. j

27. O dabo means D. m

A. come

B. good-bye 32. U je apeere


A. akoto D. tan

B. amin ohun

C. faweli 37. Ile nla ni Ayo ko. kin ni idakeji oro ti a


fala si labe loke yii
D. iparoje
A. Alara

B. Didara
33. Faweli airanmupe Yoruba je
C. Kekere
A. 6
D. Peteesi
B.7

C. 8
38. Olowo ni baba re oro miiran fun olowo ni
D 12
A. alani

B. alaso
34. Apeere iro konsonanti ni
C. oloko
A. A
D. oloro
B. E

C. I
39. Omo ti o ba n se daradara ni baba re maa n
D. R
A. dojule

B. feran
35. Toka si eyi ti ko si ninu alifabeeti Yoruba
ninu iwonyi C. je niya

A. f D. korira

B. gb

C. o 40. Aya mi kii mu eko aya tumo si

D. q A. aburo

B. baba

C. egbon

GIRAMA D. iyawo

36. Ade ti je amala naa tan, Oro-ise inu


gbolohun yi ni
41 Ewo ni a fi n se elubo ninu awon ounje
A. Ade wonyi

B. amala A. Agbado

C. je B. Ewa
C. Ibepe

D.Isu 46. Awon ti o n pa eran ninu igbo ni Yoruba n


pe ni

A. agbe
42. Ni ile Yoruba, bawo ni a se ri ki eni ti o
sese bimo? B. apeje

A. Aboruhoye o C. elemu

B. Aje o wogba D. eleran

C. Abunya o E. ode

D. E ku owo lomi

47. Awon wo ni o n we gele? Awon

43. Ewo ni o je oruko amutorunwa ninu awon A. agbalagba


oruko wonyii?
B. obinrin
A. Adebisi
C. okunrin
B. Ajani
D. oloja
C. Ajayi

D. Igbekoyi
48. Ibi asa Yoruba wo ni a ti n san owo ori?

A. Igbeyawo

B. Ikomojade
44. Ewo ni aso okunrin ninu awon wonyi?
C. Ile sise
A. Buba ati iro
D. Isinku
B. Buba ati sokoto

C. Iro

D. Kaba
49. Omo meji ti a bi nigba kan naa ni a n pe ni

A. Alaba ati Idogbe

B. Alaba ati Idowu


45. Aso obinrin ni
C. Idogbe ati Taiwo
A. agbada
D. Taiwo ati Kehinde
B. dansiki

C. gbariye

D. gele
50. Ewo ni a le je ni tutu laise lori ina ninu
awon ounje wonyi
A. Agbado B. Iro faweli

B. Ewa C. Iro aranmupe

C. Ibepe D. Iro faweli ati ohun

D. Iresi 56. Afomo ibere pelu oro oruko ni a fi seda

A. Eleja

B. Meje

51 Ewo ni ko pon dandan ninu awon nnkan C. Mejo


won yii nigba ti a ban ko aroko?
D. Mesan-an
A. Ifaara
B. B. Yiya Awonran
C. Ilapa Ero
57. Alitabeti Yoruba je….. lapapo
D Ikadi
A. Meedogun
52. Ewo ni ki I se aroko Alapejuwe
B. Meedin meji
A. Ile iwe mi
C. Meedogbon
B. Ore mi
D. Merinlelaadota
C. Ile ijosin wa

D. Orin
58. Ihun sitebu olu ni ….
53. Irule aroko ti o nje ki a mo egbe ti onkowo
li si ni ikadu aroko ni …. A. F-f-kt
A. Aroko Alanyanjiyan B. f-k-f
B. Aroko Oniroyin C. k—fk
C. Aroko Onisoro-n-gbesi D. F-ki
D. Aroko Alaiaye 59. Eya ara to maa n duro gbari ti a ba n pe iro
ede ni ….

A. Asunsi
54. Adiresi meloo ni lota gbofe maa n ni?
B. Akanmole

C. Afunnu
A. Meji
D. Asesi
B. Eyo kan
60. Iro ti a pe ti ko si idiwo fun eemi ni iro….
C. Eyo meta
A. Iro konsonanti
D. Eyo merin
B. Iro ohun I
55. Iro ti idiwo wa fun pipe re ni …
ro faweli
A Iro ohun
D. Iro silebu C. o

61. Awon eya ara wo lo n lo soke, sodo, nigba D. A


ti a ba n soro?
68. Apapo iro faweli airanmupe to wa ninu ede
A. Aja Enu Yoruba je…

