You are on page 1of 1

Odun ni a mo si year ni ede oyinbo. Orisirisi igba lo wa ninu odun kan.

A ni igba
eerun, igba oorun, igba ojo, igba oginnitin, ati igba oye.

Igba eerun ni igba ti ojo ba ti dawo duro ti gbogbo ile si gbe. Orun a si maa mu
lopolopo ni igba yii, ni tori ai si ojo. Igba eerun ni awon oyinbo n pe ni dry season
this is the period know as dry season in English.

Igba oorun ni igba ti ojo ko ba ro mo, ti gbogbo ile ba gbe. Orun a si maa mu
lopolopo ni igba yii, ni tori ai si ojo. Igba yii ni a mo si heat period

Igba ojo ni igba ti ojo maa n ro daradara, otutu a si maa mu pelu. Igba yii ni awon
ede geesi n pe ni igba ojo. This is the season called raining season.

Igba oginnitin ni igba ti ojo a ma ro leralera ninu odun. Otutu a si maa mu


pupopupo ni asiko yii, eyi ni o fa ti awon eeyan a ma wo aso ti o ni ipon ni igba yii.

Igba oye ni asiko ti otutu maa n mu ni tori oye. Ara awon eeyan ma n funfun ti
ete won a si ma la ni asiko yii. Igba oye ni a n pe ni harmattan season.

You might also like