You are on page 1of 2

ECWA IJABGO

IDANWO IWE ILE EKO OJO ISINMI DEC 4 2022

1. Ninu ẹkọ wa lori ileri Olorun ati awon ojuse re. Daruko meji ninu awọn ohun ti eniti o

seleri jẹ.

2. Sọ ọna meji to se gboogi(important) ti a le fig be ihinrere kalẹ fun awọn abọrisa.

3. Kinni idi to fi soro gidigidi lati jẹẹri Kristi si awọn ẹbi wa? Daruko isoro meji ọtọọtọ.

4. Daruko awọn amuyẹ fun ajere ọkan meta ọtọọtọ.

5. Kọ ohun ti ari ninu ẹsẹ akọsori yi Joshua 1:8a.

6. Ninu ẹkọ lori awon amọran lori ilepa obi fun tito ọmọ anfani, daruko awon omo ti a lo

gẹgẹbi apẹẹrẹ.

7. Nibo (iwe wo ori ati ẹsẹ wo) lati ri gbolohun tabi akọsori yi? Tọ ọmọde ni ọna ti yoo to,

nigba ti o si dagba tan, ki yoo kuro ninu rẹ.

8. Agbelebu gẹgẹbi adiitu, pari awon adiitu wonyi.

i. Agbelebu jẹ ona si paradise bakannaa o tun jẹ ami _____________

ii. Agbelebu jẹ ami ogo bakanna o tun jẹ ami _______________

iii. Agbelebu jẹ ami ibalaja bakanna o tun jẹ ami _______________

9. Kini awọn iyorisi ẹbọ pipe? Daruko meji peerẹ.

10. Darukọ meta ninu awọn awokosẹ inu Bibeli ti ati fẹnu ba ninu iwe ile ekọ ojo isinmi.

11. Ninu ẹkọ wa “awon ti olorun bu iyin fun” kini isọri awọn wonyi se?

i. Oba Ahabu ii. Awon eniyan Ninefe ati iii. Agbowo Ode

12. Kini awọn eroja fun agbayori adura?


13. Nibo lati ri akọsori yi “Olukuluku ohun ni akoko wa fun, ati igba fun isẹ gbogbo labẹ

orun”?

14. Sọ ibi mẹrin ọtọọtọ ti owo ninu ijo ti n wa. Ki si ni awọn ohun meji miran ti ijo se alaini?

15. Daruko marun (5) ninu awọn ẹsẹ ibalopo ti o wope ninu aiye loni. Ki si ni meji ninu

abajade wọn ẹsẹ wonyi.

16. Ninu iwe wo ori wo ati ẹsẹ wo lati le re akasori yi “E ma sa fun agbere. Gbogbo ẹsẹ ti

enia ndaa o wa lode ara; sugbon eniti o nse agbere nse si ara on tikarare”?

17. Labẹ koko ẹko “Iran Danieli nipa Igba Ikehin (apa kini) awọn ohun to o yẹ ni sise pari

(accomplished) daruko meji lara nkan wonyi ti oje nkan ti a gbọdọ se”.

18. Daruko awọn èrè ti A yoo pin fun awa ayanfẹ ni ijoko idajọ ti Jesu (Bema Seat).

19. Ni ọsẹ aadorin (odun) ni aye , daruko awọn ohun mẹta Pataki ti yio sẹlẹ.

20. Lerefe daruko awọn ohun meta Pataki ti yoo sẹlẹ ni ọsẹ aadọrin ni oju ọrun (igbasoke

ijo).

You might also like