B. Edo foro A. meta

C. Afipe Akanmole B. merin

D. Afipe Asunsi C. marun-un

62. …. Kii se faweli iwaju D.meje

A. O 69. Faweli aarin ni…

B. In A. a

C. e B. i

D. e C. e

63. ..….. je faweli eyin D. u

A. in 70. Meloo ni gbogbo iro faweli ede Yoruba?

B. e A. mewaa

C. u B. mejila

D. i C. Metala

64. Ninu onka Yoruba ookanlelogun je….. D. meedogun

A. 51 71. Kosonanti aramupe asesilebu ni…

B. 41 A. g ati b

C. 31 B. f ati m

D. 21 C. n ati d

65. Ona meloo ni a le pin faweli Yoruba si? D. e ati p

A. meji 72. Ko oro yii ni ilana akoto Ogbomosho

B. meta A. ogbomo

C. merin B. ogbomoshoo

D. marun-un C. ogbomoso

67 Iro faweli ti kii bere oro ninu ede Yoruba ni D. osho

A. e 73. ….. ni yoo koko waye ki to te lee ninu ede


Yoruba.
B. u
A. Aranmo
B. Ijeyopo C. Oro ise

C. Arikoo D. Oro atokun

D. Iparoje

74. Ninu gbolohun onibi …. ati …. Je oro ise 78. Oro ise je koko fun …. ede Yoruba.
ninu gbolohun yii “Ade sun,kete ti o jeun”
A. Oro oruko
A. Sun, keta
B. Awe gbolohun
B. Sun, jeun
C. Gbolohun
C. Ade sun
D. Apejuwe oro
D. Sun tan
79. Oro-oruko afoyemo n iwonyii ayafi……
75. Ise wo ni Agba se ninu gbolohun yii “iya
Agba ro amala” A. ogbon

A. Aponle B. imo

B. Oluwa C. ife

C. Eyan D. aga

D. Abo 80. Jide je ise “Toka si oro to n sise abo ninu


gbolohun yii….

A. isu
76. Ewo ni oro Aponle ninu wonyii
B. je su
A funfun
C. jide
B. mo
D. jide je
C. si
81. …… ko la ni itumo kikun ati olori awe
D. jaujau gbolohun ban kun-un

A. Oro alagbon

77. Oro Aropo-oruko eni kinni ni ipo opo ni B. Oro aponle



C. Awa gbolohun
A. wo
D. Oro alokun
B. mi
Ewo ni oro ise ninu awon oro inu gbolohun yii
C. won “Dele pupa maa wa si oja ni ola”

D. yin A.Dele
B. Si
Oro ti o maa n toka bi nnkan se ri, ti o si maa n C. Oja
sise eyan fun oro-oruko ni….. D. Wa
A. Oro Aponle 82. Ewo ni kii se oro-aropo-afarajoruko
B. Oro apejuwe A. Ewo
B. Awa 88. O ti de lati oja. ‘O’ ninu gbolohun yii duro
fun….
C. Emi
A. otp-aropo-oruko
D. Iwo
B. oro-asopo
83. Ayo pon omi …. ‘Pon’ ninu gbolohun yii
je. C. oro-ise

A. Arapa oruko D. oro-aponle

B. Oro-ise 89. Bawo ni a se seda oro yi aisun?

C. Oruko A. ais + un

D. Eyan B. ai + jo

C. a + isu

84. …… ni o maa n sa afikun fun gbolohun D. ai+sun

A. Oro ise 90 Bawo ni a se sada idajo?

B. Oro eyan A.idajo

C. Oro apejuwe B. ida + jo

D. Oro atokun C. i +dajo

85. Gbolohun Abode kii ni ju …..kan lo D. ida + jo

A. Oro ise 91. Oruko ti Yoruba n pe abiku ni okan ninu


awon oro isale wonyii
B. Oro oruko
A. Funmilayo
C. Oro atokun
B. Maiomo
D. Oro abode
C. Ogunremi
86. Ewo ni ki I se oro-oruko ninu awon oro
wonyii? D. Ogundele

A. Aso 92. Omo ti a pe ni Ayandele wa lati idile…..

B. Amo A. eleegun

C. Iwosan B. Onilu

D. Iwe C. Babalawo

87. Oro oruko aseku ni …. D. Oloye

A. omi 93. Orin ayeye igbeyawo fun Omoge to n rele


Oko ni ……
B. yage
A. Rara
C. iwe
B. Ijala
D. irawo
C. Ekun iyawo C. Idogbe

D.Olele D. Idowu

94.Awon ilu wo ni won maa n sun ijala? 100. Awon oruko bi i Ojerinde, Egunjobi,
Ojelarinnaka je mo ……
A Ilorin
B. Eko A. Alaro
C. Ekiti
D. Oyo B. Idile ayan

95. Ibudo ti won ti n ro oko, ada,obe ati ibon C. Idile eleegun


ni a n pe ni ….
D. Idile onisango
A. Agbede

B. Igbale

C. Aafin

D. Orita aperin

96. Okan lara awon iyawo sango ni …..

A. Erelu

B. Oya

C. Esu

D. Olowu

97. Awon Yoruba maa n bu pele sugbon won


maa n …..keke

A. wa

B. bu

C. sa

D. re

98. Oruko Amutorunwa ni…..

A. Alao

B. Abike

C. Kokumo

D. Kehinde

99. Omo ti abi lehin awon ibeeji ni Idowu, eyi


ti abi leyin Idowu ni

A. Alaba

B.Oke

You might also like